You are on page 1of 3

Dáhùn Gbogbo ìbéèrè tí ó wà ní ìpín yìí:

1. Ìtàn sọ pé Ìlú ____ ni Yorùbá ti wá. a. Mẹ́kà b. London d. Ìbàdàn e. Brasil ẹ. Ítálì
2. ______ ni bàbá-ńlá àwọn Yorùbá. a. Mọ̀ọ̀mọ́dù b. Jésù d. Lamurudu e. Ifá ẹ. Orunmila
3. ______ ni ọmọ Odùduwà. a. Lamurudu b. Ọ̀kanbí d. Fatimo e. Maria ẹ. Orunmila
4. Ọ̀kanbí bí ọmọ ______ a. kan b. méjì d. mẹ́fà e. méje ẹ. mẹ́jọ
5. Ìlú _____ ni orísun fún gbogbo ilẹ̀ Yorùbá. a. Ilé-Ifè b. Ìbàdàn d Ilorin e. Ìjẹ̀bú ẹ. Ondo
6. _____ ni ó jogún ilẹ̀ nínú àwọn ọmọ Ọ̀kanbí. a. Olowu b. Onisabe d. Onipopo e.
Oranmiyan
7. Faweli wo ni a kii fi bẹ̀rẹ̀ oro Yorùbá? a. a b. ẹ d. u e. i ẹ. o
8. Èwo ni kii ṣe faweli aranmupe? a. an b. ẹ d. ẹn e. ọn ẹ. in
9. Konsonanti Yorùbá melo ni ó wà? a. 26 b. 25 d. 18 e. 20 ẹ. 10
10. Faweli airanmupe melo lọ wà? a. 7 b. 8 d. 9 e. 10 ẹ. 11
11. Àmì òkè ni a mọ̀ sí _____ a. do b. re d. mí e. fa ẹ. sọ
12. Àmì ìsàlẹ̀ ni a mọ̀ sí _____ a. do b. re d. mí e. fa ẹ. sọ
13. Àmì àárín ni a mọ̀ sí _____ a. do b. re d. mí e. fa ẹ. sọ
14. Alifabeeti Yorùbá ni a tún mọ sí _____ a. àmì ohùn b. ìró ohùn d. ìró ọ̀rọ̀ e. faweli ẹ.
konsonanti
15. Gbogbo alifabeeti Yorùbá jé mélòó lapapọ? a. 10 b. 20 d. 27 e. 25
16. ___ ni fáwẹ́lì àkọ́kọ́ ni èdè Yorùbá. a. a b. e d. o e. i
17. Èwo ni kii ṣe fáwẹ́lì airanmupe? a. an b. ẹ d. i e. o
18. Àwọn ẹlẹ́ sìn _____ ni ó gbógun ti Lamurudu ni ilu Mẹ́kà. a. Oloriṣa b. Kristẹni d.
Musulumi e. Ifá
19. Ki ní o pá Lamurudu? a. ija ẹsin b. Owó d. Ilẹ̀ e. Ọmọ
20. Ọmọ mélòó ni Ọ̀kanbí bí? a. Mẹwa b. Mọ́ kànlá d. Mẹta e. Méje
21. Ìlú ____ ni Alaketu tẹ̀dó sì. a. Bini b. Ìlá d. Sábẹ́ e. Ketu
22. Ìlú ____ ni Oranmiyan tèdó si. a. Bini b. Ọ̀yọ́ d. Sábẹ́ e. Ketu
23. Ayipada de ba ọrọ̀-ajé ìlú Ilé-Ifẹ̀ lẹ́yìn dídé _____ a. Odùduwà b. Lamurudu d. Ọ̀kanbí e.
Oranmiyan
24. ____ ni ó máa ń fi ìyàtọ̀ hàn láàrin ìró kan sì ìró kejì. a. àmì ohùn b. ìró èdè d. ìró ohùn e.
àmì ìlà
25. Àmì ohùn mélòó ni ó wà. a. méjì b. mẹta d. mẹrin e. marun
26. Àmì ohùn wo ni ó wà lórí ‘ji’ (steal)? a. dò b. re d. mí e. fa
27. Àmì ohùn wo ni àmì òkè a. dò b. re d. mí e. sọ
28. Àmì àárín ni a tún mọ sí ___ a. dò b. re d. mí e. fa
29. Àmì ìsàlẹ̀ ni ____ a. dò b. re d. mí e. ti
30. Àmì ohùn wo ni ó wà lórí ‘kọ’ (write)? a. dò b. re d. mí e. fa
31. _____ ni ọ̀nà tí a ń gbà kọ èdè Yorùbá ni ọ̀nà tí ó bojú mú ju ti tàtẹ̀ yìnwá lọ. a. Ìjíròrò b.
Àkọtọ́ d. Ikosile e. Lẹ́tà kíkọ
32. Ede Yorùbá di kíkọ silẹ ni odun _____ a. 1990 b. 2005 d. 2023 e. 1842
33. Èwo nínú àwọn wọ̀nyí ni ó kópa nínú kíkọ èdè Yorùbá sílẹ̀? a. Bíṣọ́ọ̀bù Ajayi Crowther b.
Oloye Olusegun Obasanjo d. Bola Ahmed Tinubu e. Alàgbà B.J. Martins
34. Ilé ìjọsìn Methodist, Catholic àti ____ ni ó ṣe ìpàdé lórí àkọtọ́ èdè Yorùbá. a. Baptist b.
CAC d. Celestial e. CMS
Èwo ni sípẹ́lì àtijọ́ nínú àwọn wọ̀nyí?
35. a. ayé b. aiye d. ẹyẹ e. owó
36. a. Ilesha b. aya d. Ilẹ̀ e. eniyan
37. a. oúnjẹ b. Ṣadé d. obìnrin e. Shọla
38. a. ẹyẹlé b. kọ́kọ́rọ́ d. Shango e. Ọfà
39. a. enia b. eniyan d. oúnjẹ e. aye
40. a. Ido b. okurin d. ọkùnrin e. èbúté
Èwo nínú àwọn wọ̀nyí ni a kọ daradara?
41. a. Osogbo b. Oshogo d. Oṣogbo e. Oṣogo
42. a. Ebutte-metta b. Èbúté-mẹta d. Ebutte-metta e. Ebutte-meta
43. a. Ẹyẹlé b. Eiyele d. Eyeile e. Eyelei
44. a. Aiya b. Ayai d. Ayia e. Aya
45. a. Shagamu b. Ṣagamu d. Shagam e. Ṣagam
46. a. Eniyan b. Enia d. Eina e. Eniya
47. a. Okuri b. Okurin d. Ọkùnrin e. Okunri
48. a. pẹpẹyẹ b. pẹipẹye d. pẹpiẹyẹ e. pẹpẹyiẹ
49. a. ẹiyẹlé b. ẹyẹilé d. ẹyiẹlé e. ẹyẹlé
50. a. Ṣẹ́gun b. Shegu d. Shegun e. Sẹ́gu
Ìdáhùn

1. a
2. c
3. b
4. d
5. a
6. d
7. c
8. b
9. c
10. a
11. c
12. a
13. b
14. b
15. d
16. a
17. a
18. c
19. a
20. d
21. d
22. b
23. a
24. a
25. b
26. c
27. c
28. b
29. a
30. b
31. b
32. d
33. a
34. d
35. b
36. a
37. d
38. c
39. a
40. b
41. d
42. b
43. a
44. d
45. b
46. a
47. d
48. a
49. d
50. a

You might also like