You are on page 1of 1

rezo para dinero de osetura

Oriki
Adekunle oruko ti a un pe aje,ifa je ki un ni opolopo aje lowo.
O kun odede fowun oruko ti a un pe omo tuntun,
Ifa je ki un ni opolopo omo lode isalaye.
Tori ojo ti ejo ba San ni , ni oro re mu ni,
ifa kio lo mu awon omo araiye wa ba mi towo owo won.
Kankan ni ewe Ina jomo,
kiakia ni ki o lo mu awon omo araiye wa bami towo owo won.
Wara wara lomode ti oko esisi bo,
wara wara ni ki won o ma mu owo temi wa.
Ile o gba, ona o gba won , odo mi lo gbawon towo towo owo won.
Tori ti adie ba sunkun aso, eledumare a s da iye Bo,
ki omo araiye wa basiri mi.
Ori gbigbe, wa lo re gbe ori tutu wa ba mi towo towo owo won .
Tori ise ti iledi merindinlogunbba se, ose otura ni yio Jere won
Ose otura wa lo Tuko owo ode ilu wa ba mi

You might also like