You are on page 1of 58
‘SE ANUTIILE SADA Ewe afoma origi ‘Mesan, wo Jota ab te i oluwa lofi afoma ta igi NoRbe peluOFD: lore, tei on ae “g mo araye wa ma Ab tan lo eye ata jos) meg is fami ni iwa ata ko suntan oma ara wan mafi owo nla nla warm agban nian fi se om) re, a Ore Ala nla AN OO tent ENOGBE bakan na OMUN AE ve nfi owo wa kakiri okunrin gti ‘obinein be Hi. Ad fi'se eran 'tinu malu mesan je. Om) 2 fi epo ati lyo Ss! OFORE 1i ahs nh 0: ona ti : Omi nba Wonu agban kosi eni toye'ki omo araye ma: idl i nuveran ni tin eran ngbe tiff sanra inu lle mi oF shop mi ni kin ti man gba owo nla nla. OGUN AWURE OWO Ewe tagiri, ao gun pelu ose dudu aafi M200 te Inu ike, 20 wa ko Osena sinu ike na, a0 ma we ki orun tayo, ASEIE OSHOLE (AWURE OWO) Ad wa ewe onitikuti to tale wu (ewe timati) ao fi owo [u jemeta Pelu Gbolohun onitikuti ti olowo olola wa bami pelu awo lawo times. Ao Wa ja aolo pelu ata ijosi 16 a0 wa lora eja aro. a0 ges| ona merin ao fiseje ninu ikoko Isasun ibile lepa niyo. OGUN ISUKE, IBAN,IPAKE 3.1N 1 ‘Ao wa agban toni om! ninu kan, ao tu lori, a0 da etul bon gidi si, ao-gbe mu, haa ise meta ni nse, ti aba lo fun ibon taba mun ami re tan ao lofo agbon na si ori apata ni, isuke ao mu fasan ni, ATUDE TODAJU we ajeobale, egbo ajeobale, eno igi ajeobale, ao gun po mo ao pin-si ona meje, ao fiwe ni ojo kan na, inu ajadi gee i e mejeje pelu kainkain meje, ose kan kainkaln kan, ao diju we ‘ninu ajaji apere, le 9! wiwe re. AWURE TOGBONA GAN ‘plangbo toni irun dada, ao wa eso Jah pupa tone die, , a0 jo, ao fi pick milk Ie lojo merin lai(d) (¢ 4 lon ose N1,000 a gun ma: un, ifa, abere lopolapa al Amo ose, a o wa ko sinu avo funfun nla olomoriye @ pa obuko (1) a fun ose yi, sugbon obinrin Ke. gbodo de /5jti aso funtun ni ao ma fi bora lati we ase yi leeji \oSui | leémejt losu. odaju 4 KUN, lyan Sa, ileke Aworo awolu to daju gidi Ao lo wa ori owawa tioni irun to pe kan Odidi atare nla kan Ao jo po yio kunna daradara ao wa lo wa agbon eyikeyi tio ni omi ninu kan ao fi nkan lu oju meteta ti o wa lara agbon na ao da ebu ogun ti ajo na gba oju meteta agbon na ao ni je kio kanle mo ao wa fi owu imule we dada ao wa se adura si dada ao gbe ko enu ona Office tabi shop huuuu ero ama wa witiwiti Ese adura fun mi daada ki olorun shi oju anu wo mi 1RIMO ALABOYDN Kieko Talisman ni 3 sinu iwe miran | oOwu yellow meje didun si ki alaboyy mia sabe trori re sur ida Olorun a ki ost IWOSAN ATILISEGUN SCHEOL HAEL SEPHIROTH THAMY SCHAMAYI YEEHAH HOLYLYOMEOI HADAAM MAYBAY ELOHAYN Ni ago mefa owuro Friday ni ao ko Te! parchment paper tabi iwe felefe, Ao wa we ni owu pupa, pelt Lofinda Olorun didun si Ao ma korun tabi si abe irori wa a os segun aisan tah) Ogun ota fun wa odaju” : 1 SIN Gruko nasi arin awon image candle na ao wa di ni own fanfun atidudu J AI Ko oju si ara won.ao wa gbe kale ao wa pe oruko okunrin 2ixjao ) ao tun pe Efa (21x) 7x), iso oru ojo meta Thursday, a0 wa ge 2be ajOku ise na si arin. aruke awon mejeji pelu oruko iya won sinu patchment paper ao wah | fn-pe Adam (21x) ao tun pe oruko obinrir ao wa ka Ps 133 (7x) Ps. 45 (7x), Ruth pelu adura Ino fi'se ise yio, ac bere ni oj 6 Penaple kan to ba pon si meji ao phe penaple n Towu didu a lori mocti odo Hkiigbeao fiesec ileo Akiyesi ETO ADURA ISEGUN ATI ABO LOJU ALA, O TUN DARA FUN OMO TO NSUNKUN LOJU ORUN. ASO IBORA Ni ojo Thursday, a 0 gbe aso funfun fun tailor