You are on page 1of 20

OTITO ORO TO KORO

FUN ONIGBAGBO” (A
bitter truth for a
believer)

TI OMO IYA MEJI TABI ORE BA


JADE NINU ILE TI IKAN NINU
WON FA’JURO A JE WIPE IKAN
NINU AWON MEJEEJI TI BA’RA
WON SO OKODORO ORO
NIYEN, HALLELUYAH.. NKAN
TO KORO A MAA SE ARA
L’ANFAANI SUGBON OUN TO
BA DUN JU A MAA SE’KU PA NI
MO GBA LADURA PE OUN TI
YOO WUN O KO NI PA O, OUN
TI YOO PA O KO NI WUN E
LORUKO JESU.
KINI OUN TI MO TI E FE SO
LALE ONI GAN..? KOSI NKAN
MIRAN JU PE TORI O JE
ONIGBAGBO..
IWO TI O SE GBA JESU KRISTI
GEGE BI OLUWA ATI
OLUGBALA RE TI WON BA NSO
FUN E PE OKU ORIIRE SINU
OWO OLA HMMN… KI NSE
SINU ORO T’AYE YI O BI KO SE
PE O KU ORIIRE SINU IBUKUN
AYERAYE FUN TI IJOBA ORUN,
OTITO ORO NI MO SO FUN E
YI.

TORI PE O JE ONIGBAGBO
IYEN O SO PE KI NKAN O MAA
LO GEERE GE NIRORUN PELU
ADUN FUN O. ALADURA NI O
LOOTO MO FE KI O RANTI
ISELE TO SELE SI JOBU. JOBU
CHAPTER 1&2

TORI PE O JE ONIGBAGBO WA
SO EMI RE NU NINU KRISTI WA
GBE AGBELEBU RE KI O LE
TELE OLUWA RE WA SI FAYA
RAN ORISI IDANWO DANDAN
LEYI, MAAKU 8:34-38. ORO SI
NBO LORI AGBELEBU (cross)

TORI PE O JE ONIGBAGBO
IYEN O SO PE KI O MA LA
ISORO KOJA, JESU OLUWA WA
LA ISORO KOJA MELO MELO
WA LEMI ATI RE TA O NI LA
NKAN KAN KOJA..? JESU WIPE
NILE AYE E O RI IPONJU
SUGBON E TUJU KA EMI
(JESU) TI SEGUN AYE,
JOHANNU 16:33, ORIN IJO
MIMO C.C.C HYMN 701 WI
BAYI PE
EMI NI OLUWA MA SE BERU
AYE,
EMI NI IRUGBIN MA SE BERU
AYE,
MA SE BERU, OMO OLORUN
MA SE BERU AYE, MA SE
BERU, IJO MIMO MA SE BERU
AYE….. TORI PE O JE
ONIGBAGBO OO NILO LATI
BERU RARA.

