You are on page 1of 5

IS}KAL{ {MI MIM} NI }J} P{NTIK}STI

Ie Aw]n Ap]steli 2:1-47 {K} 281 --- FUN AGBA AK}SORI: Si kiyesi i, Mo rn ileri Baba mi si nyin: ugb]n [ joko ni ilu Jerusal[mu, titi a o fi fi agbara w nyin, lati oke ]run w (Luku 24:49). Ifi Agbara {mi Mim] W Ni g[g[ bi Iriri K[ta ti Onigbagb] 1 iwaju iku R, Kristi eleri iriri k[ta yii fun gbogbo aw]n Onigbagb], Johannu 14:15-18, 26; 15:26, 27; 16:7-15; Luku 11:13; 24:49; Ie Aw]n Ap]steli 1:4-8; Fi Matteu 3:11 we Johannu 1:33 2 Aw]n Woli Maj[mu Laelae paapaa ti s] as]t[l[ nipa ti itujade {mi Mim], Matteu 13:17; 1Peteru 1:9-12; Jo[li 2:21-29; Isaiah 32:15; 59:20, 21; Eseki[li 36:25-27; 39:27-29 3 Aw]n ap[[r[ ti o w ninu Maj[mu Laelae fi iriri m[ta ti o wa fun aw]n Onigbagb] ti isisiyi hn: (a) Ohun m[ta ti o [l[ lori Oke Moria, G[n[sisi 22:1-18; 1Kronika 21:18-27; 2Kronika 5:114 (b) Ipele m[ta ]t]]t] ti o w ninu Ag]-aj] ati T[mpili nibi ti w]n ti n sin }l]run, {ksodu 40:1735; Fi Heberu 9:1-12 we 10:9-22 4 Aw]n ti a ti s] di mim nikan nipa ibuw]n j[ n l[[keji ni w]n le gb agbara {mi Mim], Heberu 12:14; 13:11, 12; Fi L[fitiku 4:1-12; 6:24-30 we 16:1-28; Efesu 5:25-27; Eseki[li 36:22-29 II Dide Olutunu 1 Aw]n ]m]-[yin ]g]fa l]kunrin ati lobinrin wa ni i]kan, eyi ti o fi han pe a ti s] w]n di mim, Ie Aw]n Ap]steli 2:1; Heberu 2:11; Johannu 17:17-23; Orin Dafidi 133:1 2 Olutunu d g[g[ bi Jesu ti eleri, Ie Aw]n Ap]steli 2:2-4 3 A fun ni n ami ti o daju ti k si e e jiyn r pe eyi yii ni {m Mim] naa Olutunu, ti a ti eleri R, Ie Aw]n Ap]steli 2:5-13, 16; Jo[li 2:28, 29 4 Gbogbo itujade {m Mim] l[yin eyi ni o ni [ri kan naa bi ti iaaju, Ie Aw]n Ap]steli 10:44-48; 15:7-9; 19:1-7; 1K]rinti 14:18, 22 III Ap]steli ti o Kn fun {m Mim] ati Iwaasu R 1 Peteru ti a fi Agbara {mi ati a[ titun yii w dide, o si waasu fun ij] eniyan, Ie Aw]n Ap]steli 2:14, 15 2 O fi idi i[-iran[ r yii mul[ nipa lilo }r] }l]run ti o fi a[ ti o ri gba yii han gbangba, Ie Aw]n Ap]steli 2:16-21; 2Timoteu 4:5; 2Peteru 1:19-21 3 L[yin ti o ti fi [ri is]t[l[ yii han, O waasu nipa Jesu, Ie Aw]n Ap]steli 2:22-36; 4:12; Johannu 10:7-9 IV Ohun Ti O [l[ nigba ti A Tu {m Mim] jade sori Aw]n ti o Fetisil[ 1 Ileri Kristi [, a si fi agbara tun fun aw]n Ap]steli, Ie Aw]n Ap]steli 1:8; 2:37, 43; 4:13, 33; 6:10 2 Ninu idahun Peteru ni a ri ileri iyanu fun awa ti o w laye ni akoko Ar]kuro Ojo yii, Ie Aw]n Ap]steli 2:38-40 3 {ri nla ti ifiwni Agbara {mi Mim], ni aw]n ami ti o maa n t[le i[ iran[ aw]n ti a fi agbara naa w, Ie Aw]n Ap]steli 2:41-47; Marku 16:15-18 I

