You are on page 1of 1

Do Livro "Cantando para os Orixás" , de Altair B Oliveira, Altair T'Ogun

1- Lóòtun l'ààbò, igbó Òrìsà a kofà awo
2- Oníigbó olóodò wà nilé
3- Olóode pa eron olóodò epeja. Oba omi níìbú, olóode pa eron. Aláamòn Òrìsà
4- A kofà àgò Òrìsà igbô Ode àáròlé ó. Àáròlé ó Òrìsà Ode Ode ní ó Òrisà igbó
5- Kéere-kéere ode ó, kéere-kéere ode ó. Olóòrisà ké mi má sá, ké mi mò awo. Òrìsà ode igbó ó
dé ti ó kú eron, ode igbó ti kó là, ode igbó ti kó là, bàbá ode igbó ofà isè isè lè sórò
6- Bàbá ode ewé èjè, bàbá ode ewé èjode ewé èjèè. Ní igbó ní bàbá Òrìsà ní igbó ní bábá Lògún
n
7- Ó igbó ó Lògún ó a ode ki igbó ní ó bì igi. Igbó ewé ofà rè níigbó Lògún Ode, Lògún Ode, L
8- Ofà ode ba yíìrá ó níigbó l'óodò kòkè
9- Alákétu re sààlò ti ó dára, sààlò ti. Ó dára àáròlé sààlò ti ó dára
10- Báàyìí láse onílá ó ki a bo òní
11- Àgò lé àwa dàgòlé lé, àgò lé àwa dàgòlé lé
12- Ode ó àyè ode ó àyè
13- Àwa wò ode nílé wa, ode ki fíigbó
14- Ó báàyìí láse omi ró, ode báàyìí láse miró. Láé-láé ó ni tofà dode, ode ni tofà
15- Ofà ní ó gbé wa kòséni Lògún ó
16- Olówó a kofà rè a kofà rè wo, é a kofà. Ijó ijó Lógún ó é a kofà
17- A Lògún e máà kòofà, ode lònòn. E máà kòofà, olórí gún e máà kòofà
18- Aé aé Ode Lógún. Ode Lògún ní báàyìí. Aé aé Ode Lógún. Ode Lògún lofà mòn
19- É é é é é, é Lógún dé lé k'òkè
20- É Lògún eron eron pa Lògún pa, Lògún pa
21- Àiyé oba ní sà Lògún dé lé rè. Àiyé oba ní sà Lògún dé wa
22- Lògún ode kò ìyà kò ìyà, Lògún ode kò ìyà. Ijó ijó fíríi l'àyà, Lògún ode kò ìyà kò ìyà
23- Lògún wa olórí, Lògún a l'anu a ké njó
24- Lògún Ode e mòofà ó si òpó Lògún ará
25- Alá lá láayé é é ode máà nsé
26- Ó gbàyìí l'àse, Ode gbàyìí l'àse ó
27- E alá lá àiyé àwa njéé-jèè Ode àgbóòròn