Opé ni fún Olórun. Ìbà Olódùmarè, Oba àjíkí. Mó jí lòní. Mo wo’gun mérin ayé. Ìbà Èlàwòrì.

Àgbégi lèré, là’fín ewu l’àdò, ènítì Olódùmaré kó pà’jó e dà, Òmò Olúworíogbó. Ìbà’se ilà Oòrùn. Ìbà’se iwò Oòrun, Ìbà’se Aríwá. Ìbà’se Gúúsù. Ìbà Oba Ìgbalye. Ìbà Òrun Òkè. ibà Atíwò Òrun. Ìbà Olókun à – sòrò – day ò. Ìbà af éf é légélégé awo ìsálú – ayé. Ìbà Ògègè, Oba. Ìbà títí aiyé ló gbèré. Ìbà Oba awon Oba. Ìbà Òkítí bìrí, Oba ti np ‘òjó ikú dà. Ìbà àté – ìká eni Olódùmaré. Ìbà Òdému dému kete a lénu má fohun. .Ìbà’se awón ikù emesè Òrun……………………... Ìbà Orí, Ìbà Orí inú. Ìbà Ìponrí ti ò wa’ l’Òrun. Ìbà Kórí. Ìbà Àjàlà – Mòpín, Ìbà Ódò – Aró, ati Ódò – Ejé. Òrun Orí nilé, e óò jíyín, e óò jábò oun tí e rí. Ìbà Èsú Òdàrà, Òkunrin orí ità, árà Òké Ìtase, ào fi idà re lálè. ibà Òsóòsì ode mátá. Ìbà Ògún awo, Oníle kángu – kángu Òrun. Ìbà Obàtálà, Òrìsà Òséré Igbó. Oni kùtúkùtú awo òwúrò, Ikù iké, Oba pàtà – pàtà ì won gb ‘odé ìranj è. Ìbà Yemoja Olúgbè – rere. Ìbà Osun oloriya igún aréwa obirin. Ìbà Òlukósó aira, bàmbi omo arigbà según. ibà Àjáláiyé Àjàlórun Oya Olúwèkù. Ìbà Ìbejì orò. Ìbà Ajé – ògúngúlùsò Olámbo yeye aiyé

Ìbà Awòn Ìyáàmi, Alágogo èìswù á p’oni ma hagun. Ìbà Òrúnmìlà Elérì ìpín, Ikú dúdú àtewó. Oro tó sí gbógbó òná. Ìbà Awo Àkódà. Ìbà Awo Àse dá. Ìbà Ojubo ònòméf à

I.- ORIKI ESU I ba rabo o mojuba I ba rabo o mojuba I ba rabo o mojuba I ba kose omo deko Elegbara Elegbara Elegbara Omojuba Èsù Elegbara Èsù lòna Odara Kolori eni ijo So so so abe Kolori eni ijo Èsù tiriri Bara abebe Tiriri lòna Mojuba Èsù. Àse Itumo (Traducción) ADURA ESU Esu mase pekun Esu mase pekun Esu mase pekun Esu jeki ahon mi Ki ohun bara bara bara Jeki oro mi ni gba inu orun. ORIKI OGUN Mojuba Ogun Mojuba Ogun Mojuba Ogun Ogun osin mole Ogun awoo a laka aiye Osinmole Ogun pele o Obu Akaluusin Asogun Ogun onile owo, Olona awo orun Ogun mo ona amo fun mi Jeki ififun mimo ni serere Ogun jeki ohun mi ni gbo inu orun Ase Modupe Ogun. Ori “Mo sú re fun ori.” Jeki ori mi a gbe mi. Jeki mo ri rere orisa mi Mo su re fun ori. Àse.