Lat ba w ate eti re yipo, tailor yi gbudo seemi se ise yin ini o. yio ba wa se ami agbelebu meta meta si eti aso yiii, a o mt bucket tuntun kan, a @ bu omi okun, omi osa ati St. Michael ati lofinda alagbura mej ao pa omi agbon meta si, no fi GOLD INK han seal yii sara aso na, ao sat i yio ghe, a o ki sinu awon omi ti ase eto sile fun odidi ojo meta, a o sa gbe sinu ile ti afefe yio ti ma fe si, tio bat i gbe tan, a o ka awon psalm wonyi si ninu Psalm 12, 11, 10, 13, 120, 125, 119:153-160. Pelu tian imole isegun 21 yi po. IKILO: Aso yi ti di aso agbara,a ko gbudo fi sere o, tabi fi sepe. bee ti a ban i ibalopo, owo wa ko gbudo kan yii. A le ma fi aso yi bora sun tabi ki o ma wa labe iron wa. 7 OSHO owo nla LARIN OSU MEJI EO GBATO 2 MILLION NO REPERCUTION plo ra eiye alaka aye kan, eiye igun aye kan, Ako alaamu 16 , abo alaamu 16 , Odidi atare 16 , Ewure abo ibile dudu meji , ‘obuko ibile dudu kan ...SISERE... aola aya akala yen. Aoko jko alamu 16 sini imu .eola igun:na eoko abo alamu 16 sini inu. Fo wa da aya awon mejeji de ara won cofi akisa ori oso we dada tiko ni han rara eo gbe sinu ape ilorin tuntun nla kan. foko odidi atare 16 si pelu Eojo tio ba se dic tic tinjo co pa kan si ise yen lori ina .co du eje abo eran keji si oju ti o bawa jetan.eodu eje obuke si eran ewure ao tuntun ti eofijo ise yi jlenle ibi ti_€o So ape ijogun na si. Eo wa so ogun yi kale sori eje eran obuko yen. Eofi eran yen se gara.eolo ise yi kuna ~~ ISORI AWON OTA Ori ejo agbadu ka epo obo atare kan ao jn po ao ro sado ao ni de enu ado yen rara ooo ao wa di nikobere ao gbeko senu ona yara wa ninule ISERE Eniti o ba sa siwa laburu ejo yio ge eni na je nio odaju KILOMODEMO ASINA TIPATIPA.FUN ENI TI ONA DIMO .... Ewe ako ibepe meta aogun papo mose dudu tabi eyikeyi ao ko sinu ewe ibepe miran...ao ra padluck tuntun kekere kan ao si kale aokii sinu ose naa aogbe sibi owo..ao maa bu ose yi we larolaro... Ona yio si funwa atije atimu ko nile mo.,.. Ko ju beelo..tested ok £70 ADURA LATI DABOBO ENIA KURO NINDS WAMBA MOTOR Eniti aba fe se ise yini lati han ise'yi ni ojo tio ba wun si ara jwe funfun‘pelu Blue ink ti o ba pari kiko re tan yio we ni owu Blue yio wa kan lofinda olorun didun si yio gbe seal na kale, yio wa gbe omo olo ata le lori yio tun wa tan abela funfun le omo olo ata na lori yio wa ka ps. 919(7x) pelu oruko mimo yi TEKURIBI ABORAJAH (7x) a0 wa gbadura Abo nla lowo olorun ni gbogbo ona irinajo aye wa loriewu motor ao ma fisi apo wa jadeodaju. Scanned by CamScunner N _AT|_IBUNKUN, awe funfun ojo kan ao ra ose nt ojo monday bit ebo ewe own akese, ewe dufemika, ewe . inf ua han sara awo tangatiran qwa fiomina : ie >i aaa wala pelu je eyele ¢} keyi ao Wa fi OMT yi fo ai bse a ao Wa da MISG AH POWDER ti (Dr Adonia) 3 vaka (Isaiah 60 x7) pelt pipe mo a0 Wa po par 1 : : oruko mimo tAMATON RABULIA ASERIBURA vba olorisun tt obo jowd Ssilckun ibunkun re sile fh initor y mana fun Awon om | ru sebi two lowir 4 \ asi ma Fro. ADURA FUN: Agee iseyi pel ao wa fi omi ag Pawonsugbon awon to eb: k il nto dara Siu Tun mi ¢ i ki awon alaigbagbo m Mh njeSAU-I Kankan tuntun EYINISEALNATI AN TOKASI. 