You are on page 1of 1

01/10/2020.

ṢIṢẸGUN AWỌN OMIRAN NIPASẸ IJẸWỌ IGBAGBỌ


1 Sámúẹ́ lì 17: 33 – 51
Gbogbo eniyn ni o ma n dojukọ awọ n omiran kan tabi omiran ninu irin-jo wọ n ninu aye. Awọ n omiran
wọ nyi ni a gbọ dọ dojukọ , kọ ju-ija si wọ n, ki a si bori wọ n bi a ba fẹ ni ilọ siwaju gẹgẹ bi Kristiẹni. Gẹgẹ bi a
ti n wo awọ n omiran wọ nyi lati okeere, ti a si n kawọ n gbera gẹgẹ bi ẹni ti o ti ni ijakulẹ kọ ni ọ na abayọ ,
ṣugbọ n nini oye nipa ipo rẹ pe̩ lu O̩ lo̩ run ati ifisojus̩ e igbe̩ e̩le re̩ ninu Rè̩, pè̩lú ije̩ wo̩ is̩ e̩gun re̩ ni yó ò mu o̩
bori. Ifé̩ lati bori awo̩ n omiran aye re̩ ni o da lori igbiyanju re̩ lati ri daju wipe Oruko̩ O̩ lo̩ run ni a fi ogo fun
ati ife̩ lati rí I wipe liana O̩ lo̩ run fun ye re̩ wa si imus̩ e̩. Onigbagbo̩ gbo̩ do̩ ni oye wipe O̩ lo̩ run ga ju awo̩ n
omiran aye wo̩ n lo̩ . Ni Pataki, omiran ti o ga ju dabi e̩ l é̩te̩ niwaju O̩ lo̩ run alagbara. O̩ na ti a le gba lati bori
awo̩ n omiran aye wa ni a ti fi han wa lati inu Bíbélì. Awo̩ n ohun elo ti o wa laro̩ wo̩ to fun onigbagbo̩ bi
igbagbo̩ , adura, iwa-ododo, È̩ jè̩ ati oruko̩ Jésù , ije̩ wo̩ igbagbo̩ ati Ò̩ ro̩ O̩ ló̩ run ni ti gbe ye̩ wo pe̩ lu aridaju
agbara ati ipa wo̩ n lati igba-de-igba., iran-de-iran. Ije̩ wo̩ ti igbagbo̩ wa ma n fi ogo fun O̩ lo̩ run, yoo si tun
fun wa ni is̩ e̩gun ti o daju lori gbogbo awo̩ n omiran, ti e̩ mi tabi eyi ti a le fojuri.
1. ÌJÀ ÀTI ÌDOJÚKO̩ LÁTI O̩ WÓ̩ ÀWO̩ N ÒMÌRÁN
Orin Dáfidì 34:19; 1 Sámúé̩ lì 17:1, 10; Ìs̩ e 7:34; 2 Kó̩ ríntì 2:4; 6:4; 8:2;
Idojuko̩ awo̩ n omiran, je̩ ko-s̩ eé-má à ní fun onigbagbo̩ . Onigbagbo̩ ko̩ o̩ kan ni o ni ipin idojuko̩ lati lati o̩ wo̩
awo̩ n omiran wo̩ nyi, oris̩ iris̩ I awo̩ n omiran ni o si ma n dojuko̩ onikaluku ninu aye. Awo̩ n omiran ti e̩ mi
wa, bakan-naa ni awo̩ n omiran ti a le foju ri. Awo̩ n e̩ s̩e̩ iko̩ ko̩ , igbiynju lati gbo̩ nje̩ ge̩ , aisan, ipo̩ nju, aini,
idamu, ilo̩ wo̩ o̩ wo̩ , ìdíwó̩ si ilo̩ siwaju, ijakule̩ ni-igba-gbogbo, Aini-aini, ati awo̩ n o̩ po̩ lo̩ po̩ iru awo̩ n nkkan
bé̩è̩ ni o je̩ awo̩ n omiran ti n dojuko̩ o̩ po̩ lo̩ po̩ loni. Awo̩ n omiran miran si leè wa lati mu awo̩ n orile̩ -ede, ijo̩
tabi e̩ bi s̩ ubu. Fun Dafidi, omiran ti n dojuko̩ aye re̩ ni akoko yi je̩ Gò lá ítì to Gá à tì, e̩ ni ti o fe̩ fi oruko̩ O̩ lo̩ run
pe̩ gan, ki o si mu ogo-O̩ lo̩ run kuro ni ile̩ ná à . Nini imoye ge̩ ge̩ bi onigbagbo̩ is̩ e-pataki lati dojuko̩ awo̩ n
omiran-aye wo̩ n, ni yó ò fun wno̩ ni anfani is̩ e̩gun ni kiakia lá ti o̩ wo̩ O̩ lo̩ run. È te awo̩ n omiran wó̩ nyi ni lati
mu o̩ kan, è̩mí ati wa rè̩wè̩sì, kí ó si so̩ wa di alailagbara nipase̩ ibas̩ epo̩ wa pe̩ lu O̩ lo̩ run, nipase̩ mimu
igbagbo̩ wa ninu O̩ lo̩ run dinku sí i, ki o si mu wa padanu ilu-o̩ run nike̩ hin. Awo̩ n omiran wo̩ nyi je̩ o̩ ta-
