You are on page 1of 3

Orin Orile Ede Naijiria ( National Anthem in Yoruba )

ORIN ORILE EDE NAIJIRIA


Dide eyin ara Wa
Je ipe Naijiria,
ka fife sin le wa,
pelokun atigbagbo,
kise awon akoni wa,
ko ma se ja sasan,
ka sin tokan~tara,
Ile e tominira,
alafia so dokan.

SONG

O God of creation(olorun eleda wa)


Olorun Eledaa;
To ipa ona wa;
Fona han asaaju,
Kodoo wa motito;
Kododo atife po si i,
Kaye won je pipe;
So won deni giga;
Kalaafia oun eto
Le joba nile wa
The pledge in yoruba:
Mo se ileri fun orile ede Nageria,
lati je olododo, ati eniti o se fokan-tan,
Lati sin pelu gbogbo agbara mi, ati lati gbe ga fun iyin ati ogo re.
Ki Olorun ki o ran-mi lowo (Amin)

Ise olorun ni.


...............................................................................................
...............................................................................................
Anthem in ENGLISH:
Arise ,o compatriots Nigeria's call obey
To serve our fatherland with love and strength and faith the labour of our heroes past shall
never be in vain.
To serve with heart and might one nation bound in freedom,peace and unity .
National pledge:
I pledge to Nigeria my country,
To be faithful, loyal and honest,
To serve Nigeria with all my strength,
To defend her unity,
And uphold her honor and glory,
So help me God.
........................................................................
Re: Orin Orile Ede Naijiria Ni Ede Yoruba Ati Ni Geesi by ninja4life(m): 2:43pm On Sep 25, 2013
Lol funny,nice one op d interpretation in yoruba sounds kinda funny to me tho
(0) (Reply)

ORIN ORILE EDE NAIJIRIA

(NATIONAL ANTHEM IN YORUBA)

ORIN ORILE EDE NAIJIRIA

NATIONAL ANTHEM

Dide eyin ara Wa

Arise O compatriot

Je ipe Naijiria,

Nigerias call obey

ka fife sin le wa,

To serve our fatherland

pelokun atigbagbo,

With love and strength and faith

kise awon akoni wa,

The labour of our Heroes past

ko ma se ja sasan,

Shall never be in vain

ka sin tokan~tara,

To serve with heart and might

Ile e tominira,

One nation bound in freedom

alafia so dokan

Peace and Unity

Ise amu rele : Se akosori orin orile ede Naijiria

You might also like