You are on page 1of 1

**Ogun ito sugar**Egbo igi ipeta,a o ge sinu ike,a o wa fi kaun bilala die si,a o fi oti oyinbo re

fun ojo meta,a o maa mu ni araaro.......lehin ose meji ki a lo se ayewo lati mo iwon ti suga naa wa
ninu eje.

You might also like