You are on page 1of 1

Ijoba orun Ere Onigbagbo o Ijoba orun Ere Onigbagbo o Ma je n kuna Baba Mu mi dele o Ma je n kuna Baba se Mu mi dele o Owo

ti mo ni ko le mu mi dele o Moto ti mo ri ra ko le wa mi dele o Ore ti mo ni ko le sinmi dele o Gbogbo iwe ti mo ri ka won o le gbe mi dele o Ma je n kuna Baba Mu mi dele o ki n ma ku sajo bi efin Mu mi dele o Aye loja, oorun ni ile Mu mi dele o Aye loja yi, oorun nile se Mu mi dele o Mu mi dele o (x8) Ma ma je n kuna Baba ooo Baba ooo Mu mi dele o (x5) Ile Ile Ile Ile Ile Ile ogo ayo, Ile ayo alafia ogo ayo, Ile ayo alafia

Ijoba orun Ere onigbagbo o Ijoba oorun Ere onigbagbo o Ma je n kuna

You might also like