You are on page 1of 18

KORIN ÈWÈ

01 – Jé kó sà o - Cantiga de abertura
Ban bo yóro
Jé kó sà o
Ban bo yóro

02 – Sé sé oyó fun wà - Cantiga de abertura


Ban bo yóro
Oyo fun asé sé

03 –Sé sé oyó fun wà - Cantiga de abertura


Sé sé oyó fun asé sé

04 – Okikán ki kaké n’bale o - Okikán- cajazeira –


pertence a Ogun
Okikán ki kaké n’bale
Alà ni kosun óyó ni ekodidé
Okikán ki kaké n’bale

05 – Opéré Òsànyin insibu - Opéré – pássaro sonolento que


simboliza os
Kùkù ru ide wà kàkà ancestrais – pertence a Òsànyin
Opéré Òsànyin insibu baba
Kùkù ru ide wà kàkà

06 – Iru ajé ke Iròkó - Pertence a Iròkò


Èwè lo se mo béré
Iru ajé ke Iròkò baba
Èwè lo se mo béré

07 – Ori óba jókojé - Jókojé – jarrinha, papo de


peru, cipó mil homens-
Èwè gbògbò Orisa pertence a Osun
Ori óba jókojé baba
Èwè gbògbò Orisa

08 – Èrè wéré mojé sabi - Ojé – seiva, amasi - cantiga


genérica
Ojé mo sabi èwè
Èrè wéré mojé sabi baba
Ojé mo sabi èwè

09 – Pèrègún alará gigún o - Pèrègún – dracena – pertence a


Ogun
Pèrègún alará gigún
Obá ko ni jé róró kán
Pèrègún alará gigún

Pèrègún èwè ni fá dò
Pèrègún èwè ni fá dò
Baba ni fá dò èwè ni fá dò
Pèrègún èwè ni fá dò

Pèrègun èwè pè ti man


Pèrègún èwè pè ti man
Baba pè ti man èwè pè ti man
Pèrègún èwè pè ti man

Ára oro jóji mà


Bobo do r’ogún
Pèrègún alará gigún
10 – Tètè ko ma tè o - Tètè – bredo – pertence a Ogun
e Ososi
Ta ni so ni lè
Tètè ko ma tè o
Ta ni so ni lè

11 – Èwè pélé óbé ni t’óbé o - Óbé - faca


Pélé óbé ni t’óbé
Óbé pélé óbé wà kún pélé óbé
Akáká kún wà kún pélé óbé
Pélé óbé ni t’óbé o

12 - Mo murá mo fún jé - Cantiga genérica


Mo murá kini apá rúnké

13 – Ásá jè èwè kánsoso o - Pertence a Ososi


Ásá jè èwè kánsoso
Èwé ko mo jé ko masá
Àsá jè èwè kánsoso

14 - Tá iyólè ké iyá o - Osibàtá – Nenúfar – pertence a


Osun
Tá iyólè ké omi
Osibàtá iyólè ké r’òdò
K’òjú òlówó re ké rómi
Tá iyólè ké iyá o

15 – Kimi kimi olé ké iyá o - Osibàtá – Nenúfar – pertence a


Osun
Kimi kimi olé ké iyá
Osun odi lé ké r’omi
Osibàtá kimi apá ròkó
Kimi kimi ilé ké iyá o

16 – Awá kó sa bo lési - Àfòmon – erva de passarinho –


pertence a
Awá kó sa bo lési Òsanyin e Oluaiyè
Àfòmon ti bèré
Awá kó sa bo lési Agé

Awá kó s’agó la só
Awá kó s’agó la só
Kúkúté ti bikán
Awá kó s’agó la só Agé

Awá kó sagan ólómó


Awá kó sagan ólómó
Àfòmon ti bikán
Awá kó sagan ólómó Agé

17 – Irókò Irókò o - Pertence a Irókò


O igi iyé iyé ti temi
O igi igi kò gbò jò
A Irókò akin dégun

Akin dégun akin dégun


A Irókò akin dégun

18 – Bani senin senin - Igi opé – mariwo, dendezeiro –


pertence a Osala
Bani lowin lowin
O igi opé iyé rokó
O igi ó batá wá yin

19 – Bani senin sewá - Pertence a Osala


Bani lowin lowá
Ajalè ó baba re wá
O igi o batá wá yin

20 – O rinrin nu t’àgbàdò - Rinrin – alfavaquinha –


pertence a Osun
O rinrin nu t’àgbàdò
Nu t’àgbàdò nu t’àgbàdò
O rinrin nu t’àgbàdò ara so

