You are on page 1of 1

*ASEJE OWO **

eso opoto die iye agbe meji iye aluko meji ikode meji iye lekeleke meji ao lo gbogbo re loto loto,ao da papo ao
ge okan malu si merindinlogun ao fi eroja yi se lepo niyo ao wo aso funfun ti aba fe je aseje yi

*OSHO OWO GIDI*

odidi igun aye kan ao du sinu oti senti remy kan ao wa la laya ao ki ako alangba meta si ninu ao gbe sinu ikoko
ao ko ewe ewuro ojo topo bomole ao jo ao lo kuna dada ao ma fi oti yi lo laro monday ati thursday odaju...

You might also like