Professional Documents
Culture Documents
10 (36) Oògün Ara Yíyi 28
10 (36) Oògün Ara Yíyi 28
28
Ewé òwatètè
Igi rogbo àgúntàn
Ewé totó
Egbò totó
A ó sè é nínú omi, a ó pe ofò re, a ó si máa mu ún ní èèmeta lójoojúmó.
Òwatètè bá mi tún ara se
Rogbo àgúntàn ki í ká ti
Ewé totó ló ní kí ara mi ó máa dán
Egbò totó ló ní kí ara mi ó máa dán.
Èjiogbè,
52 (206) OÒGÚNIKÚRA
1
Ewé òjíjí Ogbè
Eja òjíjí ate,
A ó Io ó, a ó sè é pèlú eja òjíjí. A ó pe ofò re, a
óje é.
Ojíjí wá bá mi jí ara mi t 'ó kú yíí.
53 (207) OÒGÚN ÍMÚ OKÓ YO
29
Ewé abíwéré
Abéyç ògèdè
Eèsún
Òrí
A ó lò ó/a ó dà á pò pèlú òrí. A ó sín gbere yíká okó a ó si sín eyo gbere kan
si òrí okó. A ó fi ògún yií pa á.
Ejiogbè, 1
79 (293) OÒGUNARA WÍWO
Ewé keké èkeji
Ewé òdúndún
Òrí
A ó lò ó, a ó dà á pò mo òrí. A ó pe ofò re. A ó si fi pa ara.
Keké èkeji wá kó ibi kúrò Vara mi
Tútú dúndún lá á bá ç>dúndún.