08063629401 OGUN AWURE ATI EYONU ATI ASINA Ao Ewe Ewuro oojo ao olo si aju ona,ao gun ewe yi pelu ose dudu,ao fi ori,epo,ati oyin gun po dada,ao tu lofinda original kan si,ao po po,ao pa eiyele funfun kan,ao la laya,aoko ifun re kuro,ao da eyin eiyele denu awo funfun tabi ikefunfun,ao de,ao gbe sinu asunwon aso funfun,fun ojo 7,a0 mafi we ni ojo aje ati ojobo (won ma tawa lore tabi ki amari owo hee) odaju. KERUKERU ADODUN TI OKUNRIN/OBINRIN FINGBA OWO LOWO ARAWAN. Aofi ewe ajeofole my ikamudun ti obandarin loju on a, aolo mejeeji papo, aofi oripo, aomafi pa okowa, ki atolajosepo, abi ki obinrin na ofipa oju arare lasiko ti okunrin bafesunma, kosi nkan ti aolefi bere, sugban lasiko ti abanlajosepo lowo ni aobere, tiobatile bawa se adehun ,,odi dandan kobiya re,,, AO mu image candle maji ao ko Adam si ara ii | Ef si ara obinrin a0 Wa sese fiejee f oruko awon mejeji peli oruko nas: mage ti Okunrin ao ko yele runfun ti ko ni abawon lara ko. | lu oruko iya wan sinu patchment paper ao wa fi rin awen im niowu funfun atidudu nikikoojus | aruko okunrin (21x)a0 (21x) a0 tun pe Efa (21) 1 1s0 oru ojo meta lursday, a0 wa ge Adum a0 wa ka Ps Poluadura [ao fi se enaple kan t oku ise na siarin olorimoetioda EBE AWON IYAMI AGBA. Ao wa Alubosa elewe tutu ti o po die ao gun dada ao wa popo mon ose dudu. Lehin naa ao wa eyin adie Oojo ao rora fi kini kan lu lori ti ko ni fi baa Epo eyin yen je raaraa. ao jo omin eyin yi sinu ose dudu naa ao waa tun gun dada ao wa igba olomori kan ao ko ose yi si ninu ao wa fi owo waa fe oju ose yen ti polofo eyin yen ti o maa fi gba ibe ao waa fi polofo eyin yi gun ose yi lori lo gangan ibi ti ati fo eyin na ni yio koju sinu ose, Ao ma buwe nigba toba wuwa. Walahi Iseyi daju ojo tia ba bere wiwe re ojona ni yio bere ise inshalla rahaman. inira se nitori aki ridi olokw ‘akiridi ota ridi mi ki asiri mi ma: Hu Epis adura si bayi ie 1H LAHA (7x), JEHOVAH RAPHA | ao je eyin ven tiaba pada wole ite 5. ITUWOATIASINA Ewe tomato ooyo ti odawu funrare Ose dudu ojulowo Re: Ao gun Ewe tomato ati OVO Yi MO Ose dudy we niigba meje, ao wapinsionan meje. . Re: Igba meje ni ao fi we ose yi, lojojumo, Ao tits idi wa sinu ibikan ti yio wa, ito yiniaofise omi iwetia - ase yi. 2si: Alefi omi sanrawa leyin ti abati we ose yi tan. bodo kanju we ose yio. $errog oh gap nll ree ast ii selec eel Lancome, jae) ISE ANU TODJU TI AMA RI ANU GBA... Ewe oriji,;ewe owu akese,ikoide original kan,a o gun ti yio kuna dada bi eti,a ‘oo wa po lose dudu tabi funfun..Ki amawe ni araro kutukutu ki ile tomon(odaju lye agbe, iye aluko, ikoode kan, ileke itun, ileke ifa, abere meta, ewe emu, ewe didi ilufemi (ewe ata) ewe olusanu, ature kan, a0 jo ghogbo re po, ao dasi meji ao po ikan mo ose kobo mewa, ikeji oo ro sinu ado kekere kan, ao ma fi ori, 46. OGUN TLAFLNPE ENITLO BA DAKU Ao je orogbo kan ni enu, ao wa da oruko eniti o ba ku ye si, ‘OFO RE; Dundun ku o fi owo rori tetu o fi ore re ese oxtifa fun oni wanwa tin be ni iragbiji, awo ki ya ile awe, awo ma ba tire lo, ao wada oruke eniti o dakw na wipe ki ive re so pada, ao wa tu orogbo na si ni awunje ori, yio soji kiakia, 47. OGUN TLENIYAN BA NJA OLE TI AKOFE KO JALE MO. ‘Owo iki mejeji, odidi atare kan, ao jo po ao po mo ori, ao gbe fun eniti o njale ye, yio mafe pa oju ati ara koni jale mo. 48. AWORO Ori ofafiy, toni iru, a 0 ghe sinu kongo, a o da ira woro ti koni iyo si, ao ghe sile, ki esinsin pe bo, a o wa sare fi omori depa pelu esinsin nin ©, a0 ri mole ni iwaju sho, ojokojonti aba siwo, aye lamaba awon esinsin yi, koda bo se odun mefa. 49. IRIRAN Ao lete abalaye tegbotegbo, odidi atare kan, a 0 jo ninu isasun tuntun, ao da si ‘ona metal, ao la akoko pelu epo pupa, ikeji ori, adi ni iketa, 50. ‘OSELE Ao wa lili aye, a0 la mole pelu gbogbo agbara, ao gbe sinu ape, a0 fi owo mejeji bu oka baba si lekan, aa ko ewe ominsimisi onitakan sibomo lel, ao ko iye agbe 10 si, iye aluko 10, padi ature kan, ao jo po, ao lo kuna, ao ma fi milk olope lo ni idaji. 