Ori Alata toro ewon oduduwa eni ara ro ni i raro mo Babalá rére ló d´ifá ori Ori nti orun bo w´aye Won ní kí orí rú bo Orí rú ebo Orí t´ó w´ayé t´o l´oun o ni l´owó Oso mo f´orí mi sun o ifá jé kí ní owo l´ ode ayé Osún Orí to w´ayé t´o l´oun o ni l´ aya tabi l´oko Osun Mo f ori mi sun o ifá jé ki nl´ aya tabi l´oko l´ode aye Ori t´ ó w´ ayé t´o l´ óun o ní iré Osun mo f´ orí mi sun o ifá je ki nní iré gbogbo l´ode ayé Ori Ká jí ni kutukutu Ká mú ohun ipín ko´pín D´ifá fún Olomo-ajíbá´re-padé Emi ni mo jí ní kutukutu ti mo f ohun ipín ko´pin Emi ni mo bá iré padé lí óla Orisa mo pe o………………. Mo pe o sotito Mo pe o iwa rere Mo pe o ire Mo pe o sawo Wa de de wa IKIN Mojuba re…………………. Baba o Iya mi Mo jí mo kí o,orisa mí Pele o orisa mí Eni rowo m oba Orisa sere o Eni ko rowo a ja Wara wogbo lo

Mo jí mo ki, orisa mi …………….. Ji oooooooooooooooo Mo jí mo kí o O jí ire o O jí ire o, òrìsà mí ORIKI OBATALA Obanla O ri n’erù Òjíkùtù sèrù Oba n Ile Ifón, Alábáláse Oba patapata n ilé Irànjé O yó kelekele, O ta mi l’ore; O gbà a giri l’owo osika, O fi l’emi asoto l’owo; Oba Igbo, Olùwaiye rè e o, Ke bi owu là, O yi lalà, O sun l’álà O fi koko álà rumò Oba Ìgbò YEYE IPONDÁ: Iya mi o ma jíre o, Iya mi, Iponda wá lokunkun. Pele ojú re tan de odo mi. Omí a san rere w’osa. Ipondá o ma jire o. Obinrin jenjenlé, Bi eni p’ega, yeyé mi. Emi lomo Ipondá. Ipondá ariwaju reyin. Ipondá gbe mí o

ORÍKÌ ELA Ela omo osin. Ela Omo Oyigiyigi ota omi. Awa di oyigiyigi. A ki o ku wa. Ela ro a ki o ku mo, okiribiti. Ela ro (Solake) Orunko Ifá. Entiti ngba ni l’a. Nwon se ebo Ela fun mi. Ko t’ina, ko to ro. Beni on (Ela) ni gba ni la n’Ife, Oba – a – mola. Ela, Omo Osin mo wari o! Ela meji, mo wari o. Ela mo yin boru. Ela mo yin boye. Ela mo yin bos is e. .Ela poke. Eni es i so wa s oro odun. Odun ko wo wa sodun. Iroko oko. Iroko oko. Iroko oko. Odun oni si ko. Ela poke. Ela ro. Ela ro. Ela ro, ko wa gbu’re. Ela takun wa o. Ela ro o. Eti ire re. Ela takun ko wa gbu ‘re. Enu ire re. Ela takun ko gbure. Oju ire re. Ela takun ko wa gbu ‘re. Ela ma dawo aje waro. Ela ma d ‘ese aje waro. Atikan S ikun ki oni ikere yo ikere. Ipenpe ‘ju ni s i ‘lekun fun ekun agada ni si ‘ekun fun eje. Ogunda ‘sa, iwo ni o ns ilekun fun Ejerindilogun Irunmole. Ela panumo panumo. Ela panuba panuba. Ayan ile ni awo egbe ile, ekolo rogodo ni awo ominile. Eriwo lo sorun ko do mo. O ni ki a ke si Odi awo Odi. O ni ki a ke si Ero awo Ero. O ni ki a ke si Egún o s us u abaya babamba. A ke si Ero awo Ero, ke si Egún o s us u abaya babamba a ni eriwo lo si Orun ko de mo, won ni ki Ela roibale. Ela ni on ko ri ibi ti on yio ro si o ni iwaju on egun. Eyin on o s us u agbedem ‘nji on egun o s us u, awo fa ma je ki ‘iwaju Ela gun mori on tolu. Òrúnmìlà ma je ki eyin Ela gun mosi Olokarembe Òrúnmìlà ma je ki agbedemeje la gun Os us u. Ela ro. Ifá ko je ki iwaju re se dundun more on tolu. Ela ro. Ifá ko je ki eyin re se worowo. Ela ro. Ela ni ‘waju o di Odundun. Ela ni eyin o di Tet e. Ela ni agbedemeji o di worowo. Ase.

