You are on page 1of 1

ORK AGONGON GOJA

s Agongon Goja, ereja. s Agongon goja lasunkan. s Agongon Goja ola ilu.
A ki i lowo la i mu ti s Agongon Goja kuro. Ase.

ORK S ELEKUN

Abimo tunmobi. s Elekun mo be mi. Iwo lo bi lagbaja to fi dolori buruku.


Iwo lo be tamodo to fi dolori ibi. Iwo lo be toun ti ko fi roju aiye re mo.
s Elekun mo be mi. Abimo tunmobi. s Elekun or mi mo je un ko oo.
s Elekun or mi mo je un ko oo. Elo lowo re s Elekun. Okan lowo s
Elekun. Ase.

You might also like