Welcome to Scribd. Sign in or start your free trial to enjoy unlimited e-books, audiobooks & documents.Find out more
Download
Standard view
Full view
of .
Look up keyword
Like this
8Activity
0 of .
Results for:
No results containing your search query
P. 1
FIL666

FIL666

Ratings: (0)|Views: 108|Likes:
Published by rerb21

More info:

Published by: rerb21 on Apr 13, 2011
Copyright:Attribution Non-commercial

Availability:

Read on Scribd mobile: iPhone, iPad and Android.
download as DOC, PDF, TXT or read online from Scribd
See more
See less

06/18/2013

pdf

text

original

 
Òsá Ìretè A
Ifá pé eléyìun ó móo rífà je láyé. Èmíi rè ó gùn, okàan rè ó balè, kó móo náwó, kó sìyawó.Gbìnngbinyìnkìntìn Awo ilé Olóyan gìdìgbíLó díá fún Olóyan gìdígbíOmo a gúnyán nlánlá bo IkinBó bá dìgbà tí ó bàá bo Ifá èA gúnyán sílè ràbàtàGbogbo èèyàn ó bàá móo wá jeunEní ó bà sì yawóTí n se nnkan rereNnkan rere nínlá náà níí ríBí gbogbo wón bá jeun tánWón ó bàá móo sàdúà fún unOlóyàán, yóó dáa fún oÈmíì ré ó gùnIré bá dé fún OlóyanÓ ní Gbìnngbinyìnkìntìn Awo ilé Olóyan gìdìgbíLó díá fún Olóyan gìdìgbíOmo a gúyán nlánlá bo IkinIyán nlánlá lOlóyàán fí n bo IkinGbìnngbinyìnkìntìnÌfà nlánlá lOlóyàán n jeÌfà ajéÌfà ayaÌfà omoÌfà iléÌfà nlánlá lOlóyàán n jeGbìnngbinyìnkìntìn
Òsá Ìretè A
Ifá dice que esta persona conseguiría los regalos gratuitamente para disfrute. Él viviríamucho tiempo y tendría descanso. Ifá lo manda ser generoso.Gbìnngbinyìnkìntìn el sacerdote de la casa de Olóyan gìdìgbíAdivinación lanzada para Olóyan gìdìgbíEl niño de A gúnyán nlánlá bo IkinCuando es tiempo por él observar su fiesta de IfáÉl prepararía mucho ñame machacadoTodos vendríamos a su casa para comer Y él es generosoY también haciendo las cosas buenasTambién conseguiría las cosas buenas en manojos (bultos)Cuando todos ellos habían tenido la comida para comer Ellos empezarían a orar para élOlóyàán, sería bueno para usted en la vida'' ' '' ' ' ' ' ' ' ''' '' '' '´´ ´´''''' ' '' ''´´´´´´``'``' '' ' ''''' '' '' '' '' '´´'' '´´'´´''´´´´´´ ´´'''' '
 
'Usted tendrá la vida larga', uno a otro diríaLas cosas buenas empezaron entrando para OláyàánÉl dijo Gbìnngbinyìnkìntìn el sacerdote de la casa de Olóyan gìdìgbí,Adivinación lanzada para Olóyan-gìdìgbíEl niño de A gúnyán nlánlá bo IkinBastante ñame mahacado que Olóyàán usa como el ofertorio a IkinGbìnngbinyìnkìntìnSon grandes regalos que Olóyàán está disfrutandoLos regalos libres de RiquezaDe esposasDe niñosDe CasaSon regalos libres que Olóyàán está disfrutandoGbìnngbinyìnkìntìn
Òsá Ìretè B
Ifá pé ire ò níí pé eléyìun sílè. A ò níí rin ìrìn àrìndànù.Ó sá réteÓ rìn réteÀgbàrá gorí òkèA sáré réteA rìn réteA díá fún ÒrúnmìlàNíjó ire gbogbo kò tí ò yalée rè móÀwon ire tí ón yaá lo yìí?Wón yà wá báyìí?Wón ní gbogbo iré ní o móo ya ilé èWón ní kó tójúu eran oyàWón ní kó fi rúboÒrúnmìlà se béèÓ fi eran òyà bo òkè ìpòrí èIre gbogbo bá n yalé èN ní wá n jó n ní n yòNí n yin àwon BabaláwoÀwon Babaláwo n yin IfáÓ ní béè làwon Babaláwo tòún wíÓ sá réteÓ rìn réteGabarra gorí òkèA sáré réteA rìn réteA día fún ÒrúnmìlàNíjó ire gbogbo kò tí ò yalée rè móKín ló níre ó yà wálé Awo?YààyàLó níre ó yà wálé Awo' ' '''''''' '''''' '' ' ''' ' ' ''''''' ' ''' ' ' ' ''´´´´'´´´´´´'''' '' '' '''''' ' ' '

Activity (8)

You've already reviewed this. Edit your review.
1 hundred reads
hoyos george liked this
nelawo liked this
iogara liked this
ROCKO6709 liked this
Giuseppe liked this
antsantana liked this

You're Reading a Free Preview

Download
scribd
/*********** DO NOT ALTER ANYTHING BELOW THIS LINE ! ************/ var s_code=s.t();if(s_code)document.write(s_code)//-->