You are on page 1of 5

OLORUN NINU ISAKOSO

Chorus:

Olorun ninu isakoso, Isakoso awa eniyan

Olorun ninu isakoko, Isakoko eto eniyan

Call: O da ile, O da omi, ninu akoso eniyan

Resp: Olorun ninu isakoso, isakoso awa eniyan

Call: O’deniyan O’deranko, Ninu akoso eniyan

1) Olorun to po ni ipa, to tun po l’agbara

O da nikan se’joba Iwo logo ye
I am that I am, Almighty Father
E da oke, E d’ohun gbogbo, ninu akoso eniyan

Chorus:

2) Ijoba Re Baba, Iwo nikan l’oye

Ko tete ye Josefu, lojo ojo yen
Won taa s’oko eru, ase k’ala re le se ni
Ere ni awada ni, o di prime minister
Gbogbo ogo ye fun o, Oba to s’akoso Josefu

Chorus

3) K’ilofa ‘poruru okan, baba ati mama?

Olorun isakoso o mbe lenu ise
O da si ti Josefu, O dahun si Jabesi
Niwoyi amodun, e o de wa sope
Ohun l’Olorun isakoso, isakoso gbogbo eniyan

You might also like