You are on page 1of 1

Ogunda Meji

I I I II I I I II

Gunnugun nii ṣe yigbo yigbo Akalamọgbo nii ṣe yigbo yigbon No one knows where it would be established the next time Cast divination for Lakannigbo The mother of Ọlọja mẹrindinlogun Don't you all know? All observers of rituals All you observers of rites Don't you all know that we all are running around because of wealth? The Vulture is here Gẹẹ Ore It was when we placed good thing on the ground That the Vulture stepped in

Gunnugun nii ṣe yigbo yigbo Akalamọgbo nii ṣe yigbo yigbon Ẹnikan o mọ ibi ti o sọlẹ si lọla A dia fun Lakannigbo Eyi tii ṣe iya Ọlọja mẹrindinlogun Eyin o mọ ni Gbogbo Isoro Gbogbo Isọpẹ Ẹyin oomọ pe are aje laa n saa kiri? Igun mọ de o Gẹẹ ore Igba taa gbe ohun rere kalẹ Nigun wọle de