Page 1 of 5

ALAY Gbogbo aw]n Onigbagb] toot] lode oni ni o ni anfaani ologo, yala w]n m b[[ tabi w]n k m. Akoko mi Mim] ni a wa yii akoko Ij] }l]run. Igb yii j[ akoko ti a n fi [kunr[r[ iriri ibukn }l]run fun gbogbo aw]n ti o ba fi igboya w si ibi it[ ore-]f[. Akoko yii ni aw]n Woli Maj[mu Laelae n foju s]na si p[lu iyanu ati ireti. Akoko yii ni nnkan w]nni ti aw]n ang[li f[ lati ri [l[. Akoko yii ni a le ri, ti a si le m, ti a si le gb nnkan w]nni ti aw]n [ni mim igba n f[ ri, ti w]n f[ m, ti w]n si f[ gb. Abaj] ti Jesu fi s] wi pe [ni ti o kere ju l] ninu Ij]ba yii p] ju [ni ti o tobi ju l] ni igb Maj[mu Laelae! Ohun ti Jesu s] k fi han wi pe awa tay] aw]n ti igba n ninu iwa mim, tabi ododo tabi iwa-bi}l]run, nitori pe ohunkohun ti o wu ki a j --ati eyikeyi ti aw]n ti igb n j -- nipa oore-]f[ }l]run ti o fara han ninu Kristi Jesu ni. Ohun ti Jesu n s] fun wa ni pe ojue ati afo ti a ni lati d nipa ipe ti a pe wa tay] ti w]n, paapaa ju l] ay ti a w ni akoko ik[yin yii nipa ojue wa ni ti ipadab] R l[[keji. {kun Ibukun Iriri Nipa iyipada ninu ohun gbogbo bi ]dun ti n yi lu ]dun, itum] aw]n ]r] miiran ninu ede ti a n f] a maa yipada, nigba miiran [w[, ohun ti ]r miiran duro fun nisisiyi le fun ni ni iriri tun. Ni ]dun pup] s[yin, ja-a-niyan-danwo ni ede ti a maa n lo nigba ti a ba n s]r] nipa iriri Onigbagb ti o daju; fun ap[[r[, iriri ologo ti idalare ati is]dimim] patapata. Ohun ti ]r] yii duro fun nigba n yat] si ohun ti itum] r j[ ni ode-oni. Nigba naa a maa n pe i[ oore-]f[ ti o daju ti }l]run pese fun aw]n eniyan R ni igbagb] ja-a-niyan-danwo. ugb]n itum] ]r] yii ti yat] si ti igba n ninu ede asiko paapaa ju l] nisisiyi ti ]kn ]m]-eniyan t si ati gb ireti ati igbagb r kal[ lori ]gbn ay ati ero kukuru ti [da. Kaka ki aw]n eniyan ni iriri aanu ati oore-]f[ }l]run l]j] oni, ohun ti w]n n e ni pe w]n n gbe e wo bi b[[ ni tabi b[[ k]; nitori eyi igbagb] ja-a-niyan-danwo ko fi han bi [ni pe a ni iriri ati idaniloju oore-]f[ igbala }l]run yii gan an, agbara iw[num] ati agbara {mi }l]run. Igbagb nipa iriri ni ede ti a n lo nisisiyi dipo igbagb] ja-a-niyan-danwo, nitori pe ohun ti }l]run le fi fun ni ani eyi ti O n fi fun ni -tay] ohun ti a n gbe wo pe o ri b[[ tabi k ri b[[. Irir ni, ti o daju gbangba, a si m] b[[, o fidi mul[ inin p[lu. Aw]n ti igba n ni iriri idariji [ ati iw[num] ]kn. W]n ni idalare ati is]dimim] nipa itoye {b] Pip ti Jesu n b] wa r, nipa wiwo Agbelebu nipa igbagb ti }l]run fi sinu ]kn w]n. Ak]sil[ nipa igbesi-aye w]n, ]r] iwuri ati ip]nni ti a ri ka nipa w]n ninu Bibeli ati oungb[ at]kanwa w]n ti aanu ati oore-]f[ }l]run t[l]run fi han wa pe w]n ni idande kuro ninu [ l]na ti k yat] si ti wa. A t]ka si w]n ninu Maj[mu Titun g[g[ bi ap[[r[ igbagb ati iwa-bi-}l]run (Ie Aw]n Ap]steli 2:29, 30; 28:25; 2Peteru 1:21; Heberu 11). Nitori naa o daju pe nigba ti Jesu eleri Olutunu, ati nigba ti O wi pe Olutunu naa k ti i de, ati pe k si le de bi k e pe Oun (Jesu) ba goke re }run, ki i e eyikeyii ninu aw]n i[ oore-]f[ mejeeji ti aw]n ti igba Maj[mu Laelae l]kunrin ati lobinrin ri gb lati igba n ni o n t]ka si. Agbara {mi Mim] ki i e iriri is]dimim patapata, g[g[ bi aw]n miiran ti n k ni, nitori pe a n s] aw]n eniyan di mim] nigba laelae. Olutunu k ti i de, b[[ ni ki yoo si de -- k til[ le s]kal[ -- sori aw]n Onigbagb] bi k e pe Jesu ba goke re }run. Maria, iya Jesu, j [ni ti a ti s] di mim], sib[sib[ o j[ kan ninu aw]n ti o duro, ti w]n si gba {m Mim] (Ie Aw]n Ap]steli 1:14). A k ninu Iwe Mim] pe is]dimim] a maa mu ki a w ni i]kan p[lu ara wa ati p[lu }l]run (Johannu 17:21, 23; Heberu 2:11). A si tun ri k pe aw]n ]g]fa (120) eniyan ti o gb ileri Baba w ni i]kan (Ie Aw]n Ap]steli 2:1). K si na miiran ti a tun le tum] [s[ Bibeli yii si ju pe gbogbo aw]n ]g]fa eniyan naa ni a ti s] di mim patapata. Adura ti Jesu gb fun is]dimim aw]n ]m]-[yin R ti gb aaju ]j] P[nt[k]sti. Gbogbo w]n w ni ]kn kan ni ]j] naa! Maria mim], iya Jesu, ti a ti s] di mim] w ni ]kn kan p[lu Ap]steli n ti a tun mu pada b] sipo l[yin ti o ti s Oluwa r ni ]j] di[ iwaju. Ap]steli oniyemeji n w ni i]kan p[lu aw]n Ap]steli ti w]n n af[ri ipo ]l ninu ij]ba Jesu. }kunrin ti o ti j[ agbowo-ode ri ti aw]n eniyan korira n, wa ni i]kan p[lu [ni ti a le pe ni ajihinrere kin-in-ni laaarin aw]n ]m]-[yin -- ]kunrin ti o ro ihin ay] dide Kristi fun [ni ti yoo di alabai[p] p[lu r[ ninu }gba Ajara Oluwa. Gbogbo w]n ni o w ni ]kn kan! Aw]n w]nyi ni {m Mim ba le! K si ohun kan ti o le fun ni ni iru i]kan b[[ bi k e i[ iw[num] pip. O oro fun aw]n ti a ti s] di mim] ati aw]n ti a k i ti s] di

Page 2 of 5

mim] lati w ni i]kan. Gbogbo w]n gb]d] ni iriri i[ oore-]f[ keji ni igbesi-ay w]n ki iru i]kan b[[ to le wa. K oro fun ni lati ri i nigba naa pe nigba ti a ba n s]r] nipa [kunrr[ aw]n iriri ibukun ti o daju w]nyi, a n s] nipa iis[ m[ta ti a k gb]d] e alai ni. Lna kin-in-ni, a ni lati dari [ wa ji wa ki a to le s] wa di [bi }l]run. L]na keji [w[, a ni lati s] wa di mim] nipa ibuw]n {j[ n l[[keji