You are on page 1of 5

Cantigas Osogiyan

ILÚ

1. Awa s’oro

Awa s’oro n’ile

Oro ipe o

Awa s’oro

Awa s’oro n’ile

2. Bo lo ro ti fe in sin

3. Awa jun si

Awa jun si t’ogun

Oro ipe o

4. Ajagunan biti e

Ajagunan bitiode

5. Ajaguna bitiko

Ajaguna bitinmole

6. Bi ero bi ero

Orisá oko bi ero ode

7. .Orisa danko bi ero ire

bi ero bi ero
8.  Awa S’oro mele rin

Orisá oko s’oro fé in sin

9. S’oro mele rin

Omore kun s’oro fe in sin

10. Gbeleje gbeleje

Atoriman ajan be l’eje atori

11. A ina k’oro pank’ala

E pank’ala e pank’ala

Ina k’oro pank’ala e pank’ala

12. A ina k’oro iya ipe o

. E iya ipe o e iya ipe o

A ina k’oro iya ipe o

E iya ipe o

13. Ajagunan gba wa o ajagunan (BÍS)

Elemoso baba olorogun

Ajagunan gba wa o

14. Baba e ire baba

Baba ko gba osogiyan

Orinsala ke epa

15. A ka ka un bó

O ku o (oko de)
16.  Ipê funfun Ipê r’ipe o

Ipê r’ipe o ipê funfun

Ipê ri m’ode ipê r’ipe o

17. Baba oro

Baba oro

Baba oro kafujian

Baba oro orisala

18. Ajaguna biti (bis)

Ajaguna bitiko

Ajaguna biti

19. Akinjolé baba oge o

Ipê awa o

Akinjolé baba oge o

Ipê awa o

20. Akinjolé baba atori (bis)

Akinjolé nko giyan

Un lor’ogun baba atori

21. Baba kan bi Kan bi ode

Baba kan bi kan bi ode

22. Kunbalé mi sire re o

Kunbalé mi sire re o orisa r’oko

Kunbalé mi sire re ko

Oj’aro

23. Orisa r’oko kun fe iyewe Ita ni mo w’imo omo mimo (bis)
Orisa r’oko afefe iku

Ita ni mo w’imo omo mimo

Orisa r’oko afefe ira o

Ita ni mo w’imo omo mimo

24.m’ada ara o l’epe min

M’ada ara ala nle p’okan

25. Baba okuto okuto n’íle

Baba

Okuto okuto n’ile

26.Inako oro ala ipe l’eja

Olo r’ipe

MODUBÍ

27. Barere ke mi barere

Abuke ke mi barere sin

28.Kun barere kun barere sin sin

Kun barere

29.E un ko é un aloro

E un aloro kewa lese

30.Baba Burukan bi ile

Baba Burukan abi etu

31.Baba burukan e yawo


Baba burukan e yawo

32.Kunle kunle mado b’ewa

Fein fein baba

NLO

(ILÚ)

33.Ati egbe a ipe murelo

Ipe o

Ati egbe a ipe murelo

Ipe o

You might also like