You are on page 1of 25

DEEPER LIFE HIGH SCHOOL

SECOND TERM: E – LEARNING NOTES


SUBJECT: YORUBA
CLASS SS 2

Zv3kal2 Ix1
Ọsẹ Ìsọrí ọrọ

1 (a) Èdè-Àgbéyẹwò Ìdánwò sáà kínní

(b)Àṣà- Àgbéyẹwò Ìdánwò sáà kínní

(d)Lítíréṣọ- Àgbéyẹwò Ìdánwò sáà kínní

2 a.Èdè:Ìhun ọrọ orúkọ :Àlàyé kíkún lórí bí a ṣe ń ṣẹdá ọrọ orúkọ.

b. Àṣà: Ìtẹsíwájú òwe ilẹ Yorùbá àti ìwúlò wọn

d. Lítíréṣọ:

3 Èdè: Ìhun ọrọ orúkọ: Àlàyé kíkún lórí bí a ṣe ń ṣẹdá ọrọ orúkọ nípa ṣíṣe àpètúnpè

Zxz: Cl1v1j1v1 tqb7 Iir=s7r=.

Litiréṣọ:

4 a. Èdè: Ìhun ọrọ atọkùn:Àlàyé kíkún lórí bí aṣe lè dá ọrọ atọkùn mọ àti lílò wọn.

b. Àṣà:Ìtẹsíwájú òwe ilè Yorùbá àti ìwúlò wọn

d. Lítíréṣọ:

5 a. Èdè: Znk90 fawcli

b. Àṣà: Ìtẹsíwájú lórí owe to jeyo ninu asa ìsìnkú, ikini, abbl

d. Lítíréṣò:K7ka 8w3 t7 8j[ba yzn

6 a.Èdè:Àlàyé kíkún lórí àpólà ọrọ orúkọ. Àpólà ọrọ ìṣe àti àpólà àpónlé

b. Àṣà: Ogun j7jz ni il2 Yor6bq.

d. Lítíréṣọ:K7ka 8w3 t7 8j[ba yzn.


7. ISINMI RANPE TI IDAJI TAAMU

8. a. Èdè: Akàyé-Ewì( Ìtọsónà lórí àkàyé ewì)

b. Àṣà: Ìtcsiwaju lori ogun jija

d. Lítíréṣọ:Kíka ìwè àpilẹkọ tí ìjọba yàn (ewì)

9 a.Èdè :Àkàyé-(yíyan àyọkà ewì fún àwọn akẹkọọ)

b. Àṣà: Ìtcsiwaju lori ogun jija

d.Lítíréṣọ:Kíka ìwé àpilẹkọ ewì tì ìjọba yàn.

10. a Èdè: Akàyé-Ewì( Ìsorongbesi)

b. Àṣà *t2s8wqj5 *vzv- Yor6bq n7pa )r8xz

d. Lítíréṣọ:Kíka ìwé àpilẹkọ tí ìjọba yàn (ewì)

11&12 Àtúnyẹwò iṣẹ sáà kejì àti ìdánrawò

IṢẸ: YORÙBÁ

KÍLÁÀSÌ: SS 2

Ọsẹ Kiini Ìsọrí ọrọ

(a) Èdè-Àgbéyẹwò Ìdánwò sáà kínní

(b)Àṣà- Àgbéyẹwò Ìdánwò sáà kínní

(d)Lítíréṣọ- Àgbéyẹwò Ìdánwò sáà kínní

Ose keji

Èdè:Ìhun ọrọ orúkọ :Àlàyé kíkún lórí bí a ṣe ń ṣẹdá ọrọ orúkọ nípa lílo àfòmọ.

Àṣà: Ìtẹsíwájú òwe ilẹ Yorùbá àti ìwúlò wọn

Lítíréṣọ:

Ẹka iṣẹ: Èdè

Àlàyé kíkún lórí bí a ṣe ń ṣẹdá ọrọ orúkọ


*xcdq =r= j1 =nz t7 a n vz x2dq =r= tuntun ninu ede Yorubq. M-f78m5 ni a n l0 lqti fi x2dq =r=
ninu ede Yorubq.

M-f78m5 ni w5nr2n t7 9 kere j6 l[ t7 a fi n x2dq =r=. Or7xi m-f78m5 mej8 ni o wz, aw[n ni:

1. M-f78m5 adqd5r9

2. . M-f78m5 afarahc

M_F&*M% AD%D%R(: Ey7 ni m-f78m5 t7 9 le dad5r9, t7 9 s8 n7 8tum=. Ohun nqz ni a t5n n


p4 n7 m-f78m5 *p8l2, o dq itum= tir2 n7, k0 s8 xee pin s7 w1w1. Zw[n ni: =r= oruk[ ati =r=
8xe. Zpccrc: omi, oj5, il3, et7, cs2, 8w3, l[, s5n , f0, ow9 abbl.

M_F&*M% AFARAHC: $y7 ni m-f78m5 t7 k0 le dqd5ro k7 o n7 8tum=, gcgc4 b7i or5k[ r2, ko
le dadur9, zyzfi t7 a bq l09 m- m-f78m5 adad5r9. Ohun nqz ni a t5n m= s7 Zf0m-. Orixi zf0m-
m3j8 ni 9 wz ninu 4d4 Yor5bq, aw[n ni: zf0m- 8b2r2 ati zf0m- zqr7n.

ZF)M_ *B@R@

Zf0m- 8b2r2 ni 4y7 t7 9 mq a n jcy[ sqqj5 m-f88m6 8p8l2 n7n5 =r= Yor6bq. B7 zpccrc:

(i) q -, a -, -, z -, 4 -, c -, i -, 0 -, = -, a -, c -, e -, i -, o -, [ -, z8 -, 0n -, on -, zti -.

on7 -, oni –

ZF)M_ ZZRIN

Zf0m- aarin mqa n wz lqarin m-f78m5 adqd5r9 mej8. Zpccrc:

- K7 -, - rz - , - n7 - , - ji -, - kan -, - d3 -, - s7 – abbl

=r= or5k[ + zf0m- zzrin + =r= or5k[

(i) [m[ + k7 + [m[ _ [m[k-m[

(ii) ay3 + ra + ay3 _ ay3ray3

(iii) ip0 + k7 + ip0 _ ip0k7p0


Orix87 =nz ti a n vz x2dq =r= n7n5 4d4 Yor5bq.

1. A l4 x2dq =r= n7pa h7hun zf0m- 8b2r2 p= m- m-f78m5 adqd5r9 t7 9 j1 =r= 0r5k[. Zpccrc :

(i) on7+ isu _ on7su

(sii) oni + ew3 _ el3w3

(iii) on7 + il3 _ on7l3


(iv) on7 + as[ _ alqs[

2. A l4 lo zf0m- 8b2r2 p2l5 =r= 8se lqti s2dz =r= or5k[. Zpccrc:

i. a + d3 _ ad3

ii. 4 + r0 _ 4r0

iii. 0 + k5 _ 0k5

iv. z8 + s6n _ z8s6n

v. z8 + k5 _ z8k5

vi. 0n + d4 _ 0nd4

vii. zti + mu _ ztimu

3. A le lo zf0m- 8b2r2 p2l5 zp0lq 8se. Zpccrc:

(i) a + k[ + orin _ ak[rin

(ii) a + dq + cj- _ adqj-

(iii) on + k[ + iwe _ 0nk=w3

(iv) 0 + s4 + er3 _ 0s4r3

.4 A le se zp4t5np4 k7k5n f5n =r= or5k[ p2l5 zf0m- zzrin. B7 zpccrc:

- K7 -, - rz - , - n7 - , - ji -, - kan -, - d3 -, - s7 - abbl

=r= or5k[ + zf0m- zzrin + =r= or5k[

(i) [m[ + k7 + [m[ _ [m[k-m[

(ii) ay3 + ra + ay3 _ ay3ray3

(iii) ip0 + k7 + ip0 _ ip0k7p0

(iv) 0v9 + n7 + 0v9 _ 0v9l9v09

5. A l4 x2dq =r= n7pa h7hun =r= or5k[ m3j8 =t==t= p=. Zpccrc :

i. il3 + [m[ = il3[m[

ii. Il3 + 8w3 = il34w3

iii. oj5 + omi = oj5omi


*v3l3w=n:

1+nq m3l09 ni a n vq s2dq =r= or5k[ n7n5 4d4 Yor6bq . Dqr5k[ w[n.

2 Ṣqlqy3 p2l5 zpccrc m1rin, m1rin b7 a se lo zf0m- 8b2r2 ati zf0m- zqr7n lqti s2dq =r= or6k[.

3Kọ ọrọ ìpìlẹ márùn ún sílè.