ki a ba le d aworan }l]run ti a ti s]nu pada sinu ]kn wa, eyiyii ni Iwe Mim pe ni ododo ati iwa mim]. Lopin gbogbo r, niw]n bi o ti e e e fun aw]n ti igba Maj[mu Laelae lati ri aw]n riri mejeeji w]nyi gba, ti o si daju pe aw]n ]g]fa eniyan ti o w ni Yara Oke tun ni iriri miiran ti o daju, eyi ti Jesu ti eleri, ti aw]n woli Maj[mu Laelae si s] as]t[l[ pe aw]n ti Maj[mu Titun ni ileri yii wa fun, a le ri i nigba naa pe iriri iis[ m[ta ti o daju w fun wa. Iriri nla ologo k[ta yii ni gbigb {mi Mim] Olutunu ti Jesu s] nipa r (Johannu 14:15-18, 26; 16:7-15). Eyi ni baptismu {mi Mim] ati in ti Johannu Baptisti s] nipa r (Matteu 3:11). Baptismu {m Mim] ati Ina Nigba ti Jesu fi aw]n ]m]-[yin R sil[, O s] fun w]n pe Olutunu yoo wa lati t w]n si na otit] gbogbo, yoo fun w]n ni agbara fun i[ isin, yoo b araye w niti [, ododo ati idaj] ti o n b] wa. Gbogbo nnkan w]nyi ti [, o si n [ l]w]l]w]. Adura Jesu fun is]dimim] aw]n ]m]-[yin R gb, a si ti mu iler R pe Oun yoo ran {m Mim] [. A k s] fun aw]n ]g]fa ]m]-[yin n bi {m Mim] yoo e fi ara R han. B[[ ni a k s] fun ni gan an bi Oun yoo e w, bi yoo e fi ara R han, tabi ohun gbogbo ti yoo fi w e, ti yoo e ninu wa, tabi ti yoo e nipas[ wa nigba ti a ba r wa b] inu R. ugb]n k si iyemeji l]kn aw]n ]g]fa n tabi l]kn aw]n ti o w ni tosi nigba ti {m Mim d. {m ki i saba fi ara R han ni na kan naa, ugb]n aw]n ohun kan w ti Oun ti n e nigba gbogbo, ti k yoo si e alai e nigba kan. O e pataki fun ni lati y[ }r] }l]run w lati m ki ni aw]n ohun pataki w]nyi j[. Lna kin-in-ni, {mi Olutunu a maa fun ni ni agbara fun i[-isin. Oun yoo si maa t wa. {m Mim] yoo t wa si na otit] gbogbo. Oun yoo rn wa leti ohun gbogbo. Nigba ti a ba fi {m Mim] w wa, yoo maa gbe inu wa, ugb]n t[l[ ri, O w p[lu wa ni. Oun yoo e wa ni [l[ri fun Kristi, yoo si ran wa jade lati tan ihinrere kal[. }p]l]p] ninu aw]n alaf[nuj[ Onigbagb lode oni ni o gb pe {m Mim n e gbogbo nnkan w]nyi. ugb]n eyi nikan k ni O n e; ki i si e [ri w]nyi nikan ni n fara han nigba ti O ba w] inu Onigbagb. Aw]n ami ati [ri miiran gbogbo fara han nigba itujade Ak]r] Ojo ni atetek]e. Aw]n alatako [k] }r] }l]run ti o yanju ketekete n jiyn pe bi kan ninu aw]n ami iaaju ba j ohun danindanin ti a gb]d] ni loni, a k gb]d] gboju fo aw]n iyoku d. Laisi ani-ani, ohun ti o ni lati [l[ ni ]j] nla naa, ti ilana ti atij] k]ja l], ti Maj[mu Titun si b[r[ p[lu gbogbo [kunrr[ iriri ni lati j ohun nla gidigidi. Bi a ba til[ wo bi ]j] naa ti e pataki to, o ya ni l[nu bi ohun ti o [l[ k fi p] ju