You are on page 1of 1

88- BASIRI OWO TODAJU

Ao lo ra Ojuda Awo Ekun ti yio to bo sere ato nla kan, Awo funfun nla kan, Eiye Kowe
odindin kan, Ori ewure ti o ti nbi omo ri daada kan, Odindin atare nla kan..Sise re: Ao
koko ran awo ekun naa mo sere naa lara ti yio bo de enu, ao wa jo Eiye Kowe, Ori
ewure ati Odindin atare kan po daada, ao lo kunna ti a ba jo tan, ao wa ro Ogun naa
sinu sere ti a fi awo ekun bo yen, ao gbe sinu awo funfun nla naa..Lilo Ogun yi: Ni
gbogbo igba ti a ba nti nfe toro owo, ao maa fi odindin eiyeile funfun ooye kan bo, ao
maa fi etu inu ado naa foko mu, ao si maa da ado naa pada sinu awo funfun
naa..Kaayefi: Ni iwonba igba ti a ba ti nfi eiyeile funfun ojuda bo sere yi, Etu inu re yio
maa posi ni, kaa tan.. Danwo, kio gba wipe Awon agba ojohun ndan nkan wo, kii sere,,
yio je fun yin lase edumare!!! Eseun..

You might also like