You are on page 1of 1

AGBELEPOTA TO LAGBARA

Iwo Maalu(Cow'shorn), iyo die(salt), igbin (snail), ose dudu(blacksoap). Ao lo Igbin(snail) naa mo ose
dudu(blacksoap), ao wa fi iyo die(little salt) si. Ao waa kogbogbo re sinu Iwo Maalu(Cow's horn).

OFORE:-Nijo ti igbin ba fi enu kan ose, nijo naa loroikariko nde ba. Nijo ti Igbin ba fi enu kan iyo, ijonaa
nii re orun. Ki gbogbo eni tobanla si emi l Omo l maa re orun loni dandan(ase!).NB:-Ao gbodo fisere
ooo,Ao lo Igbin pelu ikarahun nio,Ao maa tola ni,Eekan losu lao maa tola tabi ti aba se akiyesinkan
buburu kan.

You might also like