Professional Documents
Culture Documents
Apostilas de Itefa Orikis PDF
Apostilas de Itefa Orikis PDF
1 OLODUMARE:
IBA OLODUMARE, OBA AJIKI AJIGE. OGEGE AGBEKIYEGUN OKITIBIRITI OBA TI NAP OJO
IKU DA ATERE KAIYE AWUSIKATU OBA A JOKO BIRIKITIKALE, ALABURKUKE
AJIMUKUTUWE OGRIBADIGBO OBA TI FI IMOLE SE ASO BORA OLUDARE ATI,
OLUFORIJI, ADIMULA OLOFIN AIYE ATI ORUN.
ALATE AJIPA OLOFA ORO OB A DEKA DAJO AWOSU SEKAN. OBA AJUWAPE ALABA
ALASE LORI OHUN GBOGBO.
OYIGIYIGI OBA AKIKU ATI OBA NIGBO, OBA ATENILE FORIGBEDI AWAMARIDI
OLUGBHUN MIMO TO ORUN.
ELA FUNFUN GBO O OBA TOTO BI ARO, PAMUPAMU DIGIJIGI EKUN AWON ASEKE.
ABOWO GBOGBOGBO TI YO OMO RE, NINU OGIN AIYE ATI ORUN IBA TO TO TO .
ORIKI OLODUMARE:
OLODUMARE MOJILONI MO WO GUN MERIN AYE.
IGUN KINI, IGUN KETA IGUN KERIN OLOJO ONI GBOGBO IRE GBA TIOOBA WA NILE WA
FUN MI TEMI, T’ AYA, T’ OMO, T’ EGBE, T’ OGBA .
WA FI ELENI SETEMI.
A NI KOSI IGI MEJI NINU IGBO BI OBI EYITI O BA A YA KO’ A YA BIDUN DUN DUN DUN .
2 ORIKI ELA:
IFA L Ó L ONI, IFA L O L OLA IFA L O L O OTUNLA PELUE E ORUNMILA TO MERIN OSA
DAYE IFA RO WA O, ELA RO WA O O. BI O NIBE LAPA OKUN.
KO RO MOO BO. BI O O NI WANRAN OOJUMO.
ORIKI ELA:
ÉLÁ S’ O OGBO S’ OGBO.
Ó F´ IROSUN S´OSORUN RÉ ;
ORIKI ELA:
ORUNMILA ELERIMPIN IBIKEJI OLODUMARE AJE JO GUN OBIRITI A PI JO IKU AS.
OLUWA MI OLOWA AIYERE OMO ELESEIN ILE OYIN OMO OL OPE TO S AN AN DOGI
DOGI.
OLOWUA MI ATO IBA JAIYE ORO A B IKUJ IGBO OLUWA MI AJIKI OGEGE A GBAYE GUN,
3 ORIKI ORUNMILA:
IFA OLOKUN ASORO DAYO
ORUNMILA NI BABA WA, O E AWA KO NI OBA MEJI, IFA TO OBA O ORUNMILA NI BABA
WA IFA TO OBA O KA MO KA LA O KA MA TETE KU,
ONILE ORI OKE TI NI AFOPIN EYE S´AYE S´ORUN IBINI ATO I FI ARA TI BI OKE.
IKUFORIJI.
AKERE SOGBON.
AFEDEFEYO.
BA MI WO OMO TEMI YE O
IGUN KINI IGUN KEJI IGUN KETA IGUN KERIN OLOJO ONI.
ORIKI ORUNMILA :
ETI NIGBO INXOMO ELA.
ETI INFO AWO OMONI PAXA NIFE XETI WERE DJI,
KI O O BORRUN TI UM MA FO,
KI OGBO MORE
TI UM XA MARIWO APA KO
KI UNTO WA LONI
MO TI JUBA ASE DA
MO TI JUBA ERIN MI
NILE ADO
ARAGBA LO TU IFE.
GBOGBO IN KAN TI MO
BA SO LONI
KI O LO SILE
ORIKI ORUNMILA:
ORUNMILA DAKUN DABO,
AJA IKOTO ARA ADO ARA EWI ARA OKETASE ARA OJUMO.
ORIKI ORUNMILA:
ORUNMILA BARA AGBONIREGUN,
ADESE OMILESE A MO KU IKUFORIJI OLIJENI,
ODUDU PASA AKI IGBO OGUN I LAJULE ORUN DA ARA ORUNMILA A KI IFAGBA,
ORUNMILA
MO JO MO KI ATOLA, MO KI ASULA.
