You are on page 1of 1

**Ogun oju ti o daju gan**

Abeere ti o po daada,alubosa ayu,atale,iyere,kananfuru,eru awonka.....a o bo epo ara


abeere,ayu,atale....a o wa gun gbogbo re papo daada,a o da sinu ike kan a o bu omi si lehin 24
hrs...o di mimu.
Omode...ilaji shot laaro lale
Agbalagba ..ekun shot kan laaro lale.

You might also like