Esinsin abedo knnknni; Osanyin a ri ibi ri ohun. Bi Eledumare. Alase Ew. Osanyin! Nibo ni Orunmil nl ti ko m Exu dani. Nibo ni Orunmil nl ti ko m Osanyin dani. Aroni elese kan xoxo. Bab ni alax ewe fun Orunmil ati gbogbo awon okanlenigba imal. Akp nigb rn k sunwn Els kan j els mj lo. A niyi kaye bi Eledumare Agba ax |Ogun ta gie-gie Aroni elese kan ti o gba olokunrun kal. Bi Eni gbe omod. Aro obi-oko lielie. Ewe o, ewe o, ewe o! A np o, wa j wa ooo. Omo awo ni nx Oogun. Osanyin wa j w.