oò ri' báyé nwá doríto dò tó dobúépo ọmọ ò gbọ́ tí baba mo, baba ò gbó dimọ má, aya ò gbọ́ lọkọ mo gbogbo rè wá polúkúrámusu nílé ayé o Elédùmarè e, Olódù só màre Òbá wá bá wa túnlé ayé se Transcription of the Yoruba: Káyé ó máse dàrú má Káyé ó rójú, káyé ó ráàyè Kóòdè ó gba gbogbo wa nílé ayé Torílé ayé yìí kansoso la wá Àjò sì nilé ayé Gbogbo wa la ó padà relí bóbá dọjọ́ kaa Elédùmarè o o o Ìwọ mà lọ̀ mọ̀ ràn tí moyún ìgbín nínú ìkọrọhua Ìwọ mà leni tó tọgbọ́n mọgbá orí Ìwọ mà leni tó dá gbogbo wa rílé ayé Tí wọ́n ti ń pelé ayé nílé dúníyàn o Elédùmarè ọba toto bọ bí orí Bíyá tín bì ó díè kórí ire ó lè wá Bo lè dámí l'óhùn gbogbo ohun tí mo bá bèrè lọ́wọ́ ò ré lújúọ tòní o Oba atérere káré ayé, Ọba kòṣeuntì Òbàmùbárá matéré bamba Elédùmarè Ènìyàn wèròwèsò tí ò sée lowó wàdùwàdù mú Enítóbá tasè àgèsè pérén Kódà á sanwó láyé, á wá lo rèé sekà lórun ni Elédùmarè o o o Ọba ńlá, tí ò seé gbíjá, ọba tí ò seé gbìjà Torí mọ súmóba níwọ̀ n egbèje Mo jìnnà sóba níwọ̀ n egbejà mi ò mà róba fín torá róba fiń loba ń pa Ọba tótó bí aró, ọba rèrè bí osùn Eléní àtèká gbogbo mekùn oòyè Òpó àndù oyè Ọba tí wọ́n kìí bá du oyè láíláí L'elédùmarè ọba tèmi Ọ̀ bá dákun o gbébè mi Ọ̀ bá dákun o gbébè mi Káyé ó ńjú fún wa Káyé ó ńjú fún wa Kílè yí ó sàn wá Kílè yíí ó san wá Kámáse rógun àdáyà Kámáse rógun àgbédá Kámáse rógun àkóbá Lólá Elédùmarè jóo bá jé gbó àdúrà wa Mose tótó, mo se sákì olú Gbogbo èyí náà, ko ba lè gbóhùn èbè mi ni Ọ̀ bá dákun wá gbọ́ o o o