You are on page 1of 62

APOSTILAS DE REZAS NA HORA DO

ITEFA!
1 OLODUMARE:
IBA OLODUMARE, OBA AJIKI AJIGE. OGEGE AGBEKIYEGUN OKITIBIRITI
OBA TI NAP OJO IKU DA ATERE KAIYE AWUSIKATU OBA A JOKO
BIRIKITIKALE, ALABURKUKE AJIMUKUTUWE OGRIBADIGBO OBA TI FI
IMOLE SE ASO BORA OLUDARE ATI, OLUFORIJI, ADIMULA OLOFIN AIYE
ATI ORUN.
A FUN WEN AKE WEN OWENWEN AKE BI ALA.
ALATE AJIPA OLOFA ORO OB A DEKA DAJO AWOSU SEKAN. OBA
AJUWAPE ALABA ALASE LORI OHUN GBOGBO.
ARABA NILA TI NMI IGBO KIJIKIJI.
OYIGIYIGI OBA AKIKU ATI OBA NIGBO, OBA ATENILE FORIGBEDI
AWAMARIDI OLUGBHUN MIMO TO ORUN.
ELA FUNFUN GBO O OBA TOTO BI ARO, PAMUPAMU DIGIJIGI EKUN
AWON ASEKE.
AWIMAYEHUN OLU IPA OBA AIRI. ARINU RODE OLUMORAN OKAN.
ABOWO GBOGBOGBO TI YO OMO RE, NINU OGIN AIYE ATI ORUN IBA
TO TO TO .

ORIKI OLODUMARE:
OLODUMARE MOJILONI MO WO GUN MERIN AYE.
IGUN KINI, IGUN KETA IGUN KERIN OLOJO ONI GBOGBO IRE GBA
TIOOBA WA NILE WA FUN MI TEMI, T AYA, T OMO, T EGBE, T OGBA .
WA FI YEYE WA KI OF F ONA HAN WA.
WA FI ELENI SETEMI.
A LAIYE O ALAIYE O. AFUYEGEGEGE MESEEGBE.
ALUJONU ENIYAN TI NF OWO KOLE.
A NI KOSI IGI MEJI NINU IGBO BI OBI EYITI O BA A YA KO A YA BIDUN
DUN DUN DUN .

2 ORIKI ELA:

IFA L L ONI, IFA L O L OLA IFA L O L O OTUNLA PELUE E ORUNMILA


TO MERIN OSA DAYE IFA RO WA O, ELA RO WA O O. BI O NIBE LAPA
OKUN.
KO RO MOO BO. BI O O NI WANRAN OOJUMO.
IFA DI ORUNMILA BI O LO L OKO KI O WA LE O BI O LO L ODO DI WA
LE O, BI O L O L ODE KI O WA LE O.
MOJU BA O MOJU BA O MOJU BA O ASE ASE ASE.

ORIKI ELA:
L S O OGBO S OGBO.
L S ATO S ATO.
F ODUNDUN S OBA EWE
F IROSUN SOSORUN R ;
FOKUN S OBA OMI.
F OSA S OSORUN R.
-S EYIN WA S EIYN BO.
WON N ELA S AYE RE.
L BINU TA KUN O R RUN.
OMO ARY WA N KIGBE.
L DDR L O MAA SOCALE WA GBURE.
L DDR! L HIZO.

ORIKI ELA:
ORUNMILA ELERIMPIN IBIKEJI OLODUMARE AJE JO GUN OBIRITI A PI JO
IKU AS.
OLUWA MI AMOMIMOTAN AKO MO OTAN KO SE.
ABA AMO OTAN IBA SE KE.
OLUWA MI OLOWA AIYERE OMO ELESEIN ILE OYIN OMO OL OPE TO S
AN AN DOGI DOGI.
OLUEA MI OPOKI A MU IDE S OJU EKAN KO JE.

K EHUN HORA ASAKA AKUNOMO OSO GINNI T APA TI NI EWE NINI


OMO OSO PA DE MOWO PA DWE MESE O MBERRE AT EPA JO
OLUWA MI IGBO OMO IYAN BIRIKITI INU ODO
OMO IGBA TI N SOBE JIAJIA
IKU DUDU AT EWO ORO AJ EPO M APON
AGIRI ILE ILOBON A B A B OLOWA DIWERE M ARAN
OLOWUA MI ATO IBA JAIYE ORO A B IKUJ IGBO OLUWA MI AJIKI OGEGE
A GBAYE GUN,
ODUDU TI IDU ORI EMERE OTUN ORI TI KO SAIN SE,
OMO EL EJO TI NRIN ODE WA SAKA SAKA.
ORUNMILA ABORU ORUNMILA ABOYE ORUNMILA ABOSISE.

3 ORIKI ORUNMILA:
IFA OLOKUN ASORO DAYO
ELERIN IIPIN, IBIKEDI OLODUMARE.
ORUNMILA NI BABA WA, O E AWA KO NI OBA MEJI, IFA TO OBA O
ORUNMILA NI BABA WA IFA TO OBA O KA MO KA LA O KA MA TETE KU,
AMOLA IFE OWODAYE.
OKUNRIN DUDU OKE IGETI,
OLUWA MI AMO TAN OLUNAAMI OKITIBIRITI
TI NPOJO IKUDA A KO MO O TAN IBA SE ,
A BA MO TAN IBA SE, A BA MO TAN IBA SE.
BARA PETU BABA KEKERE OKE IGETI,
ORI AS TI O FI GBOGBO AYE FI OJU ORORI SI PATAPATA.
A BI ARA ILU BI AJERE,
ORISA TI NGEBE NKAN OLE GUN FA GUNWA OKO OKEKU.
OLOMU NLA A BO NI MA RU BABA ESU ODARA ORI SA TI
NGBA NI LOWO ENI TI O NI IKA NINU

BABA AKERE FI INU SE OGBON,


OPITAN IFE A FUN NIDA.
A TUN ORI ENI TI KO SUNWON SE,
FONRON OWU KAN SOSO AJE JU OOGUN,
ARA YWORAN NI IBI TI OJU RERE TI IMO WA,
BABA ELEPO PUPO MA JE ADIN.
ONILE ORI OKE TI NI AFOPIN EYE SAYE SORUN IBINI ATO I FI ARA TI
BI OKE.
OGEGE AGBE AYE GUN AGIRI ILE IL OGBON,
OMO ADO BABA TI I W EWU OOGUN AJANA ETA TI I NU ORI
EKUN NSE BO SURUSURU.
ORISA KO AJE. OLOJHOBAN A RI APA ERAN SE OGUN,
ASE EYI TI O SORO ISE.
EDU OLOJA ORIBOJO OBA A TUN OMO DA BI EWU,
OKURIN ATO EYIN ERIN NI FIFON
OKITIBIRITI A PA OJO IKU DA.
IKUFORIJI.
OBA OLOFA ASUN L OLA.
ERINTUNDE. OMO EJO MEJI.
AKERE SOGBON.
AKONI L ORAN BI IYEKAN ENI
AFEDEFEYO.
IKU DUDU ATEWO ORO JE PON MA PON, ORO A BA IKU J IGBO
ELEEI IPIN AJE JO GUN
ORUNMILA IFA OLOKUN ASORODAYO.
OLOORERE AIKU JE JOOGUN.
BA MI WO OMO TEMI YE O

AJI PA OJO IKU DA.

ORIKI ORUNMILA:
OLODUMARE MO JI LONI MO WO GUN MERIN AYE.
IGUN KINI IGUN KEJI IGUN KETA IGUN KERIN OLOJO ONI.
GBOGBO IRE GBA WA TI OBA WA NI LE. WA FUN MI TEMI.
TAYA TOMO TOGBE TOGBA
WA FI YEYE WA. KI O OF FONA HAN WA.
WA FI ENI ELENI SE TEMI.
ALAYE O ALAYE O. AFUYEGEGEGE MESEEGBE.
ALUJONU ENIYAN TI NFOWO KOLE.
A NI KOSI IGI MEJI NINU IGBO BI OBI EITI O BA YA KO YA.
ABIDUN DUN DUN DUN ALAYE O ALAYE O.
IFA WA GBO TEMI, ESU WA GBO TEMI.
JEKI ENI YE MI, JEKI ENI YE MI, JEKI ENI YE MI.
KI OLA SAN MI T AYA, T OMO, T IBI, T IRE, LO NIRIN PAPO NI.
ILE AYE. WA JEKI AYE MI. KIOYE MI. ASE

ORIKI ORUNMILA :
ETI NIGBO INXOMO ELA.
ETI INFO AWO OMONI PAXA NIFE XETI WERE DJI,
OMO AGBONIREGUN, ORUNMILA TE ETI,
KI O O BORRUN TI UM MA FO,
IFA XETI WERE WERE DJI WERE,
IFA XETI WERE.
KI OGBO MOKAN XETI WERE,
KI OGBO MORE
DJE XETI WERE,

KI OGBO MOKAN XADJAMO


OMO EGUNGUN ONIFE,
TI UM XA MARIWO APA KO
KI UNTO WA LONI
MOTI JUBA AKO DA
MO TI JUBA ASE DA
MO TI JUBA ERIN MI
NILE ADO
ARAGBA LO TU IFE.
GBOGBO IN KAN TI MO
BA SO LONI
KI O LO SILE
ASE, ASE, ASE,

ORIKI ORUNMILA:
ORUNMILA DAKUN DABO,
AKODA KUN DABO KOYE SESE.
ORUNMILA ELERIN IPIN AJE JO GUN.
IBIKEJI OLODUMARE AKOKO OLOKUN ASORO DAIYO.
AJA IKOTO ARA ADO ARA EWI ARA OKETASE ARA OJUMO.
IBITI OJO TI NMI WAYE ARA OKE OGETI OKEJI OJE
ERIN FON O LAGILAGI OKUNRIN TI NMO ARA OGDAN LE ALAKETE
PENNEPE.
PARI IPIN OLO TO KAN TOKU LAYE,
OBA IKU JA GBA OMO RE SILE ODUDU TI NDU OR EMERE,
MA BA JO OTUN ORI TI, KO SUN WON ASE ASE ASE.