ORÍKÌ ELA Ifá l ó l ‘òní, Ifá l ó l ‘Òla, Ifá l ó l òtounla pèlú è. Òrúnmìlà lo nijó mérèèrin òòsá dá ‘áyé.. Èlà mo yìn burú. Èlà mo yìn boyè, Èlà mo yìn bos ise. Èla rò. Èla rò. Èla rò. Mo júbà o, mo júbà o, mo júbà o. Òrúnmìlà mo pè. Òrúnmìlà mo pè. Òrúnmìlà mo pè. Ifá mo pè. Ifá mo pè. Ifá mo pè. Ifá ji o Òrúnmìlà, bí o lo l ‘oko, ki o wá lé o, bí o lo l ‘odo, dí o wá lé o. Bí o lo l ‘ode, kí o wá lé o. Mo júbà o. Mo júbà o. Ifá rò wá o. Èlà rò wá o o. Bí ò n be lápá òkun. Kó rò moo bo. Bí ò n be ní wánrán oojúmo. Ase.

ORUNMILA Eni a bá wá de lá a bá re´le Eni ajá bá wá ni ajá mbá lo D´ifá fun eji koko iwori Eyi ti yó te´jú mo akápo re giri giri Ifá te´jú mo mi ki o wo mí ire Eji koko iwori Ifá te´jú m+o mi k´o wo mi ire Eji koko iwori Ifá te´jú mo mi k ´owo mi ire Eji koko iwori Ti o bá te´jú mó mi ma á l´ owó lí owó Eji koko iwori Ifá té´jú mó mi k´o wó mi ire Eji koko iwori Ti o bá te´jú mó mi ma á ní´re gbagbo Eji koko iwori Ifá te´jú mó mi k´o wó mi ire Eji koko iwori

Ìreè-Òpère Ayé ni rére Àwòní jòjò Àwon ni wón dífá fún Òrun-un-mi-Òrun Àwon ni wón dífá fún Èla mi Èla Ifá ní tení bá jí Kéni ó sá maa kí.ni Aláìkíni sá lodi eni o Òrúnmìlà mo jí Mo kí o lónìí Omo Olókùn ràn mí lówó Ò bá ràn mí lówó Kí n gbórùn lé seguí o Eni tó bá tètè ká lá Ni yóó ká sègi Ifá seguí lèmi í ká Èmi òká.kàn nílé Ìsófín Díá fún Òrúnmìlà Yóó tún Orí Akápò o rè se Ifá jé kí n lówó Kí wón kí mi kú orí ire Ifá jé kí n l.áya Kí wón kí mi kú orí ire Ifá jé kí n bímo Kí wón kí mi kí orí ire Ifá jé kí n níre gbogbo Kí wón kí mi kú orí ire E kú orí re làá kí eni tó bá lówó E kú orí re làá kí eni tó bá l.áya E kú orí ire làá kí eni tó bá níre gbogbo Ifá jé kí won ó fi ìlú jìn mí o Gbogbo Òtòòkùlú níí filúú jìn oríjìn

La muerte no conoce a un Awó, el cielo no conoce un médico. La

muerte mató a Olamba y preocupó al rey de Ejio extensamente. Esta mató a Eji– Ogogo– Agbebikopon´wola. El viento en el lado derecho está dando que hacer a la hoja de coco violentamente. El viento en el lado izquierdo está dando que hacer a la hoja de coco violentamente. Ifá fue adivinado para Orunmila Agbonniregun, quien iba a hacerle Ifá a la muerte (Iku). Él escogió Ago (excusa) para que fuera el celador. La muerte que podría haber matado a Awó hoy, retrocede, retrocede. Awó está yendo, retrocede, retrocede. Awó está yendo, retrocede, retrocede. La enfermedad que podría haber matado a Awó hoy, retrocede, retrocede. Awo está yendo, retrocede retrocede.

