Welcome to Scribd, the world's digital library. Read, publish, and share books and documents. See more
Download
Standard view
Full view
of .
Look up keyword
Like this
5Activity
0 of .
Results for:
No results containing your search query
P. 1
11 odu de ika

11 odu de ika

Ratings: (0)|Views: 182|Likes:
Published by Baba Ire

More info:

Published by: Baba Ire on Oct 01, 2011
Copyright:Attribution Non-commercial

Availability:

Read on Scribd mobile: iPhone, iPad and Android.
download as PDF, TXT or read online from Scribd
See more
See less

08/07/2013

pdf

text

original

 
Ifadowole
Ìká Méjì A
Ifá pé ire fún eléyìn. Ifá pé òun ó gbà á kalè lówó ikú, lówó àrùn, òfò àti gbogboajogun. Ifá pé ká fi aaka kún ebo rú. Ifá pé ire ó to lówó.Káwó fún miKí n kásè fún oA díá fún OníkàámògúnOmo Aláaka káwó ikúWón ní ó sá káálè ebo ní ó seWón ní ó fi aaka kún ebo è rúKò kúKò rùnKà sàì kábi kúòAkikaAkika kà sàì kábi kúòAkika 
Ìká Méjì A
Ifá desea bien a esta persona. Ifá dice que él lo salvaría de las garras de la muerte,enfermedad y pérdida. Él debe agregar Aaka a su sacrificio.Káwó fún miKí n kásè fún oAdivinación lanzada para OníkàámògúnEl niño de Aláaka káwó ikúLe pidieron que cuidara de la tierra y ofreciera sacrificioLe pidieron que agregara Aaka a sus objetos de sacrificioÉl no se murió de nuevo Ni él no se cayó enfermo¿Qué rodarían todas las malas fortunas lejos?AkikaAkika rodarían todas las malas fortunas lejosAkika
Ìká Méjì B
Ifá pé kó síkú mó , kò sí àrùn mó fún eleyiun. Ebo ni kó rú.Agbáágbá Orí etuA díá fún ÒràmolèÈyí ti n rayé ìlaì níí kúEbo n wón ní ó seÓ sì gbébo nbèÓ rúboÒgún odún òní nkó o?Òkè n be láìkúGbonhingbonhin n tòkèÒkè gbonhingbonhinOgbón odún òní nkó o?Òkè n be láìkú
Ifadowole
1'''''''''''''''''''''''''''''''´´''''''´´'''´´'´´''''''''´´'´´'
 
Ifadowole
Gbonhingonhin n tòkèÒkè gbonhingbonhin Kèè pé o Kèè jìnnà E wáá bá ni láìkú kangiri Àìkú kangiri làwá wà
 Ìká Méjì B
 Ifá dice no hay ni muerte ni enfermedad para esta persona. Él debe ofrecer sinembargo por completo su sacrificio. Agbáágbá Orí etu Adivinación lanzada para Òràmolè El que sobreviviría la muerte en la tierra Ellos le pidieron que realizara sacrificio Él oyó hablar del sacrificioY lo realizó¿Veinte años de hoy? El Montañés todavía exista sin morir Gbonhingonhin es para la Montaña La Montaña es el gbonhingonhin existenteTreinta años de hoy La Montaña existe sin morir Gbonhingonhin es para la Montaña La montaña existe sin morir  Antes de mucho tiempo En el futuro más cercanoVenga y encuéntresenos fuerte sin morir  Nosotros estamos viviendo sin la muerte y en la vitalidad 
Ifadowole
2''''''
 
Ifadowole
 Ìká Ogbè A
 Ifá pé òun pé iré fún ení ó dá odù yìí. Yóó joyè nlá. Wón ó móo sòrò korò lórí è, Ebo nikó le ségun. Aboyún kan n be nítòsí eléyìun tí ón n pé ó kù bí ó ti bímo è, Ifá pé kó rúbodáadáa torí tibi tire ni eléyìun ó bìí. Ìká gbè mí  N ó joba Ìlá Ìká ò gbè mí  N ó joba ÌláÒòsà ìkà níí gbe ìkà A díá fún Ìkookò Èyí ti n lo rèé lóyúun méjì níkùnÒun le bímo láyé yìí?Wón ní kó rúbo Ìkookò sì lóyún nnúWón ní kó níí séwu Ìkookò bá rúboÓ bá bímo è Ayé ye Ìkookò Ní wá n jó ní n yò Ní n yin àwon Babaláwo Àwon Babaláwo n yin IfáÓ ní béè làwon Babaláwo tòún wí  Ìká gbè mí  N ó joba Ìlá Ìkà ò gbè mí  N ó joba ÌláÒòsà ìkà níí gbe ìkà A díá fún Ìkookò ti n lo rèé lóyúun méjì níkùn Èyí ti ón ní ó níí lè biWón ní kó sá káalè kó jàre Ebo ní ó seÓ wáá gbébo nbè ó rúboTùúnhìnMo bí tibi tireTibi tire làfòón wòMo bí tibi tireTùúhìn
 Ìká Ogbè A
 Ifá desea bien a esta persona. Ifá predice que él ascendería un trono. Las personasdirían las cosas malas sobre él pero él debe realizar sacrificio, hay una mujer embarazada cerca de esta persona. Los enemigos habían excluido su embarazo quedice que ella no debe entregar su bebé; Ifá le pide a la mujer que ofrezca sacrifiquebien. Ella entregaría el bebé.Si Ìká me ganaYo ascendería el trono del rey de Ìlá La maldad no me gana yYo ascendería el trono del rey de Ìlá
Ifadowole
3'´´'''''´´'´´''''''´´'''´´'''''´´´´'´´''´´''''''´´´´''''''''''''

You're Reading a Free Preview

Download
scribd
/*********** DO NOT ALTER ANYTHING BELOW THIS LINE ! ************/ var s_code=s.t();if(s_code)document.write(s_code)//-->