4Ṣàlàyé ìlò àfòmọ ìbẹrẹ onísílébù méjì láti ṣẹdá ọrọ orúkọ pẹlú àpẹẹrẹ méwàá.

@K_ KEJ*

D#$T* :

.Ẹka Iṣẹ : zxz

Orí Ọrọ:Ìtẹsíwájú Òwe Ilẹ Yorùbá àti Ìwúlò Wọn.


+r1 0 va cl1ta, el3j8 l=r1 vz. N7n5 =bzrz m3j8 w-n s[ p3 “pclcbc 8d7 zw0d8 0k4 lzq w0, kq
t9 m[r- agogo. N7n5 0t5r5p-n 2w2 a s[ p3 [l-v-n kan k0 ta k9k9 omi l3t7 as[, m=rzn m=rzn kan 0
m[ye 44p2 il2.
)we mq a s5y[ lqti in5 zzl-, b7 zpccrc zl- 8jzpq n7n5 zl- 8jzpq kan a mq a s[ p3 “$3b5 zl[ ni ti
ahun, ti zb= ni ti zna r2”. N7n5 zzl- m87rzn 2w2 a mq a n s[ p3 “+t==t= 4y7 ni zna 8v7n. )we s8
t5n mq a s5y[ n7n5 8tzn Yor6bq b7 zpccrc: Ogun j7jz b7 “Ak7ni j1 ak7ni, afinihzn j1 afinihzn
4wo ni nl1 o arq 8jzy4 l9j5de )g5nm-lq.
N7n5 zsz 8v3yzw9 2w2, a le r7 0we b7 i 8yzw9 d6n l-s8ng7n, [k[ t5n mi v3 mo f1 soge.
Z8rinj8nnz lq 8 r7 abuk3 =k1r1, cni bq dcsz j8nnz y99 pa cja ar[. “Z8r8nj8nnz lz8r7 bi t7 w-n
fod9 8b7l2 jcun.
A t5n l4 s2dq 0we n7n5 2s8n b7 i “ay3 la bqfq, ay3 la bq m=le, =sqn gangan ni 8vzv- w[l3”.
Lqti in5 or7k8 or7l2 “ 9 wu ol9w9 l9 dqs[ sqnyqn, 9 wu Ol50j3 l9 daw[ ajq bora.
N7pa zk7y4s7 zy7kq cni b7 i “lqqlq t9 r0k4, il2 l9 n b=”.
N8pa 8h6was7 s7 b7 i “$3f7n n8wz r7r5 n7 i r5”
N7pa 8tzn 8s2nbqy3 “ Ta n m[ 0k0l0 L’[y=-.

Ìgbéléwòn
1 Pa òwe márùn ún kí o sì sọ ìtumọ wọn.
2Ṣe àkọsílẹ ìlò òwe márùn ún.
3Sọ ìtumò àwọn òwe wọnyìí:
i Ẹṣin kìí kọ eré àsárelé.
ii Ìgbẹyìn ni aláyò ń ta.
iii Iṣẹ ni oògùn ìṣẹ.
iv Òrí kọ ni oògùn iké.
Agbójúlógún fi ara rẹ fún òṣì ta
Ìwé ìtọkasí:Èdè Àṣà àti Lítíréṣọ Yorùbá ,SS1Adéwọyin, S.Y
@K_ KCTA : L7t7r3s=:K7ka 8w3 t7 8j[ba yzn
Ose Keta

Èdè: Ìhun ọrọ orúkọ: Àlàyé kíkún lórí bí a ṣe ń ṣẹdá ọrọ orúkọ nípa ṣíṣe àpètúnpè

Asa: Ìpolówó ọjà ní ilẹ Yorùbá àti ìwúlò wọn

Litiréṣọ:
@K_ K&NN& : $D$

Ẹka Iṣẹ : *hun =r= or5k[:Àlàyé kíkún nípa bí a ṣe ń ṣẹdá ọrọ orúkọ nípa ṣíṣe àpètúnpè

*s=r7 k7nn7 : L7lo 8lznz zp4t5np4

Zp4t5np4 j1 8v3s2 m[f-l-j8, ti a mq a n l0 lqti s2dq =r= tzbi 8s[ tuntun lqti ara m-f78m6 8p8l2
pzqpzq j6l[ lqti ara m-f78m6 zdqd5r9 tzb7 on7tum= zdqm-.

+nz m3j8 ni a n vq lqti s2dq =r= oruk[ p2l5 zp4t5np4. Zw[n nqz ni: Zp4t6np4 k7k5n, Zp4t5np4
cl1bc

ZP$T%NP$ K&K%N

$yi ni zp4t5np4 t7 a mq a n l0 lqti s2dq =r= n7pa lílo odidi m-f78m6 8p8l2 tzb7 zsop= m-f78m6
8p8l2.

6. A t5n l4 x2dq =r= n7pa x7xe zp4t5np4 f5n =r= zp9lz 8xe. Zpccrc :

Zp0lq 8se + Zp0lq 8se = =r= or5k[ t7 a s2dq

Wol3 + wol3 = wol3wol3

Pcja + pcja = pcjapcja

Gb1nz + v1nz = v1nzv1nz


7. A t5n l4 x2dq =r= n7pa x7xe zp4t5np4 f5n =r= or5k[. Zpccrc :

+r= or5k[ + =r= or5k[ = =r= or5k[ t7 a s2dq

[m[ + [m[ = [m[[m[

=s2 + =s2 = =s==s2

[d5n + [d5n = [d[[d5n

Oṣ6 + oṣ6 = oṣooṣ6

Ìgbèléwọn

1Kọ àpẹẹrẹ ọrọ ìṣẹdá alàpètúnpè kíkún mẹta.

2Kọ àpẹẹrẹ ọrọ ìṣẹdá alápètúnpè ẹlẹbẹ mẹta.

ZP$T%NP$ CL!BC

Zp4t5np4 cl1bc ni 4y7 t7 9 mq a n s2dq =r= n7pa l7l-p= apq kan n7n5 m-f78m6 8p8l2 t7 o j1
=r= 8xe.

8. A t5n l4 x2dq =r= n7pa x7xe zp4t5np4 cl1bc f5n =r= 8xe. . B7 zpccrc

L[ ] l7l[, ga ] g7ga, jc ] j7jc, mu ] m7mu, v3 ] v7v3

Tz ] t7tz, rz ] r7rz.

N7n5 zw[n zpccrc 0k4 y87, n7vz t7 a se zp4t5np4 f5n zw[n =r= 8se, a y[ fqwcl8 zk-k- k5r0, a
wa fi fqw2l8 ol9h6n 0k4 d7p0 r2

L[ ] l[l[ ] l7l[

*v3l3w=n:

1 Ṣe 2k5nr1r1 zlzy4 l9r7 “zp4t5np4” g1g1 bi 8v3s2 f5n s7s2dq =r= or5k[.

2Bqwo ni a se s2dq zw[n =r= w=ny7 (a) dqnzdqnz (b) wol3wol3 (d) 0nk=w3 (e)
ak=w3

3Kọ àpẹẹrẹ ọrọ ìṣẹdá alàpètúnpè kíkún mẹta.

4Kọ àpẹẹrẹ ọrọ ìṣẹdá alápètúnpè ẹlẹbẹ mẹta.

.Ẹka Iṣẹ : zxz


Orí Ọrọ: Cl1v1j1v1 tqb7 Ir=s7r=.

Zw[n babanlq wa lo maa n powe kan pe’ cv1 cni laa gunyan ew6rz d4. N7vz t7 a ba n s=r=
cl1v1j1v1 tqb7 Ir=s7r=, [j- or7 ni a n s=r= bq, tori pe vovo eniyan k9 d-va l-j- or7. Zw[n eniyan
ju ara w[n l[ l-j- or7, n7p9, n7pa ow9, 8m= ati avqra. Zw[n cni t7 [j- or7 w-n ba d-va ni w-n n j-
r8n p=, ti w[n y90 s8 j[ wz nin5 cv1 kan nqz. Cv1 cyc lcyc n f09 t=. Ot= ni 8huwzs7 [m[de,
ag6nbqnir=, zvz ati ar5v9.

P&NP&N CDQ EN*YZN S& CL!V!JCV!.

1. {m[ [m5 s7 [m[ 8r8ns2.

2. Mzj4s7n – [m[ [d5n m1ta s7 mqr6n – 5n

3. {m[d3 - [m[ [d5n m1fz s7 m1tzlq.

4. Zg6nbqnir= - [m[ [d5n m1r8nlq s7 og5n [d5n.

5. G3nd3/ *g8r8pq- [d5n m-kznl3l9g5n s7 og9j8 [d5n.

6. Zvz - og9j8 [d5n s7 zqd-rin [d5n.

7. Ar5v9- zqd-rin [d5n l[ s9k4.

AK&Y$S&: {m[de k87 pe 4d4 zb6k6 s7 cni t7 o bq j65 l[.

