You are on page 1of 1

Okànràn kan síhìn ín

Õkànràn kan söhùn ún

Õkànràn méjèèjì

Abìdí gbòdí

Adífá fún Oya Òkàrà

Tí n' relé Ìtilê réré

Èyin Omo Oya dà?

Àwa rèé ó!

Hèè éé, a n'bo Oya wa

Eeepa Oya Oriri

Oya Òkàrà!

Aya Sàngó.

La gran madre que con su fuerza doblega al búfalo!

Aború Aboyé!

You might also like