You are on page 1of 9

Cantigas de Omolú

NPA NJÉ

1. Sa huni kota
Sa hunde
Go ro go ro
Go ro go ro
Sa hun

2. Obaluwaiye
Senin senin k’ode
Senin senin k’ode atoto
Senin senin k’ode araiye

IGUIDÁ

3. Eji popo
Saba lê ju á
Na wa e
Jô jô ori korio
Omolu sa lê ju a
Na awa e
jô jô ori korio

4. A ida fará
Faro gi
Ida fará
Fare jô
Eji popo
Omonile
A ida fará
Fare jô

5. Omolu bre
Fará e
Omolu bre
Fará o
Omolu bre
Fará e
Omolu bre
Fará go go

6. Danko ba ewa
Tani bo
Koni sa welé
Tani bo
Koni sa wele
Tani bo
Eru jo jô

7. A fara jô
Koni sar’ewa
Sar’ewa
Kaja
A fara jô
Koni sar’ewa
Sar’ewa
Kaja

8. A fara jo
Koni sawe lê
Irile gbale
Afara jo
Koni sawe le
Irile gbale

9. Oni lewá
Lese orisá
Ofe ire
Oni lewá
Lese orisá
Ofe ire

Mo giri lowo
kolobo Sin sin
Sin sin kolobo
A kolobo wo
kolobo
Sin sin
Sin sin
Kolobo

10. Unji a la
Wure
Ase lebe le
Be ko oro
Gi toke
Gi koko ruo
Ase lebe le
Be ko oro
Unji koko ruo
Ase lebe le
Be ko oro

11. Eruyan
Eruyawo
Afa rajo
Ko n’ile o
Onie ara e
Eruyan
Eruyawo

12. Eruyan
Eruyawo
Baba sare
L’oja rewá
Onie ara e
Eruyan
Eruyawo

13. Ta la be okorin
Egi owo
Ta la be okorin
Aso duro
Lori jena
Olowaiye
Ta la be okorin
Oni a lori jena
Aso duro
Lori jena olowaiye
Ta la be okorin
Gan in gan insewe basi l’otun
Gan in gan insewe
Aso duro lori jena olowo t’ala be okorin

14. Adaba o
So ju
Mo fere
Adaba o
Aje luman ye
Adaba o
So ju
Mo fere
Adaba o
Ki sajo
15. Mofori mowa
Mofori mowa
Mojé mojé
Mofori gbalé
Mofori mowá
Mojé mojé

16. A baila beruja


A baila beruja
A baila e
A baila beruja

17. Awasa re loni


Lode ba iwa
Lodo o banba
A e lode ba iwá
Lodo ba isá

18. Awa de kete


Awa ni sare loni o
Bele iko
Salare
Sare loni
Bele iko

19. Omolu kwe olore


Kan ure koabo
Omolu kwe olore
Kan ure koabo

20. Aro aro law’ejo


E ni gbogbo ase bowa
Ni gbogbo Omo nile
Aro aro lawejo

21. Mafa mafa


Jure mafa
Araiye jojo
Arawe Omo nile
Araiye jojo

22. Omolu npa j’oba ala iko


Oni e
Omolu npa j’oba ala iko
Oni e
23. Toke da juá
Toke da juá
Toke da juá e
Toke da juá

24. Ejo a lê ijo


E jô ale ijo
Ejo ale ijo afarajo
Ejo ale ijo a um bele

25. A unji m’ada rao ma d’ago


A munha munha
Onie unji um já de

26. Osi e k’ogbo ale o


L’ori njena bamba
Osi e k’ogbo ale
L’ori njena bamba

27. Ejo ala ke w’ajo n’ilé ( bis)


Ara e oju n’ilé
Ejo ala ke w’ajo n’ilé

28. Nilo niloye


Nilo niloye
Mahun mahun gba
Nilo niloye
Nilo niloye
Mahun mahun gba

29. Araiye baba onijale


Araiye baba onijale
Onie araiye baba onijale o

Azunsu araiye
Baba onijale o
Afomon araiye
Baba onijale o

ILÚ

30. E janbele kewa o


E ke’wao ofã rajo

31. Ni kogbe n’ise


Kini kini sare loni
E sare loni
32. Mo in mo in
Lase
Ase m’ori wo

33. Gbele ni ko gbele


Saworo lese
Arawa

34. Ewa ka ki ba iwa o


A ka ki ba iwa

Kole kole saworo


Kole kole saworo

35. Eru yé
Ori un má
Jagun na
B’ori un má

36. Sasara gbalé fun wa o


Gbalé gbalé
Sasará gbalé fun wa o
Gbalé gbalé

BRAVUN

37. Omolu Kaká mo da kue re 2x


Sobo idan
Azoane
Sobo idan
Azoane

38. Savalú kue humbono


Savalú kue ma l’oye
Ae ae ae
Savalú kue ma die

39. Molu fie


Omolú k’ayo
Ae aze
Oko fi
Omolú k’ayo
Ae aze
40. Bozila bozi zumba
Bozila bozi zumba
Bozila e vodun maiokwe
Bozila e vodun maiokwe

41. Me hunto ti la l’oye ae


Ae aze
Me hunto ti La l’oye ae
Ae aze

42. Omolu bagadaye m’odi di monaye (2x)


E mao ida w’ero
E mao ida w’ero
Ie e

43. M’ako gbo nun to to to e m’ako gbo nun ago ojise (2x)
Azunsu e k’ojise
Azunsu e k’ojise e me hunto
M’ako gbo nun to to to e

SATÒ

44. E vodun maiokwe


Sasara zon ma l’oye
A njo e vodun maiokwe

45. E ma se to
Ma se to
Ma se to to de
Ahun jelé me huntó
Ma se to to de

46. Inle pipokan


Inle pipokan
Sin sin
Inle pipokan
VAMUNHA

47. Ae ae aparada
Ae ae aparada o

48. Olorinjena ewa pade


Olori pa
Olorinjena ewa pade
Olori pa

49. Ewe fu o ae
Ewe fu o ala ina
Ewe fu o jagun
Ewe fu o ala ina

50. Nji bara t’oke ni bara mi


Nji bara l’oko

51. Elobi w’aiye t’ori gbami


Jan pepe

52. Omolu m’oni gbinin


Fara fara fara nji

53. Agbo l’oin Omolu ja


Gbo l’oin ago

54. Nji d’ago l’ona k’ewa saoro


D’ago lele
D’ago l’ona k’ewa saoro
D’ago lele

55. E n’ado nagba iwa


M’oba wa ima wa
E n’ado nagba iwa
M’oba wa i m’awa e
ILÚ-K’ORIN IDÁ JAGUN

56. Aiye ee baba ekitio (2x)


Olorun iko Jagun o baba ekiti o
Olorun iko Jagun o baba ekiti o
Aiye ee

57. Baba agemo r’ewo


Baba Jagun oba iko

58. Alapa Jagun aiye (2x)


Alapa aja wo
Alapa Jagun aiye

59. L’oja l’oja osogbo Jagun


L’oja osogbo

NLÓ
(IGUIDA)
60. Owo la gbanba
Eji owo
La gbanba

61. Fele fele mi gba iro


E un ji Omolu do
Fele fele mi gba iro
Azunsun awa nile

You might also like