ORIKI ORUNMILA:
ORUNMILA BARA AGBONIREGUN,

ADESE OMILESE A MO KU IKUFORIJI OLIJENI,


OBA LOFA ASUNLOLA NINI OMO LONI
OLUBESAN ERIN TUNDE ABIKUDIGBO ALAJOGUN IGBO OBA IGDE,
PARA PETU OPITAN ELUFE AMORANMOWE DA ARA RE ORUNMILA IWO
LO O KO OYINBO L ONA,
ODUDU PASA AKI IGBO OGUN I LAJULE ORUN DA ARA ORUNMILA A KI
IFAGBA,
MERINDINLOGUN AILE K ASINA
MA J AMA RO LERIN IPIN IBIKEJI EDUMARE FONANHAN NI
ORUNMILA
IBURU IBOYE IBOSE ASE.

ADURA ORUNMILA OLUWA MI AJIKI:


ILA JI ORUNMILA, ILA JI ORUNMILA ILA JI ORUNMILA.
MO JO MO KI ATOLA, MO KI ASULA.
MO KI ASURUNENENE. INA KU KU L AHERE.
ENIA KU KU L ABA ADIFA FUN OGOJO L IMO OGBOJO.
O NI TI AWO YO OGBOJO TI AWO YO OGBOJO.
NJ O LUWA MI MA JIKI TIRE YO O.
AWO AJIKI L AWO AJIKI AWO AJIKI L AWO AJIKI.
AWO AJIKI, L A IPE AWO AJA ALE GBHUN A DA A AWON META NLO BO
ORI ELU.
ORI ELU KO GB EBO LOWO WON.
AWO AJIKI L AWO AJIKI. AWON AJIKI L AWO AJIKI AWO. AJIKI L AWO
AJIKI.
AWO AJIKI LA IPE AWO AJA ALE GHUN.
A DA FUN IKI T O ON YIO BO ORI ELU.
YIO GBA IBO L OWO ON.
IKI JI O WEWO FINI.

O WA IMU OBI O NA A SI ORI ELU.


ORI ELU GBA LOWO RE.
ONI LOWO IKI ELEIYNJU EGE L A TO MI IBO E IGBANA NI IKI MEKU S
EKUN IGBE.
O M OHUN YERE NKORIN WIPE.
GB OBI PA O! A WO AYE GB OBI PA O AWO AYE GBO OBI PA O AWO AYE
ASE.

ORIKI ORUNMILA:
ALAPANKO AWO MA JU AWO LO
AWO LE GBAWO MI TORITORI
ODIDERE FO O GORI IROKO
O FI OHUN JO AGOGO LO SE IFA FUN IFAKOREDE
A REMO OLODUMARE OMO ATE ENI TEM KO TO FI
ORI SE AGBEJI ARA.
O NI E BA MI SO FUN ALARA E PO MO RIREO NI E BA MI SO FUN AJERO
E PE MO RIRE
IRE TO SOUN IRE DE IRE TO
SONU IRE DE
BI IRE BA WOLE E JE KI A NA SUNRU SI NI INU BA LE LALE JU IRE O
WOGBO
AGBO YAYAI ARAIN OMOM NI SUN
MO GO PORO LALEDE OMO WEERE W ABA MI HESAN
OLOGBO JI GOLO AWO AWO LILE AWO
OLONI ADIPON YAYA NI IGODO AWO LO SO OKA AWO LO SE ERE
AWO LO EKUN LANIN AWO MAA REE AWO AWO LILE AWO ASE.

ORIKI ORUNMILA:
ORUNMILA AJAMIRANRA AGBONIRTEGUN IBI KEJI
OLODUMARE ELERIPIN

OMO OPE KAN TI NI SORO DOGI DOGI


ARA ADO ARA EWI ARA IGBAJO ARA IRESI,
ARA IKOLE ARA IGETI ARA OKE ITASE,
ARA IWORAN IBI OJUMO TI NMO WAIYE,
AKOKO OLOKUN ORO AJO MA PON,
OLAGO LAGI OKUNRIN TI NMU ARA OGDAN LE,
OBA IKU J GBA OMO E SI LE
ODUDU TI NDU ORI EMERE O TUN ORI TI KO SUNWON SE,
ORUNMILA AJEKI, ORUNMILA AJEKI,
ORUNMILA NI O DI FI ORO RERE L O ASE.

ORIKI ORUNMILA:
ORUNMILA MO PE, ORUNMILA MO PE, ORUNMILA MO PE
IFA MO PE, IFA MO PE, IFA MO PE,
ODUDUWA MO PE ODUDUWA MO PE ODUDUWA MO PE.
IGI NLA SUBU WONAKANKAN DETU ORUNMILA NI O DI DARAJ
MO NI O DI DARAJI. ASE ASE ASE.

ORIKI DOS OLODUS PARA CONSAGRAO


ORO OPELE E CONSAGRAO DE
ORUNMILA:
EJIOGBE MEJI:
ALELEKUN LOO JE E E OMI NI NKUN
ERIN O SE YI PA DA KUN
ATATA BI AKUN OKUNRIN KUN
KUN KUN LORU
AKO AJA LOLA

AKO AABALA LOSU


OMO ABOKUN
OMO ENI WON ABOYINDE
OMO ENI OSE DI JE LEKE
KAFI LEKE SI TO MO
ELOMIN
OMO ENI
LOMO ENI JEE
A DIFA FUN ORI DESE PUPA
TOKE APA
TITIKU TARUN NKALE RE RE
AJOGUN GBOGBO NKALE RE
NI LILO NI LILO
ONIKUN NA SO NI BO DEDE PA
ASENIA MO, ASNIA MO
KI ARUN MA SE ONIBODE SE
ASENIA MO ASENIA MO
ASENIA MO
ASENIA MO.

ODU OYEKU MEJI:


AGBA YEKU YEKU ORI GBA
IGBA OWO AGBA YEKETE OSO KALE
ADIFA FUN OLOMO AWAIYE KU
WON NI O RUBO AIKU KO SE POPA
OGUN ODUN ONIO
OKENBE LAIKU GBOIN GBOIN

GBOIN GBOIN NI TOKE


OKE OKE GBOIN GBOIN
IGBA ODU ONIO
OKENBE LAIKU GBOIN GBOIN
GBOIN GBOIN NITOKE
OKE OKE GBOIN GBOIN
IGBA GBOGBO OKENBE LAIKU GBOIN GBOIN
GBOIN GBOIN NITOKE
OKE OKE GBOIN GBOIN

ODU IWORI MEJI:


IWORI MEJI KO BAKUN KO BA WA SE
PA BI O SE DA OSE DA LAWO WON LODE TORI
AKATANPO JAKUN ODO RIRI KALE
ADIFA FUN ORUNMILA
IFA LO NTAIYE OLUFE ORUN SOYE ENI TI SOGBA
TA NI IYO WA BA WA TAIYE WA WON IY SO
EWE ODEDE TI LEE SO
ORUNMILA NI OBAWA TAIYE WA WON YI SO
EWE ORERE TI LEE SO
BA RA PETU NI YIO BA WA TAIYE WA WON YI SO
EWE OPEPE TI LEE SO

ODU ODI MEJI:


ODI MEJI KODA KUN KO BA WA SE
ODI MEJI DIMA IKU DIMA ARUN
ODI MA KURU KURU WALE
OSA ABADA OYE BATA

SAKI NI O TORUN GBO BOROBORO


AFEWO ORUN DIFA,
NI AS AWO OSAIN NI KARO
AGBOFA ATAN GIRIGRI
TI MOMI OJU SOGBERE IRE GBOGBO
OTA BA WA KOWA A TAWA JO
ATAN GIRIGIRI BA WA ATAWA JO
OKE NI KO IWA EBE JO
OBA BA WA KOWA A TAWAJO
ATAN GIRIGIRI
BA WA KOWA A TAWA JO

