You are on page 1of 18

RUM

DE
ÒṢÚN
ÌJÈṢÀ

-Pergunta
Àdábá ọrọ n’màá fẹ, Aboto
Àdábá ọrọ n’màá fẹ, máà lẹyìn ọ
-Resposta
Àdábá ọrọ n’màá fẹ
-Pergunta
Màá fẹ lẹyìn ọ
-Resposta
Àdábá ọrọ n’màá fẹ

-Pergunta
Olúwa ayé mọ̀ ọ́n, ṣòro mọ̀ ọ́n ilé ifè ṣòro odò
-Resposta
Ìyè ìyè ìyè, o ìyè o ṣòro odò

-Pergunta
Ìyè, ìyè ọ; Ìyè, ìyè ọ
Ìyá Òṣún n’ilé, ìyè ìyè Òṣún n’ilé
Ọmọ n’ilé ọkàn mimọ
-Resposta
Ìyá Túndé ìjèṣà, ìyá Túndé ẹku àgbo
Omi rẹwo ìyè ìyè ọ
Ẹku àgbo irẹ ọ, ẹku àgbo ìjèṣà
Ẹku àgbo irẹ ọ, ẹku àgbo Ypondá
-Pergunta
Irẹ ọ ọmọ
-Resposta
Ìyè ìyè
-Pergunta
Irẹ ọ bàbá
-Resposta
Ìyè ìyè
-Pergunta
Irẹ ọ ìyá
-Resposta
Ìyè ìyè ọ
MODUGBÍ
-Pergunta
Ìyè màgbà ìyè ìyè mi mọ ọwọ
-Resposta
Omi kókó ọmọ rẹ

-Pergunta
Ẹwà mògídì à mọ k’ejà
Ejà mi mọ ọwọ
-Resposta
Ẹwà mògídì à mọ k’ejà
-Pergunta
Ejà mi mọ ọwọ
-Resposta
Ẹwà mògídì à mọ k’ejà

-Pergunta
Lè f’igbo l’Ọya Olóṣùn
Lè f’igbo l’Ọya ọmọ ìyá àgbà ọ
-Resposta
Lè f’igbo, lè f’igbo l’Ọya Olóṣùn
-Pergunta
Ìyá òmìnìbù omi rọ Òrìṣà ọ Ìyè ìyè
-Resposta
Ìyá òmìnìbù omi rọ Òrìṣà ọ Ìyè ìyè

-Pergunta
Òní Ìyá àgbèrè, òní àgbèrè ọ, òní Ìyá àgbèrè ọ
Òní àgbè kò, má yín má
-Resposta
Òní Ìyá àgbèrè, òní àgbèrè ọ, òní Ìyá àgbèrè ọ
Òní àgbè kò, má yín má
-Pergunta
Òṣún ajá àgbè rè
-Resposta
Òní àgbè kò, má yín má

-Pergunta
Ji’ṣe bá òsì l’ọtun m’oyo bí ìyè mọ̀ ọ́n
M’oyo bí ewé
M’oyo dín dín, m’oyo ọmọ rẹ ejà
M’oyo bí ewé
-Resposta
Ji’ṣe bá òsì l’ọtun m’oyo bí ìyè mọ̀ ọ́n
M’oyo bí ewé
M’oyo dín dín, m’oyo ọmọ rẹ ejà
M’oyo bí ewé
-Pergunta
M’oyo dín dín m’oyo ọmọ rẹ ejà
-Resposta
M’oyo bí ewé

-Pergunta
L’ọmọ wúrà, l’ọmọ wúrà modugbí yẹ yẹ
L’ọmọ wúrà ìyá l’Òṣún
L’ọmọ wúrà modugbí yẹ yẹ
-Resposta
L’ọmọ wúrà, l’ọmọ wúrà modugbí yẹ yẹ
L’ọmọ wúrà ìyá l’Òṣún
L’ọmọ wúrà modugbí yẹ yẹ
-Pergunta
L’ọmọ wúrà kenṣen kenṣen
-Resposta
L’ọmọ wúrà modugbí yẹ yẹ

