You are on page 1of 2

IWULO ATI AGBARA "EWE ETIPONLA" PART 1>

Etiponla je lara awon afaani kabiti kan ti Eledumare fi ta wa lore. O koja ki a fi


se ise Osole, Itaja, tabi awure. Ko da ti a ba mu enu ba ise re bayi enu a ya wa
wipe ��yen etiponla na��?
Ninu imo sise ogun fun iwosan, iwadi fi ye wa wipe Etiponla je ewe kan lara awon
gbogbonise ni eyi ti a le fi koju oniruru arun ati aisan.

Ki a ma ba opo lo ile oloro. Ko si eya kan lara Etiponla ti ko wulo lona kan tabi
ikeji.
Iwadi fi ye wa wipe meji ni Etiponla, Pupa ati funfun. Funfun yii gan ni ise re pe
ju pupa re lo. Nitori na ti a ba fe fi se iwosan, funfun re ni ki e je ki a wa. Amo
ko si eyi ti ko dara ninu re.

IWOSAN TI ETIPONLA GBO


Etiponla je a tun ara se ti si n fun ara lokun, idi niyen ti a fi npe ni marugbo ta
kebe.

EDO
Ewe yi dara pipo nipa kiko iwosan ti o peye ba edo wa. Ti aisan kan ba wo ara wa,
oun ti yio koko se ni wipe yio ko wahala ba edo ni eyi ti yio fa ki o ma reni lati
inu wa tabi ki ara ma se sii, Ti a ba se akiyesi yi igba yi gan ni o ye ki a gbe
Etiponla lura. Yio fun ara lookun pada yio si ba awon arun tin ba edo ja bi Iba
Jedojedo ti a npe ni Hepatitis ati bebelo.

ARUN ILE ITO


Etiponla je ewe ti o ma nje ki eyan to daadaa,latara eleyi yio ma je ki a to awon
arun ara jade ni eyi ti yio ma ko iwosan ba ile ito wa ti ko si ni gba jejere laye
tabi iseto tabi iru awn arun be ti o le ko iyonu ba ile ito wa.

ARA ASANJU
Lati ara wipe o nyo idoti ara wa jade lai ko ipalara ba ara wa. Yio ma di ora ara
ku ti ao fi ni sanra asanju, beeni o mu ni ya igbe woroworo ni iwonba.

ITO SUGA
Gbigbo Etiponla mu yio di ito suga ku, a si tun eya ara ti o baje ti aisan yi fi fe
ko iyara si wa lara se.

ARUN OJU
O gbo arun oju bi ki o ju ma su tabi oju wiwu, a o rora ra ewe na mo owo a ma kan
si oju na.

OLO INU
O dara pupo fun Olo inu nipa yiyo idoti ninu eya ara na ti yio si ko Alafia ba olo
inu wa.

AWOKA
Ti a ba mu ewe yi ki a gun tabi ki a ra mo owo ki a le mo apa ibi ti ara ba ti nro
wa tabi ti o wu kiakia ni yio ma ko iwosan ba ara na.

FUN NKAN OMO OKUNRIN


Ti a ba lo eso Etiponla kunna ki a ma fi mu ogi lowuro yio ma ko iwosan ba nkan omo
okunrin, boya o san ni o, ko le to nio ati gbogbo nkan ti o ba nyo wa lenu lapa
ibe. Koda o ma nmu ara le daadaa fun okunrin ati obirin.

FUN INU RIRUN


O dara fun inu rirun ati gbogbo iru arun be ti o ba nyo wa lenu ninu. A o lo egbo
re kunna daadaa ao ma fi mu ogi gbigbona lemeta lojumo o kere ju.
JEJERE
Etiponla je okan gbo o gi ninu egbogi ti o n wo arun jejere. Iwadi fi han wipe ti a
ba lo ewe, egbo ati eso re po ti a ba n mu yio gbo arun na be si ni ko ni je ki iru
re seyo lara wa.

AIRI ORUN SUN


Ti a ba se Ewe Etiponla fun mimu yio je ki a sun daadaa, O dara fun awon ti o ba ni
aisan airi orun sun pipo.

IKO ASTHMA
A o lo egbo re kunna daadaa mo ebu ata ile pupa, ki a ma fi lo omi to lo wooro
lemeta lojumo.
TO BE CONTINUED.....

THANKS FOR CHOOSING ILE IWOSAN.

Hazzan Eyiowuawi 07088808731


Olabisi Lolawa 08060217168

You might also like