ODU IROSUN MEJI:


IFA KODAKUN KODABO KOFIYEDENU
IROSU MEJI KODAKUN KO BA WA SE
IBA BURU NA LAWO IBA BURU
IBA BURU NA LAWO IBA BURU
IBA BURU LAWO IIBARAKATA
ADIFA FUN IIGBA
NIJOTI IGBA TO FI NS AWO RODE OYO0
IGBA
OYO NILE O IGBA
EMI LEEE WA DOKO
IGBA MO SEBO OLA TUTU IGBA
MO SEBO OLA TUTU IGBA
MO SEBO OSUN TUTU
MO WA UM GBERIGI ALO TAN ARA TU MI NININI

ODU OWORIN MEJI:


IFA KO DA KUN KODABO KOFIEDENU
OWORIN MEJI KO DA KUN KOBASE
OWON OWO ANNAWO
OWON OMI ANDESUN
OWON ONIJE NI LA NPE NIRIYAN
ADI AFUN YO WON
TI NSOMO OBA LEYO ADUN NI OBA
AJODA EEMI IGBA ARA
OBA AJESE YOKUN TOOTOO LEYO
ONI E SURE WA KE WA RAJA
OOMO OBA ENYIN EGBO OSESE WA
KE WA ROHON YOWON
ESURE WAO E WA RAJA OMO OBA

ODU OBARA MEJI:


ISE OSOHUN AMUSIE
IYA OSOHUN AMO SAWODA
A DIFA FUN EJI OBARA
TI NRA AGBON OLA
TI ABOGBA ARAIYE NRI ELEGDE MEREE
ELEGEDEE MEREE
EJI OBARA KI NLOTA
KI NLOTA TOOFI DA LAIYE
ELEGEDE MEREE.

ODU OKARAN MEJI:


OYA NI OSA A RA

KURU KURU OTA MANA MANA


AKO APARO
ABA APARO
WON LAABE LORI SAI SAN
LO DIFAFUN OLOFIN, OLOFIN NROTE
WON NI O GBODO KUTE ONASE
AYA RE NSOJOJO ARUN
WON NI O GBODO KU ARUN
OKAN BI OMO RE NI SO REGDE
WON NI E E FOREGDE KU
ONI DUDU GBA DUDU
ONI PUPA GBA PUPA
ALAYIRIN GBA AYIRIN
BARA PETU OBA MAMA KOKU O KARUN
BARA PETU

ODU OGUNDA MEJI:


OGUNDA MEJI AWO BOM
LO DIFAFUN BON
NIGBATI NIFI NJE NI ROPO OTA
ENU TI IBON FI NFOHUN
LOFI ISEGUN EROPO EROOFA
E WA BA WA ISEGUN
ARUISEGUN LAA BA NI LESE OBA ORISA

ODU OSA MEJI:


OSA MEJI KODAKUN KOBA WA SE
OSA MEJI LA KOJA
OOGUN YANKAN YANKAN LOJU OPON

ADIFA FUN OLUBAMBI OLUKOSO LALU


OMO ARIGBA OTA ISEGUN
NIGBA TI SANGO NFE NI BE LARIN OSIRI
TI OLUBAMBI TOFI NBE LARIN OTAA AIYE
NJE LARIRA FI SETE
LIGB OTA
LIGBOTA LARIRA FI SETE
LIGBOTA.

ODU IKA MEJI:


IKA MEJI KODA KUN KO BA WA SE
BA FADAKA
BA PADAKA
ADAKA
OOSALA NLO MASO AKADAKA
AKARA KARA OJU KANGANRAN
OKANJO ENIA DAWOJO WOKE
YANYAN EJO NI O OKOMO TIE
LEHIN YO YO YO MAJE
KANO OKO
ADIA DUN ALAYINRIN OKEPE
NIGBATI NFE NJE NIROGBUN OTA
ONI LAO PA YI NRIN
OLALAO PA YI NRIN
ENIKAN O LEE PA YI NRI MA O
TITUN LA TA YI NRIN SE
AYINRIN MAMO DE ARA OODE IWOYA

ODARA OODE IWOYA


ARA OODE LWOYA
ONI LAOO PA YI NRIN
OLALAOO PA YI NRIN
ENI KAN O LEE PA YI NRIN
ENIKAN O LEE PA YI NRIN MOO
TITUN LA TA YI NRIN SE
AYINRIN MAMA DE
ARA ODE LWOYA

ODU OTUROPON MEJI:


OTURUPON MEJI
ANI OSOHUN TO DOA
ADIFA FUN GANNI GANNI
OKE EYO TI O MA SOWO EGAN
KIRI KARI AIYE
AWA MAMA LOWO KEE MA YAN WA O
GANNIGANNI
EGAN O POYN MA DUN
GANNI GANNI MO MO LOWO NLE
EMO GAN MI O
GANNI GANNI
EGAJN O POYIN MA DUN
GANNI GANNI
MO BIMO KUNLE EMO GAN MI
GANNI GANNI
EGAN OPOYIN MADUN

GANNI GANNI

ODU OTURA MEJI:


AGBADA BALE OROKOGO
ITEWU BALE SE SII
ADIFA FUN BABAMALE
BEWO GEREJE TI O MA
FI GBOGBO AIYE SO FE JE
KIN LAJE NI LLARE E WA IFA

ODU IRETE MEJI:


ERUNYAN NFODO KETE
ADIFA FUN ATOKAA
EEYI TI SE LARIO OLODUMARE
LLARI OBA OROKO
EMI IIBA SE ILARI IFA
EMI AAYO SESE
LLARI OOBA OROKO
ERO IPO
ERO OFA
ENYIN OMO PE ILARI IFA
LEMI SE

ODU OSE MEJI


AGBALAKEE LA LE
ADIFA FUN ORUNMILA
IFA OO ISEGUN LAIYE
IFA OO SE TORUN
IFA ISEGUN LAIYE

IFA SE TORUN
ASE KOSI IRONMOLE BII IFA
IFA ISEGUN LAIYE
IFA SE TORUN
KO SI IRUNMIOLE
BII IFA

ODU OFUN MEJI:


IFA NI ADEOWOLE LAWO ALAJIKI
AIYETUTU LOWO AJIWORAN RERE
ADIFA FUN ORUNMILA IFA TOLOREGBE
AIYE TUTU NIYAWO
NJE IJIALO LO REGBE
AIYETUTU NIYAWO
AIYE IFA TUTU OJOMILO O
ONI AIYE IFA TUTU JOMILOOOO
AIYE IFATOTO OJOMILO YIAWO LO OGBE
AIYE IFATOTO NIYAWO AIYE TOTO OJOMILO

ORIKI OLODUMARE, DOS ODUS QUE SE


USA PARA CARREGAR EXU E ORIKI DE
EXU :
1 OLODUMARE:
IBA OLODUMARE, OBA AJIKI AJIGE. OGEGE AGBEKIYEGUN
OKITIBIRITI OBA TI NAP OJO IKU DA ATERE KAIYE AWUSIKATU
OBA A JOKO BIRIKITIKALE, ALABURKUKE AJIMUKUTUWE
OGRIBADIGBO OBA TI FI IMOLE SE ASO BORA OLUDARE ATI,
OLUFORIJI, ADIMULA OLOFIN AIYE ATI ORUN.
A FUN WEN AKE WEN OWENWEN AKE BI ALA.

ALATE AJIPA OLOFA ORO OB A DEKA DAJO AWOSU SEKAN. OBA


AJUWAPE ALABA ALASE LORI OHUN GBOGBO.
ARABA NILA TI NMI IGBO KIJIKIJI.
OYIGIYIGI OBA AKIKU ATI OBA NIGBO, OBA ATENILE FORIGBEDI
AWAMARIDI OLUGBHUN MIMO TO ORUN.
ELA FUNFUN GBO O OBA TOTO BI ARO, PAMUPAMU DIGIJIGI
EKUN AWON ASEKE.
AWIMAYEHUN
OKAN.

OLU IPA OBA AIRI. ARINU RODE OLUMORAN

ABOWO GBOGBOGBO TI YO OMO RE, NINU OGIN AIYE ATI


ORUN IBA TO TO TO .

ORIKI OLODUMARE:
OLODUMARE MOJILONI MO WO GUN MERIN AYE.
IGUN KINI, IGUN KETA IGUN KERIN OLOJO ONI GBOGBO IRE
GBA TIOOBA WA NILE WA FUN MI TEMI, T AYA, T OMO, T
EGBE, T OGBA .
WA FI YEYE WA KI OF F ONA HAN WA.
WA FI ELENI SETEMI.
A LAIYE O ALAIYE O. AFUYEGEGEGE MESEEGBE.
ALUJONU ENIYAN TI NF OWO KOLE.
A NI KOSI IGI MEJI NINU IGBO BI OBI EYITI O BA A YA KO A YA
BIDUN DUN DUN DUN .