1

Iretet Opere esekan ola Ayé ni rére Awo ni jojó Otara-tárá ni odo nsa Téré-téré ni omi eri nsun D´ifá won ní orun mí, orun oun A bu fún wo ní elá mi ela Eyin ará orun mi orun oun Eyin ará ela mi ela Ifá ni ti bá ji Kí eni má a kí´ni Alái kí´ni ni odi eni Ifá mo ji mo kí o l´ónií mo yin´ború Ope agunká mo jí, mo kí o l´ónií mo yin´boye Ifá mo jí mo kí o l´onií, mo yin´bo sise
1

Ifá o jí ire l´oní,. Mo rí oyin ná Ope agunká o ji ire l´onií, ajija mogbe isele Ifá o jí ti kikan ekun, ogidan tii m´oju ogun le Ifá o jí ire l´ onií omo olire Ifá o ji ire onií enikan saki bí abi Ifá o i ire lónii omo elépo pupo ko gbódo j´adin Ifá o ji ire l´ onií , omo eléran pupo ko gbódo je eran ti ó ni egungun Ifá o jí ire l´onií elekuru tebo-tebo elé idó Ifá o jí ire l´ onií omo okan s´ayé lébé-lébé bí abá owú Ifá o jí l´ onií omo ihoró etí ko´gb´eleji ní rínrin Ifá o jí ire l´onií, omo etí ibá gb´eleji ní rinrin, mba mú owó rindo má mú pon omi re e wá si´le. Ifá o jí ire onií omo olókun na mí kí ngb´ese lé sui Ifá o jí ire l´onií barapetu o ji ire Ifá i jí ire olí onií omo olókun ranmi.ranmu eni eti odi Ifá o jí ire l´onií omo eyití o ba teke ka´lá ni y o tete ká ikán Ifá o ji ire l´onií omo eyitó o bá tete ká ikan ni y´o tete ká ororo omo okan sofinni Ifá dákun má se jé ki o pé ki o tó gbé mi Ifá má se, je o pé kó o tó la mi Ifá tori ewé dá ´monito li i fi itó d´ola kí o tó da mo Ifá dákun má se jé kí owo tán l´owo mi kí nto ni omiran si Nitori wipé ERU ki i tán ní´bi wón ti nje e Ori i mi di ori efun adó nígbayi o. Eni rere e t´oke r´ré wá, ki e wá bá mi o, eni rere Kí e wá bá mi t´owó t´o mbe l´owó o yin. Eni rere e ti oke reré wá, ki e wá sin mi o, eni rere. Ifá dákun ti mo bá se o f´ri jun mi Igba ni ewé oríjin, won ka saí fi oran t´emi jin mí o, igba l´ewé orijin Torí ti akuko adiye bá ko keke-réeke, a fi ona han awon asina. Eni rere e t´okeere wá ki wá sin mí t´ owó owó o yin

Iwure a ifá para Dinero, de irete Osé (irete alaje) Oponsa l´otun un Oyé be s´osi Agbedegbe orun han firi firi firi O s´owo oje yanrna yanran Olú ibini pele o Agba ibini pele o Omo ari´gba akara digbe Olomo sin-in-ringingin Olomo sin-in-rinringin es un nombre alabado Awon lo se ifá fu orunmila Won ni odun odun ni ni ola ifá pe Orunmila ni t´ o ba je odun ni ni ola t´oun ba pe, awon wo ni ki oun de si Won ni ki o ke si alaba Won ni ki o ke si alase Ki o ke si awon agba girisa Ki o ke si awon adelé Ii o ke awon adebiopom eyinkunle orunmila Mo ba omi kan o nsan tere tere tere .Mo ba omo tun tun a bi atelese roki roki Ase awon ni won fi kokoro ola temi le l´ owo Omo tuntún o to gege ki o silekun ola te mi fun mi Ewe abiyindin lo ni ki gbogbo ire o bi yindin sime n´ile Apada lo ni ki aje o pa ri da wa si odo mi Ifá ma ma je ki nmu ire temi ti l´aye Nitori wipe enu eja ki i b´omi l´odo Irete alaje se aje were were temi wa a ba mi ase .

Sign up to vote on this title
UsefulNot useful