IPA T& CL!V!JCV! N K( LQZR&N ARA W{N ZTI LQW^J{

 Zw[n zg6nbqnir=, *g8r8pq,ati zw[n zvz l0kunrin lobinrin a maa bc ara won ni
[w2 lati fi xe ixc t7 w[n ba fc xe bii: il3 kik[, ixc oko r7ro, xixe zmojuto inqw9,
od0 v7v1, =nq y7y2 ati xixe zmojuto av4v4 tzb7 zy7kq w[n. W[n a tun maa ran
ara won l[w[ ow9
nipa 4s5s5 ati zj[.
 Lode oni, zw[n zg6nbqnir=, *g8r8pq n kopa ninu eto ixel5. W[n n di axofin,
k[m7sznnz, alaga ij[ba ib7l2, gomina, minisita ati arc pzqpzq.
 Zw[n cl1v1j1v1 n kopa ninu eto =r= aj3 lati m5 un gber5 s7i ninu ixc zv2 bii cja
pipa, oko d7dq, ax[ 7hun abbl
 Zw[n cl1v1j1v1 n kopa p2l5 ninu er3 8dqrayq l[l[kan 0j=kan.
 Zw[n cl1v1j1v1 t5n n kopa pztzk8 ninu eto am5l65d6n.
 Zw[n zg6nbqnir=, *g8r8pq n kopa ninu eto ogun j7jz.
 Zw[n cl1v1j1v1 n kopa ninu [d5n 8b7l2 bii: [dun egungun, [xun, or0 abbl.

@K_ KCTA : L7t7r3s=


*S+R& IS! : *w3 t7 8j[ba yzn.

4 Èdè: Ìhun ọrọ atọkùn:Àlàyé kíkún lórí bí aṣe lè dá ọrọ atọkùn mọ àti lílò wọn.

Àṣà:Ìtẹsíwájú òwe ilè Yorùbá àti ìwúlò wọn

Lítíréṣọ:

@K_ K&NN& : $D$

Ẹka Iṣẹ : *hun ọrọ atọkùn:Àlàyé kíkún lórí bí aṣe lè dá ọrọ atọkùn mọ àti lílò wọn

+R+- AT_K^N

+r= at-k6n ni 9 fi 8bqxep= t7 9 wz lqzrin =r= kan zti 0m7rzn hzn. Zw[n ni 9 mqa n saqj5
=r= or5k[ t7 9 j3 zb= n7n5 v9l9h6n. A l4 fi zw[n =r= y87 w3 zw[n zw0r0 t7 9 mqa n xe zt=k6n
f5n e3g5n n7tor7 p3 w-n n xe zt=k6n f5n =r= m87rzn ni. Zw[n =r= zt-k6n nqz n8w=ny7: ni, s7,
t7(f5n)

B7 zpccrc: i.+gz d3 $k9 d3 P[tq.

ii.Owo wz n7 il3

iii.{dc l[ s7 8v1.

IX! T& +R+- AT_K^N MQA N XE

A l4 dq =r=-at-k6n m= n7n5 v9l9h6n nipa ix1 t7 w[n n xe.

a. +r=-at-k6n mqa n fi ibi t7 4n8yzn tzb7 nnkan ti n b= hzn.

i. B-lq ti oko wq s7 il3.

Ii .Mo ti il3 wq s7 s-=s8.

iii.W6m7 ti oko y[ s7 Ab1ok6ta

iv.B-lq ti [jz y[ s7 oko.

v.Zw[n cv1 ak1k=- ti *bzdzn d3 Zb5jq.

(b). +r= at-k6n mqa n s[ ibi t7 4n8yzn tzb7 nnkan n l[. “s7”ni at[ka f5n 4y8.B7 zpccrc:

i.Mo l[ s7 [jz.

ii.W6m7 l[ s7 oko.
iii.B-lq wq s7 $k9 lqnzq.

iv.Ol5 l[ s7 ibi t7 9 ti wq.

v.Tqy3 l[ s7 il3 8w3.

(d). +r= at-k6n mqa n s[ ibi t7 nnkan wz zti [j=. “n7” ni at-ka 4y7. B7 zpccrc:

i. Bzbq wz n7 il3.

ii.Ad3 y[j5 n7 2w=n.

iii.A 9 xe zy2w0 n7 =la.

iv.B-lq l[ n7 znq.

v. Baba d3 n7 es8.

. @K_ KEJ*

.Ẹka Iṣẹ : zxz

Orí Ọrọ: . Ìtẹsíwájú òwe ilè Yorùbá àti ìwúlò wọn

L&L) )WE
1. A mq a n fi 0we szlzy3 =r= t7 9 bq ta k9k9 tzb7 =r= t7 a f1 s[ n7 p=n5n tzb7 =r= t7 9 bq
vcg1.
2. A mq a n lo 0we lqti f5n 4n8yzn n7 8s7r7 <encouragement>.
3. A mq a fi 0we f5n 4n8yzn n7 8m=rzn b7 zpccrc “[b2 t7 bqql3 il3 k8 7 jc, 8yql3 il3 k8 7
s4 3.
4. A mq a n lo 0we lqti fi 8f[w-sow-p= hzn b7 i ‘zj4j3 [w- kan 0 v1r6 d9r7’.
5. A mq a n fi 0we par7 8jz. B7 zpccrc: B9j5 bq n se ipin, a mq a y[ fi han oj5 ni.
6. A mq a n lo 0we lqti fi t-ni s-nz. B7 a bq g3gi n7v0 kq fi =r= ro ara cni w0.
7. A mq a n fi 0we t-ka is1 t7 4n8yzn n se zti f5n 8voyz b7 i : A 8 d1r6 0g5n b[dc, z 8 d1r6
eb4 bq zv2.
8. A mq a n lo lqti fi 8vzv- hzn b7 i: {m[ k0 n7 zy=l3 cni [m- sin l9 b7m[.

Ìgbéléwòn

1 Pa òwe márùn ún kí o sì sọ ìtumọ wọn.


2Ṣe àkọsílẹ ìlò òwe márùn ún.
3Sọ ìtumò àwọn òwe wọnyìí:
i Ẹṣin kìí kọ eré àsárelé.
ii Ìgbẹyìn ni aláyò ń ta.
iii Iṣẹ ni oògùn ìṣẹ.
iv Òrí kọ ni oògùn iké.
Agbójúlógún fi ara rẹ fún òṣì ta
Ìwé ìtọkasí:Èdè Àṣà àti Lítíréṣọ Yorùbá ,SS1Adéwọyin, S.Y
@K_ KCTA : L7t7r3s=
*S+R& IS! : Kíka ìwè àpilẹkọ tí ìjọba yàn

+x2 Kar6n]5n

Èdè: Znk90 Fqw1l8.

Àṣà: Ìtẹsíwájú lórí owe ninu asa ìsìnkú ati alo

Lítíréṣò
@K_ K&NN& :

Ẹka Iṣẹ :$d4


ZNK() FQW!L*/ *JCY{P+ FQW!L*
Znk90 fqw1l8 ni 8bqr8n tzb7 8bqk1v1 zwon fqw1l8 in5 4d4 kan. *bqk1v1 y87 l4 j1 n7pa
b7 zw[n fqw1l8 xe j[ra l-nz fon1t78k8, 8j[ra y87 l3 j1 n7pa b7 zw[n fqw1l8 w=ny7 xe ga s7,
yqlz w-n j1 fqw1l8 iwqj5 tzb7 t2y8n. W-n l4 fi roboto tzb7 pcrcsc j[ra. Zb6dq y09 w6 k7 w-n fi
j[ra,w-n l4 j1 it=s2 f5n znk90 fqw1l8. ( xe3xe n7vz m87rzn k7 zj[r8n zw[n fqw1l8 in5 4d4 kan
p7n w[n s7 =w-. T7 4y7 bq wqy3, znk90 ir5 4d4 b12 k5n.

Nivz m87rzn 2w2,9 xe3 xe k7 9 mq s87 znk90 kan t7 9 yanj5 lqzqr7n zw[n fqw1l8 3d3
k7 8fir5ra wz n7n5 b7 zw[n fqw1l8 nqz xe p7n s7 8s=r7. T7 4y7 bq wqy3,a j1 p3 ank90 fqw1l8
7r5 4d4 b12 k0 k5n.

Lqti t[s2 fqw1l8, a 9 wo cy[ =r= zti zl0p= zw[n =r=.