GBO MI, TORI PE O JE


ONIGBAGBO IYEN O SO PE KI
O JERE GBOGBO AYE YI O, TI
O BA LE GBIYANJU LATI JERE
OKAN IYEN POJU OWO ATI
ORO REPETE TI NDA NI LAAMU
LO.. MO GBO PROGRAM
PASTOR ADEBOYE NI NKAN BI
ODUN MARUN SEYIN, BABA
SO PE AWON NBA OLORUN
SORO LOWO NINU ADURA,
OLORUN NA NBA AWON SORO
LOWO LOJIJI NI OLORUN SO
FUN AWON PE
OLORUN: “OMO MO NBO WA
MO WA PELU RE
PASTOR ADEBOYE: DADDY NI
BO LE NLO..?
OLORUN: MO FE SARE DA
OMO MI KAN LOUN NI..
PASTOR ADEBOYE: AH AH
DADDY BAWO..? HOW COME..?
BAWO LENI YEN SE JE..?
OLORUN: IRANSE TO
NGBADURA SI MI LOWO LOWO
YI, KOSI ENI KAN LAYE TO MO,
KI NSE ENI TO LORUKO RARA
TORI PE O JE TALAKA,
SUGBON EMI MO AWON OGUN
ORUN SI MO ENI YI DAADA”.
Ah. IGBA TI EMI FEMI SAMUEL
NGBO PROGRAM YI LOWO I
WAS SHOCK, MO WA
CONFUSE, KO YE MI, KI NMA
PARO MO SO PE IRO NI
PASTOR ADEBOYE NPA, TORI
MO WOYE PE SE O POSSIBLE
KI EYAN MAA BA OLORUN
SORO BAYI..? MO TUN WA
NWO PE SE OLORUN LE SO
FUN YAN PE OUN NBO OUN FE
LO DA’YAN LOUN NA LAI TI
KURO LODO PASTOR
ADEBOYE..? MO WA NWO PE
TI OLORUN BALE NI OUN FE
LO DA ENI YI LOUN O TUNMO
SI PE ENI YI JE ENIYAN KAN TO
WUWO (heavy with a great
value) TO SI JE ENIYAN ARA
OTO LODO RE, TI O BA JE BEE
LOOTO A JE PE AWON OGUN
ORUN NA NI LATI MO
OKUNRIN YI NA NIYEN.. SE O
LE JE OOTO PE AWON OGUN
ORUN ATI CHORISTER LORUN
MO OGBENI YI LOOTO..? (emi
ni mo tun nro nkan yi lokan mi)
AWON IBEERE WONYI NI MO
NBEERE LOKAN MI TORI MO
WO PE BAWO NI OLORUN SE
MA SO FUN ‘YAN PE OUN BO
SEBI ABETI LU KARA BI AJERE
NI OLORUN WA..? LOJIJI NI MO
GBO OHUN YEN NINU OKAN
MI, ONA MEJO L’ANGBA
GBOHUN OLUWA, LARA RE NI
OHUN KELEKELE NINU OKAN
WA AWON TI WON NIRU EBUN
YI YOO MO OUN TI MO NSO YI
(the small still voice, those who
have that gift of hearing will
understand what I’m saying)
OHUN NA WI BAYI PE “EMI NI”
AH IGBA TI MO GBO OHUN
YEN TO SO PE “EMI NI” ARA MI
BALE BI IGBA TI ENIYAN BA SE
MU OMI TUTU, AH INU MI
DUN, SUGBON MO TUN NWO
PE OLORUN LO MA NJE EMI
NI? (iyen ninu okan mi again)
LOGAN NI MO RANTI OUN
META TI OLORUN YI JE, “O WA
NIBI GBOGBO LEEKAN NA”
(omnipresence), “O MO OUN
GBOGBO TAN” (omniscience,
“O SI TUN NI GBOGBO
AGBARA NI IKAWO EYI TO
KOJA IMO OYE ENIYAN”
(Omnipotence), IGBA TI MO
NRO NKAN META YI LOWO NI
ERO MIRAN TUN SARE WA SI
MI LOKAN, LOGAN NI MO
RANTI AWON OKUNRIN MEJE
KAN TI WON JE OMO BABA
KAN TI WON FE L’EMI ESU
JADE KURO LARA OKUNRIN
KAN SUGBON OKUNRIN ELEMI
ESU YI BORI WON O SI FA
WON LASO YA O SI SE WON
LESE NITORI PE KO DA WON
MO. KINI OUN TI MO FE FAYO
NIBI BAYI..? E BAMI WONU IWE
ISE AWON APOSTELI 19:13-16,
E WA BAMI WO VERSE 15 YEN
“EMI BUBURU NA SI DAHUN, O
NI, JESU EMI MO, (PAULU EMI
SI MO); SUGBON TA NI EYIN?”
IGBA TI MO RANTI NKAN TI
BIBELI SO NIPA NKAN TI EMI
ESU TI NBE NINU ARAKUNRIN
NA WI NI MO TO WA MO PE
DAJU DAJU TI EMI ESU YI BA
LE MO POOLU APOSTELI A JE
PE IJOBA OKUNKUN DA ST
PAUL MO NIYEN, TI IJOBA
OKUNKUN BALE DA SAINT
PAULU MO DAJU DAJU
(automatically) AWON OGUN
ORUN NA NI LATI DA POOLU
APOSTELI MO NIYEN.. IGBA TI
MO RO NKAN YI TAN NINU
OKAN MI, MO PARIWO SITA
MO SE AH, TORI OKAN MI TI
LO MO TI WA NI IPELE (realm)
MIRAN TI KI NSE TI ARA MO
LASIKO IGBA NA, IGBA TI MO
SE AH YI LAWON TO WA
LAYIKA MI NWO PE KI LO NSE
OGBENI YI, NOW, MO FE BI
IWO TO NKA ORO YI NI IBEERE
TI YOO RU E SOKE, MO FE PE
O NIJA (challenge) PELU
IBEERE YI, NJE OLORUN DA O
MO? NJE AWON OGUN ORUN,
AWON ANGELI TI NGBE INU
IMOLE SOLA DA O MO PELU..?
NJE O LE KUNLE LORI ESE RE
BI WOLI DANIELI KI O
GBADURA KI OLORUN SI FUN
O NI AKIYESI (attention) PE EMI
NI YI OMO MI? KI NMA FA ORO
GUN OUN TI MO NGBIYANJU A
TI SO NI PE TI AYE KO BA MO
E, JE KI AWON ORUN DA E MO,
ORIN C.C.C HYMN 190 KO PE