AWO AJIKI, L’ A IPE AWO AJA ALE GBHUN A DA A AWON META NLO BO ORI ELU.
AWO AJIKI L’ AWO AJIKI. AWON AJIKI L AWO AJIKI AWO. AJIKI L AWO AJIKI.
ONI LOWO IKI ELEIYNJU EGE L A TO MI IBO E IGBANA NI IKI M’EKU S’ EKUN IGBE.
GB OBI PA O! A WO AYE GB OBI PA O AWO AYE GBO OBI PA O AWO AYE ASE.
ORIKI ORUNMILA:
ALAPANKO AWO MA JU AWO LO
SONU IRE DE
AWO LO EKUN LANIN AWO MAA REE AWO AWO LILE AWO ASE.
ORIKI ORUNMILA:
ORUNMILA AJAMIRANRA AGBONIRTEGUN IBI KEJI
OLODUMARE ELERIPIN
ORIKI ORUNMILA:
ORUNMILA MO PE, ORUNMILA MO PE, ORUNMILA MO PE
ERIN O SE YI PA DA KUN
OMO ABOKUN
OMO ENI WON ABOYINDE
KAFI LEKE SI TO MO
ELOMIN
OMO ENI
TOKE APA
NI LILO NI LILO
ONIKUN NA SO NI BO DEDE PA
KI ARUN MA SE ONIBODE SE
ASENIA MO ASENIA MO
ASENIA MO
ASENIA MO.
ATAN GIRIGIRI
BA WA KOWA A TAWA JO
IGBA
KE WA ROHON YOWON
ELEGEDEE MEREE
ELEGEDE MEREE.
AKO APARO
ABA APARO
WON NI E E FOREGDE KU
BARA PETU
LO DIFAFUN BON
E WA BA WA ISEGUN
LIGB OTA
LIGBOTA.
BA FADAKA
BA PADAKA
ADAKA
LEHIN YO YO YO MAJE
KANO OKO
OLALAO PA YI NRIN
OLALAOO PA YI NRIN
TITUN LA TA YI NRIN SE
AYINRIN MAMA DE
GANNIGANNI
EMO GAN MI O
GANNI GANNI
GANNI GANNI
GANNI GANNI
BEWO GEREJE TI O MA
FI GBOGBO AIYE SO FE JE
ERO IPO
ERO OFA
LEMI SE
IFA OO SE TORUN
IFA SE TORUN
IFA SE TORUN
KO SI IRUNMIOLE
BII IFA
AIYETUTU NIYAWO
ALATE AJIPA OLOFA ORO OB A DEKA DAJO AWOSU SEKAN. OBA AJUWAPE ALABA
ALASE LORI OHUN GBOGBO.
OYIGIYIGI OBA AKIKU ATI OBA NIGBO, OBA ATENILE FORIGBEDI AWAMARIDI
OLUGBHUN MIMO TO ORUN.
ELA FUNFUN GBO O OBA TOTO BI ARO, PAMUPAMU DIGIJIGI EKUN AWON ASEKE.
ABOWO GBOGBOGBO TI YO OMO RE, NINU OGIN AIYE ATI ORUN IBA TO TO TO .
ORIKI OLODUMARE:
OLODUMARE MOJILONI MO WO GUN MERIN AYE.
IGUN KINI, IGUN KETA IGUN KERIN OLOJO ONI GBOGBO IRE GBA TIOOBA WA NILE
WA FUN MI TEMI, T’ AYA, T’ OMO, T’ EGBE, T’ OGBA .
WA FI ELENI SETEMI.
A NI KOSI IGI MEJI NINU IGBO BI OBI EYITI O BA A YA KO’ A YA BIDUN DUN DUN DUN
.