ZNK() FQW!L* N&N% CY{ +R+ N&N% YOR^BQ

N7n5 4d4 Yor6bq,znk90 fqw1l8 mqa n jc y[ n7n5 =r= t7 9 bq n7 j5 s7l3b6 kan l[.
Fqw1l8 z8rqnm5p4 ni a 9 fi xe zlzy3 n7t9r7 9 dzb7 cni p3 0t3 de ibi t7 zw[n zrqnm5p4 ti l4
s5y[ n7n5 4d4 nqz. Zw[n fqw1l8 t7 o l4 b2r2 =r= ninu 4d4 Yor6bq ni : a, e, c , i , o , [. (F1).
Fqw1l8 ‘u’ ati vovo fqw1l8 zrqnm5p4 k87 b2r2 =r= ninu 4d4 Yor6bq x6v-n w-n le j1 (F2).
ZTC ZNK() FQW!L*

B7 fqw1l8 zk-k- bq Zw[n fqw1l8 t7 9 l4/k0 l4 bq a k1v1


j1

Fqw1l8 kej8 (F2)


Fqw1l8 k7 n7 (F1) a e c i o [ U an in cn [n un
A + + + + + + + + + - + +
E ] + ] + + ] + - + - - +
C + ] + ] ] + + + + - + +
I + + + + + + + + + + + +
O ] + ] + + + + - + - - +
{ + ] + + ] + ] + + - + +
 + <bq k1v1>
 ] <k0 le bq a k1v1>

T7 a bq wo zw[n zpccrc t7 a xe zti ztc at-ka t7 a v3 kal2 n7 0k4 y87, a r7 i p3 fqw1l8


/i/,/a/,/u/ f1r2 bq vovo fqw1l8 in5 4d4 nqz r8n. A t5n r7 i p3 <c,o> zti <e,o> k87 bqra k1v1.
N7bi t7 /c/ tzb7 /o/ bq ti jcy[ n7n5 m-f78m6 b12. B12 nqz ni b7<e,o> bq jcy[ n7n5 m-f78m6
kan, …c,o† k0 l4 jcy[ n7n5 m-f78m6 nqz.

*v3l3w=n:

1. Fqw1l8 wo ni k87 b1r1 =r= n7n5 zw[n w[ny7? A. 3 B. u D. 1 E. o

2. T7 fqw1l8 ‘a’ bq b2r2 =r=, fqw1l8 y87 k0 le bqa r8n. A. e B. o D. 1n. E. –

3. Wq zpccrc =r= m3j8m3j8 f5n =k[[kan zw[n 8r9 fqw1l8 y87 b7 w-n bq j1 f1 ‘’ o, c, e, i.

. @K_ KEJ*

.Ẹka Iṣẹ : zxz

Orí Ọrọ: . : Ìtẹsíwájú lórí owe to je yo ninu asa ìsìnkú ati alo

EKA ORI – ORO 2


BI ASA SE JEYO NINU OWE YORUBA: ASA IKINI ATI ISINKU.
Ipede Yoruba maa n fi asa ikini won han. Asa ikini se pataki laarin Yoruba, se eku ti
won maa fi n bere ikini won fun orisirisi igba ati akoko bii aaro, iyaleta, osan, irole, ale, aajin,
eerun, ojo, oda, oginnitin abbl lo je ki awon oyinbo fun won ni suuna “AKU” ni ile saro leyin ti
owo eru dopin.
Owe Yoruba to so pe “eni ti ko kini kaabo, o padanu e kuule” n fi han pe dandan ni ki a fi
ikini da eni to ba ki wa lohun ninu asa wa. Olundu nikan ni ko le kini pada nigba ti a ba kii. Oba
ilu maa n ju irukere lati fihan pe o n dahun nigba ti awon emewa oba yoo maa so pe oba n ki o
fun eni to n se oba ni Kabiyesi.
Alo-apamo to so pe “iya kose omo inure se e ni pele” n fi asa ikini laarin Yoruba han.
Itumo alo yii ni erula (eso ila).
Awon owe to n fi asa isinku nigba laelae laarin awon Yoruba han ni won yi (1) Eni to n
gbele lo n sinku ariwo la’san leni to n sokun n pa (2) Oku n sokun oku, akasoleri n sokun ara
won (3) Orun dede mo-kan-an-ju gbogbo wa lo n bo (4) Adie irana kii se eran ajegbe.
Owe 1 n fi asa pipa oku mo tabi bibo oku mole han se Yoruba kii je oku tabi sunun jona ki won
si pa eeru re mo bi ko se pe ki won sin in.
Owe 2 & 3 n fi igbagbo Yoruba pe ko si eni ti yoo ju saye ti ko ni ku bo ti wu ko pe laye to han.
Bi owe 4 se n fi han pe gbese ti gbogbo eniyan yoo san ni iku, lo tun n fi asa Yoruba nipa fifi
adie se irana nigba ti won ba n lo sin oku han se inu igbo ni won maa n sin oku won si ni igba
laelae.
Lona miiran, ibon ni won fi n tufo oku oba, bee ni Yoruba kii so pe oba ku tabi oba so, Bi
ko se pe oba waja ti oba ba fowo-rori ku. Oba sigba tabi se bi okunrin ti ko ba fowo-rori ku.
Awon ipede bii waja, sigba, se bi okunrin n fi ona itufo oku oba nigba laelae han. Pelupelu ipede
“Erin wo, Ajanaku sun bi oke, opalamba oti oyinbo fo onigbaso ko lee ri so” ati ipede orin
Yoruba to so pe oku olowo odun meta, oku otosi osu mefa oku olomo aseesetan n fihan pe
Yoruba maa n se ayeye ni akoko isinku ati pe bi omolooku ba se lowo-lowo to ni yoo so bi ayeye
naa yoo se larinrin to.
Lakootan ipede “A kii ri ajeku oro” n fi han pe orisirisi iku to ba pa oku ni yoo so ona ti
won yoo gba sin in. Bi oku eko se wa naa ni oku ofo wa. Oku to ba ku lona akanse, ona akanse
naa ni won yoo gba sin in bi apeere. Awon onisango lo maa n sin oku eni ti ara san pa leyin
etutu ti won yoo se. Eti odo ti omuwe ba ku si ni won n sin in si, bee ni akope to ba jabo lorun
ope pelu.

)we mq a s5y[ lqti in5 zzl-, b7 zpccrc zl- 8jzpq n7n5 zl- 8jzpq kan a mq a s[ p3 “$3b5 zl[ ni ti
ahun, ti zb= ni ti zna r2”. N7n5 zzl- m87rzn 2w2 a mq a n s[ p3 “+t==t= 4y7 ni zna 8v7n. )we s8
t5n mq a s5y[ n7n5 8tzn Yor6bq b7 zpccrc: Ogun j7jz b7 “Ak7ni j1 ak7ni, afinihzn j1 afinihzn
4wo ni nl1 o +pc 8jzy4 l9j5de )g5nm-lq.
N7n5 zsz 8v3yzw9 2w2, a le r7 0we b7 i 8yzw9 d6n l-s8ng7n, [k[ t5n mi v3 mo f1 soge.
Z8rinj8nnz lq 8 r7 abuk3 =k1r1, cni bq dcsz j8nnz y99 pa cja ar[. “Z8r8nj8nnz lz8r7 bi t7 w-n
fod9 8b7l2 jcun.
A t5n l4 s2dq 0we n7n5 2s8n b7 i “ay3 la bqfq, ay3 la bq m=le, =sqn gangan ni 8vzv- w[l3”.
Lqti in5 or7k8 or7l2 “ 9 wu ol9w9 l9 dqs[ sqnyqn, 9 wu Ol50j3 l9 daw[ ajq bora.
N7pa zk7y4s7 zy7kq cni b7 i “lqqlq t9 r0k4, il2 l9 n b=”. N8pa 8h6was7 s7 b7 i “$3f7n n8wz
r7r5 n7 i r5” n7pa 8tzn 8s2nbqy3 “ Ta n m[ 0k0l0 L’[y=-.
@K_ KCTA : L7t7r3s=
*S+R& IS! : Kíka ìwè àpilẹkọ tí ìjọba yàn

OSE KEFA

ÀLÀYÉ KÍKÚN LÓRÍ ÀPÓLÀ +R+ ORÚK+, ÀPÓLÀ +R+ ÌXE ÀTI ÀPÓLÀ ÀPÓNLÉ

*hun Zp9lz +r=] Or5k[:

A l4 p7n v9l9h6n Yor6bq s7 2ka m3j8, 2ka k==kan q s8 j1 zp9lz kan. *p7n nqz n8y7:

<i>Zp9lz =r=]or5k[
<ii>Zp9lz =r=]8xe
Zp9lz =r=]or5k[: j1 cy[ =r= tzb7 zk9j[p= =r= t9 n xix1 n7n5 v9l9h6n g1g1 b7 ol6wz tzb7
zb=.
Zw[n 8s=r7 =r= t9 mqa n wz n7n5 zp9lz =r=]or5k[ ni<a>=r=]or5k[<b>=r= ar-p0]or5k[<d>Ar-p0
afarajor5k[ zti @yqn.