Baiye ko mo mi
Sugbon awon temi momi
E ke mimo s'oba
Imole wole
AWON WO NI TIRE..? AWON
SINU IMOLE NI TIRE, ENI TI
NGBE INU IMOLE SOLA, AWON
OGUN ORUN LA NSORO NIPA
RE BIBELI WIPE “IBA SE PE
EYIN NSE TI AYE, AYE IBA FE
AWON TIRE; SUGBON NITORI
TI EYIN KI I SE TI AYE, SUGBON
EMI TI YAN YIN KURO NINU
AYE, NITORI EYI NI AYE SE
KORIRA YIN” HALLELUYAH,

IGBA TI ANGELI GABRELI BE


DANIELI WO NI ELEEKEJI
DANIELI 9:23 E WO BIBO SE BA
DANIELI SORO NIBE YEN. IGBA
TI ANGELI KAN TA O MO
ORUKO RE FE BE OLORO KAN
WO NINU IWE ISE AWON
APOSTELI 10, SE EYIN O RI BI
O SE BA OLORO TI NFOWO
SAANU NA SORO NI..? IGBA TI
GABRIELI BE SAKARIAH WO
NIBI PEPE SE EYIN O RI NKAN
TO SE FUN OGBENI SEKARIAH
NI..? GABRIELI PA SAKARIAH
LENU MO O MU YA ODI NITORI
O MO PE ASE NBE LENU
SAKARIAH, IGBA TO MO PE
ASE NBE LENU RE IYEN
TUNMO SI PE O DA SEKARIAH
MO DAADAA, TORI O MO PE TI
SAKARIAH BA LE SORO LORI
ORO PE “EMI ATI AYA MI MA TI
DOGBO TAN?” O SEESE KI
ILERI NA MA LE WA SI IMUSE,
NITORI IDI EYI GABRIELI MU
BABÀ YI YA ODI, LUKU 1:18 -19
HALLELUYAH, PABANBARI RE
IGBA TI GABRIELI BE IYA
OLUGBALA, MARIA WO E WO
BO SE BA MARIA SORO NINU
IWE LUKU 1:28 YEN..

IWO TI O NKA ORO YI MO FE BI


E LEERE NKAN KAN NJE AWON
ORUN DA E MO TORI PE O JE
ONIGBAGBO? BI RA RE LEERE
NINU OKAN RE

ONIGBAGBO MEJI NI NBE LAYE


ODE ONI, (genuine Christians
and microwave Christians)
EWO LEMI ATI RE NSE? ORO
NBO LORI RE TI JESU BA FA
BIBO RE SEYIN.

TORI PE O JE ONIGBAGBO
AIYE YOO KORIRA RE TORI EYI
NI WA SE JAGUN NILE AYE YI,
KI NSE IKORIRA PE NIPA TI ARA
O. BAKAN MEJI LORO ILE AYE
YI, TI IWO O BA LE SEGUN
WON WA DARA PO MO WON TI
IWO O BA WA FE DARAPO MO
WON A FI KO JAGUN IGBAGBO
, ERE NLA SI NBE FUN ENI
TO BA JAGUN IGBAGBO
IFIHAN 2:26-28, IFIHAN 3:5,
20:6, ORO SI NBO LORI ILERI
NLA MEJE TI OLORUN SE FUN
AWON TO BA JAGUN SEGUN
TI WON SI BORI AYE..
HALLELUYAH..
TORI PE O JE ONIGBAGBO AYE
A TUN KORIRA RE TORI AYE KO
OTITO ORO, OTITO SI RE O
KORO BI AGBO TI YOO SE ARA
LANFAANI, JESU WIPE TI EYIN
BA MO OTITO, OTITO YOO SO
YIN DI OMINIRA, OPO AWA
ONIGBAGBO LA NFI RA WA
SABE IDE INIRA TORI OPO WA
LA MO OTITO SUGBON A O FE
TELE TORI PE O JE OUN TO
KORO TI KO SE E GBEMI (bitter
pills to swallow).

