You are on page 1of 2

1.

ISUN kan wa to kun f'eje

O yo nihan jesu

Elese mokun ninu re

O bo ninu ebi.

2. ‘Gba mo f'igbagbo r’isun na

Ti nsan fun ogbe Re

Irapada d’orin fun mi

Ti ngo ma ko titi.

3. Ninu orin to dun julo

L’emi o korin Re

Gbat‘akololo ahon yi

Ba dake n’iboji.
4. Mo gbagbo p‘O pese fun mi

Bi mo tile saiye

Ebun ofe ta f’eje ra

Ati duru wura.

5. Duru t'a tow’Olorun se,

Ti ko ni baje lai

T'a o ma fi iyin Baba wa

Oruko Re nikan. Amin

You might also like