You are on page 1of 3

12 (45) OÒGÚN ÈHIN DIDÚN Ogbè wèhin, 18

Ewé fèjè sèhin


Orno ataare mérindílógún
A ó lò ó. A ó pe ofo re. A ó sín gbéré mérindílógún si èhin, a ó si fi pa á.
Fèjè sèhin bá mi wó èhin sàn
Ataare ti mi 1 'éhin. 12 (45) OÒGÚN ÈHIN DIDÚN Ogbè wèhin, 18
Ewé fèjè sèhin
Orno ataare mérindílógún
A ó lò ó. A ó pe ofo re. A ó sín gbéré mérindílógún si èhin, a ó si fi pa á.
Fèjè sèhin bá mi wó èhin sàn
Ataare ti mi 1 'éhin.

13 (47) OÒGÚN ÈHIN DÍDUN Ogbè wèhin, 18


Ewé àsokára
Ewé ègbèsi
Egbò ègbèsi
Èèpo ègbèsi
A ó sè é nínú omi, a ó máa yó omi ré mu ní èèmçta lójoojiímó, a ó si máa pe
ofò rè pèlú.
Asokára májé kí arún se mi lára
Ègbèsi bá mi wo èhin mi.
14 (49) OÒGÚN ÈHIN DÍDÚN Ogbè wèhin, 18
Ewé ekhue
Egbò gbogbohse
Eso èèríi ijú
Egbò ipetà
A ó sè é nínú omi, a ó pe ofò rè, a ó si máa mu ún ní àràáro.
Ekhue kó èhin Io kó sàn
Gbogbonse se àrún èhin kó sàn
Eèrú ijú kó rú ú si ijú
Ipetà kó ta á dànú.

27(108) OÒGÚN AREMO Èjiogbè,


1

Ewé ikín irúkè


Ewé èsisi ilè
Egbò ògbòlò
Kán-ún bílálà
lyò
A ó gún un, si sá a gbç, a ó fi tefá, a ó pe ofò rè, a o si máa mu ún pèlú èko
gbígbóná 1 'ójoojúmó.
Ewé ikín gbómo wá
Orno roro ni ti èsisi ilè
Orno ki í tán nídí ògbòlò
Kán-ún bílálà Ia ònà orno wá
lyò kí ó yo orno wá.
28(110) OÒGÚN AREMO Èjiogbè, 1
Egbò enísà oògún )
Odidi ataare méwa
Ogèdè àgbagbà dúdú
A ó lò o pò, a ó fi tefá, a ó pe ofò rè, a ó gún un pò mó ògèdè àgbagbà dúdú
(léhin ti a bá ti yo èèpo rè). A ó máa mu ún pélú otí líle tàbí èko.
Enísà oògún bá mi sà oògún sókó mi
Kó máa ní agbára
Agbára káká ni ti ògèdè àgbagbà
Ara yíyá gagá ni f'ataare.

31(132) OÒGÚN AREMO Ogbè òsá, 25


Ewé àpòngbé
Ewé ògbòlò
Egbò tipè tipè
Odidi ataare kan
Igbín kan
Jó o, fi tefá, pe ofò rè, pò ó pò, si máa mu ún pèlíí èko gbígbóná 1'ójó meta
meta.
Apòngbé pon orno wá
Ògbòlò gbé orno wá
Tipè tipè Io rèé fa orno temi wá
Àtomodómo láá bá igbín
Ara yíyá gagá ni t'ataare.

42 (181) OÒGÜN À TÒSÍ Ogbè bàrà,


22

Ewé abéròdéfè
Ewé àgbásá
Èèrú
Aidan
A ó gún won pó, a ó sè é, a ó pe ofò rè, a ó fi sínú igò. A ó mu síbí kan
láàrò.
Abéròdéfè bá àtòsí kúrò Vara
Agbásá ní kí ó ma á sá Io
Èèrú k'ó rú ú kúrò
Aidan rnáà jé kí ó dan mi o.
43 (182) OÒGÜN ÀTQSÍ Ogbè òtúrá,
28

Ewé òbò esin


Eèrú
Ewé itàkún òkéré
Ògèdè agbagba dúdú
Kán-ún bílálà
A ó gún won pó. A ó pe ofò rè. Mu ún pèlú èko gbígbóná.
Obò esin ní i wo àtòsí sàn
Èèrú ru àtòsí kúrò
Itàkún òkéré ki í I 'átòsí
Kán-ún bílálà ni o fi kán-an
Ògèdè àgbagbà ki í se àtòsí.

42 (181) OÒGÜN À TÒSÍ Ogbè bàrà,


22

Ewé abéròdéfè
Ewé àgbásá
Èèrú
Aidan
A ó gún won pó, a ó sè é, a ó pe ofò rè, a ó fi sínú igò. A ó mu síbí kan
láàrò.
Abéròdéfè bá àtòsí kúrò Vara
Agbásá ní kí ó ma á sá Io
Èèrú k'ó rú ú kúrò
Aidan rnáà jé kí ó dan mi o.
43 (182) OÒGÜN ÀTQSÍ Ogbè òtúrá,
28

Ewé òbò esin


Eèrú
Ewé itàkún òkéré
Ògèdè agbagba dúdú
Kán-ún bílálà
A ó gún won pó. A ó pe ofò rè. Mu ún pèlú èko gbígbóná.
Obò esin ní i wo àtòsí sàn
Èèrú ru àtòsí kúrò
Itàkún òkéré ki í I 'átòsí
Kán-ún bílálà ni o fi kán-an
Ògèdè àgbagbà ki í se àtòsí.

48(195) OÒGÚN ÈDÀ Ogbè sá, 25


Ewé amújè wéwé
Eèpo amújè wéwé
Alúbósà eléwé
Kán-ún bílálà
A ó lò ó. A ó pe ofò rè. Si màa mu ún pèlú eko gbígbóna lojoojumo.
Amújè mú èdà Io
Alúbósà k'ó sa èdà kúrò
Kán-ún bílálà ká èdà Io.

66 (241) OÒGÜNLÓBÜÚTÜÚ Ogbè òyèkú, 17


Ewé èsisún
Egbò èsisún
Èèrú
Òrí
A ólò ó pèlú òrí. A ó tefá lórí iyèròsún, a ó pe ofo rè, a ó da á po. Fi ra ara.
Èsisún sún lóbúútuú Io.
Èèrú kó ru lóbúútuú Io.

You might also like