ODUS QUE SE CARREGA ESU:


OSETURA:

OSETURA LADAFUN UNIBATILO LEAJA BENIJO


TETE NO NSJO INDA OIYN AFERE EWEWE

AIYANA DIDE AFERE WEWE AYABA


DIDE AFERE WEWE OSETURA OMI UNROSO ATI ASHA
OLODUMARE EBO MORESILE ODARA

ODU OSETURA:
OSETURA AWON ALARA LODIFA FUN ALARA
OMO AMURIN KANDAGBA AGOGO IDE
PSETURA AWO AJERO LODIFA FUN AJERO
OMO OGBOLU KORO IJALE
AJESE OGANNA IMASE
ADIFA FUN OSETERE OMO BUBA OYE OSEKE O JE KOMU
OSE NGBE BO RORUN WAYI IGBA NI OLUO DIDE
OKIKI EBO ASI KANKUN
AWA TETERU KOTETEDA
KEBO WA OTELEDELE OLODUMARE

ODU OSETURA:
OSE OTURA
GBA ERU KI EBO FIN
GBA ERU KI EBO DA
GBA ERU KI EBO DODE ORUN DAN DAN DAN
OSETURA TURA TURA TURA
OSE TURA (JUGANDO COM PALAVRAS)
DIFA FUN APARO YEYE
O NRE OKO ALERO L ODUN
IKU KII MO ILE ELEBO
ERO ONAKAN KII I MO ILE APARO
NKAN BURUKU KO NI MO ILE MI
TO NI TI OLUWO

TUFEEEE NI TI JUGBONA ORO TI AWO BA SO S ILE A DI EGUN


DIFA FUN ARUGBO A BI ETI KOKO O NLO BA WON NA OJA
EJIGBOMEKUM
TI OUN ASE L OWO
AKUKO NDA AJA ENI BA TI SUN KO DIDE

ODU OSETURA:
OSETURA LADAFUN ONI BA TILO LEAJA
BENIJO TETE NO NISHO INBA OYIN AFERE WEWE AIYANA DIDE
ARERE WEWE
PSETURA OMI UNROSO ATIE ASHA OLODUMARE
EBO MO IRE ODARA

ODU OSETURA:
PENPE LESEE
ELA AGEMO NI O TO GELE
IBA TO GELE
NBA UM RELE LOO WE
AD IFAFUN AWURELA
TI N SAWO RODE IJEBU
APEJIN LAA PE AWURELA
NI JEBU
OSE AWURELE AWO IRE NI O

ORIKI ODU OWORIN SOGBE PARA


CARREGAR ESU:
ODU OWORIN SOGBE:
ESU KU ORI EGBA KU ORI
A DIFA FUN WON NIJESA OMO EKUN

A DIFA FUN WONNI JESA OMO ERAN


A DIFA FUN ONI JESA OMO ENI
ALABE MA NRINGBATIE KO MA NYAA LO
OWORIN SOGBE KE ESU EGBA
OWORIN SOGBE KE ESU EGBA
OWORIN SOGBE KE ESU EGBA

ORIKI ODU OWORIN SOGBE:


OWORINSHONGBE TABAKOYU
BAIN IKU BAIN BAIN JOBATI
ADIFA FUN OUN BABALAWO
MERIDILOGUN TINLODIFA
ILE OLOFIN

ORIKI ODU OWORIN SOGBE:


OORE NI IGUN SE
NI IGUN FI PA L ORI
OORE NI AKALA SE
NI AKALA FI YO GEGE L ORUN
IJO MII IJO MII
KI ENI MA SE OORE MIO
DIFA FUN IJIMERE
TI NLO BA OLOKUN PESAN ODUN
WON NI KO RU BO
OGB EBO O RU
EGBE MI O
PEERE PEKUN OPE

ODU OKARAN SA PARA CARREGAR SEU:

ORIKI ODU OKARAN AS:


OKARAN AS
AWO EJO LO DIFA FEJO
EJO NBE LAARIN OTA NJE ITAKUN LAARIN OTA
NJE ITAKUN LEJO
TI OBA SI ORI
A BA MEJO DI IGI
ITAKUN LEJO
KI ORI GBE WA NIJA

ODU OKARAN SA:


OKARANSA MUKISI BILARI ONE BABALAWO BILORI OMA
BABALAWO LORUN KABOLOSI OBAKARANSA KOSHE SHANDO
ELO
ADAMAKOSI BILOR KOGUN GUN GUN ADIFAFUN IKOKO

ODU OKARAN SA:


ALEERE BIDI PETE
A D IFA FUN OWOOMO ASEKU MODI
OSIKALEKA NI NFI OWO OTUN GBE EBO FUNMI NI KI TOSI IGBA
MOFI OTUN GBE FUN MOSIFI GBAA
TOBA GORI OPON KOFIN TOBA OWO TOBA KANLE TAN ORN
ELEBO NI NLO

ODU OKARAN SA:


OKARAN SA
IYA IGBA O LE MO ON WE
KOMO RE O BERI LO
A D IFA FUN TENTERE OPE
TI NLO RERE GBE ELEBO LEKE

NJE BIKU NBO WA


KO GBE ELEBO LEKE
TENTETE OPE GBE ELEBO LEKE
NJE BIKU NBO WA
KO GBE ELEBO TENTERE
OPE
GBE ELEBO LEKE

ORIKI DE ESU NA HORA DO ORO

ORIKI EXU
2 ORIKI ES
Iba Esu Lalu
Esu oga onilu
Etobajaiye eleso ogun
Otili loogun
Aigada eye
Oroko-ni-ojo-ebo-Ie
Esu tabirigbongbon
Abonijawa-kumo
Esu olafe aseni-bani daro
Esu iwo se babalawo
Ojo metadinlogun 10 gbe odo oya
Esu ma se mi omo elemiran ni 0 se

Esu ma se mi lu enia lumi


Esu ki nkan ma se omo mi
Esu ki nkan ma se awon ara ile mi
Ma jeki a ri ija re
Iwo se oba ti won ti yo loye
Iwo se iyawo ti 0 fi ko oko re sile
Esu ma se mi omo elomiran ni 0 se
Iwo se enia to fi binu soku
Iwo se enia to fi ko soda
Esu ma se mi omo elomiran ni 0 se
Ibukun pupo ni emi fe lodo re
Esu iwo ni ilera
Abo igbega ire oro mbe Iowa re
Jowo ki 0 wa fun mi ni nkan wonyi
Esu elegbara gbo mi kiakia
Esu ma se mi omo elomiran ni ki 0 se
Ase ti Eledunmare
Eledunmare Ase

ORIKI ES

ALAKEGUN K RINGUN IERI


OJINLE AERE K RAIE MOKUNTELE
ARINJINA K ROJU RO MO RE TOL
JE KARON KARON GBE TIUA GBO
JE KARON KARON SORO ARA UA
JE KARON KARON GBE TAIE TARA UA
ORUK IF O LAPE ORUKO IF O LAPE
MO GBAIE PEFA E GBA MIO EGBA MILA
AI TOTO O E DARIJU MIO EIN MOPE
KASORIKI IF KASORIKI S
S BURUKU , S ON
S ABENUGAN, S ORIT
ORUKO GBOGBO IN MI MOPE LA PEPO
EJE OIE MI O LORUKO IYA MI OSORONG
ATOJE NUA TOKAN JE DO
EJ OIE MI KALE O

ORIKI ES

S, S DR, S, LLU KIRI K. KNRIN


OR ITA, A JO
LANGA LANGA LLU.
A RIN LANGA LANGA LLU. ODE IBI IJA DE MOLE.
IJA NI OTARU BA
DELE IFE
TO FI DE OM WON. ORO EX, TO TO TO AKONI. A O
FI IDA RE LALE.
S M SE MI O. EX M SE MI O. EX M SE MI O.
OMO ELOMIRAN NI K O SE. PA ADO ASUBI DA. NO
ADO ASURE SI WA
SE

ORIKI ES

Exu ota orisa, osetura ni orukobaba mo


o.alagogo ija ni
oruko iya npe e,
Exu odara , omokunri idolofin, o Le sonso
si ori esse elese
Ko j ko j ki eni nje gbe mi, akii lowo lai
um ti exu kuro, akii loyo lai um ti exu
kuro, asontun se osi lai ni itiju, exu apata
somo olomo lenu, o fi okuta dipo yio,

Loogemo orum , nla kalu, paapa wara ,


a tuka mase as exu mase mi Omo
elomiran ni ose exu laroiye , ase ase

ORIKI ESU
Iba exu odara , a BA ni wa oran ba o ri da
, o san sokoto penpe ti nse onibode
olorum,
Oba ni il ketu,
Alakesi emeren aji e aji e m u, ogun, a
lun se , wa se ibini , laguna J igbo bi oro
Exu foli Fo o fi oko Fo oju anan re La nyan
hamana, ika ko boro boro, ko La ko Ra o
ba ona oja il su agbo l ara a yaba ma PA
mo, abemu, o se firi oko erro oja
Bara fi imu fon awon sebi oko l o si , ero
palemo wara wara.

