You are on page 1of 1

Oriki a eshu

Eshu laalu, Ogiri oko, Onile orita.
Oba elekun sun ekun,
Elekun n sun ekun-
laaroye n sun eje
Eshu masemi , Omo elomi ni kio se ooooooooooooooo
Ela rowa 3x, Ifa rowa 3x, Orunmila kio rowa 3x,
Bio ba roko kio de Ifa 3x, Ifa bio ba rodo kio bo 3x,
Ere tete n teku agege 3x, Abiamo kii gbekun omo re ko duro 3x,
Abiamo kii gbekun omo re komo tati were. Haa Ela ro, ela ro, ela ro!!

Oriki a otura meji
Pere nio toni se, adifafun Otu tiun sawo rode ipapo,
won ni okale eboni kowase. ogbebo lopo lopo orubo,
Igba Otura ru ahun meji lola yebe- yebe bi Oba ereke