b[[ l]. A mu Ileri naa [. Olutunu naa ti de. Okunkun ti o dudu ti rek]ja, a si ti b[r[ si fun ni ni [kunrr[ ibukn. Otit] ni, ]p]l]p] iipaya ati ami ni o fara han nigba n, iru eyi ti k si m] ni akoko yii. K le e alai ri b[[ bi a ba wo bi ]j] naa ti tobi t ati bi i[l[ naa ti j ohun ribiribi t. ugb]n [ j[ ki a y[ aw]n ami ati iipaya w]nyi wo. {fuufu lile si wa. Awa paapaa k ha ti ni iriri [fuufu lile bayii nigba ti {m }l]run ba s]kal[ saarin aw]n ]m] }l]run, bi w]n ti n ]na, lati kn inu [ni kan ati lati fun un ni agbara fun i[ isin ninu }gba Ajara }l]run? O e e e ki a m fi eti ode-ara gb iro naa ni akoko yii, ugb]n bakan naa ni i[ {m. Ohun gbogbo ti }l]run wi pe {m Mim yoo e fun [ni ti n wa iriri yii ni o n e nisisiyi g[g[ bi ti igba n. {la ah]n bi ti in si y] si w]n, o pin ara r o si b le olukuluku w]n ni akoko itujade Ak]r] Ojo ni atetek]e; eyi paapaa ti ri b[[, nipa ti [mi ni akoko Ar]kuro Ojo. In ti a le foju ri k y] m lati igb itujade iaaju, ugb]n i[ ti {mi Mim n e ati aw]n [ri ti o ti eleri j[ ]kan naa nisisiyi g[g[ bi ti igba n. }p]l]p] ariyanjiyan ati iyemeji ni o ti w ninu ]kn aw]n eniyan lori [ri kan ti o k ti a f[ m[nu kan yii. ugb]n eyi k y[ ki o ri b[[. K gb]d] si iyemeji rara. Bibeli s] fun ni pe gbogbo aw]n ]g]fa (120) w]nyi ni a fi {m Mim kn, ugb]n pup] ninu aw]n alaigbagb] ni k f[ fara m] iyoku [s[ r] }l]run naa. O s] bayii pe gbogbo w]n si br[ si ifi de miran s]r], g[g[ bi {m ti fun w]n li ohn.

Page 3 of 5

I ha e pe ami yii k si m]? Igb ib[r[ Ij] nikan ha ni ami yii wa fun? Ni toot], di[ ninu aw]n ami naa j ti ]j] P[ntek]sti ni ak]k]b[r[, a gbagb] b[[, o si han p[lu pe a k tun fi iru ami b[[ fun ni l[yin ]j] yii! Gbogbo w]n kn fun {m Mim; ileri naa wa fun wa bakan naa loni ati fun aw]n p[lu. P[lup[lu, gbogbo w]n ni o fi ede miiran s]r] g[g[ bi {m ti fun w]n ni ohn. {ri yii ki i e fun ]j] P[ntek]sti nikan, ugb]n o w fun awa naa loni. Eyi j[ ami ti Bibeli fi lel[ fun [ri gbigba agbara {m Mim] ati in. Eyi ni edidi {m Mim] ti o fi han pe i[ naa ti e. Gbogbo [ni ti o ba ri [bun agbara yii gba yoo ri i pe }l]run gb t ati ah]n w]n, w]n si b[r[ si yin }l]run p[lu de ti [ni ti n s] ] k m] t[l[ ri, ugb]n ede kan pato ni, ti o e e e ki [ni ti o w ni tosi gb, ani nigba pup] ni aw]n [ni ti o w ni tosi n gb de yii. Dajudaju eyi tay] sis] ]r] jagba-jagba, were-were ti k ni itum]. Ki i e ohun ti a k le akoso r ti yoo mu ki a maa gbn pp tabi ki a maa ta-lu-gi-ta-l]p[ ki a si maa fo anl[. Ki i e d ti [nik[ni k m] itum] r ni aye yii. Ede kan