21 – Odùndùn baba téro ré - Odùndùn – folha da costa –


pertence a Osala
Odùndùn baba téro ré
Baba téro ré baba téro ré
Odùndun baba téro ré

22 – Ógbó kimi kimi mo de - Ógbó - rama de leite – pertence


a Osala e
Ógbó kimi kimi moyó Òsanyin
Ógbó balufán nlá gbá
Ógbó balufán òlòwó

23 – Ópa ló n’apá agógó - Agógó – árvore africana muito


alta, no brasil
Ópa ló n’apá agógó louva-se o instrumento
Igi pá agógó n’béré
Ópa ló n’apá agógó

Guràna guràna
Guràna guràna
Ópa ló n’apá agógó
Igi pá agógó n’béré
Ópa ló n’apá agógó
24 – A inse Irunmolé - Atori – goiabeira – pertence a
Ogun e Ososi
A insába bain baró
A insába nana kosun baba Atori
Firiri ewa’tori o
Firiri ewa’tori
Firiri ewa’tori o
Firiri ewa’tori

25 – Omode kèkèrè eniyn - Cantiga genérica para arbustos


Awá nse idi kan nlá
Kawa fun won l’asé o
Awá nse idi kan nlá

26 – Èwè dandá darà mo dá o - Dandá – tiririca – pertence a


Esú
Èwè dandá darà mo dá
Èwè dandá darà mo dá o
Èwè dandá darà mo dá
O mà dá o erò
Baba dá òrò
Èwè dandá darà mo dá o

27 – A fi pá bùrú - Etiponlá – pega pinto –


pertence a Sango
A fi pá bùrú
Etiponlá a fi pá bùrú
Inje i inje oma
Etiponlá a fi pá bùrú

28 - Èwè njé ògún njé - Cantiga genérica para amasi


Èwè ti kó jé èwè re ni kó pè

29 – Èwè gbógbó ati se’gún - Cantiga genérica para amasi


Èwè gbógbó ati se’gún
Èwè akikan baba sakojé rèrè
Èwè gbógbó ati se’gún

30 – Alá fulewá mama keién - Cantiga genérica para


amasi
Leri ase kikén
Alá fulewá mama keién
Leri ase kikèn o

31 – Awá nbá ko sire - Akòkò – n. laeris – pertence a


Òsanyin
Awá nbá èwè akòkò
Kasolé okán lambó
Awá nbá èwè iyo

32 – Ósùn boinbó mabi bulé - Ósùn – urucum – pertence


a todas as Iyás
Igára dúra ganga la b’òsún
Osún boinbó mabi bulé
Lakán lakán losé awó

33 – Ejá tútú fé rumbó - Pertence a Òsanyin


Ejá tútú fé rumbó
Mo gbo Òsanyin elébó
Ejá tútú fé rumbó
34 – Ti o rinrin banbá - Rinrin – alfavaquinha –
pertence a Osun
Ti o rinrin banbá
Awon la mejé k’èwè o

35 – Èwè lé iyómi - Pertence a Òsanyin


Awón la meji iyómi
Otintin lé iyómi
Èwé binbá èwè ba jó ba

36 – Bólo kiti awá tá epò - Epò – óleo – cantiga genérica


Bólo kiti awá tá epò
Epò po lowó epò po lésé
Bólo kiti awá tá epò

37 – Okún má lu wá o - Okún – oceano – pertence a


Olokún e Iemojá
Èwè okún mà
Okún má lu wá o
Èwè okún mà

38 – Èwè èwè mi re o - Pertence a Òsanyin


Èwè mi re o
Ilé ilé o
Òsanyin belòdò

39 – Séri awó è awó - Pertence a Òsanyin


Séri awó Òsanyin odúndún

40 – Otún de má be leri - Otún – direita – pertence a


Osala (único Irunmole
Awà leri omo sòrò da direita)
41 – Èwè akòkò - Akòkò – n. laeris – pertence a
Òsanyin
Akòkò
A lèsè meji ti okutá