31. TURARI AWURE ASIRI BIBO oni IPARA. Ao lo #1000 kuno daada lori olo, A o ja EWE OWU AKESE to po daada die, Ao walora ORORO ONALIA ..Ao gbo EWE OWU AKESE yii daada,ti aba Igbo tan,ao wa se pelu ase.. Ao kokan1000ti a lo yii sinu ike RAGOLISI,a o da omi EWE OWU AKESE ti ase yii sinu re,a oo wa da ORORO ONALIA yen naa sinu re.. Ao wa mi papo daada,ti aba ti se eleyi tan,a o wa fi ma para ni OWURO ti aba ti we tan.. Fun ekunrere alaye RITUAL{Ose Awure Todaju}, Irun Ori Were, Ewe Isaju, Ewe Ajeobale, Akuko Adiye Kan, Eiyele Kan, Akuko Adiye Ati Eiyele Yen, Ao Fi Ese{leg} Wa Ja Ori Re, Ao Wa Jo Po, Ao Po Mo Ose, Ao Ko Si Inu Ikoko Ajere, Ao Fi Aso Funfun Te Isale |koko Naa, Ao Wa Gbe Ko Enu Ona Aba Wole, Ao Wa Bu Ose Na We. IBA 0000, |BA... OGUN IMULE AWON AGBA ASEJE ,EWE IRELE AJEOBALE ,EYE ONBE META 3, IYERE DIE,EJA ARO META 3 ,HA O GUN PAPO HA O FI OMI SE,HA 0 SO SI ORI OSUKA ,FROM anamo, ewe si kinimini obo j ati oyin ao ma fi sin’oju ara yil loun yi si ejiogbe 1 -adura si. =r a ba jo tan ao da sinua sobi ao wa tu epo le lor etiponola tutu, agbon odidi KO tutu. Ao |u agbon meteeta i inu re, ao fi gbo ewe mejegii On. ao Sa ewe yen loorun, al 10 maa we, ao tu lofinda o -¢tu ion, Iginla, a gun poao lo kuna dada, ko sin ewe opege apbagha noma fi foowo AWURE [LANA A sjiogbe si paper tabi opon ifa ao pe j, 20 se adura si, ao fe de nusi ita ghangba lehin | esi kanrin awo idagbe okan ran, awo olupege t Uni d’eso bolu ki tokunrin tobinrin wa fi owo. p basiriemi omo loni cjiogbe loni wo de mi lade 6 OGUN ASINA OWO TO CONFIRM EYIN PEPEYE TO MO N DADA MEJI, EYIN ADIE IBILE TO MON DADA MEJI, EYIN EYELE MEJEJI TOSESE YE, AO TO WON SINU APE, AO KO OPOLOPO EWE OMONIGELEGELE AO KO BO LORI TI YO BO DADA, AO JO (ISE YI 0 NI ATARE 0) AO GBODO SIWOTITI TI YO FI JO TAN O, TO BA TI JO TAN AO SO, IDIRE ONI KAN LE, AO LO AO MAFI OMI AYE LO LAROLARO. EWOISE YI NI PEAO GBODO SIWO TITI YO FI JO TAN O. EYIN MEFEFA TAFE LOYI, AO GBODO LO OBU EYIN O, TI OYO KAN BAJE OBU NI BE, AWON AGBALAGBA YONA IRU ENIBE LEGBA NIO. OGUN ISHORI APAJE PA OLOGUN ,epo apa iwo ale iwo aro epo iroko iwo ale iwo aro ewe aje kobale, eso rere pupo ao jo gbogbore papo a oro sinu sere a o gbe sere na sile a o si enure sile a o na akuko diye kan si ao so pe pa ediye yi bi ose ma pa awon ota mi yio mu ejere tan pata ako ni je ki ediye yi ku tan a o du ao fi eje die kan sere na lara, ao ma fi fo eko mu ni ekan losu odaju edan wo ke fun ile labo ATUDE ADERA TI BUKATA O MAN BIYAH Igbin nla kan aoyokuro ninu karaun aogunpomo ose pelu omi idi igbin yen,aowa lo egbo tude kuna Dada aofite odu Ikameji, aope gbolohun re si aowapomo ose aomafiwe. -Ti ohun buruku Ju okun,ti abilu WO osa,ti arun ko ko kowogbe,ti ewu buruku WO Igbo rawurawu,tutu lanro ide, Tutu lanro baba,tutu lanro oruka oje,orunmila ni ti oba sepe beni odi ero pese,ero pese niti igbin, kameji loka gbogbo owo buruku kuro larami,tude otumisile nibi igbekun ahiri owo na mi, airi owo lo,airi owo se omoluabi mi,kin mari owo na,kinmari owo se omoluabi,aduaa, And every