Oríkì ọbàtálá

You might also like

You are on page 1of 2

Oríkì ọbàtálá

Ọbàtálá ọbátárìsà
Ọba pátápátá tí ń bá wọn gbóde iránjé
Ọba nílé Ifọ́ n
Ò sùn nínú àlà
Ò jí nínú àlà
Ò tí inú àlà dìde
Ba ńlá ọkọ yemoo
À wúwo bí erin
Òrìṣà wun mi ní budo
Ibi Ire l'òrìsá kalẹ

Ọbàtálá ọbátárìsà (o rei do pano branco ‘ala’ e rei entro os orixás)


Divindade que mora em Iránjé
O rei que vive em Ifọ́ n
Ele dorme em roupas brancas
Ele acorda em roupas brancas
Ele se levanta em vestes brancas
Pai adorado marido de Yemoo
Òrìṣà me encanta como ele está no lugar
É um lugar maravilhoso onde Òrìṣà está entronizado.
Orin:
Ó fúruru lóòréré o
O kẹ ruru l’ejibo
Ó fúruru lóòréré o
O kẹ ruru l’ejibo
Ile ifẹ mo ti wa o
Ejibo reere mo tibọ
Ẹ ni nimi ẹyá wá o
Ẹyá wá wọrọ ẹ wa wéṣe!
Ẹ ni nimi ẹyá wá o
Ẹyá wá wọrọ ẹ lẹse kan.

You might also like