-Pergunta
Àṣẹ gbó mí ala ọkàn
-Resposta
Òṣún àlà yin sí, àṣẹ gbó mí ala ọkàn
Òṣún àlà yin sí

-Pergunta
Ábèbè tí bí wù í lọkàn
-Resposta
Òṣún tí bí wù í, ábèbè tí bí wù í lọkàn
Òṣún tí bí wù í

-Pergunta
Idẹ wère wère, idẹ Òṣún
Idẹ wère wère
Idẹ wère wère, idẹ Òṣún
Idẹ wère wère, idẹ ìyá
Òṣún Ypondá idẹ Òṣún
Kenṣen kenṣen idẹ ìyá
Idẹ wère wère
-Resposta
Idẹ wère wère, idẹ Òṣún
Idẹ wère wère
Idẹ wère wère, idẹ Òṣún
Idẹ wère wère, idẹ ìyá
Òṣún Ypondá idẹ Òṣún
Kenṣen kenṣen idẹ ìyá
Idẹ wère wère

-Pergunta
Ìyè ìyè ìyè ìyè ìyè ọ, kòmá gbun mọ ọla
Ìyè ìyè ìyè ìyè ìyè ọ, kòmá gbun mọ ọla
Kòmá gbun mọ ọla aṣọ
Kòmá gbun mọ ọla
Kòmá gbun mọ ọla aṣọ
Kòmá gbun mọ ọla
-Resposta
Ìyè ìyè ìyè ìyè ìyè ọ, kòmá gbun mọ ọla
Ìyè ìyè ìyè ìyè ìyè ọ, kòmá gbun mọ ọla
Kòmá gbun mọ ọla aṣọ
Kòmá gbun mọ ọla
Kòmá gbun mọ ọla aṣọ
Kòmá gbun mọ ọla
-Pergunta
Ìyá mú ná ná ofà ábèbè ṣòro
Ìyá ofà ábèbè ọ
-Resposta
Ìyá mú ná ná ofà ábèbè ṣòro
ÌLÚ

-Pergunta
Ofà ábèbè ṣòro, ofà ábèbè ṣòro
-Resposta
Ewé r’ewé r’ewé, ofà ábèbè ṣòro
-Pergunta
Àwa ṣe n Ìyá lóde, àwa ṣe n Ìyá lóde
-Resposta
Ewé r’ewé r’ewé, àwa ṣe n Ìyá lóde

-Pergunta
Ìyá n’jò é, ìyá n’jò kókó là l’ọna
Ìyá n’jò é, ìyá n’jò kókó là l’ọna
-Resposta
Ìyá n’jò é, ìyá n’jò kókó là l’ọna
Ìyá n’jò é, ìyá n’jò kókó là l’ọna
ALUJÀ

-Pergunta
Ayé mú r’ejò, jingele jingele mú r’ejò
-Resposta
Ayé mú r’ejò, jingele jingele mú r’ejò

-Pergunta
Njẹ ìlà, njẹ yín lọrọ
-Resposta
Òṣún Òṣogbo

-Pergunta
Orí àlà àlà ọ, è n’kéré è n’màrìwò odò
Ìyá yín sù mọlé, n ìyá onílè ọ
-Resposta
Orí àlà àlà ọ, è n’kéré è n’màrìwò odò
Ìyá yín sù mọlé, n ìyá onílè ọ

ÌJÈṢÀ

-Pergunta
Ìyá ẹkọ, ìyá ìyè ìyè
Ìyá lóde, ìyá ọrọ
Òrun mà ìyè ìyè ọ
Ìyá inmọlẹ l’odò
Òṣún ìyá, ìyè ìyè ọ
-Resposta
Ìyá ẹkọ, ìyá ìyè ìyè
Ìyá lóde, ìyá ọrọ
Òrun mà ìyè ìyè ọ
Ìyá inmọlẹ l’odò
Òṣún ìyá, ìyè ìyè ọ

