You are on page 1of 1

Oshole

ori olongbo tonirun meji, odidi atare meji, ewe ejinrin tutu topo dada, ao pin ewe
ye si meji, ao fi won tele ape meji nikookan, ao fi ori olongbo kookan le lori, ao
fi atare odidi kookan si, ao wa fi owo eyo tikoluju 21 sibi okan, ao wa gbe won
lena ao jo won, ao lo won loto to, eyi tafi owo eyo siye ni ao teni odu ifa
ogundabede ao pe
OFORE: ti abafa ejinrin, ejinrin afa igbo, ki eni tomomi kolepe eni tikomomi wa,
kiwon wa fi owo nla nla se ise lodo emi L omo L, olongbo koni dara titi komajale,
ogundabede o olori ole, kowa lo dagara owo nla wa funmi leni bose jinjin, bose
wiwo, bose yiya, kowa lo dagara owo nla wa funmi. Ao fi eyi tape ohun si po ose, ao
ko sinu ike fufun, ao mafi we laro laro, ao mafi Ikeji lo oti, tabatiwe dari
ODAJU

You might also like