Zp9lz +r=-Or6k[ Zp9lz +r=-8xe


Xade Se ixu.
Mop3 G5n iyan.
Mo ti r7 i.
{ba k- il3 8kzw3 nlq f5n wa.
A pari 8danw0 lqnzq.
G9m7nz k- il3 8woszn nlq f5n wa.
*w[ 8bq va 2b6n kqn7 o wq
@yin k- ni Zkznk1 n b5.
Il3 [ba ti l1wz ju ti zt7j[ l[.
Er3 b==l6 jc D3l3 l-kzn p5p=
{m[b8nrin l1g1l1g1 t2l3 [l-pzq nqz w[l3.
Ax[ funfun ni mo w=.
*yq nqz n7 aqj0 [m[ p5p=.
Il3 [ba t7 9 j9 Bu cwz kun un ni.
Ax[ y7n Wz l9r7 8k- n7 yzrq
Zvzdo t7 av8n B=k6z b=k6z

*hun Zp9lz +r=]8xe.

Zp9lz =r=]8xe ni =r= tzb7 zkoj[p= =r= t9 s[ ohun t7 oluwz xe,0hun ni k9k9 v9l9h6n. Lq8ss7
zp9lz =r=]8xe k0 le s7 v9l9h6n.Zp9lz =r= 8xe l4 j1 cy[kan soso t9 dq d5r9 b7i v9l9h6n t7 a fi
pzxc. B7 zp22rc
Wq\ K7ve\ Dqk1\ J9k09\ D7de\

Zw[n 8s=r7 =r= t7 a mqa n r7 n7n5 zp9lz =r=]8xe (a)=r= ixe<b>=r=]8xe zti zb=<d>=r=]8xe
zti =r= zp-nl3<e>=r=]8xe.zb= zti 2yqn<c>axqqj5 =r=]8xe zti =r=]8xe k7k5n<f>=r=]8xe,ak1y7n
=r=]8xe zti zb=.

Zpccrc b7i:

Zp9lq =r=]or5k[ Zp9lz =r=]8x3


)j9 r=
F[lq Pariwo
Saf1 F1 aya rere
Alqpqmqxix1 K0 vọ́dọ̀ jcun
T5nd3 s6n f[nf[n
Mop= ti k[rin
Ìgb3l3wọ̀n: Pín gbólóh6n wọ̀nyí sí ẹ̀ka m3j8

(a) Àpólz ọ̀rọ̀-orúkọ zti Àpólz ọ̀rọ̀-8xe.


1. Zw[n ak1k=- kilaas8 kcta xe asey[r7.
2. Ẹ̀yin náz k9 tí 8 parí ixẹ́ yín.
3. Ọdún mẹ́tamẹ́ta ni wọ́n ń gba zjẹsára.
4. Ajá dúdú bu [m[ náz jẹ lóru.
5 .Mo gbọ́ gbogbo zlzy3 tí ẹ xe.
*HUN ZP(LZ +R+-ZP_NL# ZTI IX! W{N

+r=-zp-nl3 ni zw[n =r= t7 9 mqa n p-n =r=-8xe tqb7 yqn =r=-8xe n7n5 v9l9h6n. +r=-zp-nl3 t5n
mqa n fi k5n 8tum= f5n zp9lz 8xe n7n5 v9l9h6n. B7 zpccrc:
 Ey7n B-lq funfun p8n-7n.
 {m[ nqz s6n valaja.
 Ad3 n lzqg6n y=b=.
 W-n n h9 g44.
+r=-zp-nl3 sqqbz mqa n jc y[ t2l3 =r=-8xe n7n5 v9l9h6n.
+r=-zp-nl3 p-nb3l3
 Ax[ r2 m- ton7.
 ( pupa f00.
+r=-*xe +r=-Zp-nl3 T9 L4 Bq +r=-*xe Xix1
S6n Gbalaja,f[nf[n
M- T9n7t9n7
Pupa F00
R8n Jz6jz6
Ga F7of7o, gogoro
P-n W22, rzk=rzk=, r1s5r1s5
Funfun Bqlq5,p8n-8n,gb00
M-l2 Rokoso.
IX! T& +R+-ZP_NL# N XE
( mqz n xe zw[n ix1 w=ny7:
Zp-nl3 Alqs8k0: Zpccrc→ w3r3w3r3, k7qk7q,k7qm-sq, abbl.
<a> Xad3 l[ w3r3w3r3.
<b> Ol5 d3 k7qk7q.
Zp-nl3 On7bi: Zpccrc→ rokoso, rzk=rzk=, bqlq5, f00, y=b=, gb=ngb=nrzn, rq5rq5,abbl.
(a) )x6pq m-l2 rokoso.
(b) ( d5d5 fafa.
Zp-nl3 On7x3s7: Zpccrc→ jz6jz5, s66, y=b=, p2l1p2l1, Abbl.
(a) {m[ nqz n r8n jz6jz6.
<b> ( n w0 s66.
Zp-nl3 ol9diw=n/ On7v4d3ke: Zpccrc→ w9m5w9m5, bqm5bqm5, rq5rq5, pqtqpqtq,abbl.
<i> Il3 nqz j9nq rq5rq5.
<ii> W-n par7 ix1 nqz pqtqpqtq.
*V#L#W+N
<i> K7 ni =r=-zp-nl3?
<ii> Dqr5k[ ix1 m1ta t7 =r=-zp-nl3 n xe p2l5 zpccrc m3j8m3j8.
*B#$R$ $WON*DQH^N
1. Fq 8lz s7 8d7 =r=-zp-nl3 n7n5 zw[n v9l9h6n w=ny7:
<a> K5nl3 d5d5 fafa.
<b> B-lq wq k7qk7q.
<d> Il7 nqz ga f7of7o.
<e> F8lz Tol5 funfun v00.
*s=r7 is1: ZXZ
Zk09n5 is1: Ogun j7jz
Ogun j7jz ni 8k[l6 lqzqr7n zw[n 4n8yzn kan, 8l5 tzb7 8let0. $y7 t9 fa l7lo zw[n ol9gun zti nnkan
8jz ogun n7n5 4y7 t7 =p=l[p= nnkan 1l1m87 zti alq8l1m87 ti mqa n parun t55t55.
)g5n Lqkqaye ni 9 dq ix1 ogun j7jz s7l2 n7 il2 Yor6bq. *d7 n8y7 t7 a fi n pe ogun n7 ix1 )g5n.
Zw[n Ohun T9 n Fa Ogun Lqy3 Ztij-
<i> Il2
<ii> Oy4
<iii> *xqk-l2 tzb7 k7k[ zs8nvz
<iv> Zzlz il2 8l5
<v> S6nm=m7 v7v3
<vi> Y7yc zd3h6n
<vii> +r= ob8nrin
<viii> Z7fzvz f5n cni tqvz t- s7.
<ix> +nz lqti ycj5 8j0y4 ogun
<x> Avqra d7dqnw0
<xi> K7k= lqti ta o5njc f5n 8l5 kan
<xii> @f2 ak[.
Zw[n Ohun T7 K0 Yc K9 Fa Ogun Lqy3 Ztij-
1. @s8n
2. Cl1yzm2yz
3. Og5n p7np7n
4. *xqk-l2
5. *x4l5
6. Oy4 j7jc
7. *yzw9 n7n7<8jz ob8nrin>
ZW{N OHUN $L) OGUN
1. *b[n
2. Zdq
3. [fz
4. K6m=
5. Idz
6. +pqgun
7. Apata
8. Ev3
9. K9nd9
10. {fz/Kznnzkznnz
11. {r5n
12. *s5j5
13. Gb4tuv4tu
14. Aycta
15. )k7v1
Orixirixi Ogun to ti ja ni ilc Yoruba
i. Ogun jalumi ii. Ogun Kiriji iii. Ogun vanamu iv. Ekiti parap[
i. Ogun Arakanga 1834 (Egba / Ibadan ) viii. Ogun Owiwi 1832 (Egba / Remo)
ii. Ogun ijebu 1851, Ogun idahomi 1844 ati 1851 Ogun ijaye 1860 – 1862
abbl
*GB#L#W+N
1. K7 ni ogun j7jz ?
2. S[ awon nnkan mqr6n-5n t7 9 l4 fa ogun j8jz
IX ! ZM%REL# : Yzt= s7 zw[n ohun elo ogun jijz ti a mcnu ba, daruko ohunelo ogunjijz ode
oni marun un.