42 – Sé kún bòro bè wà o - Odúndún – folha da costa –


pertence a Osala
Sè kún èwè odúndún

43 – Abè là abè là mà - Pertence a Òsanyin


Abè là abè là mà
Oba din’wá olu Òsanyin
Abè là abè là mà iyé iyé

Abè lu abè lu mà
Abè lu abè lu mà
Oba din’wá olu Òsanyin
Abè lu abè lu mà iyé iyé

Baba s’omo ré
Baba s’omo ré
Oba din’wá olu Òsanyin
Baba s’omo ré iyé iyé

44 – Etiponlá ipá òrò - Etiponlá – pega pinto –


pertence a Sango
Etiponlá ipé òrò
Ipá olówó ipá olomàn
Etiponlà ipá òrò
45 – Èwè ma ti bóróró - Cantiga genérica para amasi
Èwè mà si bólo mi
Èwè ma ti bóróró
Èwè mà si bólo mi
Ibá mi do ke iyó
Mà ti bó mà si bólo mi
Ibá mi do ke iyó
Mà ti bó mà si bólo mi

46 – Bá mi okàn sòrò iyó - Cantiga genérica


Sòrò mi iyé iyé
Emi okàn sòrò iyó
Sòrò mi iyé iyé

47 – Èwè mi lòlòkò - Cantiga genérica para amasi


Ògùn màn lo màn
Èwè ògún màn
Èwè ása jé ògún màn lo màn
Èwè ògún màn

48 – Èwè mi lòlòkò - Cantiga genérica para amasi


Asinsá lòlá
Èwè asinsá
Èwè ása jé w’asinsá lòlá
Èwè asinsá

49 – Ígi ígi otá omi o - Cantiga genérica para amasi


Ígi ígi otá omi
Aládò ígi ígi ògún man
Ígi ígi otá omi

50 – Fára balé kosumàn o - Kukundukun – batata doce –


pertence a
Fára balé e kosumàn Osumare
Kukundukun olodí èwè
Fára balé e kosumàn

51 – Èwè ni àgbàdo sé - Pertence a Òsanyin


Èwè gbògbò Orisa
Èwè ni àgbàdo sé Òsanyin
Èwè gbògbò Orisa

52 – Odò júmàn ewúró - Ewúró – aluman – pertence a


Ogun
Kútú kútú la odi
Odò júmàn ewúró
Kútú kútú la odi o

53 – Ipésán o èlèwà - Ipésán – bilreiro – pertence a


Sango e Oya
Iyé iyé tálo ké mò mà se só
Ipésán o èlèwà
Iyé iyé tálo ké mò mà se só

54 – Airá fi sé té - Pertence a Sango


Inda ro tálá
Airá fi sé té
Inda ro tálá

55 – Mi r’odo bi o - Pertence a Òsanyin


Alà Òsanyin
Mi r’odo bi o
Alà o

56 – Èwè mo sokún - Pertence a Òsanyin


Àwédé
Èwè mo sokún
Àwédé

57 – Òdé onàn o - Cantiga do Itá


Ola ki wá
Injé o injé omàn
58 – Èniréré gbá n’pá o - Cantiga do Okutá – louva-se
todos os Odús
Èniréré gbá n’pè (Okanran meji, Oyeku meji,
Ogundá meji,
Okanran meji gbá wá se o Irosun meji, Ose meji,
Obara meji, Odi meji,
Gbá wá se o Ogbe meji, Osa meji, Ofun
meji, Owonrin meji,
Èniréré gbá n’pè Iwori meji, Ika meji,
Oturupon meji, Otuwa
meji, Irete meji)