ORIKI ES
Esu eni enire eni enire ki lana koma la eni enire
Enire titi enire dalaku lana cwo lana Omo
Lana alafia fin mi seu mase mi Omo
Eloniran ni 0 se.

ORIKI ES
Iba Eu ogri oko abaneworan ba 0 rida
Eu apatapiti apitipata 0 da okuta si iyo oniyo
Eu ma se mi omo elemirim ni ose.

ORIKI ES
Ojumo ti mo mo PE
Eu odara ranse
Ojumo ti mo mo ki legbara
Ojumo 0 mo fun mi
Ko mure mi ko mi

Ork s
Laro y Alktu aki Alktu.
s Alaketu Or mi ma je nko o.
s Alktu BA
Nse ki imo. s Alktu kr o ba onimimi.
s Alaketu, fun mi ofo ase, mo pl rsa.
s Alaketu alajiki juba.
se.

ORIKI ESU YANGI


s, Bb Als,
Ki nnkan m se omo mi
Ki nnkan m se aya mi
ti mi n
M se mi lu niyn, m se nyn lu mi
Ln ow, ln omo kn mi o
s m se m, omo elmrn ni o se
Asro lgo aktpe lgb
lrn m j ki ar j s o

Ork fn s
s pl o, okanamaho, ayanrabata awo he oja oyinsese,
seguri alabaja, olofin apekayu, amonise gun mapo
Nko o
s, ba nse ki imo
s, keru o ba onimimi
s, fun mi ofo ase mo pele rs
s, alayiki a juba
se
ORIKI ES

INVOCAO)ALAKEGUN KI RINGUN IERIOJINLE AERE KI RAIE


MOKUNTELEARINJINA KI ROJU RO MO RE TOLJE KARON KARON
GBE TIUA GBOJE KARON KARON SORO ARA UAJE KARON
KARON GBO TAIE TARA UAORUK IF O LAPE ORUKO IF O LAPEMO
GBAIE PEFA E GBA MIO EGBA MILAAIE TOTO O E DARIJU MIO EIN
MOPEKASORIKI IF KASORIKI ESES BURUKU O, ES OONAES
ABENUGAN, ES ORITAORUKO GBOGBO IN MI MOPE LA PEPOEJE OIE
MI O L ORUKO IYA MI OSORONGAATOJE NUA TOKAN JE DOEJE OIE MI
KALE O

ORIKI ES
ESU ORO MA NI KO. ES ORO MA NI YA KO. ES ORO FOHUN TERE
SILE.
SEU ORO OHUN NI IMA WA KIRI ASE

ORIKI ES
AJIBIKE OWURU J SOGUN ISELE AFAJA B ORUN
BE ENI ELETI GBEFO BGAROYE
A BI ETII LUY KA BI AJERE O SORO L ANO O SEE
LONI SONGO O GBODO PE TESU O SI SI
OYA O GBODO PE TSEU O SI SI IFA GBODO
PE T ES O SI SI SEU OPIN GBOONGBON KI GBONGBON AJIBIKE
OWURU J SOGUN ESU MA SE MI O
AJIBIKEMA SE MI O ES MA SE MI O
MO RU BO ESU OPIN O ASE ASE ASE OOO

ORIKI ES
ESU ISERI GANGA TO LOJO ONI MO

FIKU MI RO SO RUN RE AYE LE O


MO FIKU MI RO SORUN RE AYE LE O MO
FIKU MI RO SORUN RE ESU ISERI
TO LOJO ONI
MO FIKU MI RO SORUN RE ASE

ORIKI ES
ESU GOGO O ORI MI MA JE NKO O
ESU GOGO O ORI MI MA JE NKO O
ELO LOWO RE GOGO
OOKAN LOWO ESU GOGO
BABA AWO ASE

ORIKI ESU
ESU WARA NA WA O ESU WARA O
ESU WARA NA WA KO MI O ESU WARA O
BA MI WA IYAWO O ESU WARA O MA
JE ORI MI O BAJE O ESU WARA O
MA JE ILE MI O DA RU ESU WARA ASE

ORIKI ESU:
ESU IJELU ESU IJELU ESU IJELU O GBE YIN O
ELEGBEJE ADO ESU IJELU ESU IJELU

ESU IJELU O GBE YIN O ELEGBEJE ADO


ESU IJELU LATOPA ESU IJELU KENKE
LATOPA ESU IJELU KENKE LATOPA ESU IJELU
LA SE ENI DAKO ONI LU O
ESU IJELU DAKO ONILU O ASE.

ORIKI ESU
OO RERAN RE OO RERAN RE ESU JEKI EBO DA
OO RERAN RE OO RERAN RE
ESU JEKI EBO DA OO RERAN RE
ESU JEKI EBO DA OO RERAN RE ESU JEKI EBO
RERAN RE DA GBE ENI SEBO LOORE O ASE

ORIKI ESU:
ESU AGONGON GOJA EREJA ESU AGONGON
GOJA LASUNKAN ESU AGONGONGOJA OLA ILU
AKII LOWO LA MU TI ESU AGONGON GOJA

ORIKI ESU
ABIMO TUNMOBI ESU ELEKUN MO BE MI
IWO LO BI LAGBAJA TO FI DOLORI BURUKU
IWO LOBE TAMODO TO FI LO DORI IBI IWO
LOBE

TOUN TI KO FI ROJHU AIYE RE MO


ESU ELEKUN MO BE MI ABI MO TUNMOBI
ESU ELEKUN ORI MI MO JE UN KO OO
ESU ELEKUN ORI MI MO JE UN KO OO
ELO0 LOWO RE ESU ELEKUN OKAN LOWO
ESU ELEKUN ASE

ORIKI ESU:
ESU AROWOJE OKUN UN NI O SI O KI E LU RE
YE
TORAY ESU AROWOJE BOMI TA AFI
ESU OROWOJE BEMI TAAFI ESU AROWOJE NI
MO BA DO JIMI TETE NUWA ASE.

ORIKI ESU:
ESU LALU OBEMBE NIJO ESU LALU LOGEMO
ORUN
A KI I LA YO LA I MU TI ESU LALU KURO
A KI I SE OHUN RERE LA I MU TI ESU LALU
KURO MO JUBA ESU LALU. ASE

ORIKI ESU
ESU PAKUTA SI EWA MA NI KO ESU PAKUTA SI
EWA MA NI KO ESU PAKUTA SI EWA MA YA

KO ESU PAKUTA SI EWA MA YA KA NDA ASE.

ORIKI ESU:
KOO TA ESU KEWE DUNJE LORE
ESU KEWE KII GBE
LOGIGO LASAN
KOO TA ESU KEWE
LE DUNJE LORE ASE

ORIKI ESU:
LA ROYO AKI LOYO AGURO TENTE LONU APA
GUNWA KA MA SESE ARE LE TUNSE
OBA MULE OMO BATA OKOLO OFOFO OKOLO
ONI NI OKOLO TO NI KAN
OFO OMO RO OGUN OLONA ALAJIKI AJUBA
ASE

ORIKI ESU:
ESU EMALONA O JE YEYE O E MA FAGBUNWA
SIRE ESU EMALONA O MA FE YEYE O
E MA FAGBUNWA S IRE E MA FORO ESU
EMALONA SE YEYE SE YEYE O

E MA FAGBUNWA SIRE ESU EMALONA O MA FE


YEYE SE YEYE O
E MA FAGUNWA SIRE ASE

ORIKI ESU:
ESU LAROYE KERU O BA ONIMIMI
NFIMU MI ESU LAROYE NFI
GBOGBO ARA MI MI AJERE ESU MASEMI O OMO
ELOMIRAN NI OSE
TORI ENI ESU BA NSE KI IMO
BO BA F OHUN TIRE SILE OHUN OLOHUN
NI IMAA WA KIRI
ASE

ORIKI ESU:
ESU MASE MI O ESU MASE MI O ESU MASE MI O
ENI ESU ANANAKI BA SORI RE KI O RO ESU MASE MI
O
EGUNGUN OLOMO
EGUNGUN OLOMO ESU ANANAKI BA ABEBI
BABA
DUN SIN EGUNGUN OLOMO
EGUN LE RI UN N EGUNGUN LERI UN
ESU ANANAKI AGBO BABA DUN N SIN

ORISA LE RI UN ASE

ORIKI ESU:
ESU OKOBURU GBE ENI SEBO LOORE O ESU
OKOBURU GBE E ENI SEBO LOORE O
ESU OKOBURU GBE E ENI SEBO LOORE O ESU
OKOBURU GBE E
ENI SEBO LOORE O ESU OKOBURU ESU OKOBURU
GBE E
OKUNRIN KUKURU BI IKU
ESU OKOBURU GBE E OKUNRIN
GBALAJA BE IKOLUN AKURU MASE IGBE
ESU OKUBURU GBE E OLOPA OLODUMARE ESU
OKUBURU GBE E ENI SEBO LOORE O ESU
OKOBURU GBE E KO SUN NILE FOGO GI KUN
ESU OKOBURU GBE E
ESU OKOBURU LO JI OGO KOKO O ESU
OKOBURU GBE E ENI SEBO LOORE O O
BO NIMI KERU O BONIMI ESU OKOBURU GBE
E O BELEKUN SUN LERU OB ESU O BELEKUN O
ELEKUN NSUKUN LAROYE NSUN EGE ESU
OKOBURU GBE E ESU ESU OKOBURU LO DA OKO
ONILU
O ESU OKOBURU DAKE ONILU REBERBE
ASE.