time tiabafewe oseyi aotun mape gbolohun yii ba kan na Ejekia gbiyanju lati dan ise AWURE OWO yi wo kia fi wa owo odun. Adan kan, eru Alamo die, ewe tagiri tutu, ao gun papo mo ose dudu ao fi eje malu po papo daadaa, ao wa fi #1000 tuntun kan tele inu awo funfun olomori kan tabi ike funfun olomori kan, ao fi ekiri eran malu le owo ye lori, ao ko ose yi le lori, ao depa fun ojo meje, leyin ojo meje, ao mafi we lararo pelu gbolohun re, gbolohun re:- Adan loni kie fi owo nlanla dan miwo, eru loni kie ru owo nlanla wa funmi, tagiri loni kie tagiri wa fi owo nlanla tamilore, nitori owo nlanla la nkolo fun oni malu. Pee ee Vi ee ee alee ee IMULE AWON ELEYE Eyie adan,eyie onbe, atare odindi kan,a o Jo papo,ao wa ro sinu ado,lehin naa ao wa lowa Awo Sobi,Ao bu ebu yii sinu e pelu epo pupa lilo e ni ago kan oru ni ihoriho omoluabi ao fi ESE OSI ti ara ogiri ODAJU:::OFORE-BI OSO BADIN AJE NI TU NI/ BI AJE BA DE NI OSO NI TUNI,/BI EMERE BA DE NI TOSO TAJE NI TU NI,/BI TOSO,TAJE, TEMERE,BA DE NI EYIN IYA MI OSOROGA NI TU NI SILE TO BA WA RI BEE GBOGBO IDE KU DE TI E DE EMI LOMOL KO MA TUU BAYI GBOGBO IDE ARAWA LOMA TU PATAPATA TIAWON AYE SIMA YONU SIWA IBA AWO TI OFUNMI NI ASIRIYIO Idupe re nani emina feri ninu commment yoje funyin oo Moni kin sare soro ranpe lori ise alalubarika tounpe owo wole lotun losi fun awon alfa Ajesi adiye, ewe anu, ewe sawerepepe, eru alamo, ewe atewogbare, ao lopo mo ara won ao fi po ose eyikeyi, ao ko ose na sinu ajere, ao mafi we pelu gbolohun re. Gbolohun re:- ojojumo ni ajesi adiye ma ngba alejo, ki emi | omo | gbalejo olowo loni, sawerepepe lo bami pe olore ati alanu mi wa loni, ewe atewogbare loni kin tewo mi gba ow nlania loni, eru lo bami ru won wa towo towo owo won, ona kona lomi ngba wonu ajere, ona kona nikin gba ri alanu ti yio fi owo nlanla sanu mi loni. Lati owo oludasile egbe ASIRI OWO(ASIRI BIBO) Eye lekeleke odidi kan ao fi orisi owo meji eyokan lapa otun, ikan lapa osi e.g (1000 naira and 500naira) or 200/100 Ao gbe sinu agbada ao ko opolopo ewe aje lelori ti yio bomole ao wa fi odidi atare meta si ati oko atare meta ati eyo atare meta ao jo ao ma fi miliki olope lo lararo kato soro si eniyan odaju Ise yi dara debi wipe taba lotan osukan si meji atun ma sise lo larawa, lekeleke ki rinrin idoti asiriwa yio bo, ise yi daju tobarise oti kuro ninu egbe otosi. Danwo o confirm E jeki a dan turari awure yiwo walai ise to yanju tara ni TURARI AWURE lleke itun topo, ileke ifa topo, abeere, ewe aje ati afomo igba, SISE RE :- ao gun gbogbo awon ikan won yi papo, ao wako sinu ike funfun olomori kan ao tu lofinda bintu mate si ao fipo turari yi ao wade pa fun odidi ojo meje, leyin ojo keje ao mafin turari yi ninu ina nfi turari yi ire ni lati fibe se ibugbe. Odaju pupo AJEGUN TODAJU Ifun ako alangba, ewe jeminiho, iru oga, ase okete, oruka onirin, Ose dudu. Sise re..ao gun awon eroja yi lotooto, ao wa poo papo mo ose, ao ko awon oruka iyekiye lee lori. Lilo re...ao ma bu ose na fowo loree koree, ao si ma fi oruka naa sowo. Odaju _ moki gbogbo wa wipe aku ojo meta 0, ao nigbo laburu si arawa lase awon toni ile aye. OSOLE OWO TODAJU. Ebami wa ori owawa kan toni irun lara, ori olongbo kan toni irun lara, eyin adiye ororo mewa, pelu opolopo eru awonka. SISE RE.....Ao fi enu ori owawa ati ori olongbo yi korawon ninu ape ijoogun, ao wa to eyin ibile mewa yika re, ao da opolopo eru awonka