pato ti o le tete ye ni ni, ati eyi ti aw]n eniyan oril[-de ti o n s] de yii le m ki w]n si j[ri si bi w]n ba wa ni tosi. r] ti o ja gaara, ti o si kn fun ]gb]n ni; eyi ti o n ti inu }l]run wa, ti {m Mim] si n gbe jade lati t am yii. Ki i e ohun ti o n mu {m }l]run ti o w ninu aw]n [ni ti o w ni tosi binu, ugb]n Oun a maa gba [nu aw]n eniyan s]r] to b[[ ti gbogbo aw]n [ni ti o ba w nib[ le ri ibukun, imul]kanle ati is]ji {m gba. Ami ti Bibeli fi lel[ yii ha tun fara han nigba miiran bi? B[[ ni, nigba ti aw]n ara ile K]rneliu gba {m Mim] ni nnkan bi ]dun m[j] l[yin }j] P[ntek]sti, w]n fi oniruuru de s]r], w]n si n yin }l]run logo (Ie Aw]n Ap]steli 10:44-48; 15:7-9). L[yin ]dun m[talelogun ti a tu {m Mim] jade ni iaaju, Paulu l] si Efesu, nw]n si nf de miran (Ie Aw]n Ap]steli 19:1-7). Ni igba mejeeji w]nyi, k si ak]sil[ wi pe ir [fufu lile w tabi pe [la ah]n bi ti in b le w]n, ugb]n }l]run yi ah]n w]n pada lati s] de titun g[g[ bi [ri Bibeli fun i[ aepe ti fifi {m Mim] w ni. I[ {m yii k pin si ]j] kin-in-ni ti a k fi I fun ni, ugb]n o tun fara han ni igba mejeeji ti a ti m[nukan yii, lai s] ohunkohun nipa [gb[[gb[run igb miiran gbogbo ninu itan Ij] }l]run, nigba ti a tun ti tu {m Mim] jade. Ar]kuro Ojo Nigba ti Peteru e iwaasu iyanu r ni }j] P[ntek]sti, o fi as]t[l[ woli Jo[li gbe ]r] r l[s[ nipa ohun nla ti o [l[. Fi ara bal[ k ]r] iwaasu r, iw] yoo si rii pe apa kan ninu as]t[l[ Jo[li nikan ni o m[nu kan. Apa kan ninu ]r] ti Peteru fi pari iwaasu r ni pe fun nyin ni ileri na, ati fun aw]n ]m] nyin, ati fun gbogbo aw]n ti o jna rre, ani gbogbo aw]n ti Oluwa }l]run wa p. Nitori naa, as]t[l[ yii tabi fifi {m Mim w ni g[g[ bi ti ]j] P[ntek]sti ki i e fun akoko aw]n Ap]steli nikan. Ileri naa wa fun gbogbo aw]n ti Oluwa }l]run w p; o w fun gbogbo aw]n ti o jina rre. Ileri ti o w ninu as]t[l[ yii j[ ti wa p[lu. Nitori naa bi a ba n rin ninu [kunrr[ im]l[ Ihinrere ti a si n e af[ri aw]n iriri Onigbagb ni [kunrr[ -- awa p[lu yoo ri {m Mim gb. Awa naa p[lu yoo ha fi de titun s]r] nigba naa, g[g[ bi {m ti fun wa ni ohun? Dajudaju, lai si aniani! Agbara }l]run, Et R, }r] R, ati aw]n ileri R wa bakan naa lana, loni ati titi lae. Ifedef] g[g[ bi {m ti fun ni ni ohun j[ [ri ti Bibeli fi fun ni nipa aepari i[ yii. {ri yii e danindanin l]j] oni, g[g[ bi o ti e pataki n ]j] kin-in-ni n ti a t {m Mim] jade ati igb miiran gbogbo l[yin naa ti a k] ak]sil[ r fun wa. Niw]n bi apa kan ninu as]t[l[ Jo[li ti Peteru lo ninu iwaasu r ti j[ m] itujade {m Mim ni }j] P[ntek]sti nikan, o y[ ki a y[ gbogbo as]t[l[ naa wo lati ri aw]n nnkan w]nni ti o j[ m] wa. Jo[li s] as]t[l[ itujade orii meji: ekinni yoo dabi ak]r] ojo ti il[ Pal[stini, ekeji yoo dabi ar]kuro ojo aaju igba ikore. Ak]r] ojo ni a fi n gbin irugbin ni il[ Pal[stini, ar]kuro ni o si n mu eso gb fun ikore. Bakan naa ni itujade {m Mim] yoo ri. Ak]r] Ojo ni lati fi [s[ Ij] }l]run ti akoko Maj[mu Titun yii mul[ -- ni ib[r[ idagbasoke r. Ar]kuro Ojo wa fun aepe Ij] }l]run fun ikore. Fiyesi aw]n nnkan w]nni ti Jo[li m[nukan nipa aw]n itujade w]nyi. A k s] akoko ti Ak]r] Ojo yoo r] fun ni, ugb]n a s] akoko ti Ar]kuro Ojo yoo r] fun ni pato pe ou kin-in-ni ]dun aw]n Ju ni yoo j[. A s] fun ni pe akoko ti eyi ba [l[ ni yoo j[ opin aye! B]ya a le wi pe aw]n }m] Isra[li nikan ni as]t[l[ w]nyi w fun ati pe aw]n as]t[l[ nipa Ar]kuro Ojo t]ka si akoko ipadab] aw]n Ju, bi k e pe Ap]steli ni fi eyi kn un p[lu pe ileri yii w fun aw]n ti o jinn rre p[lu, ani aw]n ti Oluwa yoo pe. A k k aw]n Ju si oril[-de ti o jna rre. Aw]n Keferi ni
Page 4 of 5

]r] yii t]ka si, aw]n ni a si maa n s] pe o w lokere rre, lode, alejo, igi orro igb. Itum] meji ni ]r] as]t[l[ yii ni, otit] ni eyi. A k s] pe aw]n Keferi ti igb n nikan ni a t]ka si bi aw]n ti o jina rre, bakan naa ni [s[ }r] }l]run yii k t]ka si aw]n Onigbagb ti o jina rre ni akoko igba naa -aw]n ti o n wa agbara {m Mim] ni akoko Ar]kuro Ojo. Ileri yii wa fun orii aw]n eniyan (Onigbagb]) meji w]nyi. Ifedef g[g[ bi {m ti fun ni ni ohn j[ kan ninu aw]n ohun ti }l]run eleri pe Oun yoo e ni akoko itujade k]]kan. Enia gbogbo Ju ati Keferi yoo ri I gb; a si fi eyi kn un p[lu pe, Aw]n ]m] nyin ]kunrin ati aw]n ]m] nyin obinrin yio ma s]t[l[. Aw]n ohun ti o tun fi [s[ aw]n it]ka w]nyi mul[ g[g[ bi a[ ati iyanu to w ninu ifedef loni ni aw]n ohun iyanu miiran gbogbo ti }l]run tun eleri p[lu pe yoo [l[. A o maa fi [bun ala ati iran fun ni; niti pe gbogbo [ni ti o gba {m Mim le alai ni eyikeyi ninu aw]n [bun mejeeji w]nyi han gbangba, nitori pe aw]n kan yoo maa la ala, aw]n miiran yoo si maa riran. Ni ou k[rin, ]dun 1906, ti i e ou kin-in-ni ]dun aw]n Ju, ni Los Angeles ni Am[rika ati ni deedee akoko kan naa ni ibi pup] ni aye a tu {m Mim] jade sori aw]n w]nni ti a ti s] di mim] patapata ti o n duro de ileri Baba. As]t[l[ Jo[li [ titi kan ou naa gan an ti o s] fun ni, gbogbo aw]n ami kan naa ti {m Mim] fun ni, ti a k] sil[ pe o han nigba aye aw]n Ap]steli ni o tun han ni ipil[[ itujade Ar]kuro Ojo naa. Gbogbo aw]n ti a fi {m