You are on page 1of 1

Ọbara Meji

I II II II I II II II

Osolo the priest of Awọn Casts divination for Awọn On the day he was going to wash his Ori of wealth in the river Would it be easier for me=? He asked They told him that it would be easy for him But he was advised to perform sacrifice to Ọṣun He offered the sacrifice Life then pleased him He started having children He afterwards took all his children to Ọṣun `Death must not kill the child of Awọn' they instructed Life pleased than so much Ọṣun took good care of him and his children And also petted them all He was dancing and rejoicing He was praising his Babalawo His Babalawo was praising Ifa He said it was as his Babalawo had said Osolo the priest of Awọn Casts divination for Awọn On the day he was going to wash his Ori of wealth in the river Osolo is here really He is the priest of Awọn Don't you all know that good Ori is what Awọn washes in the river?

Osolo Awo Awọn Lo difa fun Awọn Nijọ ti n lọ ree wẹri Ọla lodo Ara rọ Oun bayii? Wọn lara o rọ ọ Wọn ni ṣugbọn ko rubọ fun Ọṣun O ba rubọ Ara ba dẹ ẹ Ni ba n bimọ Lo ba ko ọmọ ẹ lọ fun Ọṣun Wọn niku o gbọdọ pa ọmọ Awọn Aye yẹ ẹ Ọṣun n tọju ẹ N n ge ẹ N ni wa n jo n ni n yọ Ni n yi awọn Babalawo Awọn Babalawo n yin Ifa O ni bẹẹ lawọn Babalawo toun wi Osolo Awo Awọn Lo difa fun Awọn Nijọ ti n lọ ree wẹri Ọla lodo Osolo mọmọ de o Awo Awọn Ẹ o mọ pOri rere lAwọn n wẹ