DIDE AFERE WEWE OSETURA OMI UNROSO ATI ASHA OLODUMARE EBO MORESILE
ODARA
ODU OSETURA:
OSETURA AWON ALARA LODIFA FUN ALARA
ODU OSETURA:
OSE OTURA
TO NI TI OLUWO
ODU OSETURA:
OSETURA LADAFUN ONI BA TILO LEAJA
BENIJO TETE NO NISHO INBA OYIN AFERE WEWE AIYANA DIDE ARERE WEWE
ODU OSETURA:
PENPE LESEE
IBA TO GELE
AD IFAFUN AWURELA
NI JEBU
MERIDILOGUN TINLODIFA
ILE OLOFIN
NI IGUN FI PA L ORI
OORE NI AKALA SE
WON NI KO RU BO
OGB EBO O RU
EGBE MI O
TI OBA SI ORI
A BA MEJO DI IGI
ITAKUN LEJO
OSIKALEKA NI NFI OWO OTUN GBE EBO FUNMI NI KI TOSI IGBA MOFI OTUN GBE FUN
MOSIFI GBAA
TOBA GORI OPON KOFIN TOBA OWO TOBA KANLE TAN ORN ELEBO NI NLO
IYA IGBA O LE MO ON WE
KOMO RE O BERI LO
OPE
ORIKI EXU
2 ORIKI ESÚ
Iba Esu Lalu
Otili loogun
Aigada eye
Oroko-ni-ojo-ebo-Ie
Esu tabirigbongbon
Abonijawa-kumo
Ma jeki a ri ija re
Ase ti Eledunmare
Eledunmare Ase
ORIKI ESÚ
ÈSÙ, ÈSÙ ÒDÀRÀ, ÈSÙ, LÁÀLU ÒKIRI ÒKÒ. ÒKÙNRIN ORÍ ITA, A JO
A RIN LANGA LANGA LÁÀLU. ODE IBI IJA DE MOLE. IJA NI OTARU BA
D’ELE IFE
ÀSE
ORIKI ESÚ
ORIKI ESU
Iba exu odara , a BA ni wa oran ba o ri da , o san sokoto
penpe ti nse onibode olorum,
Oba ni ilê ketu,
Alakesi emeren aji e aji e m u, ogun, a lun se , wa se ibini
, laguna Jô igbo bi oro
Exu foli Fo o fi oko Fo oju anan re La nyan hamana, ika
ko boro boro, ko La ko Ra o ba ona oja ilê su agbo l ara a
yaba ma PA mo, abemu, o se firi oko erro oja
Bara fi imu fon awon sebi oko l o si , ero palemo wara
wara.
ORIKI ESÚ
Esu eni enire eni enire ki lana koma la eni enire
Eloniran ni 0 se.
ORIKI ESÚ
Iba E§u ogri oko abaneworan ba 0 rida
Ojumo ti mo mo PE
Ojumo ti mo mo ki legbara
Ojumo 0 mo fun mi
Ko mure mi ko mi
Oríkì Èsù
Èsù Alákétu BA
Àse.
Ki nnkan má se omo mi
Ki nnkan má se aya mi
Nko o
Àse
ORI KOO DA MI RE
ORI KOO DA MI RE
ORI KOO DA MI RE
ORI KOO DA MI RE
OKRI KOO DA MI RE
ORI KOO DA MI RE
ORI KOO DA MI RE
ORI KOO DA MI RE
ORI KOO DA MI RE
ORI KOO DA MI RE
ORI KOO DA MI RE
ORI KOO DA MI RE
ORI KOO DA MI RE
ORI KOO DA MI RE
ORI KOO DA MI RE
ORI KOO DA MI RE
ORI KOO DA MI RE
OFULEFULE
OFULEFULE
IWORI MEJI:
ORI SE MI RERE
ORI SE MI RERE
APA N GBOKO
APA N DADE
ORUURU WON A WEWU EJE KANLE GBONGBO GBON
WON UM JE OLOWO
WON MU JE ELEJELUU
ELEJELU PELE O
IKIN MI AGBOGBO
IKIN MO ABOTO
OPE TEE RE EREKE ADO O
EIRIGI ABOLA
IKIN TEE RE E YI O
ERIGI ABOLA
ODIDI KIRIDI
NIGBA TI APA DE
KEREKERE
KEREKERE
NIGBA TI ESSE DE
KEREKERE
KEREKERE
IROSUN MEJI
OBA OJU
OJU BA BUUBU
O BA KOOKO
O SA BO SINU OJU
INA KU
OSUN KU
WON NI ORII RE NI KO BO
O SI GBEBO NBE
O RUBO
SESEEGA
[SESEEGA
O BORI BORI
ORII RE PA