le lori tikoni han sita mo, odi jijo. LILO RE....Ao mafi omi aye lo ebu na lararo. O, EWOO' [JO II EDA BASUN, II O DIDE MO, NI GBOGBO OGBO' IMA’ ATI OYE RE PIN, N Tl ABA SE LOMI ITAN NI LOLA, FUN AWON ONI ISEOWO, ATI ONI ISOWO, AWORO ARIMOLE AGBADU olongbo aye Kan, akara kengbe 201, ewe alupaida 201, eyo atare 201, Ori(chif butter) AO gesi 201, igo epo pupa Kan, ikoko olomori tuntun, akuko adie togbo dada Kan, SISERE":; ao ko akara kengbe tele inu ikoko na, ao da Ori lelori, ao ko gbogbo nkan toku si, ao wa tu epo igo Kan lelori, ao se adura nkan ti an fe si eti olongbo aye na, ao wa gbe olongbo aye na sinu ikoko na, ao wa fi omori ikoko na depa, ao wa gbele sinu shop wa, ao wa GBE ikoko na sinu koto ti a gbe na, ao wa pa akuko adie lelori, ao jeki eje re ro dada sori ikoko na, ao wa ge ori adie na lelori, ao ko oju re sita, ao wa da eepe bomole. ISE TO GBERA DADANI, FUN IBERE TABI ASIRI NLA MI. E WHAT'S Ring ETO IPESE ATI IBUKUN Ao ka Psalm 72, 82, 42. Sinu omi pelu awé , bi ao ti ma gba awé na ni yi : awé funfun meta Lati agogo Mmejila oru si ago mejila oru ojo keji fun igba meta pelu omi ati ororo olive oil, bintu, six flower ati bangoma , ao papo sinu awo funfun , awon oruko ti ao ma lo ni yi fun iyasimimo : TELUBUSIH,, LATIBUSIH , KALUBUSIH , ALLOSIH , ADUSIH , HULU , ABUH , ADONAI, ELOJINAH , EKATIH. Ao ma fi para nigba gbogbo beni yo ri lase oluwa ' By woli ijile agbara emi mimo OWO NLA' RESPECT Ado ajere Kan, owo eyo toloju meji, awo ijimere die, omo in atare 20, omo inu eru 30, owu imule, SISERE':; ao da Ado na lu Lori, ao fi eyo atare 20 sinu e, ati omo inu eru 30 sinu e bakana, AO wa fi awo ijimere die di ibi ti a dalu yen, ao mu owo eyo Kan si otun, ikan toku SI OSI, AO fi owu imule we owo eyo na dada molara, LILORE':; AO ji si eti otu pelu ofore, atu ji si eti osi pelu ofore, OFORE’; jogu jogu kan kin jogu omo atare, jogbon jogbon Kan ki jogbon omo eru, Ado alajere kin rinu korosi, ojo ti ijimere ba fi oju Kan alapinmi ojona ni ima inu e baje, imo buburu inu okurin, tinu obirin, ko bere sin baje ti won bati fi oju kanmi., ao mo fisapo jade, EWOO' OWO ELEYIN KINSE OWO OMODE O, ISE MARU LON DE NSE., GIDI NI. Anu ati IFERAN E JE Ki A WA ewé ewuro eyo kan to fe ti ko lu ju. A 6 lo Jaa laaro kutukutu lai fohun. E kii sinu parfum Divine grace pelu owo eyo kan ati owo tuntun kan. E je kia gbe e pamo fun ojo meta. Leyin naa ki a maa fi sara ki a si maa fi won ibi Itaja wa. Ire d! ASIRI YI WA FUN TI OKUNRIN BA TETE RELEASE LORI OBINRIN, ao fi eru Alamo tele inu igo.ao ge orogbo si wewe aoda lelori. ao tunge obi gbanja funfun si wewe ao dasi.ati egbo igi Grover. ao wada omi agbon si.ao gbe pamo fun ojo meje.leyin ojo meje.aomo muni aro ati ale.fun ojo meta lai sunmo obinrin fun ojo meta hmmmm ,Odaju pupo *OSE IPARI IJA LARIN ENIA ATI AWON ELEIYE:* Oro agogo ao gun loto, Epo obo gidi ao gun loto, Ewe afeloru ao gun loto, Ao wa da meteta papo ao gun pelu ose dudu tabi ose aganyin yio kuna dada, lehin na ao wa eru idana ao jo, ao fi te odu ifa Osa- Eleiye ao wa pe ofo re si, ao po pomo ose yen, ao ma we ni agogo kan loru ninu toilet wa. OFO RE: Akinsoro3x, Agoke odo soro 3x, Be len soro ti e nfi Ori orule se enu ona, ati aje ati ajeobale won jijo ngbe ilu ni, won kin di arawon lowo beni won kin yo arawon lenu, bi akoko ba so igi nise ni ma bowo fun igi oro, ewo orisha ekolo ki dabu eru, eni ti o ba