You are on page 1of 45

[12/16, 10:40 AM] Mentor: *ASIRI OJO IBI IRAWO*

Mimo ni fun olohun toni ikapa aiye ati orun mimo ni fun olohun toni ikapa ohun toko sinun aiye. Mimo
ni fun olohun toni imo yipo modupe fun olohun ti se iyanun nipa Asiri towa ninu Irawo Eda irawo Da
gegebi titan Atupa Si Isoro Ati Ona Abayo re ni, Eda kookan Loni Odu toba waye besini Eda kookan Loni
Ipin Irawo kookan tio Je Oludari Funwon.

Pataki Ni Iwadi Irawo ati Akosejaye Je Nitoripe ti Eda koba mo nipa nkan Mejeeji Yii, Oseese Ki Eda Ma
wa ninu Idaamu besini Laimo Ibiti Idaamu na tiwa,

Opolopo Eda Ni Iseda re kogbodo wo Aso dudu ati pupa. Koda kogbodo wo aso ti won baya Aworan si
sugbon nigbati kose Awari ara re, nkan ewo re ni lo bi aso dudu na Loyan Laayo

Awon Itosona kan wa ninu Irawo Eniyan toyeki Eda kookan mo sugbon Laise wipe Eda sewadi irawo re,
Eda kolemo nkan yen rara nitoripe ohun topamo ni..

Imo irawo ati Akosejaye tiwa Tipetipe besini Lati aye awon Anabi olohun ni Imo na tiwa nitoripe Olohun
Lofun Awon Anabi na Lagbara ati Imo yen Gegebi Anabi Idhirusu ati Yunusa......

Eniyan Yoo ma mo nipa Irawo re Latara Sise iwadi Pelu Oruko, date tabi Atelewo Omo Eniyan.

Mimo nipa Irawo ati Akosejaye kii Jeki Eda daamu rara nitoripe O ti ma mo bio se ma Se, Gegebi Saara
todara fun, Ise Asela, Oko tabi Aya Todara fun Enikookan ati bebelo..

Eni awifun oba jio gbo

[12/16, 10:40 AM] Mentor: *IWULO AWON IRAWO KOOKAN*


Awon iwulo(quality) meta kan wa tojewipe awon NI won N Dari awon irawo Mejila ti a ni,tosije wipe
awon quality meteeta yi , awon na se Afikun iwa fun awon irawo to sope won nbe , awon ami idayato
nani ;-

* Cardinal

* Fixed

* Mutable

Cardinal Yi Ko Awon Irawo Mefa kan sabe ti a mo si :-

Aries (Ina) Cancer (Omi), Libra (Afefe) ati Capricorn (irawo yerupe) pelu irawo jemini tise {irawo Afẹ́fẹ́}Ati
irawo virgo {irawo iyepe}

Awon irawo ti a mo wipe won lo *cardinal* yi , Won ni awon iwa ti kolo gere tabi tiwa won koduro soju
kan rara , iwa won maa N yi kakiri NI besini orisirisi Iwa lowa lowo won Idi niyi tiwon Fi je *Cardinal*
(Nkan ti koduro soju kan) , Awon irawo yi feran Latije ki nkan tesiwaju , Won feran idagbasoke, Won ma
N jaramo Ise , sugbon won koni Emi Ipari Ise rara , won ma saaba kuro nibi Ise kan Si Omiran , won je
eniti O ni Okun ati Agabara pupo , won feran kiwon ma yin won , Won feran jije olori nibikibi tiwon Ba
wa , Alebu won ni wipe won ma m bere nkan NI sugbon won Nikita latipari re , idi niyi tofije wipe awon
omo ti O Ba wa labe irawo maa N feran ara won pupo besini Ife won ma N jinle daada ,

Amoran MI SI awon tiwon wa labe irawo tasoro re yi ni wipe kiwon ma gbiyanju latini emi suuru ati Ipari
Ise , Olohun konidawa laamu .

Mo ma N salaye fun eyin eniyan tema bere ibeere Lori whatsapp' ati ninu group. Egbiyanju latini iwe yi
lowo nitoripe ekunrere Alaye wa ninu re daada, Lara irawo *Cardinal* Yi , irawo ina wa nibe , irawo
Afefe wa nibe , irawo Omi wa nibe pelu irawo yerupe , Se irawo Omi ati irawo ina towa ninu ile
*Cardinal* yi bafe ara won se wahala maa wa funwon ? E lo ra iwe yin fun Ekunrere alaye , Irawo ina ati
irawo Omi Le fera tabi sise papo daada tikosinisi wahala kankan. GBINYANJU lati ni iwe Akosejaye lrawo
1&2 5000 waba Asiri nibe.

