You are on page 1of 1

Oriki for protection from all negativity

Grind ewe ajeobale(a leaf) into powder, mix the grinded leaf with iyereosun , mark
the odu irosun meji on the powder on opon ifa, chant this oriki on it with prayers.
Blow off the powder with your mouth in the air outside your home in the morning

Oriki
A soso mo soku ni se eye won lode igbori .
Ala rere gosun ni se eye lode ofio.
Metibo leye aje nje.
Omo araiye dawojo won mu asoso mo soku eye ode igbori won paje.
Won dunyinka alarere gosun eye ode ofio won paje.
Woni awon o pa metibo eye aje je.
ONI bi won ba ba ohun ni,won iba pa ohun ni o un fi sa to o wa o orunmila.
Owo mi wa ba ewe olubi obale mi,eye buburu o ma ri mi ba le.
Irosun meji Loni ki ibi o sun seyin fun mi.
Irosun meji loni ki eleye o ma sun ire temi wa ba mi.
uwo a sa pe Ola, ogbo ato,ogbo edan,ogbo alaworo nife

You might also like