ORIKI ESU:

Mojuba baba mojuba yey


Mojuba akoda mojuba aseda
Mojuba araba baba won nle ife moju ba
olokun mojuba olosa
Mojuba eyin iyami osoronga ewi aye wi
Ni egba orun i gba biaba ge gi ni nu igbo
olugboun
A gba a ki oro ti omode ba nso le
Ma se lomode ba mos lowo a ni ki ose
Bi agbalagba ba mo se lowo
A ni ki ose ko se niti ila kose ase
Wa ni ti ireke bi ilakose ba kola a de un
omo e re
Ire oyoyo ire godgbo mbe lenu
Ienu ila kose
Ire ti a wi fun ila fi ni so ogun ire ti a
Wa iroko to opoto la igi idi re.

ORIKI DOS ODUS QUE CARREGAM ORI:


ODU EDIOGBE MEJI:
ORI KOO DA MI RE
ORISA MA JEE N SOWO ASENU
A DIFA FUN OKANKAN LENIRUWO IRUNMOLE
NIGBA TI WON N TORUN BO WA ILE AYE
ORI LO KOKO DA ORUNMILA DA SI OKE IGETI
ORI KOO DA MI RE
ORI LO DS OSUN SODE IJUMU
ORI KOO DA MI RE
ORISA MA JEE N SOO ASENU
ORI KOO DA MI RE
ORI LO DA OBATALA SODE IFON
ORI KOO DA MI RE
ORISA MA JEE N SOWO ASENU
OKRI KOO DA MI RE
ORISA MA JEE N SOWO ASENU
ORI KOO DA MI RE

ORI LO DA AWON IYA MI AJE SODE OTA


ORI KOO DA MI RE
ORISA MA JHEE N SOWO ASENU
ORI KOO DA MI RE
ORI LO DA SANGO SODE KOSO
ORI KOO DA MI RE
ORISA MA JEE N SOWO ASENU
ORI KOO DA MI RE
ORI LODA OYA SI ILE IRA
ORI KOO DA MI RE
ORI LO DA OGUN SI IRE
ORI KOO DA MI RE
ORI LO DA ESU SI KETU
ORI KOO DA MI RE
ORISA MA JEE N SOWO ASENU
ORI KOO DA MI RE
ORI LO DA ORISA OKO SI IRAWO AGBA
ORI KOO DA MI RE
ORISA MA JEE N SOWO ASENU
ORI KOO DA MI RE
ORI LO DA EEGU SI ILE JE
ORI KOO DA MI RE
ORISA MA JEE N SOWO ASENU
ORI KOO DA MI RE

ODU OYEKU MEJI:


OYE IHIN

OYE OHUN A DIFA FUN OLOYE GELE


OMO ORI RERE T N RU BI OSE
KIN LORI RERE TI N RU
OFULEFULE
N LORI N GBEMI DOYE A FII JOBA
OFULEFULE

IWORI MEJI:
ORI SE MI RERE
ORI SE MI RERE
OLUWO IGI MEJE NI N BE LODE ISALOYE
APA N GBOKO
APA N DADE
ORUURU WON A WEWU EJE KANLE GBONGBO GBON
OLOGUNSESE WON A SIN OMO OKUN KANRUN BE RERE
IROKO WON A YABIRA NIBA [
ARIWONYANGUI AWO WON NILE ALADO
ADANLA AWO WON ODE IJESA
KOTO ONA NII SAWO IMUJIN GBUGBUUNGBU A DIFA FUN ORUNMILA
NIJOTI TI NSUNKUN OMO LO SII ODE IJESA
NJE OMO NI MO BI TA LARA WA MI
WON UM JE OWA OGA OGEE GBEBU
OMO EPO YEYE
OMO EPO KAN SI SII SI LEYIN TENA
OMO NI MO BI TAN LARA TU MI
WON UM JE OBA OLOOTU IFE RERE OMO NI MO BI TAN LAR AJO
WON UM JE ONIGBAAJO ILOSI

OMO A DISAN MEMU


OMO NI MO BI TAN NI WON MOWOO TA
WON UM JE OLOWO
OMO ARA GEJGEJE
OMO NO MO BI TAN NI WON JELULU TA
WON MU JE ELEJELUU
OMO ARIGBA ELUKUKUU KE ESU
KO SEEYAN TO MO IKE SU BI ELEJELU
ELEJELU PELE O
OMO ARIGBA ELU KUKUU KE SU
IKIN MI AGBOGBO
IKIN MO ABOTO
OPE TEE RE EREKE ADO O
EIRIGI ABOLA
IKIN TEE RE E YI O
ERIGI ABOLA

ODU ODI MEJI:


ODIDI KIRIDI
AWO ORI LO SEFA FUN ORI
ODIDI KIRIDI
AWOO GBOGBO ARA LO SEFA FUN GBOGBO ARA
NIJO TI WON N BO WALE AYE
WON NI WON O KAALE KI WON O SEBO
NIGBA TI APA DE
APA WAA BORI DURO
KEREKERE

ORII MI O SAI DELENI


KEREKERE
NIGBA TI ESSE DE
ESSE WAA BORI DURO
KEREKERE
ORII MI O SAL DELENI
KEREKERE

IROSUN MEJI
OBA OJU
OJU AS BO SINUU KOOKO
OJU BA BUUBU
O BA KOOKO
O SA BO SINU OJU
OJU WA N SE MONPE MONPE
A D IFA FUN EJI IROSUN
NIJO TI N SUNKUUN PE OUN O NIBUDO
WON NI KO KAALE SEBO
INA KU
INA FEERU BOJU
OSUN KU
OSUN FEGUN AALA SILE
EGIN AALA GBOJU OLORUN SABA GEGEEGE
A DIFA FUN LABAALE
OMO EGBA ALAKE
NIJO TI N FOMI OJU SERAHUN IRE GBOGBO NI NINI
WON NI ORII RE NI KO BO

O SI GBEBO NBE
O RUBO
NJE KIN NI O WAA SO IL DOJA FAWO
SESEEGA
NI O SO IL DOJA FAWO
[SESEEGA
SESEEGA YI O SAI SOJA DILE

ODU OWORIN MEJI:


AHORANGBON LAWO LODE ORE
AHORANGBON LAWO ODE IJESA
AGBA KAN HANRANGBON HANRANGBON LA DE LOKUN MOLE KA TOO
JAGUN IGBOHIN AYE LE KOKOOKO
A DIFA FUN LAWUSI OKOLE
OMO AFIROKO SEHUN EBO
NIJO AYE E RE LE KOKOOKO BI OTA
O BORI BORI
ORII RE PA
NIBI TI GBE N BORI
BEE LORAAN RE O DARA O BOOSA BOOSA TITIITI
IGBA OOSA SI JU
BEE LOROO RE O SUNWON WON
LEEGUN NI KO MOO BO
O BOOGTUN BOOGUN BOOGUN
IBOJI JIN GBURUGUDU
LAWUSI NI HAA EBORA O LE GBE OUN MO
IGBA O SE GBOGBO E TI O GUN
O BA TO AWON BABALAWO E LO

WON NI ORI OLORI NI O BO KAAKIRI


TI ORAAN RE O TI O GUN REGE YOO SI BO ENU ELENU
WON NI KO SE IJE

KO SE IMU
KO SI PE GBOGBO AWON EEYAN JO
ARAYE BA N WURE
OHUN YOOWO TOO BA TORII RE SE KO DARA
ORII LAWUSA BA GBA GBOGBO IWURE YI
NIRE BA DE
NJE ORI LA BA BO
A BA FORISA SILE
JKIN LA N BO NIFE KA TOO BO IKIN
ENU ENIYAN

ODU OBARA MEJI:


EMI LEMI IGODO
AYAN LAYAN IBARA
AWO KOTO KOTO KOTO
OOUN LOJUU MI O TO
A DIFA FUN AHUN TO TORI IRE GBOGBO DI FA
A D IFA FUN AHUN EYIN TO ORI IRE GBOGBO ADIFA
NJE O MO DO KO AWEDORO
ORI RERE TI AHUN NI O
O MO DOKO AWEDORO

