You are on page 1of 5

Cantigas de Oba

MODUBÍ

1. Alakoro kini sagun (bis)


Baba sagun
Sagun lepe

2. Obá Sagun
Oba Sagun já pele pe o

3. Obá Saba
Obá Saba basa rewa o

4. Ile inu o
Oba d’uro de
Oba saba o
Oba d’uro de
Sari ejo

Ogun t’ode
Sari ejo

5. Obá eleko
Aja osi
Saba eleko aja osi
Oro oba olo oba
Obá eleko aja osi

6. Inu oja la oje


Saba oja la oje
Inu ofa fara man
Ofa loja la oje*

7. E nu ere ofá were


E nu ere ofá were o

8. Fere re kun fere re


Olo firi a tafa r’oman
9. Na jize na jize
Moba do sokun
Ure ure
Moba do bi man
Ure lekó
Moba do sokun
Ure ure

10. Olua mi de koabo (bis)


Obani oyo koabo
Olua mi de koabo*

11. Oba l’oba were


Oba l’oba were
Oba oluwo koabo
Oba l’oba were*

12. To to to ofa l’ewa


Ni popo leluo*

13. Oba funfun fun fohun


Olowo biri biri orun

Oba ni gbuse se ke ni l’aiyagba


Oba ni gbuse oloore oni papo

14. Oba leke moyo


Oba leke moyo
Guere san guere san koja bere
Guere san guere san ki soba
Oni po b’oye
Oni po b’oye ajale*

15. Oba onikan eru ja\ja


Biri biri ikan gbero gbero ja
Osi eleko
Biri biri ikan gbero gbero ja

16. Oba niye


Niya kamure
Oni gb’orun
Osi osi asaw’ere

17. Osi t’awa mini iji kiti igbu


Oba injena t’awa

18. Erun l’oko erun l’oko


Oba b’ena erun l’oko

19. Olowo biri wo


Aiyagba k’osun afere ja

20. Oba nigbu dan dain


Oba nigbu dan da ore
Iru ofa ofa
Oba nigbu dan dain

AGUERE

21. Oba iwoba ferere nazana


Oba nazana l’osun gba l’aja*

22. Najize toto wa


Oba m’osokun b’orikan
Oba m’osokun berunja
Totohun berunje
Oba m’osokun b’orikan*

23. Oba in oba berunja (bis)


Oba aja osi
Oba in oba berunja*
EGÓ

24. Oba ezo k’were


Dabi aro

Oba ezo k’were


Dabi aro
Oba ezo k’were
Akara o

ILU

25. Ogun l’ode o


Si l’odo iye*

26. E l’oya sibor’oja


Si bor’oja uni

27. Oba l’aka lobe we


Oba l’aka

28. Iya m’ogun k’olo gbolo gbo a sire


Oba binikan

29. Oba bi l’oya o


Oba bi l’oya o
Oba sare l’oja
Oba bi l’oya

30. Biri biri eleko


Oba sarin a t’ode
Biri biri eleko
Oba sarin a sil’ewa

31. A sahunto
Oba sahunto
Fere we ofa leje
A sahunto*

32. Baba sagun o


Baba sagun oberunja

33. Ilu mi panda meje


Oba sarewa

34. A iru k’omo oba


Ta ni iya k’omun a berunja

35. Alakore
Alakoro

Fere akun fere


Ogun fara já o

36. Ode l’ode o


Si l’odo iye

37. Ma un ma un
Ode in Oba tafa ra

38. Aja igbo mi o


AJa k’oro de ofa r’aja

39. Ta t’oju ke dabi Omã


Oba tafa
Dabi Omã

40. Mona mona mona ofa gere


Aja osi

41. Ofa ofa ge gere


Jo kologbo mor’ofa
Ofa ofa ge gere
Kologbo gbo mor’ofa

ALUJA

42. E kopa kopa pe Obá


Kopa kopa pe Obá o

43. Oba sarewa


Ere omo je ege
Godo godo la o dere ese
Oba sarewa

44. Oni lekere


Oni lekere
Oba l’ajo*

NLÓ

(ALUJA)
45. Oba arae pere o
Oba erun jo jo

You might also like