You are on page 1of 2

Orikis de olokun

Iba Olókun, iba’ge Olojo Oni, a dupe o. A dupe Òrúnmìlà

Elerin ipin ibi keje Olodumare. Èsù pèlé o. Olókun pele o

Olókun mo pe o, Olókun mo pe o, Olókun mo pe o. Ni igba meta.

Okuta la pe mo se jê, eti’g bure obi ri kiti. Ni ‘ka Le,

Olókun pele o. Olókun Fe mi lo’re, mo dupe.

Olókun fun me lo mo, mo dupe. Olókun fun me lo’mo, mo dupe.

Olókun fun me la lafia, mo Du pe. Oro ti ase fun Olókun ni awon Omo re wa se fun oyi o

Olókun iba se, Olókun iba se, Olókun iba se o.

Olókun nuaa jeke awon o’iku. Ma ja kiki wa Orun. Olokun ba me.

Nu ni o si o ki e lu re ye toray. B’omi ta’afi a row pon ase ase ase’se o.

Oriki Olókun

Malokun bu owo wa, jimi tete nuwa o. Oba omi ju Oba oke.

Malokun ni mo ba da jimi tete nuwao. Oba omi ju Oba oke.

Ase.

Oriki Olókun

Iba Olókun Fe mi lo’re. Iba Olókun Omo re wa se fun oyi o.

Olókun nu ni o si o ki e lu re ye toray. B’omi ta’afi. B’emi ta’afi.

Olókun ni’ka le. Mo juba. Ase

Ofo Ase Olókun

Ajibaaje

Oba Omi.

You might also like