You are on page 1of 2

rificar doenças

Odù Ọ̀bàrà-Bogbè (Ọ̀bàrà-Ogbè)

Ikú yò ó
Àrùn yò ó
A Dífá fún wọn lóde Ìdó
Ọmọ atannà rorò le ikú lọ o
Ọmọ atannà rorò le àrùn lọ o
Ọmọ atannà rorò le gbogbo irunbi lọ o
Wọn ní wó n kàrá nlé, ẹbọ ní ki wọn ṣe
Wọn gbẹ́bọ, ó rùbọ
Njẹ, Ikú tó ń bẹ nílé yìí kó máa lọ o
Òwìrìwìrì, a ó finá Ifá wì wọn lára o
Àrùn tó ń bẹ nílé yìí kó d’ẹrú rẹẹ kó máa lọ o
Òwìrìwìrì, a ó finá Ifá wì wọn lára o
Gbogbo àìsàn (Vírus Ebola) tó ń bẹ nílé yìí kó d’ẹrú rẹẹ kó máa lọ o
Òwìrìwìrì, a ó finá Ifá wì wọn lára o

Tradução:
Morte, afaste-se!
Doença, afaste-se!
Consultou-se Ifá para os habitantes da cidade de Ìdó
A descendência do clã que usa o fogo para espantar a morte;
A descendência do clã que usa o fogo para espantar a doença;

vamos queimá-los com o fogo de Ifá! . a morte da casa arrumou suas malas e se foi Òwìrìwìrì. Então. vamos queimá-los com o fogo de Ifá! Que todas as enfermidades (Vírus Ebola) desta casa arrumem suas malas e se vão! Òwìrìwìrì. Eles aceitaram e realizaram o ẹbọ. Para que vencessem todos os males. vamos queimá-los com o fogo de Ifá! Que a doença desta casa arrume suas malas e se vá! Òwìrìwìrì. foi-lhes recomendado que realizassem ẹbọ.A descendência do clã que usa o fogo para espantar todos os males.