7. *SINMI *DAJ* TQZM^

8. Èdè: Akàyé-Ewì( Ìtọ sónà lórí àkàyé ewì)

Àṣà: Ìtcsiwaju lori ogun jija

Lítíréṣọ :Kíka ìwè àpilẹkọ tí ìjọ ba yàn (ewì)


*s=r7 is1: $D$
Zk09n5 is1: Zkzy3 <2) Ew8
Zv3kal2 Zk09n5 is1: Zkzy3 <2) Ew8
+nz t7 a l4 va xe zxey[r7 n7n5 zkzy3 t7 9 dq l9r7 ew8 k0 fi bc2 yzt= s7 4y7 t7 a fi =r=
geere v3kal2. X6v-n a v-d= jc k7 9 y3 wa p3 zv3kal2 ew8 yzt= s7 ti [l-r= geere. *lz 8lz ni a n
k[ ew8, 0nk=w3 k87 xe zlzy3 kan l[ t7t7.N7tor7 nqz lqti l4 n7 0ye t9 t- l9r7 ew8:
<i> a v-d= fara bal2 ka vovo cy[ =r= zti v9l9h6n t7 a fi v3 ew8 kal2.
<ii> a k0 v-d= fi 8tum= =r= t7 a ti m= tcl2 f5n =r= t7 a bq pzd3 n7n5 ew8.A v-d= v8yznj5 lqti
m[ 8tum= =r= k==kan gcgc b7 ak3w8 xe l09 n7n5 ew8 t7 a n t7 kz.
Ka zy[kz 8szl2 y87, k7 o s8 dqh6n zw[n 8b34r4 t7 9 t2 le.
A k5nl2 a yznp7n
A d=bql2 a yznm=rzn
A dqy3 tqn, oj5 n yqnni
Ak[ t9 j7 n7l3 ay3,t9 fc pa-m7-n-k5 lqya,
G8r8pq t9 lqya r2 n7 k6t6,
T9 v3 agqnnigzn n7yzw9
( ti v9k65 zpar0,
( ti vcxc aqp[n
*yzw9 clc2kc 43b5, ab-k[-b7-cn7lqyin
A x0w0-4t4-mq-k6tz, pa-m7-n-k5
T77 xor7 bcnbc s-k[ w[n
Zp-n 8r=r6n
( yq j6yzw9 zk9bq;
Or7 9 k9 wa y[ l-w- ir5 w[n ni
Zb7? In5 d7d6n l-=d2
K- n77 m9r7 yq ni n7l3 cni?
$n8yzn t-kzn r2 0 r9j5
9 se l4 rqnt7 ztik-l3 re;
9 se l4 dqm=rzn zt7 r2w6 s-r6n
D3bi k9 farabal2 l-=d2
K7 won 9 p4te [m[ f5nra won.
Dqh6n zw[n 8b34r4 y87
1. Ir5 8yzw9 wo ni a n s=r= r2 n7n5 zy[kz y87? *yzw9 t7 9 ......................
<a> n7 8fc [k[ <b> n bq arq zd6v0 jz <d> n bq [k[ jz <e> n t-j5 [m[.
2. ‘v9k65 zpar0’ n7n5 zy[kz y87 t5m= s7...................
<a> k[jq zy4 r2 <b> x2 s7 0fin [dc <d> v3 0k5 cyc <e> xe or7 ire.
3. K7 ni k9k9 t7 zy[kz y87 dql3?
<a> {k6nrin v-d= kqpq 8yzw9 <b> 8yzw9 bur5k5 0 sunw=n n7 ==d2
<d> O yc k7 [k6nrin t4t4 n7 8yzw9 <e> K0 yc k7 q kqnj5 n7 il3 ay3.
4. “Pa-m7-n-k5 t7 7 xor7 bcnbc s-k[ w[n” t5m= s7 k7 ob8nrin..............
<a> jc alq8v[rzn <b> jc alqg7d7 <d> mqa xe zv4r4 <e> n7 22kc 43b5.
5. {k6nrin t7 [kzn r2 k0 bal2 k0 l4...................
<a> fc 8yzw9 <b> jc zpar0 <d> k- il3 rere <e> pa apzr0.
6. Or7x87r7x87 8wz wo ni ob8nrin bur5k5 mqa n h6 s7 [k[ r2?
7. Bqwo ni ob8nrin bur5k5 xe jc zk9bq f5n [k[ r2?

.Ẹka Iṣẹ : zxz


Orí Ọrọ: Itcsiwaju lori ogun jijz
Orixirixi aw[n eniyan ni a v[ wi pe o ti jagun ni ilc Yoruba ni aye atij[ titi di oni ni
a xi n xe iranti ohun ti w[n ve xe. Lara w[n ni :
i. Ogedenve Avogunvoro ti ilc Ijcxa
ii. Lisabi Agb0nv0 Zkzlz ti ilc Cva
iii. Aarc Latoxz ti ilu Ibadan
iv. Cf5nr9y4 Tin5b5 t7 @vq
v. Xodckc ti Cva
vi. Bax[run )g5nm-lq ti ilu Ibadan abbl.
Zw[n ol9y4 ogun

Lqzrin zw[n 2x- ni a ti mqa n yan zw[n ol9y4 il2 yor6bq n7tor7 p3 w[n o n7 is1 m87rzn t7 w[n
n se ju is3 ogun j7jz l[. B7 zpccrc: Zzrc +nzkakanf= ni ol9r7 ogun il2 yor6bq, bal9gun ni baba
8szl2 zw[n ol9gun, S3r7k7 ni cni t7 9 bq le se zk9so zw[n ol9gun t7 9 j1 t=d-, As7wqj5 ni 9 mqa
n t2l4 S1r7k7 0un ni cni t7 9 mqa n s7wqj5 n7n5 ogun, +t5n )s8 ni olus=gb4 S1r7k7 n7n5 ogun,
Szr6m7 ni ol9r7 zw[n t7 9 mqa nfi cxin jz ogun abbl. *ran zw[n on8k0y7 ni ati n yan p5p= lqra
zw[n ol9y4 ogun s6gb-n k87 se zw[n n8kan l9 n jagun il2 Yor6bq.Lqra zw[n 8ran m87rzn t7 a ti
mqa n yan zw[n [m[ ogun ni 8ran 8r4m0g5n,Olu=j2, ol5gb-n, Ar2sz, 8r4s3 abbl.

Anfaani Ogun jija


i. Ogun n jc ki aw[n ilu kekeeke m[ ava ni cv[n
ii. O n s[ aw[n oloye ogun di [l[r[ [san gangan
iii. O n jc ki a m[ aw[n [kunrin ti w[n to vanva sun l[yc
iv. O n xe afikun aw[n ilu kereje.
v. ( n s[ =p= 4n8yzn di alqvqra
.$t0 *dqb0b0 *l5 lqs8k0 ogun
Ara 4t0 t7 a se f5n 8dqzb0b0 8l5 ni odi m7m[, k7k- il3 8s-, v7va al9re, w7wa yzrz y7 8l5 po.
Odi
odi m7m[ j1 =kan pztzk8 lqra =nz t7 a n gbz dqzb0 bo 8l5 lqy3 ztij=. B7 8l5 bq se t9bi t9 ni a se
mqa n m[ odi y7 i po. Odi mqa n ga t9 cx2 bztz m1wzq k7 qw[n =tq mq bzq le g6n 5n b12 s8 ni
9 mqa n f2 k7 zw[n =tq mq bzq le b87 w9. Or7si odi m3j8 ni =p= 8l5 mqa n n7, odi zk-k- ni odi
zsqm5 n7vz t7 odi kej8 nj1 odi zsqlz t9 kqngun s7 *l5 pqtqpqtq. *l5 *bzdzn n8kan l9 n7 odi
m1ta 4y7 t7 a n p4 n7 odi *b7k5nl3.
Yzrz
Yzrz n7 k0t0 t7 a wz y7 8l5 kq l1y8n 8gbz t7 a bq ti m[ odi y7 8l5 kq tqn k7 9 bzq le s0ro f-tzq
lq ti g6n. N7gbz m7rzn a l4 wa yzrz s7 zw[n ibi kan t9 le r[r6n f5n zw[n =tq lqti g6n k7 9 mqz
y7 8l5 kq.
Al9re
Al9re ni zw[n t7 9 mqa n d5r9 s7 cnu ibod4 k==kan. Zw[n al9re ni 9 mqa n wo zw[n 4niyzn t9 n
w[l3 tzb7 t9 n jqde. Zw[n ni k87 j1 k7 zw[n am7 rqzy4 w[l3. Zw[n al9re ni 9 mqz ns[ f5n arq 8l5
b7 ogun bq n b= k7 w[n bzq le gbqrad8
*velew[n: a. Xe alaye ilo aw[n nnkan w[nyi ninu eto aabo ilu; Yara, odi, ile ix[
b.S[ anfaani ogun jijz merin.