ODU OKARAN MEJI:


AGBELE GBIBO ARAYE O MOO PE SIN EEGUN

GBOGBO ARAYE NI N PE SIN EEGUN


OBA OMINRINNIPASA LORUKO TI AA PE ORUNMILA
OYEKU MEJI LO TE ORUNMILA NIFA
O NI GBOGBO AYE NI N PEE JO SIN ORUNMILA
ATOBA ATIJOYE
GBOGBO O WON NI N FORII BALE FUN IFA
WON N FORI BALEE FUN IKIN
BABA BORI JAJAJIGI LORUKO A PE OSANYIN
IWORI MEJI LOTE OSANYIN NIFA
O NI GBOGBO AYE NI O PEE SIN OSANYIN
GBOGBO AYE NIN NPE E JOO SIN OSANYIN
AFUNKEKE FALA JAYE LORUKO TI A PE ORISA OBATALA
ODI MEJI LO TE OBATALA NIFA
O NI GBOGBO AYE NI O MOOPE JO SIN OBATALA
GBOGBO AYE NI N PEE JO SIN OOSA LLAWE
A JAYE GBINDINGBINDIN MO SAAN KU LORUKO A PE OSUN
IROSUN MEJI TE OSUN IFA
O NI GBOGBO AYE NI O MOO PE SIN OSUN
GBOGBO AYE NI N PEE JO SIN IWO OSUN
AJEJEJE UM JAIGBO LORUKO O A IWO LLEELE
OWONRIN MEJI LO TE ILEELE NIFA
O NI GBOGBO ARAYE NI O MOO PE SIN LLEELE
GBOGBO ARAYE NI N PE SIN LLEELE
SALUJE MO JOMO AWO LORUKO TI AA PE EYIN IYAMI AJE
OBARA MEJI LO TE IYAMI AJE NIFAO NI GBOGBO ARAYE NI O MOO PE
SIN EYIN IYAMI AJE
GBOGBO ARAYE NI N PE JO SIN EYIN IYAMI AJE SE KII ALAGBAJA

TE FII ALAALAAGBAJA LORUKO TI A PE SEU ODARA NIFE OOYE


OKANRAN MEJI LO TE IWO SEU ODARA NIFA
O NI GBOGBO AYE NI O MON PE JOO SIN IWO SEU ODARA
IFA O TO GEGE KOMO ARAYE O MOO PEJO WAA SIN MI O
ORI KAN SOSOOSO O TO GEGE
ORUNMILA O TO GEGE
KOMO ARAYE O WAA FI RERE OWOO WON FUN MI
ORI KA SOSOOSO LORUKOO NI
EWE OJUSAAJU LO NI WON O MOO GBE RERE SE ISAAJUU MI
ORI MEJI NI O GBODO SI
ORII TEMI NIKAN SOSO NI KO WA DENI APESIN
ORI KAN SOSOOSO LORUKO NI
IFA O TO GEGEEGE KOO WAA SERE TEMI FUN MI
OGBE MEJEEJO
EYIN LEE PE SIKITI TI E E LA BABALAWO LODE ISALAYE
EYIN LEE PE SIKITI TI E E LA BABALAWO LODE ISALAYE
EYIN LEE PE SIKITI TI E E LA OGBERI LODE ISLAYE

ODU OGUNDA MEJI:


Orunmila lo dodede nibere
Ifa mo ni to lo to alasaan BA oruko
Sango ni oun to alassan BA rokun
Won ni nje boo BA rin titi
Bo o ba burib burin
Bo o ba de koso

Ilee babaa re nko


Bi won BA se gbegiri
Bi won BA roka
Bi won ba bun o lorogbo
Atakuka adiee kan nko
Sango ni bi mo ba ti yp tan
N o pada silee mi ni
Won ni sango o to alassan BA rokun
Orunmila lo dodede nibere
Ifa mo ni ta lo to alasaan BA rokun
Oya ni oun to alasaan BA rokun
Won ni nje to o bar in titi
Bo o ba burin burin
Bo o ba dele ira
Ilee babaa re nko
Bi won BA poda to tobi
Bi won ba fun o ni ikoko egboo kan nko
Oya ni bi mo ba ti yo tan
N o pada silee mi ni
Won ni oya o to alasaan BA rokun

Orunmila lo dodede nibere


Ifa mo ni ta lo to alasaan ba rokun
Oosaala ni oun to alasaan BA rokun
Nje boo bar in titi
Bo o ba burin burin
Bo o ba dele ifon
Ilee baba a re nko
Bi won PA agbebo adie to royin sinu
Bi won ba mu igba igbin
Ti won ti se ni osiki nko
Oosaala ni bi mo BA ti yo tan
N o pada sile e mi ni

Osa meji
Ahoeo lo ni di
Ni n lo ree fihaa jokoo
A d ifa fun molamela
Nijo to loun n loo Ra ore leru
A d ifa fun oge eyi ti won ni o rubo
Ko Le baa ri eru to sunwon Ra
O ba rubo
O ba kori soko eru

O debe lo ori ore


Ore wu u pupo
O bara a
O dele tan ni ore n sise
Ibuu molamela n dun
Oun waa Le bo loko eru
Ni ore naa rubo si
Won ni koun naa o rubo
Won ni ko bo ori e
Ore naa BA rubo
Won ni ko Ru ebiti
Ko sir u agbon meridinlogun
O si sehum o rubo
Won BA gba iyerosun ifa si ebiti ohum
Won ni ko de si eti oko ti n RO won ni nijo ti ebiti
ohun BA um ekute
Ojo naa ni o boo loko eru
Ore BA se bee
O de ebiti ohun o to iwon orun meji
Ko um nnkankan
O BA FEE kaaare
Ojo to pinnu PE oun o nii de ebiti ohun
Lojo naa lo PA eku eda

Ekute ohun waa tobi pupo


Sugbon ibi ori ekute ni ebiti um

Ika meji
Aagba
Oun won ni won joo se inu igbo
Ijokun
Oun won ni won joo se ile lodan
Keekee
Oun won ni won joo se oyo ajakaye
A d ifa fun olouweri
Eyi ti won ni o rubo
Ko bori e
Nijo ti b loo gbe oko niyawo
Nje ogbere
Omo oko
Ori lo mo ibi oko n re o
Eni Toto lati BA eni wa nnkan La n PE ri ori

Oturupon meji
Ologbon kan o gbon gbon gbon
Ko ta koko omi meti aso
ENIYAN KAN O MORAN MORAN KO MOYE EEPE ILE
ENIYAN KAN O SI JE ALARINNAKA

KO PE OUN MO IBI ILE GBE PEKUN


A D IFA FUN ORUNMILA
NIJO TI N F OMI OJU S OGBERE OMO
ORUNMILA FEYAWO FEYAWO
OKANKAN O ROMO BI
O SI FI FE WON DORRI MERIDINLOGUN
OUN WAA LE BIMO BAYII
WON NI KI ORUNMILA O RUBO SI ORII RE
WON NI KII SE WORO KASN NI YOO BII PAAPAA
ORUNMILA BA RUBO
ORII RE BA GBE EBO DODO ENI KE JI ORUN
OSU OHUN NI GBOGBO AWON IYAWO ORUNMILA
MEREERINDINLOGUN LOYUN
NI WON BA N BIMO
GBOGBO O WON SI JE OKUNRIN
BI AWON ENIYAN O BAA WI
WON A PE ORUNMILA BI OMO
ORUNMILA O PEE IRO O
BABA LOUN BI
OUN O BIMO
DIPO KI WON O MOO PE OMO ALAWO
WON BA N PE BABA ALAWO
BEE NI WON SE N PE GBOGBO AWON OMO NAA NI BABA ALAWO
ORUNMILA LEYIN O MO PE BABA LAA PE KA TOO PE AWO

OTURA MEJI
PE KA N GBE NU IGBO RUN TE
ERE GBA BATA GBA RUN OYE

A D IFA FUN ORI OLA


A D IFA FUN ORI ISE
EBO NI WON NI KO SE
ERRO IPO
ERRO OFA
ONI ISE KO MA NPE ORI OLA TI RUBO

IRETE MEJI
IWO OTE
EMI OTE
OTE ODE MEJI ODO OTITO
OTE OD EMEJI ODO ODO
A D IFA FUN BABA LORI IRE RE
MAA LE NSE ERERE
IFA JEKI NLORI RERE
KI NSE LESE ERERE
EBO NI WON NI KO SE
O SI GBEBO NBE O RUBO
KO I PE KO I JINA
E WA BA NI JEBUTU IRE GBOGBO

