Professional Documents
Culture Documents
Iba Oo
Iba Oo
Ose Otua iwo loo saaju ebo , Iwo loo sii kanyin
ebo
To ni Oluwo
Tufee ni Odugbona
Oro kan
Oro Kan
Eyi ti Babalawo b aso sile a degub lailai
Ase ale ase oworo
A d fn argb abor kokooko
Nijo ti n lo ree ba won naja ojugboromekun
Won larugbo oloso
O oloun loso
Won larugboo lajee
O loun o lajee
O nin sugbon oun lafose lenu
Nje eni t oba sun ko d ide
Igba Akuko n daja
Eni o ba sun ko d ide
2. wnrn ajise (wnrn br)
Ose Otura(2)
Bolu b alo! Olu nii sin in Osetura waa ba ni
lase si elo yii
Atepo
Arepo
Awon me jeeji ni won jojo faakara n uwo
A d ifa fun f ejerindilogun orodo
Nijo ti won n gbegbo lo sode orun
A d ifa fun Osetura
Eyi ti n ba won gbebo lo sode orun
O gbo riru ebo o ru
O gbo Eeru o si tii eeru
Nje taa lo tete gbegbo de bode
Ose Otura
Ose Otura lo tete gbegbo de bode
Iwmo Akinoso
Ose Oninare
Ose awurela je K ebo o fin
Eji Ogbe
Eji Ogbe dakun dabo fiye denu koo fiye dekun
Okaran Meji
Okaran Meji , ebo yii ti di eboo re koo bani se
dandan koo segun awon otaa re
Owonrin S Ogbe
Esu peere jegede!
Egba peere jegede!
A d Ifa fun Ologeeesa
Eyi ti o koro leje tomotomo
Ebo araye ni won ni ko waa se
Eje awa koro awa o ku mo
A dewee j ogbo
Eje awa momo koro
Obara B Ogbe
Obara B Ogbe ! ebo yii di tire, koo je k ebo o
fin ki eru o da ko dode orun ko se si toloore
Pa Igunnugun b ofa
Awo won nle Alara
Pa awodi bo Ose
Awo oke ijero
Pa Atioro Bogun
Awa araka ni mode
Agbonmi nii wole eja
Apajuba nii bile aparo wo
Olugbongbo tiila
Ni won fi n segun ogulutu
A dia fun layigbo ogege
Ti won mole iku e tan laye
Won n pilee torun
Ifa lo domimi mi ogege
Ela ba ni wole orun
Barapetu ba wa tun taye mo
A bu won lorun awa o w amo
Iwariwari orun
Ota a bori poogodo
Ile iku mo n wo lorun
Ogerere ile iku mo n wo lorun
Ko ni bu o layigbo
Arundu o ko nii bu o layigbo
Arudu
O tu raka
O rin raka
Erigi l awo Agbasa
A d ifa fun won ni Seese-agere
Nibi won ti ji ti won ti n wa ohun ebo kin
Won tun ko ohun ebo sile tan
Won tun n wa alawoo kiri
Owo ti n be nile yi
Ohun ebo nii se
Erigi l awo Agbasa, Ifa a rohun ebo
Agabado ti n be nile yi ohun ebo nii se
Erigi l awo Agbasa, Ifa a rohun ebo
A bu si tun yin
A dia fu nojo
Ojo tii o sai tun fi yin in leyinwa
Nje a bu si tun yin
Ojo loko agbado
A bu si tun yin
Ogundabede (2)
Bd
Awo won lode Ipo
Awe
Awo ode Ijesa
Ominrinminrin ara iramori
Igi ganganran mose gun mi loje
Olorun d ebiti oran kale
A kii ralawo si rejereje
Awon lo dia fun Olofin
Nijo ti won k ebo keedi ti oun
Olofin ni ki won o mase k eo
Keedi ti oun
Orogbo kan
Oduso kan
Bomode ba kokin gagaaga
A f Oduso sile
Esun o pelesuun
Ere o peleree
Ogundu ogan
Ni o jin lori araa re
Araa won ni won o moo jin
Araa won ni won o moo gbonrangandan
Gbogbo awon ti n ba lagbaja sota
Gbogbo awon (nome do cliente ou meu) ki
won o moo ku gbonrangandan
Okan yeeyee
A d Ifa fun Olugun awerooro
Omo Aleku gori odi lo
Ebo ogbo n won ni ko waa se
O gbebo n be
O rubo
O gbo eeru
O tu eeru
Ifa ba leku lo nigba yi awa o ku mo
A momo s ebo Okanran yeeyee
Ifa ti ba wa lebi lo
Oseroyin (Osewori)
Oseroiyn (1)
lalade orun
Oke le gege mo ye
A di ifa fun libi tii s omo ogun
Ad ifa fun Libi tii s omo ija
A d ifa fun Libilibi tii s omo Osoosi
Nijo ti won jo n roko ode
Ebo ni won ni won o waa se
Won gbebo nle
Won rubo
Won gbo eeru
Won tu eeru
Nje libi perin o perin
Libi perin
Libilibi perin perin
Iwure: Ifa ise ti ba n se mo je ki o di . Ise moo
n lowo, Ifa je ki ona o la fun-un
Oseroyin (2)
Bomode ba mosee je
Won a jonize
Bi won o si moo e
Won a je Oluse
Ise lawa ti n je f oba awa lailai
A d ia fun Oba oropo iyun eyi ti n lo ree jise
ola feebo
Nje jeere o
Ose Pawori
Jeere o
Bo ba dele koo jise owo
Koo jise omo
Jeere Ose Pawori
Jeere
Ose Otura(3)
Osetura pele oo! Awurela Akinnoso! Bo oba
saaju ebo si kanhin ebo
Iwure:
Osanwo iku
O sanwo arun
O sanwo ofo
O sanwo gbogbo ajogun
Okanran Osa (2)
Prayer:
Abudi, the Babalawo of the Mother Earth, cast
divination for the Mother Earth.
Children would not scoop sand without
overing it up again.
Elders cannot scoop the Mother Earth without
covering it up again.
Prayer:
Abudi, o Babalawo da Me Terra, lanado
adivinhao para a Me Terra.
As crianas no iria colher areia sem Overing-
lo novamente.
Ancios no pode colher a Me Terra, sem
cobri-la novamente.
VII Adimu:
1) The cliente is asked to kneel in front of
the Babalawo and use both of his hands to
cover either the opele or Ajere Ifa,. As the
cliente does this, say the following praye.
Iwure:
Nijo l iku n bo, k ifa o bo o
Nijo arun n bo, k ifa o bo o
Nijo ofo n bo, k ifa o bo o
Nijo ija n bo, k ifa o bo o
Nijo ese n bo, k ifa o bo o
Nijo egba n bo, k ifa o bo o
Nijo gbogbo ajogun n bo o bo o
Sugbon nijo t ire aje, ire aya, pipe l aye,
gbogbo ire ba de k ifa o si o s ile.