TORI PE O JE ONIGBAGBO
IYEN O SO PE “THE LORD IS
GOOD ALL THE TIME” MA JE
NATIONAL ANTHEM RE, TORI
IDI EYI NI WA SE NIFARA DA,
(lara eso Emi leleyi je) TI
ENIYAN BA NWO BI ILU
NAIJIRIA SE RI YI ENIYAN O
WONU AYE EYAN O SI BAWON
PELU OBO JAWURA.. MO FE
KO RANTI AWON ISELE TO
SELE SI JOSEFU NIGBATI
AWON EGBON RE TA TO FI DI
ELEWON NILE EGYPTIAN K’O
TO WA DI PE O DENI OBA NILE
AJEJI NA.

TORI PE O JE ONIGBAGBO
IYEN O SO PE KI ENIYAN NI
OWO LOWO BI DANGOTE O,
ASIRI BIBO LOJU, AANU NI KI O
TORO FUN, ORIN IJO C.C.C
HYMN 813 WIPE,
AANU RE BABA LA N TORO,
OLUBUKUN AYERAYE,
IRE LOBUKUN FUN EYE IWO
JOWO WA BUKUN WA”,
HALLELUYAH BIBELI WI NINU
IWE OWE 10:22 PE: “IBUKUN
OLUWA NI NMU NII LA LAI FI
LAALA KUN” TI IBUKUN
OLUWA BA TI DARÀ PO MO
AYE RE KI LO TUN KU..? TORI
PE O WA JE ONIGBAGBO O TI
RO PE BY FIRE BY THUNDER O
GBODO NI OWO TABUA
BAYEN..? HMMMN..
SOLOMONI SO NINU IWE OWE
30:7-9 PE OUN KO FE OWO
TABI OSI NITORI TI OWO BA PO
LAPO JU O LE MU IFE OLUWA
DINKU LOKAN ENIYAN, BEE NI
EMI KO FE OSI TORI TI OSI BA
PO LAPOJU A MU NI SIWA
WU.. TORI PE O JE
ONIGBAGBO SE OJUSE RE
GEGEBI ONIGBAGBO NILE
OLORUN KO LE FUN E NI
BUKUN RE.

TORI PE O JE ONIGBAGBO
IYEN O SO PE SATANI ATI
AWON OMO OGUN RE O NI
GBOGUN TI E O, OPO AWA
KRISTENI LA MA NRO EYI
LOKAN, IYEN O NI KO WA MAA
SO PE “IJA DOPIN OGUN TI
TAN OLUGBALA JAGUN MOLU
ORIN AYO LA O MAA KO (beeni
Orin isegun wa leyi) SUGBON
IJA DOPIN OGUN TI TAN YEN,
LO TU DANU TI O BA TI GBA
JESU SINU AYE RE O TI
FAJOGBON LESE O, TORI O TI
BO SINU IMOLE, BIBELI WIPE:
“FUN AWON KAN, AWA JE
OORUN IKU SI IKU, ATI FUN
AWON MIRAN OORUN IYE…..”
SATANI KO NI GBA FUN IWO
TO JE ONIGBAGBO LATI JE
OORUN IKU FUN OUN ATI
AWON OMO LEHIN OUN, KONI
GBA KI O JE OORUN IYE FUN
AWON TO TI PA SINU OORUN,
NITORI EYI NI YOO SE
GBOGUN TI IWO TO JE OMO
IMOLE, PAAPA LATI JE
MUNDUN MUNDUN AYE YI
KONI GBA RARA TORI OUN
LONI AYE YI SATANI LO SI NSE
IJOBA TI AYE YI, 1 JOHANNU
5:19, SUGBON TI O BA TI LE
FORIBALE FUN SATANI YOO FI
OUN TI AYE YI FUN O, MO FE
KA WO IGBA TO NDAN JESU
WO TONI PE KI JESU OLUWA
W KAN FORI BALE FUN OUN
PE OUN O SI FUN NI GBOGBO
AYE YI, IYEN TUNMO SI PE
SATANI YI LO NI GBOGBO AYE
YI NIKAWO RE LOOTO,
SUGBON TI O BA SI DURO
LORI ESE RE GEGEBI
ONIGBAGBO TI O KO LATI FORI
BALE BI JESU, SATANI YOO
DOJU KO E PAAPA LATI LE
JOGUN IYE AINIPEKUN TORI O
TI DE’BI AYO NLA NILE OLOGO
NIGBA KAN RI KI O TO SUBU
PELU AWON TOUN NA TAN JE.