da eru ni eru nto. N.B= Ao ma we ni agogo kan oru 1am. OSE ASINA SOLUDE..... Eran elede tikolawo lara aogun kunna ninu odo, ikun ojia ojulowo topodie aogun Jubulubu loto,eepo obo aogun kunna loto, ewe ola topo aolokunna loto, aowada gbogbore papo aofi ose dudu ko aofi oyin gidi po pelu oronro maalu tiwonpa loojo, aowakosinu fitila oloju 16, aoti candle white bo laarin aaro kutu tabi ale patapata tiabatifesun lamanwe sugbon tiabafewe aopa gbogbo ina towa ninu yara ti iseyiwa aowatannasi candle yen aobu iwonba tiafefiwe ninu oseyen aolowe tiabatidaride aola oyin gidi aowapa candle yen kojubelo sugbon ti alaye mi kobaye e mawule se iseyio kiomabakoba arare oo, iwe ASIRIAYE BIASELEDI OLORO siwanile fun tita oo tiabari enitosetan atira tie naa IFA AWORO TODAJU Ao wa ori ofafa kan Owududu Qwupupa Owu funfun lrun oya topo die Epo Sisere.......a0 so ori ofafa sinu omi tiyoo fi de(soft)dada leyin to ti soft ao wa (mixed)awon owu yen pomon arawon ao fi bo gbogbo ori ofafa ao wa gbe ile ao ko irun oya tele re ao wa gbe ori ofafa tiati fi owu bo yen le lori ao wa ro epo si enu ofafa yi ao wa se adura pe ofafa lofa enidudu,eni pupa,enifunfun wa funmi kiwon wa fi owo owo ra oja timon ta..... oya Loni ki eyin ero(crowd) maya wabami ra oja timo nta hmmm ao wa fi pako toba flat le ori koto yen kato da iyepe bo hmmm mosese pari iseyi fun client mi kar ni isetodaju ni Mosekoje kosiloro oogun yi EYONU ASINA TOMANSISE BI OSHOLE NI ademanlo iseyi fun gbogbo nkan tobajepe awon agba niwonwa nudie:.... Odidi awo igala kan tope aogesi 16,odidi state 16, opolo gbigbe 1, ikode 16, eku asin 16, iye agbe 16, iye aluko 16, oga gbigbe 16, odidi kowe kan, esuru pupa odidi kan aogesona 16, obi ipa 16, obi ifin 16, orogbo kan totobi aogesona 16, eye ega tako tabo, ori igun kan, aokogbogboe sinu ikoko tuntun, aojo aomafi ata ijosi konare titi yofijotan aorosinu ato tabi igo funfun, tiabafelofun eyonu aobudie sinu ikekan aobu oyin si aomafi ika aarin la sugbon tobajepe afefitu eeyan sile ni boya enitowalori aare abi were abi ide aye anything tiabaripe owo awon agba lowanibe aowa awo ipese totilo totibo aomabu ebuyen sibe diedie eninaa yomafi epo pupa la lale kosigbodojade losi anywhere mo tobatilotan..... lwe ASIRIAYE BIASELEDI OLORO siwanileo fun gbogbo Enitofe ilosiwaju ayere konifi igbiyanju sile nio... Eleyini AWURE OWO TODAJU motipost e nigbakan ri enitose to confirm e lotun ni kintun post isenaa niyi...... Ologbo dudu totobi daada, eku asin 4, ori oka 4, opolo ijokun 4, odidi estate 4, agolo owerenjeje 4, aojopapo aolokunna aodasinu shinap aomamuni gas kokan..... lwe ASIRIAYE BIASELEDI OLORO siwanile fun tita oo tiabari anitilatiratin AWURE AFERO...... Ori eye owiwi, egbo gbogbonise, ewe atori, ewe oowo, aogun gbogboe pelu ose dudu aofi iyerosun tefa ejiogbe aope ofore si aawapomo oseyen aomafiwe lojo tiamanwe ose... Ofore.... Owiwi wifunwon wipe mowanile kiwonwa bamirajami (tabi kadaruko nkan tiabanse si) gbogbonise losofun okunrin, obirin, omode, agbalagba ilu wipe momo oogun todara se (tabi kadaruko ise tanse layeyen)oowo kiolowo won wa towotowo owo won, atori lopekietowabami towotowo owoyin, ejiogbe wagberetemikomi loni ooo000.... lwe ASIRIAYE BIASELEDI OLORO siwanile fun tita oo tiabari enitonifesi nitori anfani towaninue kolafiwe OSE OSOLE OWO.....itun.ifa-anbere. yl, die.eyele funfun 1.ewe ajeobale tutu. aogun gbogbore