Mim] kn ni o ti ni is]dimim] t[l[. {m Mim] fi agbara fun w]n fun i[ isin nigba ti O b le w]n: gbogbo t ti o dak[ j[j[ t[l[ ri wa b[r[si j gidigidi fun Igbagb], aw]n ojo adak[j[j[ ti w]n ki i f]hun rara t[l[ ri wa di onigboya eniyan }l]run l]kunrin ati lobinrin. W]n fi de titun s]r] g[g[ bi {m ti fun w]n ni ohun; lai si iyat] si ti igba m[t[[ta ti a k] sinu Bibeli. L[[kan si i aw]n ]m]-[yin tun jade lati tan Ihinrere ka gbogbo agbaye p[lu agbara {m Mim], {m Olutunu n si n e am]na w]n. Ko si ohunkohun ninu ]kn [ni ti oungb[ ododo n gb[ ti o n f[ lati diw]n tabi s[ eyikeyi ninu i[ }l]run ninu ]kn aw]n eniyan. Gbogbo aw]n ti ebi npa ati ti ongb[ ngb[ sipa ododo a maa fi itara e af[ri lati gba gbogbo ibukun ti }l]run f[ fi fun w]n. Bi iyemeji ba w ninu [ni kan nitori pe w]n j[ ope tabi nitori ero ti o ti w l]kn w]n t[l[ ri, l[s[k[s[ ni {m Mim] yoo mu iyemeji b[[ kuro, nitori o ti eleri lati t wa si na Otit] gbogbo. O w ninu aye loni, Oun yoo si t gbogbo aw]n ti o ba f[ it]ni, O wa p[lu gbogbo aw]n ti ]kn w]n n fa si }run; nigba ti w]n ba si gba ibukun iriri ologo yii sinu ]kn w]n, Oun k yoo wa p[lu w]n nikan, ugb]n yoo t wn w ninu ir[p] ]tun. Lati igba naa l], ati niw]n igba ti w]n ba j[ olooot] si }l]run, Oun yoo maa gbe inu w]n. kan ninu aw]n ami pe O n gbe inu w]n ni pe nigba ti O w inu w]n O gba [nu w]n s]r] ni de ti w]n k m]. AW}N IBEERE 1 Ni akoko wo ni Kristi eleri Olutunu? T]ka si di[ ninu aw]n ileri w]nni bi iw] ba le e b[[. 2 Aw]n as]t[l[ Maj[mu Laelae wo ni o s] fun wa nipa itujade {m Mim]? 3 e alaye bi a ti fi aw]n iriri m[t[[ta w]nyi han ni ap[[r[ ti Maj[mu Laelae. 4 {s[ Bibeli wo ni o fun ni ni ikiya lati s] pe [nik[ni ti o ba n wa {m Mim] ni lati k ni is]dimim]? 5 S] aw]n ohun ti o d]gba ninu ak]sil[ iyasimim] T[mpili S]lom]ni ati itujade {m Mim] ni Yara Oke. 6 Ki ni {ri Bibeli nipa fifi agbara {m Mim] w ni? Nj[ iru [r yii tun fara han nigba w]nni ti a tun fi {m Mim] w ni ni gba aye aw]n Ap]steli? Ami yii ha fara han ni ak]b[r[ itujade ti Ar]kuro Ojo? Aw]n ti n gba {m Mim] loni ha n ri [ri kan naa? 7 Ka Heberu 13:8 Ki o si s] ohun ti [s[ yii ni i e p[lu [ri Bibeli nipa fifi {m Mim] w ni l]j] oni. 8 Anfaani wo ni irr ologo yii e ninu i[ iran[ aw]n Ap]steli? S] iyat] ti o w ninu igbesi-aye [ni k]]kan ninu aw]n Ap]steli ki w]n to gba {m Mim] ati l[yin ti w]n gb {m Mim]? 9 Ki ni itum] pe ki a e i[-iran[ [ni ni aepe? 10 K] Ie Aw]n Ap]steli 2:39 sori ki o si ka ileri ti a e nipa awa ti igba ik[yin yii.

Page 5 of 5

You might also like