You are on page 1of 3

1.

Babaláwo mo wá bebe

alugbirin
Oògun to se fún mi lerikàn

alugbirun
O ní ng má ma f'owó kenu

alugbirin
O ní ng má ma f'esè kenu

alugbirin
Gbo n gbò ló yo omi gègè

alugbirin
Mo f'owó kan obè mo mu k'enu

alugbirin
Mo f'ojú wo ikun óri gbendu

alugbirin
Babaláwo mo wa bebe

alugbirin
2.

Awa lo nsere egbe omo ibile akorin.

Awa la lode oni

Awa lawa nkorin

Awa la sotan Oduduwa, Atetedaye

Onile akorin.

Aterere kaiye ajakaiye

Ako erin ti njewe gbegbe

Oro gudugudu lodo egudu

Awa lawa nsere ayo

Ere Ayo tegbo seti.

Awa lawa nsere ayo

Ere Ayo tegbo seti

Aterere kaiye ajakaiye

Oduduwa ni baba

Ni gbogbo Yoruba

Oun ni Baba

Awa lawa nsere ayo

Ere Ayo tegbo seti.

Awa lawa nsere ayo

Ere Ayo tegbo seti


Aterere kaiye

Oju baba wa ko ma riran o

Apa ti maa see.

Olugini, Arin gini

Loruko Orunmila

Orunmila Baba Ifa.

Ifa la obo

Orunmila la obo.

E lo w’akoko

Ke lo woju Ifa

Eloju baba wa ko ma riran o

Apa ti maa see.

Olugini, Arin gini

Loruko Orunmila

Orunmila Baba Ifa.

Ifa la obo

Orunmila la obo.

You might also like