[12/16, 10:45 AM] Mentor: ISE TI OSU KEJO NJE FUN BURUJI ABI AMERICAN IRAWO KOOKAN NIYI

---------------ONKA OJO IBI RE NI ONILO ---------

------------(may=5) 5/5/2000

-------------5+5+2+0+0+0

--------------=12=(1+2)=3----------------------------------
Buruji kookan no Lati se isiro onka ojo ibire kofimo nka ti osu yi nso fun

ONKA AKOKO-: osu yi nso nipa nkan tonilo latise tiwafi ni aseyori, oun ni wipe kosise takun takun ni wafi
ni aseyori daada ninu osu kejo yi

ONKA KEJI-: oni lati sowopo pelu elomiran abi enikeji lati fikun agbara re, leyi toje wipe yio si mu esi ayo
jade lori nkan ti eba pawopo se ninu osu yi.

ONKA KETA-: oni lati ronu nipa ona tiwagba lati firi ere je lori nkan toban se ninu osu yi, yala boya ise kan
ni, kiori wipe olo lakaye re pelu sisise daada ki nka naa kodun gbe han abi kose gbe han aye loda fun o
ninu OSU yi.

ONKA KERIN-: oni lati se nkan ti emire yiosi gun di ojo ola ti yio si mu eso rere jade, leyi totumo sipe
onilati na owo ki ofiri nkan ton fe. For example "Owo ni afin wa owo"

ONKA KARUN-: Onilati losibi ti awon alagbara wa abi ibi ayeye kan, toripe osese kori awon nkan tonilo
lati fi de ibiti onlo abi gbeo debi ti onlo.

ONKA KEFA-: Boya ise tioko ati eko tioni, ridaju wipe olowon ni ona ti owo magba jade fun e julo, toripe
osuyi nso fun e wipe kolo lakaye ati eko nkan totimo tele, tosi yeo daada niwafiri ona lo losuyi.

ONKA KEJE-: wafemu ajosepo ba ise inu emi(spiritual practce) ati oro(wealth), osi da bee fun o ninu
osuyi lati lo nkan tomose daada yen, ti daada yio fi tibe jade

ONKA KEJO-: Onilati fi nkankan lole abi gbe nkan kale ti yio wa fun ojo ola awon eniyan ti won wa iran
lowo nitoripe onilati duro gege bi oluranwo fun won abi je imonle fun won

ONKA KESAN-: Ogbon, oye ati lakaye ti oloun fun o, oun ni yio gbeo si ipo olori lati maa fa awon eniyan
mora ati latitun bo ma towon sona ninu osuyi
Oloun oba Allah loni mimo julo, pelu asere koni siwa lona o(Aameen)

[12/16, 10:45 AM] Mentor: *ÀKÓBÁ TÍ OWÁ NINU EPE SISE FÚN GBOGBO ẸDA*

Epe je nkan iyalẹnu fún gbogbo eda ènìyàn njẹ iwọ rántí pé epe kii ùn jeki Aye ẹni tẹ síwájú bẹ sini ona
mẹta nii epe tii ùn wà gẹgẹ bí àpẹẹrẹ;

*Epe IDILE ( Epe Ajogun ba)

*Epe Awofofa

*Epe Ori ahon. (Epe obi parents)

*EPE ÌDÍLÉ*

Opolopo Eda loun sise bii Erin tii won sii unjeje iliri kiku unse ejo won bii kii ba nse awon babanla won nii
wonti fiwon ya Owo Ninu ilu IPON

*ILU IPON*

Awon IDILE bayii kii nlu Aluyo nii Ile aye won epe IDILE tiba tiwonje bi wonba nii owo 💴die lowo titi
Owo💴 yii o fitan wokonimo Gbese Lori isewon gbogbo Owo toyekii Oni Awon babanla wonti gbe won
sepe ayafi kii wonbe olohun kii osorowon dayo.

*EPE AWOFOFA*
Opolopo obinrin nii Aye ee tibaje latara Aini itelorun kosi owo eniti kotilegba Owo 💴 kodeni Ife sii
Okunrin kankan ranti pe bii wonba gbe ee sepe atilu Aluyo yio nira die.

Opolopo okunrin nii Oti tosi Lara epe obinrin kosi eniti kolegba Owo 💴 lowo ee bii wonba gbe eee sepe
olohun ati idariji obinrin nikan nii olemu epe kuro nii Ori ee

*EPE LATENU ÒBÍ* .

