You are on page 1of 1

BI ASE LE LO OYIN IGANOyin Igan je okan lara ohun ti Olorun da fun lilo wa sugbon

opo wa ko mo bi ase le lo Idi niyi ti ile ise toun lo ewe ati egbo fi so die lara ona ti a le
gba lo Oyin Igan.1 OGUN OJU ; Ti Oju re ban se pin, tabi ti o nyun o, ti o pon . Po Oyin
ati alubosa funfun pomon ara won. Maa kan si oju mejeji.2. INU RIRUN; Lo Ewuro po
mo Oyin ma lo sibi meji lehin onje ale.3. EGBO; Ewuro po mon Oyin ma fi si oju egbo
na.4. EYIN OMODE; Oyin Igan ati Omi Osan wewe mon ara won. Ki o si fun Omo na ni
sibi kan lemeji lojumo lehin onje.5. IKO IFE (TUBERCULUS); Lo Atare, Ayu, Iyo ati
Orogbo pelu O yin Igan sinu Igo. Agba sibi meji ni igba meta lojumo6. AIRI ORUN SUN;
Maa mu Oyin Igan sun. Sibi meji lalale.7. AILERA NINU OSU OBINRIN; Nkan osu to
nse segesege tabi to dudu (STOMACHPAIN) Lo sibi Oyin Merinmerin ni Emerin
lojumo.8 ARONMOLEGUN; Lo Ewuro po mo oyin Igan fi pa ibi ti on ro E. Ki o lo sibi meji
li ojojumo ni owuro kutukutu.9AKANDUN TABI EEWO(BOIL). Lo Ewa ati Kaun po mo
Oyin Igan. Ma fira ibe.10. OGBE INU(ULCER); Maa mu sibi Oyin meta ni owuro
kutukutu ni wakati kan ki o to jeun aaro.11. FUN ATO KIKI(SEMEN BOOST); Po eyin
tutu po mo Oyin sibi Maarun Lo gbogbo re leekan naa.12. IKO EGBE; Po Omi Igbin ati
Oyin po mo ara won .Sibi nla meta leemeta lojojumo. Omode sibi kan laaro ati lale.13.
JEDIJEDI; Lo efirin, Omi Osanwewe po mo Oyin Igan . sibi meta laro ati lale.
Lojojumon.14. ARUN ETI; Ti eti ban se oyun tabi ti o nrin eniyan, fi omi gbigbona po iyo
die ati oyin mo ara won ma kan si eti mejeji laro ati lale.15. KOKORO ENU; Po Oyin Igan
po mo Osan wewe fifo enu ni igba meta lojojumo.16. ILE GBIGBONA; Lo ewuro po mo
Oyin Igan fi pa gbogbo ara sibi mejimeji, lemeta lojumo.17. INU DIDUN LEHIN TO
BINRIN BA BIMO; Obinrin naa yio malo oyin sibi mejimeji lemeta lojumo.18. OMO TI O
NTO SILE; Ki o maa mu sibi Oyin Igan mejimeji sun titi tiko fi ni to sile mo.19. IKO; Lo
orogbo ki o daa sinu Oyin Igan lehin nab ere si laa tabi ki o maa loo sibi kan kan ni
wakati metameta. Omode sibi kekere.20. Maafi Oyin Igan mu Ogi tabi Tea. O
dara.21.OGUN OJUPIPON; Ma kan oyin si lemeta loojumo.22. ARUNSU; Lo ewe ejirin
po mo oyin igan sibi merin lemeta lojumo.23 .ATOGBE; Omi ewe ewuro po mo Oyin
Igan sibi merin lemeta lojumo.24. ROPAROSE; Fi ito re lo Oyin Igan lale.25. EJE
RIRUN; Lo ayu po mo Oyin Igan sibi meta lojumo laro ati lale.26. OKO LILE; Ma fi ogede
dudu sise kan oyin je.27. OGUN EJE; Lo omunu ewuro po mo Oyin Igan sibi meta
loojo,.28. INU RIRUN; Po iyo mo Oyin Igan sibi meta lojumo.29. FUN ARA DIDAN; Po
Oyin Igan mo adiagbon ma fi pa ara.30. FUN IFA RUN AGBON.;Po etu mo oyin igan ma
fi pa.31.FUN KOKORO; Lo eru awon ka imi ojo etu po mo oyin igan mafi pa ara.32. FUN
ARAN; Omi osan wewe po mo oyin igan sibi meta meta lojumo.33.KI INU OBIRIN
GBONA. Lo ayu po mo oyin igan sibi merin lemeta lojumo.34FUN IBA
REFUNREFUN;Lo ayu po mo omi osan wewe eyin ati oyin igan sibi merin ni igba meta
lojumo.35. BI INA BA JO ENIYAN; Ma fi oyin pa ni gbogbo igba.36 BI OMI GBIGBONA
BA DAJO ENIYAN. Ma fi oyin igan pa.37. ALEFO LARA OMODE; Lo eru awon ka etui
mi ojo po mo Oyin Igan ma fi pa ni gbogbo igba (mase te fo rara).38. OGUN EJE; Omi
csan wewe eyin tutu mo oyin igan sibi merin ni igba meta lojumo.39. BI ARA BAUN
GBONA:- Omi ewuro ti agbo la ifi omi si ale fi iyo gbo a po mon Oyin Igan sibi meji lee
meta loju mo fi pa gbogbo ara.40. BI INU BA DUN OBIRIN; Lo ayu po mo Oyin Igan sibi
meta lee meta lojumo .41.OGUN ARUNSU; Fi iyo gbo efirin po mo oyin igan sibi meta
lee meta lojumo.42.NKAN OSU OBIRIN TO UN SE SEGESEGE; Lo ayu po mo omi
osan wewe ati oyin igan .sibi meta lee meta lojumo.43. OGUN ATOSI. Omi jaganyin
;kun die, ayu po mo Oyin Igan .sibi merin lee meta lojumo.44.KI ENI TO BA NI ATOGBE
;Ma fi Oyin Igan mu Ogi ati Tea. ma din sugar ku lara.45.Ki eni to ba tile ni OGOJI
ODUN Ma fi OYIN IGAN mu Ogi tabi Tea.46. OGUN DIDIN ISANRA KU; Ki o fi omi se
Haha agbado ki o ma fi Oyin Igan mu bi Tea laro ati lale.47. KI AGBALAGBA Ma lo Oyin
Igan lati mu Tea tabi Ogi O ma un je ki Opolo ji pepe.

You might also like