IGBA OOSA SI JU
LEEGUN NI KO MOO BO
O BA TO AWON BABALAWO E LO
WON NI KO SE IJE
KO SE IMU
ARAYE BA N WURE
NJE ORI LA BA BO
A BA FORISA SILE
ENU ENIYAN
OOUN LOJUU MI O TO
NJE O MO DO KO AWEDORO
O MO DOKO AWEDORO
ATOBA ATIJOYE
OBARA MEJI LO TE IYAMI AJE NIFAO NI GBOGBO ARAYE NI O MOO PE SIN EYIN IYAMI
AJE
ORUNMILA O TO GEGE
OGBE MEJEEJO
Osa meji
Ahoeo lo ni di
O ba rubo
Ore wu u pupo
O bara a
Won ni ko bo ori e
Won ni ko Ru ebiti
O si sehum o rubo
Ore BA se bee
Ko um nnkankan
O BA FEE kaaare
Ika meji
Aagba
Oun won ni won joo se inu igbo
Ijokun
Keekee
Ko bori e
Nje ogbere
Omo oko
Oturupon meji
Ologbon kan o gbon gbon gbon
ORUNMILA BA RUBO
NI WON BA N BIMO
BABA LOUN BI
OUN O BIMO
OTURA MEJI
PE KA N GBE NU IGBO RUN TE
EBO NI WON NI KO SE
ERRO IPO
ERRO OFA
IRETE MEJI
IWO OTE
EMI OTE
EBO NI WON NI KO SE
KO I PE KO I JINA
OSE MEJI
OSE KETE
O RIN GBAJA
O GBOGBO JI
SEU ODARA
SEU ODARA SI NNA SE IRE E MI O FUM MI
SEU ODARA
OFUN MEJI
KUDU KUDU KUDU
OOGUN OHUN O SI PO
OLOOGUN NI O FOO MU U WA
BOUN BA TI JI
OUN A WE
OUN O SI KUN
OUN A SI JOKOO
O TUN DI LOLA
ALARA LOUN O RA MO
ORÍKÌ ORÍ
ORÍKÌ ORÍ
Orí, pèlé, Atèté níran Atètè gbe ni kòòsà.
ORIKI ORI:
IJUBÁ ÒRÌ
O SE, O SE Ô, O SE Ô
OSÈ BABÁ WÁ
O SE, O SE Ô, O SE Ô
OSÈ BABA WÁ
ORIKI ORI:
ORI BURUKI WU TUULI
A KI I DA CSC ASIWEREE MO LOJE ONA
A KI M’ORI OLOYE LAWUJO
A DIA FUN MO BOWO
TI I SO OBIRIN OGUN
ORI TI JUBA LOLA
ENI KAN O MO
ORIKI ORI:
ORI LO NDA ENI
SEI ONDAYE ORISA LO NPA ENI DA
O NPA ORISA DA ORISA LO PA NIDA
BI ISU WON SUN AYEMA PA TEMI DA
KI ORI MI MA SE ORI
KI ORI MI MA GBA ABODI
ORIKI EGUN
Ki o ro wa se owo
Ki o ro wa si omo
Ki o ro wa si alàáfia
Bi bee ba ni
Ki obi o yan o.
ORIKI EGUN
ORIKI EGUN
O da sobo fun le wo
1 reza de egungun
IYA NO FE ELEGUN OJARE
FELEGUN
FELEGUN
FELEGUN
OROYI YOODARIWO BEEJE NFELEGUN
2 reza de egungun
OKOKO ADIRE BERE N KOMO YOYO
OKOKO
3 reza de egungun
KULUKULU SE
4 reza de egungun
ESA WON LEGBA
5 reza de egungun
AWA KIISE ALAKISA TIKO ROWO RASO
6 reza de egungun
EGUNGUN ODUNPE O
EGUNGUN ODUNPE
EGUNGUN ODUNPE
7 reza de egungun
ENI OJU BANTI KOWOLE
É É É É BABA O BABA O
É É É É YEYE O YEYE O
É É É É YEYE O YEYE O
BABA SO WA NU AWA O RI MO O
O SO WA NU AWA O RI MO O
YEYE SO WA NU AWA O RI MO O
O SO WA NU AWA O RI MO O
JOUN N GBOGBON
IGBA O MO O JO
É É É É TETE NDE KO OO JO O
KO BI ENI RO RO BI ENI KO BE
RO BI ENI KO BE KO BI ENI RO
JO BI AGBEGI JO BI AGBEJI JO
IGBA TI IWO MO O JO O
É É É É TETE NDE
É É É É TETE NDE O
É É É É TETE NDE KO OO JO O
É É É É TETE NDE
É É É É TETE NDE
ORIKI EGUNGUN
EGUNGUN A YE KII