You are on page 1of 20

Sã wá a dé.

Dá a dé Olókun.
Sawà a dé
Dá a dé Olókun.

Sã wá a dé.
Dá a dé Olókun.
Sawà a dé

Iworo
Dá a dé Olókun.
Sã wá (a) dé.
Dá a dé Olókun.
Sawà a dé

Eeee
Dá a dé Olókun.

Sã wá a dé.
Dá a dé Olókun.
Sawà a dé
Eeee
A wá Onílè.

A wá èrò

A wá Onílè.

A wá èrò
A wá ní Olókun

A wá èrò

Dá (a) dé Olókun.

Sã wá (a) dé.
Dá (a) dé Olókun.

Iworo
Dá (a) dé Olókun.
Sã wá (a) dé.
Dá (a) dé Olókun.
Sawà (a) dé

Agána Erí
Dá (a) dé Olókun.

Sã wá (a) dé.
Dá (a) dé Olókun.
Sawà (a) dé
Eeeee
A wá Onílè

A wá èrò

A wá Onílè

A wá èrò
Óketé óma

A wá èrò

Dá (a) dé Olókun.

Sã wá (a) dé.
Dá (a) dé Olókun.
Sawà (a) dé

Dá (a) dé Olókun.
Sã wá (a) dé.
Dá (a) dé Olókun.
Sawà (a) dé

Éooo
Olókun
Ìyà gbà, gbà wa o
Olókun Bàbá o
Ibú Asesú
Oló omí dára

Ibú Ashabá

Oló omí dára

Awó yo, le mi sí
Enì Yemayá

Olókun
Mofòribalè

Imò sitó, (I)mó sitó


Olókun l’adé
kó (ọ)mọ şókótó

Imò sitó, (I)mó sitó


Olókun l’adé
kó (ọ)mọ şókótó

Imò sitó, (I)mó sitó


Olókun l’adé
kó (ọ)mọ şókótó

Imò sitó, (I)mó sitó


Olókun l’adé
kó (ọ)mọ şókótó

Imò sitó, (I)mó sitó


Olókun l’adé
kó (ọ)mọ şókótó
Imò sitó, (I)mó sitó
Olókun l’adé
kó (ọ)mọ şókótó

Imò sitó, (I)mó sitó


Olókun l’adé
kó (ọ)mọ şókótó

Imò sitó, (I)mó sitó


Olókun l’adé
kó (ọ)mọ şókótó
A máā yó e.
Éeee

A máā yó e
Éeee

A máā yó e.
Éeee

A máā yó e
Éeee

A máā yó e.
Éeee

A máā yó e
Éeee

Aaaa mbá wá şíre.


A mbá wá ọ sìn
Aaaa mbá wá şíre.

Aaaa mbá wá ọ sìn

Aaaa mbá wá şíre.

Aaaa mbá wá ọ sìn

Aaaa mbá wá şíre.


Aaaa mbá wá ọ sìn

Aaaa mbá wá şíre.

Aaaa mbá wá ọ sìn

Aaaa mbá wá şíre.

Olókun là mi şẹ
A wá Òrìşà èwe kéde

Olókun Bàbá o

A wá Òrìşà èwe kéde

Olókun Bàbá o

A wá Òrìşà èwe kéde


Gbà wa Òrìşà;
gbà wa o ààyè

Gbà wa Òrìşà;
gbà wa o ààyè

Olókun gbà wa o

Gbà wa Òrìşà;
gbà wa o ààyè
Olókun Bàbá o
Bàbá Òrìşà,
Bàbá o ayé

Olókun Bàbá o
Bàbá Òrìşà,
Bàbá o ayé

Olókun Bàbá o

Bàbá Òrìşà,
Bàbá o ayé

Olókun Bàbá o

Bàbá Òrìşà,
Bàbá o ayé

Olókun
Agóoooo