papomose dudu .aofi lofinda sosoro nbia kan poo.aomafi we loojo alamisi aomafi aso funfun bora ni gbogbo ojo sungbon ninu ik e funfun ni aoko ose na si OGUN IFERAN ARAYE TODAJU ewe amunimuye ewe aje obaje ao lokuna dada ao pomo ose dudu ao ma fiwe kehinkehin tuntun ni ao malo ni gbogbo igba ti aba fewe ose na OGUN EYONU EBE AWON AGBA oga gbigbe kan pelu orogbo mewa ao jopo ao mafi oyin la ODAJU AWURE OMOSE TODAJU NIYI SUGBON MAJEMUE NIPE IWO TIOBAFELO OOGBODOSE FUNRAE.... Ori ofafa tonirun kan, ewe ogo, akufo glass tofosoju ona tosijusoke, eegun ori eshin, ile eye ega tiamuloke tikisepe ojabo katomu, aolo glass yen tomakunna daada pelu ewe ogo yen ati ori eshin ati ile eye ega yen aopomo ose dudu aofi ori ofafa yen tele inu ike white yen aowako oseyen lelori mole aomabuwe leyin ojoketa..... Iwe ASIRIAYE BIASELED!I OLORO siwanile fun tita oo tiabari enitonifesi nitori anfani towaninue kolafiwe MOKI GBOGBO AWAN AGBALAGBA TIO WANI INU ILEYI ATL AWAN MAMAWA OSOLE BASIRI Ao lowa ahan malu,ao la lati oke tio nigeja,ao fi #1000 tuntun si,ao ki ori igun si,ao tun ki odidi atare kan si, gbogbo awan inkanyi omawa larin ahan yi ao wa pade mon,ao gbe sinu agbada,ao jo papo, ao lotio kuna dada,ao mafiro ekuru funfun je. EJEKA GBIYANJU ISEYIWO KADUPE LOWO OLODUMARE PARI A. Uga oye kan, egun or! inaki die, majestic lunar rock, eja aro ooye kan, ewe abamoda tiko luju 10, ewe alupaida tiko luju 16, odidi atare kan, ao jopo, ao lo kunna daadaa, ao kosi apa kan. PART B. Owo tuntun ile wa kan to tobi ju, owo eyo tiko luju kan, ao lo ohun na kunna daadaa ao ko si apa kan. PART C. Eha ide ekun sibi meji, imi ojo pupa, ao lopo, ao kosi apa kan. SISE RE:- leyin tia tise gbogbo re si ototo tan, ao da gbogbo re papo nigbati aba fe pomo ose pelu lofinda orisi mejo, ao ko sinu awo ff olomori kan, ao gbe ise yi pamo si ibi tio ba ni owo fun ojo meje, leyin ojo meje, ao bere sini we ose yi lararo kutukutu. Lilo re:- ao mafi we pelu kaninkanin tuntun ni gbogbo ojo aje tabi ojo nbo ( Monday or Thursday ) ni aro kutukutu, ao gbodo jade lo sibi kankan rara lojo tia ba we ose yi, ao gba alejo ti yio wa bewa nise, iye owo tia bani kosan ni yio san 000, kia ri wipe ase Sara fun ise yi kia to bere lilo re, kia se iwadi iru sara ti ise vi vio aba. kia sise fun. kia si ri wide ani AKU OJUMO O EN| TOBA DAN ISE OSOLE OWO YI WO, YIO RI OWO BI OLE NI, ELO BAMI DANWO OSOLE OWO TODAJU Tagiri toni aje lara meta, ao gesi wewe, ao ko tele ape ijogun, ao ko ako alangba meta le lori ati odidi atare meta le lori, ao jopo, ao lo kunu dada, ao ro sinu igo kan, ao mafi oti lo laro kutu pelu aniyan , ise yi daju gan, ao ri owo toto owo Atona yi wa Lara awon Atona ti ko fail ri Ki si n paro danwo ki o fun ile labo re ATONA ELEPON META odidi atare 3,orogbo 3,efewu,owu dudu , funfun SISERE,aoyo omonu odidi atare kokan sinu aboototo, aoyo idotiwon pelu owo(hand)aonifi enufe idotina o,aoju orogbo kan sinu efewu aoda omoodidi atarekan tatiyo idotire lelori aofi owu dd&ff we dada,aose ikeji iketa nabe,aowadi meteta papo sojukan soso,aofi owu dd/ff seokun ifalowo si arin re,aowa sinap senu aotusi lara aosowipe ojotaba mu oti loti npani,ojoti orogbo baran sango nise ojona nije,ojoti atare babaorisa soro nigbo ojona lorisa nse gbogbo nkan tatare bafe,gbogbo ohun kohun timobafi iwo atona yi wadi ododo towa nbe kosofunmi 0,toripe akuko odeaiye kiparo

You might also like