You are on page 1of 5

Cantigas de Ayrá

MODUBÍ

1. Omo n’ilè Ayrá omo j’ilè


Ayrá Ayrá
Omo n’ilè Ayrá omo j’ilè
Ayrá Ayrá

2. Ago ago in bè o (bis


Ayrá ojo
In bè o
In bè o
In be o
Agò agò
in bè o

3. Ada o in bè o (bis
Imorosun
in bè o
Ada o
in bè o
Ada ò
iyorosun
In bè o
Iyorosun
Ada o
iyorosun
In bé o
iyorosun

4. Fire w’ajo K’opa l’aiyo (bís)


Omo indè omo r’ewá
Fire w’ajo
K’opa l’aiyo

5. Ayrá osi igba iyamí


Man saworo
Ayrá ayrá

6. Osi e da b’Ayrá
Ayrá osi berè ó

7. Ago ago fire wá


Intilé fire wá
Ayrá ojo
fire wá
Ayrá mode
fire wá
Ayrá Igbona
fire wá

8. Ayrá k’ole pa l’asè


Ago ago fire wá
Omo rewá
K’opa l’ase
Ago ago
fire wá
Ago ago
K’opa l’asè
Ago ago
fire wá

9. Onie awa d’ode erun jeje


igbonan iroko mo esa afonja
awa d’ode
erun jeje olori pe

10. Igbona k’ogbo n’ise


Ayrá o re lê (4x)

11. A intilé ni k’ojo k’opo m’ore (2x)


Ni k’ojo
K’omo ore
Ni k’ojo
K’opo omo ore

12. A unji re
Ayra o intilé ayagba
A unji o onilé on’ile baba r’ewa
AGABÍ

13. Loke baiani


Ayra mode Iná
E motinja

Ke ni’ya motinja
Ke n’iya motinja

14. Ayrá o re gede npá


O re gedè

Ayrá o ajaosi npá


Ajaosi

Ayrá o ebora npá


A Eborá

15. Loni loni motinja


Loni loni motinja oni

E motinjá motinjá loni


Ni a motinja

16. Ayra ina m’ode


L’oke ina pabo
Ayra m’ode l’oke mi fara p’abo
L’oke mi fara p’abo l’oke mi fara p’abo

17. Ayra l’ojo b’ore mi o


Ini a motinja

18. Ayra igbona lele k’oye


Ayra o
O lele k’oye

19. Mugue mugue gue


Sarere m’oro d’oje
Mugue re m’oro d’oba
Marere mor’oje

20. Kini lebi s’oba k’were


Ari jan jan kini jan

21. Oni a oke baiani


Bangbose obitiko
Bailase oni a oke baiani
Bailase

22. T’emi t’emi o T’emi t’emi odò (bís)


Ayrá o re guede re guede
Re guede saworo

Re guede
Re guede saworo

23. T’emi t’emi o T’emi t’emi odò (bís)


Ayrá o Intilé
Mo rewá
Re gede saworo
Re gede
Re gede saworo

24. T’emi t’emi o T’emi t’emi odò (bis)


Ayrá o Intilé
Mo rewá
Sekelè
Saworo
Sekelè sekelè
Saworo

Re gedè
Sekelè
Saworo

ALUJÁ

25. Firi ina firi ina


Firi ina
A ezo
Ayrá ayrá
Firi ina a ezo
Firi ina
Mu rele
Firi ina
A ezo
Ayrá ayrá
Firi ina
A ezo
A ezo
26. Ayrá l’ojo kope rese
Kope rese

27. Bamba ezo ezo bamba


Bamba ezo

28. Sango ke mi npa ke mi l’ode o


Ayra ayra
Ke mi npa mi l’ode o
Ayra ayra

29. Ayra main m’ode (2x)


Oba ayra main m’ode
Ayra main m’ode

E ala k’we un s’oro


Main m’ode

30. Popo orisa oba wa o


Popo orisa oba wa o

31. Awa n’igbo sire (2x)


Ayra main m’ode
Awa n’igbo sire

NLÓ

(MODUBÍ)
32. Ekodidé ki s’ajo (bis)
Gba un lele Oba nlo
Ekodidé ki s’ajo

You might also like