TORI PE O JE ONIGBAGBO NJE


IWO O KI NFARA RE PAMO PE
O FE KI WON ENIYAN MAA PE
O NI KRISTENI? IWE MATIU
10:32-33 WIPE “NITORI NA
ENIKENI TI O BA JEWO MI
NIWAJU ENIYAN, OUN NI EMI
O JEWO PELU NIWAJU BABA
MI TI NBE NI ORUN.” VERSE 33
WI BAYI PE “SUGBON BI
ENIKAN BA SI SE MI NIWAJU
ENIYAN, OUN N NI EMI O SE
PELU NIWAJU BABA MI TI NBE
NI ORUN” TORI PE O JE
ONIGBAGBO NJE A TI E DA O
MO NINU IDILE RE, LAARIN
AWON ORE RE, OFFICE RE
TABI NIBI ISE RE? TORI PE O JE
ONIGBAGBO NJE A TI E MA NFI
ORUKO BABA JESU ABI IYA
JESU PE O..? ABI IWO O TI E
GBA WERE MO ESIN NI TIRE
RARA..? WON TI MO E NI BABA
TABI IYA IJOGBON, NJE A TI E
MA NPE O NI PASTOR LAARIN
AWON ORE RE..? TORI PE KI
AWON ENIYAN MA BA FI O SE
EFE O NBO AMI IDANIMO
(sign) KRISTI LARA RE,
HMMMN.. TETE LO RONU RE
KI O PA IWA RE DA NI KIA KIA
LORUKO JESU A O NI DI ENI
ITANU LOJO NA.

TORI PE O JE ONIGBAGBO NJE


O LE FUNRA RE SE BI POOLU
APOSTELI TO NWO BOYA KI
OUN KU ABI KI OUN MA I TI
KU..? O DE IPELE KAN POOLU
WO PE SE KI OUN KU KI OUN
LE LO SINMI ABI KI OUN MA I
TI KU KI OUN SI LE WA PELU
AWON ARA (brethren) RE, AH..!
IRU OORE OFE WO RE..?
POOLU APOSTELI NI
IDANILOJU PE TI OUN BA KU
OOKAN AYA KRISTI NI OUN LO,
NJE EMI ATI RE NI IDANILOJU
ELEYI..? BAMI WO INU IWE
FILIPI 1:19-26, JOWO RI PE O
KA AWON ESE BIBELI YEN KI
EYI LE YE O SIR/MA.

ONIGBAGBO NI O, O.K ADUPE


FUN OLORUN, SUGBON TI O
BA KU BI O SE WA YI NJE IWA
NA TI IKU KA MO E LOWO LE
MU O DEBI TO LERE GEGE BI
ONIGBAGBO?

TORI PE O JE ONIGBAGBO
DANDAN NI KI O NI IDANILOJU
PE IBI BAYI LO NLO SUGBON
OPO ONIGBAGBO MELO LO LE
FOWO SOYA PELU IDANILOJU
PE IBI BAYI L’OUN LO TI OUN
BA KU..? ONIGBAGBO MELO NI
YOO GBO IKU TI KO SI NI
BERU? O LE DABI AWADA EYI
KI NSE AWADA RARA O.

TORI PE O JE ONIGBAGBO TI
IKU BA DE BAYI NJE O TI SE
TAN? OPO WA LA O FE KU
SUGBON A FE DE IJOBA
ORUN, HMMMN, OPO WA LO
YE KI A GBO IKU KI INU WA
MAA DUN TORI PE EYAN FE LO
SINMI NI.. FILIPI 1:23
HMMMN… OORE OFE SHA LA
N PARIWO OPO ENIYAN NI
WON O SI MO PE ORE OFE YI A
MAA N L’OPIN (EXPIR) NILE
AYE TA WA NINU RE YI..

EYI NI ITUNMO OORE OFE,


(grace) GEGEBI OYE TEMI.

G- GENERATION (IRAN WA YI)


R- RACE: (GBOGBO EYA ATI
DUDU ATI FUNFUN)
A- ACE (not yet discover )
C- CENTURY (your maximum
year to enjoy yourself with
good health in this nowadays
generation) Palm 90:10, ojo ori
emi ATI re ko lo titi
E- EXTERNAL (as a Christian
we’re an external fellow in this
world which means we’re not
been given the total grace to
be forever on this sinful
earth,..) so always be vigilant
and watchful because you’re
not of this world and for the
grace not to elapse and caught
you unaware..

DON’T YOU EVER DARE


FORGET THAT JESUS CHRIST
IS MY GOSPEL THE SAME
YESTERDAY, TODAY AND
FOREVER MORE, HALLELUYAH
..
LATI OWO FEMI SAMUEL
OLUDASILE ASIRI ATI IWULO
BIBELI PELU AGBARA IMISI
AWON WOLI (facebook group)
09017824278

You might also like