o̩ kan re̩ , ti o ko gbo̩ do̩ gba wo̩ n lá à yè lati bori.
2. ÌGBE̩ KÈ̩ LÉ ÀTI ÌJÉ̩ WÓ̩ ÌGBÀGBÓ̩ NÍNÚ O̩ LÓ̩ RUN
Rómù 8:37; 2 Tímótíù 1:12; Acts 27:22; Fílípì 4:13; 2 Tímòtíù 4:18; 2 Kó̩ ríntì 1:10
“Sáùlù sì wí fú Dáfídì pé, Ìwo̩ kò leè te̩ Fílístínì yí lo̩ láti bá a jà; nitorípé ò̩ dó̩ mo̩ dé ni ìwo̩ …” (1 Sá mú é̩lì
17:33). Ó je̩ ohun ewu bí ó bba jé̩ wipe igbese̩ wa da lori awo̩ n o̩ ro̩ ti awo̩ n eniyan n so̩ dipo ti o ye̩ ki a gba
ohun ti O̩ lo̩ run so̩ nipa awo̩ n omiran ti n dojuko̩ wa. Ninu ikaanu, awo̩ n-abani-damo̩ ran, awo̩ n ara, mo̩ le̩ bi ati
awujo̩ , leè gba wa niyan wo̩ nyi, eyi ti yó ò já si iparun wa. S̩ ugbo̩ n Dá fìdì wi pe “…Oluwa ti ó gbà mí ló̩ wó̩
kìniún, àti ló̩ wó̩ àmò̩té̩kùn, oun náà ni yóò gbà mi ló̩ wó̩ fílístínì yí… Lóni yí ni Olúwa yóò fi ìwo̩ (Gòlíátì) lé
mi ló̩ wó̩ , èmi yóò pa ó̩ , èmi yóò si ké orí re̩ kúrù ní ara re̩ …” (1 Sá mú é̩lì 17:37, 46). Igbe̩ ke̩ le ninu O̩ lo̩ run ma
n wa nipase̩ ije̩ wo̩ ipò ati ìgbà gbó̩ o̩ wa nínú Rè̩. À amì ako̩ ko̩ si ijakule̩ ni ije̩ wo̩ ti o lodi, ibe̩ ru ati ijá à yà , bakan
ná à gbese̩ ako̩ ko̩ si is̩ e̩gun lori awo̩ n omiran ni ije̩ wo̩ igbagbo̩ ti igbe̩ ke̩ le nínú s̩ is̩ ees̩ e O̩ ló̩ run. Dafidi pinu lati
wipe ohun ko ni ri Goliati ge̩ ge̩ bi omiran nipase̩ ije̩ wo̩ igbagbo̩ re̩ , oun ko ri is̩ oro ná à ge̩ ge̩ bíi is̩ oro, s̩ ugbo̩ n o
pinnu lati O̩ lo̩ run as̩ e̩da Goliati. O je̩ wo̩ is̩ e̩gun, o sì ríi gba. Awo̩ n o̩ mo̩ -Heberu me̩ te̩ e̩ta je̩ wo̩ is̩ e̩gun wo̩ n lori
ina-aileru Nebokadrinesari, wo̩ n sì ríi gba. Obinrin ara-Shunammitì ni je̩ wo̩ wipe “Ó dá ra” o si ríi gba ba ge̩ ge̩
bi o ti jé̩wó̩ rè̩. Márthà je̩ wo̩ iye lori arakunrin-aburo re̩ , Lá sá rù , o si ríi gba. So̩ ó̩ , kí o sì rí i gba.
3. ÌS̩ É̩ GUN ÀWO̩ N OLÓÒTÓ̩ NÍPASÈ̩ O̩ LÓ̩ RUN
É̩ ks̩ ódù 14:13; Dáníé̩ lì 11:32; 2 Kó̩ ríntì 2:14; Ìfihàn 12:11; 1 Sámué̩ lì 17:50
Nínú ò ye o̩ mo̩ -eniyan, Dafidi je̩ o̩ do̩ mo̩ de, alailagbara, alailoye, s̩ ugbo̩ n lati iwoye ti o̩ run wa, o je̩ jagunjagun
alagbara, e̩ ni ti O̩ lo̩ run yó ò lo lati mu ogo-Rè̩ wa si Israe̩ lì.“Bé̩è̩ni Dáfídì sí fi kànàkànà òun òkúta s̩ é̩ gun
Filístínì náà, o si pá a; s̩ ùgbó̩ n idà kò sí ló̩ wó̩ Dáfídi”” (1 Sá mú é̩lì 17:50). Oris̩ iris̩ I is̩ e̩gun ni o ma tè̩lé ije̩ wo̩
igbagbo̩ . Nigba ti a ba fi adura, iwa-ododo, igbagbo̩ ninu o̩ ro̩ O̩ lo̩ run, igboya ijolooto̩ , ati igbo̩ ran, ije̩ wo̩ igbagbo̩
po̩ mo̩ ije̩ wo̩ igbagbo̩ wa ni o ma n mu ki dide lati ran wa lo̩ wo̩ . Is̩ e̩gun lori e̩ s̩e̩, s̩ isn, ipo̩ nju satani, idojuko̩ ,
idena, iku, ai-s̩ oriire, ijakule̩ , ati oris̩ iris̩ I awo̩ n omiran miran ni awo̩ n ti o ba gbe O̩ lo̩ run wo̩ n ga nipase̩ ije̩ wo̩
igbagbo̩ yó ò ri gbà . Fi oju igbagbo̩ wo awo̩ n omiran ti n dojuko̩ o̩ loni, ìwo̩ yó ò sì ríi daju wipe ko si ibe̩ ru fun
awo̩ n o̩ mo̩ -O̩ lo̩ run.

You might also like