-Pergunta
Ọrọ mí là, ọrọ mi l’ayọ, ọrọ mi l’ayọ
Ìyá àbàdò ìyá ìyè ìyè ọ
-Resposta
Ọrọ mí là, ọrọ mi l’ayọ, ọrọ mi l’ayọ
Ìyá àbàdò ìyá ìyè ìyè ọ

-Pergunta
A ìyá Òṣún, Òṣún mi ìyè ìyè ọ
-Resposta
A ìyá Òṣún, Òṣún mi ìyè ìyè ọ

-Pergunta
Ọrọ irúnmolè ìyá má ku àgbo, ní ìta wẹ ṣe
-Resposta
Ọrọ irúnmolè ìyá má ku àgbo
-Pergunta
Ní ìta wẹ ṣe
-Resposta
Ọrọ irúnmolè ìyá má ku àgbo

-Pergunta
Ọ ìgbà là, là Òṣún, ìgbà là, là awọ
-Resposta
Ọ ìgbà là, là Òṣún
-Pergunta
Ìgbà là, là awọ
-Resposta
Ọ ìgbà là, là Òṣún

-Pergunta
Ìyá àgbẹ lọ aró, kiran n aró
Ọrọ kò lọ l’Òṣún, kiran n Òṣún
Lékeléke lọ lè ẹfun, kiran n ẹfun
Òṣún inmọlẹ ẹlẹdàá mi ọ
-Pergunta
Ìyá àgbẹ lọ aró, kiran n aró
Ọrọ kò lọ l’Òṣún, kiran n Òṣún
Lékeléke lọ lè ẹfun, kiran n ẹfun
Òṣún inmọlẹ ẹlẹdàá mi ọ
-Pergunta
Ìyá mi Òṣún mi wá, ìyá àgbà n’lè àṣẹ ìjèṣà
-Resposta
Ìyá mi Òṣún mi wá, ìyá àgbà n’lè àṣẹ ìjèṣà
-Pergunta
M’ara n idẹ
-Resposta
Àṣẹ
-Pergunta
M’ara n ọwọ
-Resposta
Àṣẹ
-Pergunta
M’ara n bàbá
-Resposta
Àṣẹ
-Pergunta
M’ara n ọkan
-Resposta
Àṣẹ
*Lógún èdè
OMELE

-Pergunta
Omi ìyá t’ala adé, omi ìyá t’ala adé inmọlẹ
-Resposta
Omi ìyá t’ala adé
-Pergunta
Omi ìyá t’ala adé inmọlẹ
-Resposta
Omi ìyá t’ala adé

-Pergunta
T’orí efòn Òṣún, t’ala jà obìrin
-Resposta
Omí ìyá t’ala adé

-Pergunta
Ọlẹlẹ n’pa
-Resposta
Ìyá laré

-Pergunta
Ìyá laré wò
-Resposta
Ìyè ìyè ìyè oló omi wò, ìyè ìyè ìyè

OMELE RÁPIDO
-Pergunta
Ìyá àgbà là Òṣún
-Resposta
Ìyá laré
OMELE

-Pergunta
Òṣún ìyá dòla, inmọlẹ l’omi
Òṣún ìyá dòla ìyá àgbà, inmọlẹ l’omi
-Resposta
Òṣún ìyá dòla, inmọlẹ l’omi
Òṣún ìyá dòla ìyá àgbà, inmọlẹ l’omi

-Pergunta
Kólé kólé ìyá àgbà, inmọlẹ l’omi ọ
-Pergunta
Kólé kólé ìyá àgbà dòla, inmọlẹ l’omi

-Pergunta
È t’Òṣún magbe ìyá là ọrọ
È t’Òṣún magbe ìyá là ọrọ
-Resposta
È t’Òṣún magbe ìyá là ọrọ
È t’Òṣún magbe ìyá là ọrọ
BÀTÁ

-Pergunta
Àwa dèké tẹ bà mi ló, bà mi ló, bà mi ló m’oyo
-Resposta
Àwa dèké tẹ bà mi ló, bà mi ló, bà mi ló m’oyo

You might also like