+x2 Kcszn]qn

Èdè :Àkàyé-(yíyan àyọkà ewì fún àwọn akẹkọọ)

Àṣà:ogun jija

Lítíréṣọ:Kíka ìwé àpilẹkọ ewì tì ìjọba yàn. .

Zv3kal2 Ix1: K7 ol6k- yan àyọkà ewì fún àwọn akẹkọọ lqti in5 8w3 *yq Ztztz

.Ẹka Iṣẹ : Zxz Itcsiwaju ogun jija


Orí Ọrọ: Aleebu /Ewu to wa ninu ogun jija.
i. Fifi cmi xofo
ii. F7fi d5k7q x0f0
iii. Ajakalcnu aarun
iv. Pipadanu aw[n cbi ati ololufc cni sinu ogun le fa ifascyin ba ivesi aye cniyan
v. Sis[ eniyan di otoxi niva ti vovo nnkan ini ati dukia rc c ba ti ba ogun l[
vi. Lcyin ogun jija, [w[n ounjc saaba maa n waye
vii. Ogun maa n tu ilu, a si s[ ilu di ahoro
viii. Ogun n fa [ta ayeraye laariin ilu kan ati ikeji.
ix. Ogun jija maa n s[ [p[ eniyan di alaab[ ara.
x. Ogun airotcle k78 jc ki ilu ni 8davasoke.

B7 A SE L$ D$NZ OGUN J&JZ


a. A n7 lqti mqa fik6nluk6n lqti yanj5 zw[n =r= t9 bq le fa 4d4 z8y3d4 lqw6j[
b. A n7 lati mqa n7 s65r6 f5n ara wa lqti yanj5 zw[n =r= t9 bq f1 ta k9k9
c. A n7 lqti m5 cs2 0f7n b[ ir5 zw[n =r= t7 0 bq f1 t4t4 yanj5 l[ s7l3 cj-.
d. A n7 lqti m[ 2t- /zzy4 ara wa
e. A 0 n7 lqti fi zzy4 va 8wz cl1s8nm2s8n tzb7 cl1yzm2yz lqw6j[
f. Zw[n 8j[ba n7 lqti mqa se zm5l0 zw[n ori ad3 zti [r6n 8l2k2 n7n5 8s4j[ba w[n.
g. Fifi ifc han si aw[n eniyan ilu tabi aw[n orilc ede to yi wa ka.
h. Yiycra fun iwa 8jcgaba lori [m[lakeji.
BI A XE N PAR& *JZ N& OJ% OGUN.
Aw[n [m[ ogun kan ti ive dun le ranxc si apa keji pe aw[n ko ja m[. W[n yoo ta ax[ funfun
soke, ja ewe tutu l[w[ bii ami pe “Ki alaafia ki o wa.” W[n yoo xeleri lati maa ru asinva fun
aw[n ti w[n bori w[n. {ba ilu tabi Balogun v[d[ wa laarin w[n laisi bcc w[n yoo ko w[n lcru,
ogun yoo si tcsiwaju. {ba ilu le ve [pa axc ranxc bi aroko. Bi ogun ba ti pari bayii, aw[n
[m[ ogun yoo bc vovo igi tutu aarin ilu naa lulc bii ami 8xcgun. {ba ilu ti o xcgun yoo yan
jagunjagun kan bii Ajclc si ilu naa lati maa soju rc.
.
*velew[n: S[ orixii [na marun un ti a le ve dena ogun ni awuj[.
S[ zl43b6 ogun j7jz m1rin .
LITIREX{ : KIKA IWE LIT. TI A YAN
Ki oluk[ wo aw[n [na ede ati 8x[w[lo ede ti o jcy[ ninu iwe naa.

IX@ )PIN +S@:

*b34r4 4wo ni 8dqh6n

1 Axoj5 t7 [ba 8l5 t9 s1gun mqa n fi t2d9 s7 *l5 t7 a s1gun r2 ni..........

a bal9gun b Al9re d Aj2l1 3 Am7

2 K0t0 t7 a wz y7 8l5 po ni a m= si..........

a Al9re b Am8 d Yzrz e @s-

3 Zm8 8s1gun ni ........

*velew[n: Xzlzye b7 axe n pari 8jz loj6 ogun.


+X@ KCWZQ
$d4: Zkzye onis[r[ves8
Zkzy3 ni zy[kz t7 a kz, t7 9 s8 y3 ni y3k3y3k3.Zy[kz l4 j1:
 Zkzy3 [l-r= geere
 Ew8 tzb7
 On7s=r=v4s8.
*v3s2 F5n Zkzy3
 K7ka zy[kz n7 zkzy3<n7n7 0ye zy[kz>
 K7kja zw[n 8b34r4 t9 jcy[ lqb1 zy[kz,
 K7ka zy[kz w0 l12kej8 lqti szm8 s7 =gangan ibi t7 8dqh6n s7 zw[n 8b34r4 ti jcy[
 X7xe zk7y4s7 zti m7m[ zw[n =r= t9 ta k9k9 n7n5 zy[kz nqz.
ZPCCRC ZKZY# ON&S+R+V$S* KAN
K-lq: B7s7,{k6nrin nqz, c mz k5 =sqn k2. C 0 til2 l4 s6n pzqpzq.
B7s7: Oorun k2? K8 7 xe l-j- 0n7.
K-lq: $wo l9 le m- [? Ta ni n v3yzw9,ta ni n k-l3-8w2? O 0 k5k5 m[ b-=l6 vq.
B7s7: X3 o r7 i,K-lq;L9n87 ni =j2 zw[n [m[ Cdc y90 w[l2.X3 8w[ nqz m= p3 [d5n kar6n -5n
t7 w-n ti n gzba l9r7 wa n8y7.
K-lq: X6v-n 2r6 mz t5n n bz m7 k2. Alqm5b- mz ni gol7 wa.
B7s7: Vzv1 2. X3 Zjz9? Ol9v0 n6-un,[k[ Eku. Oj5 4x7 lo fi n wo Zjz9. Cni t9 bq foj5 znq
wo 0k5 ni,cb[ra q b- [ lqx[.
K-lq: Nj1 o m[ ohun t7 9 t5n n bz m7 l1r6? W-n n7 zw[n [m[ m3j8 kan ti d3 s7 Cdc l-d5n
y87,zrz ni w-n.
B7s7: N7vz nqz wq nk-?
K-lq: Hqz, ( mz di il3 8w3 m3je t7 w-n ti bq vq b-=l6 l-d5n y87. B7 8v7n bq fi cnu bay=, q
k5 mz ni =r= w[n dz.
B7s7: *ycn 0 xe nnkankan j=-. Kzkz k7 zk4r3 ma dunb2 ni,tapq titan ni y90 r5n s-b2
K-lq: X3 o r7 I, t7 P1l2 bq dcw- 4g3 zg3j6 r2, r1r1 mqa run m- zw[n arq Cdc lqra.
B7s7: X3 J7d3? ( ti s[ f5n mi p3 ti fqzr7 k- ni t0n7, ti g90l6 ni. ( ni Cdc q tzn xqq ni.
K-lq: *bz mz dqra o.
B7s7: X3 o s8 m= p3 =gq il38w3 ti ra s-kz titun f5n vovo w[n. Par7 2 ni.
K-lq: H1n 2n 1n. Vovo r2 lo xq m= tqn.
B7s7: Zti jcs7 titun. Or7 zw[n [m[ pzqpzq ti wq w5.
K-lq: In5 mi y90 mz d6n o, t7 a bq l4 dqgi m- Cdc l1s2 l-d5n y87.
B7s7: *ycn 8tzn. K0 s7 wol3wol3 kan t7 9 l4 wo igi im5 cni. Cdc k0 t9 wa r7 f7n.
K-lq: X6v-n kq m5ra xq o.
B7s7: W0 9. J1 k7 n s[ f5n c. Cv2r5n Szqm5 ni, k0 l4 sq m’_l-run l-w-. Vovo =nz y9w6 t7
Cdc l4 vz y[ n7 [d5n y87,a 9 w9 w[n xqq ni. O yq j1 kq m5ra.<W-n jqde>.
T.A. Aw9n7y8, <1976:80-81> YOR^BQ ZTZTZ, On7b[n0j3 Press, 8bzndzn.
*V#L#W+N
1. K7 l9 fz q t7 =r= b-=l6 y87 fi kq w[n lqra?
A. W-n ti n nz w-n tip1.
B. Bztz titun t7 =gq rz.
D. )un ni zk-vq w[n.
E. )un ni zxekqvq.
2. K-lq n b2r6 n7tor7 p3.............
A. f78d8 w[n k0 dqra
B. alqzm5b- ni gol7 w[n.
D. 8m5ra w[n k0 t9.
E. 0j0 l4 r=.
3........... ni or5k[ g9l7 il3-8w3 K-lq.
A. Kzkz
B. Zjz9
D. Ol9v0
E. Vzv32.
4. Zk0r7 t9 bq zy[kz y87 mu ni j6 l[ ni.............
A. B7s7 zti K-lq
B. Ar3 B-=l6
D. Cv1 Avqb-=l6 Cdc.
E. Ol9l6f1 B-=l6
5. *l5 wo ni il3-8w3 t7 w-n f1 bq vq b-=l6 y90 ti wq?
A. *bzdzn
B. )xovo.
D. $k9
E. Cdc.
6. Cni t7 w-n l9 n g3 4g3 zg3j6 ni.
A. Zjz9
B. J7d3
D. Zk4r3
E. K-lq.