OSE MEJI
OSE KETE
O GBOGUBN NLE AYE
O RIN GBAJA
O GBOGBO JI
ORUNMILA LOUN O FI GBOGBO KELEKELE TOUN SERE
A D IFA FUN ORI

NIJO TI NSE OHUN GBOGBO


TI SEU ODARA SI NAA SE IRE E MI O FUN MI
SEU ODARA
SEU ODARA SI NNA SE IRE E MI O FUM MI
SEU ODARA

OFUN MEJI
KUDU KUDU KUDU
ADO TORI OOGUN SO
OOGUN OHUN O SI PO
OLOOGUN NI O FOO MU U WA
A DIFA FUN ORI ORUNMILA
NIGBA TI WON BI ORUNMILA O SE
KO LE BAA ROOKO RERE JE LAYE
ORUNMILA SI DAGBA DIE SAA
O LO TO GEGE KI WON O WA LO REE TA OUN
WON BA GBE ORUNMILA LO SODS OBA ALARA
EJI ASA Omo AMURIKAN DOKAN AGOGO
WON LAWOON FEE TA OJA KAN FUN O
WON LERU KAN NI
O BA BEERE LOWO ORUNMILA PE KINNI ISE TO MOO SE
ORUNMILA LOUN O NISE KAN
BOUN BA TI JI
OUN A WE
OUN O SI KUN
OUN O SI BO SORII OTITA
OUN A SI JOKOO

WON O SI GBE OUNJE WA BA OUN


BOUN BA SI TI JEHUN TA OUN O SI MOO SERE
O TUN DI LOLA
ALARA LOUN O RA MO
ORUNMILA NI WON O MOO GBE OUN LO SODE AJERO
WON TUN DODO OUN NAA WON SALAYE
OUN NAA LOUN O RA
WON BA TUN GBERA O DODO OWARANGUN AGA

ORIKI PARA CONSAGRAO E REZA


DIARIA:
ORIKI ORI:
r mi srere fun mi
r mi srere fun mi
r oka ni sanu oka
r ejo ni sanu ejo
Afo mope ni sanu ope
r mi srere fun mi

ORK OR
B o b maa lw, Br lw or re.
B o b ma sw, Br lw or re w o.
B o b ma kol o, Br lw or re.
B o b ma lya o, Br lw or re wo.
Or mse pekn d. Ld re ni mi mb.

W say mi di rere. Ase.

ORK OR
Or, pl, Att nran Att gbe ni ks.
K ss t d n gb lyn or eni.
Or pl, Or by, eni or b gbeboo r, k yoss.

ORIKI ORI:
IJUB R
O SE, O SE , O SE
OS BAB W
O SE, O SE , O SE
OS BABA W

ORIKI ORI:
ORI BURUKI WU TUULI
A KI I DA CSC ASIWEREE MO LOJE ONA
A KI MORI OLOYE LAWUJO
A DIA FUN MO BOWO
TI I SO OBIRIN OGUN
ORI TI JUBA LOLA
ENI KAN O MO

ORIKI ORI:
ORI LO NDA ENI
SEI ONDAYE ORISA LO NPA ENI DA
O NPA ORISA DA ORISA LO PA NIDA
BI ISU WON SUN AYEMA PA TEMI DA
KI ORI MI MA SE ORI
KI ORI MI MA GBA ABODI

ORIKI DE EGUNGUN E DOS ODUS QUE


CARREGAM EGUNGUN:

Ile mope o o,
Akisale mo pe o o,
Etigbure mo pe o o,
Asa mo pe o o,
Eti were ni ti ekute il,
Asunmaparada ni tigi aja,
Emi Omo re ni mo pe o,
Jeki nwa laaye,
Maa jeki nku,
Maa jeki nri ija igbona,
Maa jeki nri ija Ogun,
Jowo wa jemi loni,
Ki o fire fun mi, Ase.
ORIKI EGUN
Too ki odn yii
O rowa ro ese lai si iyonu
Ki o ro wa se owo
Ki o ro wa si omo
Ki o ro wa si alfia
Bi bee ba ni
Ki obi o yan o.
ORIKI EGUN

T krooro or, en ker e n awr


t krooro or, en ker e n awr
lss mojub awo
lss, lss mn
lss mojub awo
lss, lses mn
lss olwa k a gb o

Lss lss mn
op ye ye a rok,
olwa d a kse, b wa kse
Olwa d se n koja
bb rok k k s gun wa lb re
Egun bale egun bale, baba egun ati nlo.
Egun dara egun dara oni se sun egun dara.

ORIKI EGUN
Egungun kiki egungun
Baba egun ranran f awo ku opipi
O da sobo fun le wo
Baba egun bata bango egun de
Bi aba fatori na l egun asde

Oriki para egungun


Eegun mope o
Iie mope o
Etigbure mope o
Eti we niti e kete il
Asunmanparada niti gi aja
Ago kii gbo ekun omore ko man Tati were
Eegun abata arago gbale
Aroro finju ofofo aye
Egungun abala Omo aye
Ara orun kinkin
Ona mo ni lagba namo nito
Abala peleo oba olomo wa bi koribi

1 reza de egungun
IYA NO FE ELEGUN OJARE
FELEGUN
BODUN BADE MAROMO GBEJO
FELEGUN

BODUN BADE MALERO I EYIN


FELEGUN
OROYI YOODARIWO BEEJE NFELEGUN

2 reza de egungun
OKOKO ADIRE BERE N KOMO YOYO
OKOKO

3 reza de egungun
KULUKULU SE
OJO TI BALUWE SE WOWO

4 reza de egungun
ESA WON LEGBA
OPE TI KOBAYA FEEGUN
ESA WON LEGBA

5 reza de egungun
AWA KIISE ALAKISA TIKO ROWO RASO
ARAN LOKU TAAFI NDA TIWA

6 reza de egungun
EGUNGUN ODUNPE O
EGUNGUN ODUNPE
OLE ATI AKARA
AKARA OLELE LAFI NSORO NIGBALE
EGUNGUN ODUNPE

7 reza de egungun
ENI OJU BANTI KOWOLE
OJU KOTIWA ABA BABA RODE

ENI OJU BANTI KOWOLE

8 reza de egungun
BABA O BABA O
BABA O BABA O
YEYE O YEYE O
YEYE O YEYE O
BABA SO WA NU AWA O RI MO O
O SO WA NU AWA O RI MO O
YEYE SO WA NU AWA O RI MO O
O SO WA NU AWA O RI MO O
BI MO RI BABA ORO MI A DUN BI OYIN
BI MO RI YOYO ORO MI A DUN BI OYIN
JOUN N GBOGBO ALAPALAOMO A SUS MO SA
JOUN N GBOGBO KO TO BERE KO TO MO BUKA
JOUN N GBOGBON
AWON OMO LA NI WON YI A O MO WON
AWON OMO LA NI WON YI A O MO WON
DIGBOLU KOLU DIGBOLU KOLU
BO O BA DIGBOLU N O PADE TEHIN RE O
DISGOLU KOLU DISBOLU KOLU
IGBA O MO O JO
TETE NDE KO OO JO O
KO BI ENI RO RO BI ENI KO BE
RO BI ENI KO BE KO BI ENI RO
WA LA WA MO DO ORO AWA M ODO
JO BI AGBEGI JO BI AGBEJI JO

IGBA TI IWO MO O JO O
TETE NDE
TETE NDE O
E TUN GBE TETE NDE O
E TUN GBE TETE NDE
TETE NDE KO OO JO O
BO BA TI DPATI OPONA ATATA
TETE NDE
TETE NDE

ORIKI EGUNGUN
EGUNGUN A YE KII
SE BO ORUN MO JUBA RE EGUNGUN MONRIWO ILE MO PE O GBOGO
MONRIWO ILE MO PE O EGUNGUN O A KII DE WA O A KII E EGUNGUN
ILE MO PE O WON GBOGBO ARA ASIWAJU AWO WON GBOGBO
ARAALE ASIWAJU MI GBOGBO MONRIWO ILE MO PO O EGUNGUN O
MO PE GBOGBO ENYIN SI FUN MI AABO ATI IRONLOWO AGO KII
NGBO EKUN OMO RE ILE MO PE O GBOGBO MONRIWO ILE MO PE O
EGUNGUN O KI O MA TA ETI WERE BABA AWA OMO RE NI A NPE O ILE
MO PE O GBOGBO MONRIWO ILE MO PE O EGUNGUN O KI O SARE WA
JE WA O KI O GBO IWURE WA ILE MO PE O GBOGBO MONRIWO ILE
MO PE O EGUNGUN O MA JE A RIKU EWE MA JE A RIJA SEU JE A
RIJA OGUN MA JE A RIJA OMI MA JE A RIJA SOPONNA ILE MO PE O
GBOGBO MONRIWO ILE MO PE O EGUNGUN O MO TUMBA BABA
ILE MO PE O GBOGBO MONRIWO ILE MO PO O EGUNGUN O ILE MO PE
O GBOGBO MONTIWO ILE MO PE O EGUNGUN O EGUNGUN O

EGUNGUN ILE MO PE O EGUNGUN O

You might also like