59 – Bá tu lá bá tu ló - Cantiga genérica para todas as


Iyás
Ki oyin ki koròwò
Bá tu lá bá tu ló
Ki oyin ki koròwò

60 – Òsanyin èwè ni agbàdò - Pertence a Òsanyin


Lèlèrèkún lèlèrèkún oku iyó

61 – Èwè abebe o rewá abebe nbó - Abebe – erva capitão


– pertence a Osun
Èwè abebe
Abebe o rewá abebe nbó
Èwè abebe

62 – Èwè àtà kòro ojú èwè - Àtà – pimenta - pertence a Esu


A lélé kóro ojú a b’ògún
Àtà kóro ojú èwè
A lélé kóro ojú a b’ògún
63 –Àjà n‘nà bùrúrú - Inà – folha do fogo – pertence a
Sango e Oya
Àjá n’nà bùrùrú
Injo l’óru a inà

64 – Mo já èwè epé mó sóró o - Èwè epé – cansanção branco –


pertence a Sango
Mo já èwè epé mó sóró
Epé ló pi ami epé ebóra mi
Mo já èwè epé mó sóró

65 – Opé mi opè lè pè - Pertence a Sango


Sa urèpèpè
Opé mi opé lé pé
Sa urèpèpè

66 – Si di awon é awon - Cantiga genérica


Awon la me jé k’èwè o

67 – Àrà’win àrà’win - Pertence a Osala


Àrà’win alé ijò
N’tó ki odò iyó
Àrà’win alé ijò

68 – Òwèrénjéjé òwèrénjéjé - Òwèrénjéjé – jequiriti –


pertence a Òsanyin
Ibá Orisa ibá iwá
Kúkúndukun re ke òjè
Kini jé kini jé lésè Orisa
Omo jikán sabi èwè
Èwè ni até ni
Èwè ni até ni
Omo jikán sabi èwè

69 – Orisa tà iwin wá - Pertence a Osala


Èwè ogbó ta wese
Èwè ogbó ki lério
Èwè ogbó ta wese

70 – A sa ré wéré - Pertence a Osala


A ira dába èwè
A ira dába ki lério
A ira dába èwè

71 – Òlówó igbín eró ni kòró Baba - Pertence a Osala (serve


para sacrifício do igbín)
Àjà wára ke òbò

72 – Egbé ni àtàfá r’oni - Pertence a Ososi (louva a


nação)
Téré mi nàn

Egbé ni àtàfá joló


Téré mi nàn

Egbé ni àtàfá eránkó


Téré mi nàn

Temi semi olójú


Téré mi nàn

Temi semi oloiyó


Téré mi nàn

73 – Òwénrénjèjé òwénrénjèjé - Òwénrénjèjé – jequiriti –


pertence a Òsanyin
Kàn kàn mà gbó Orisa
Ibá ni Baba ibá ni iyé iyé
Ma sókun arò
A fi pá nlá d’asé omo Obatalá
Baba iyé
Oba Ajáiye

74 – Àgbá dè Àgbá Onà - Pertence a Esú Onà ( usada


para oferenda a Onà
Sésé fólo olo fó lówó no Itá)
Àgbá dé o Àgbá Onà
Sésé fólo olo fó lówó

75 – Éru fi éru dàn - Éru – carrego – cantiga para


carrego
Dà nisé b’óré wá dàn
Éru fi o éru dàn
Dà nisé b’óré wá dàn o

76 – Ogun tána tána de - Pertence a Ogun


Tána de tána de o
Ogun tána tána de
Tána de tána de o

77 – Ki ló fó inse - Cantiga de fechamento


Mariwò
Ki ló fó inse
Mariwò

78 – Bára tóró inse - Cantiga de fechamento


Mariwò
Bára tóró inse
Mariwò

79 – Biri biri biti - Cantiga de fechamento


Mariwò
Jé ko Òsanyin n’olé
Mariwò

80 – Mà kunun mà kunun - Cantiga de fechamento


Ti bi tiyè
Atin jé lolá
Ti bi tiyè
Carlos Alves de Campos
Omo Odé Inlè
São Paulo, 1998.

You might also like