Zxz: *t2s8wqj5 zw[n 0r8xz il2 Yor6bq


Litireso: Iwe kika ti ijoba yan.
{bztqlq/)r8xz-Nlq

)un ni Cl1dzq k-k- dq. T7 Ol9d6mar4 bq ti dq 4n8yzn n7 b[r[gidi tqn,{bztqlq n7 y90 m[ oj5,
im5, cnu, et7 zti 2yz ara y09k6 n7 or7. Ol9d6mar4 y90 wq m7 43m7 8y4 s7 im5 r2. *d7 n8 y7 t7
w-n fi n k8 7 n7:”Zjzlq Alqm= t7 o m- or7 tzb7 Alqm= rere.” W-n vzv- p3 zw[n abuk3,ar[,af-
j5,zf7n j1 cni 0r8xz.

Funfun ni vovo nnkan {bztqlq-ivq, zx[, 8l2k2, bztz, oj5b[<cfun ni w-n n k6n oj5b[ r2> zti
zzjz. {b2 zt1, 8v7n p2l5 iyqn ni o5njc r2, 9 s8 t5n f1rzn ob8 zti [t7kz.Omi 8dqj7 l9 mqa n mu.
Aj7p[nmi r2 v-d= j1 ar5v9 tzb7 [m[ge t7 k0 t78 m[ [kunrin. Zw[n ol6s8n {bztala k8 7 mu cmu,
jc o5njc el3po, iy=, ajq, cl1d2, tzb7 mu omi 8kzs7, ol6s8n r2 k0 s8 v[d= ru 2k5 e3g5n.

Or7x87r7x87 or5k[ ni w-n n pe {bztqlq n7 il2 Yor6bq-)g8yqn n7


$j8v0,)r8xz Akir4 n7 8l5 *kir4, )r8xz *jzy4 n7 8l5 *jzy4, )r8xz P9p9 n7 )v9m=x-,*bzdzn
zti Ad9 $k8t8 m= - s7 )r8szqlq,If2 n p4 3 ni )r8xz-Nlq.

+r5nm8lz/Ifq

+r5nm8lz ni Ol9d6mar4 f5n n7 [v-n, 8m= zti 0ye lqti wq fi t5n ay3 xe.*d7 n8y7 t7 w-n fi
n p4 3 n7 “Ak3r3 fin5 x[v-n’. K0 s7 ohun t7 zw[n Yor6bq l4 f1 xe n7l3 ay3 t7 w[n k0 n7 k-k- bi
Ifq l34r4. *tzn s[ p3 4n8yzn ni +r5nm8lz lqy3 ztij- k7 9 t9 9 b7n5 l[ s-run. $k6r- “ikin
m1r8nd7nl9g5n” l9 fi r-p0 ara r2, 4y7 l9 da ifq t7 babalqwo n dq t7t7 di 0n7.

Or5k[ m87rzn t7 w-n n pe +r5nm8lz ni: {k6nrin k5kur5 )k4 *g2t7, Ak3r3fin5x[v-n, Cl1r87-
8p7n, abbl. Zw[n ohun 4l0 ifq ni: [p-n ifq, =p2l2, ikin m1r8nd7nl9g5n, zwo ifq, 8y2r2s6n, 8r-k1,
8b0, 8r6k2r2. Ohun t7 w-n fi n b[ ifq ni 8v7n, eku, cja zr=, ew5r1, ad8yc, cl1d2, zg6ntzn.

$X^

$x6 ni [l-pzq tzb7 on7bod4.Gbovo zw[n 0r8xz ni w-n b2r6 r2,a v[ p3 $x6 k- ix1 ifq d7dq
l-w- +r5nm8lz zti p3 Il3-If2 ni 9 k-k- v3.Lqra or5k[ t7 w-n mqa n pe $x6 ni On7bod4,
Axebur5k5-xerere 0x8kz-tqn tcs2 m-r8n. )un l9 mqa n p4s4 o5njc f5n zw[n 0r8xz y09k6.*ta
vanva tzb7 2y8n odi 8l5 ni oj5b[ r2 mqa n wz,4re t7 8pzk9 r2 g6n x[b[l[ s1y8n ni zm8 8dqm[ r2.
*l5 *j4l5 $k8t8, Il3-If2, Il3xz zti Zg--*jzy4 ni w-n ti n b[ $x6 j6 l[ n7 il2 Yor6bq. Epo ni
9 f1rzn j6 l[, 44w= r2 ni zd7.

ÒG%N
{dc ni )g5n n7 ay3 atij-. ( f1rzn 8jqlq s7sun. Tzb5l5 ni 8yq r2 .Or7r7nnz ni baba t9 bi l-m[. )un ni
9 fi zdq la =nz f5n gbogbo zw[n 0r8sz y09 k6 n7gbz t7 w[n nb= lqti 8k=l3 ay3 wq s7 ay3.Ib2 ni
w-n ti fi jc oy4 {s8nm[l2. )g5n gb3 n7 il3 If1 f5n 8gbz p7p1 k7 9 t9 l[ s7 8l5 8r3.W-n n7 “ 8r4
k87 se il3 )g6n 9 yz n7b2 mcmu ni”.n7tor7 p3 )g5n f1rzn cmu p5p=.Mzr8w0 ni 9 fi n bo ara 8d7
n8y7 t7 a fi n k87 n7: ) lqs[ n7l3 fim=k7m= bora, mzr8w0 ycgbcycgbc ni as[ Og5n.Zw[n ohun
4l0 t7 a mqa n r7 n7 oj5b[ )g5n ni: [m[ ow5, =pq 0g5n, 2m5 s3k3l3, zdq, 8b[n, =bc, irin,
Ol5gb0nd9r0, zw[n nka 8jz )g5n zbbl. Lqra or5k[ m87rzn t7 )g5n nj1 ni: Lqkqay3, {s8nm[nl2,
Zw90, Ol5m=k7n, Yqnkznb7=gb2 abbl. Ajz ni w-n fi nb[ )g5n. @sun isu ni o5njc t9 f1rzn j6l[.
W-n t6n n fi zgb0, ew5r1, cycle, 8gb7n, 2wz 2yan, iyqn, zmzlz abbl.

Sàngó

Sàngó jẹ́ ọba aláàfin Ọ̀ yọ rí. wọ́n gbàgbọ́ pé ó lóògùn lórí òjò , àrá àti ìmọ̀nàmọ́ná.
Bí sàngó bá ń sọ̀rọ̀ iná a máa jáde ní ẹnu rẹ̀ àwọn ìyàwó rẹ̀ ni Ọya,ọ̀sun àti ọba.

Ọ̀ rọ̀ ìjà ni Sàgó fi fi orí oyè sílẹ̀ nígbà tí àwọn ènìyàn ọ̀yọ́ dìtẹ̀ mọ́-ọn.Wọ́n lée
jáde nínú ìlú. Sàngó bínú pokùnso nídìí igi Àyán ní kòso ìdí nì yìí tí wọn fi n pè é ní
ọba Kòso.Ọya ìyàwó rẹ̀ wọlẹ̀ ní irá, ó di odò. Àwọn àwòrò Sàngó ni adósùn àti
ẹlẹ́gùn Sàngó. Oúnjẹ tí sàngó fẹ́ràn ni àmàià pẹ̀lú ọbẹ̀ ewédú,ẹran àgbò,orógbó
àti obì. Ìdí nìyí tí wọ́n fi ń kìí wí pé :

“Sàngó olójú orógbó,

ẹlẹ́ẹ̀kẹ́ obì...........

*V#L#W+N:

K7 ni o m= n7pa zw[n 0r8xz w=ny7 n7 x9k7?

<i>{bztqlq

<ii>+r5nm8lz

<iii>$x6.

@K_ KCTA : L7t7r3s=


*S+R& IS! : Kíka ìwè àpilẹkọ tí ìjọba yàn

11. Zt5ny2w0 ix1 ati 8dqnw0.

You might also like