Opolopo omo nii owalaye bii Alaisi awon obiwon tii batiwonje latara epe obi omo tii obi basepe fun kosi
Aniani kole siju Anu wo awon obi ee iru omo bayii nii kii unri Owo 💴 fun Awon obi ee nitoripe gbogbo
igbatii oba promise awon Obi ee pe owun fefunwon nii owo wallahi konileri Owo 💴 fun won epe tii
awon obi tisefun nii

Opolopo Ile too aungbe nii olugbohun wa ninu eee Ile Osa (Oracle) nii elomiran ko ilesi epeti Abase nibe
odidandan kii omu eniti Abasefun

Akiyesi

Kini ikanti alefi wẹ Epe kuro loriwa?

Bawo nii aṣe le bọ lọwọ ogun epe ìdílé

[12/16, 10:45 AM] Mentor: *ÌPÍN IRAWO TÍ O MÚ IYALẸNU DAANI*

Ọlọhun koni jeki ari aburú njẹ awa mo pe awon ipin irawo kánkan mi iyalẹnu dani gẹgẹ bi apẹrẹ;

👇👇👇👇👇👇👇👇

*ERUPẸ FÚNFÚN VIRGO ♍*


Gbogbo Agbara tii Erupe yii nii koju Àjé 💰 lọ irawo yii nii Aje Lara gan obinrin irawo yii je Akinkanju
omo iya lowun ati Omi tutu wọn ma ùn ni agídí won fẹràn ọrọ sísọ láwùjọ tiwon nikan níí ọma ùn yewon
won ma ùn nife awọn tii obanife won dénú dénú ju ọmọ iyawon lọ besini igbedide ògo wọn níí agbara
awa maridi níí ọrọ aiye wọn

*ERUPẸ AMỌ TAURUS ♉*

Iyalenu ni irawo yii jẹ pẹlu iseda irawo Ina To NKANYANRAN nitori pe ibaṣepọ omi wa laarin awọn
mejeeji bíi awon mejeji ba jọ da isẹpo konisi Iyanjẹ laarin won besini bíi wọn bá fẹ arawọn koni sí wahala
atipe nkan ma únjẹ́ alagidi bey sini ikan ma ùn níí suru ninu awọn mejeeji yii bi won ba jọ da iṣẹ pọ tabi
bíi wọn bá fẹ arawọn.

*AFẸFẸ ALAWADA ♊ GEMINI*

Irawo yii pelu *Ina Atupa* olohun fii owun iyalenu siwon larin nitoripe awamaridi nii iru idile yii ma un jẹ
nitori pe kosi eniti o lerí arin ọkọ àti ìyàwó even kii omase owó níí ọwọ níí ọwọ ọkọ ìyàwó koni sọ sita fún
ẹnikẹ́ni

Bíi otileje pe Ina Atupa nii irawo Ina ti o kere ju oba sini niwaju irawo Afefe alawada yala okunrin tabi
obinrin.

*IRAWỌ OMI TÚTÙ SCORPIO♏*

Owun iyalenu Lori irawo yii nipe bii Omi tutu base Adura sinu Omi lasan gbogbo owun tii ounwa oseese
kii otelowo bẹ síni ìbáṣepọ̀ nla lowa bíi arin ohun ati irawo ina TONKANYANRAN ati erupe eruku.

*INÁ TONKANYANRAN ♈ ARIES*

Nkan iyalẹnu tii owá ninu iseda yii ni pe kosi ipin irawo ti kólé fẹ idi niyi tii wọn fi jẹ awa maridi fún
gbogbo ìràwọ ibinu wọn koki ùn da rara amo wọn tètè ma ùn dari jii awọn ti wọn ba sewon.

[12/16, 10:56 AM] Mentor: *IBASEPO ATI AJE TOWA LARA IRIN AJO AWON IRAWO*
Púpọ nii eda eniyan ti ko mọ pe Ajé ati irawọ ùn tele arawọn,

Nje iwọ mọ pé ọpọlọpọ irawo ni oti fii àjé ara rẹ rare latara aini akakun sugban koje iyalenu fumi
toriwipe awan ota tite oro e titi otiwo password idi niyi tii wọn fii ùn wa laye bíi aláìsí .

*AWỌN IRAWỌ TI ONISE PELU AJÉ*

*IRAWỌ INÁ*

*Bíi èyán bajẹ irawọ Ina oseese kii oni aje lára níwọ̀ nba igbati ohun ati ọmọ eléré ti oni aje lára ba fẹ
arawọn

*Ninu awọn ipin iseda irawo ina wa ti ojẹ alaje ọmọ ṣugbọn oye ki oṣe àwárí ara-re kii àjé yìí lè wúlò fún
titi di ọjọ alẹ

Bíi gbogbo iseda ba ṣe àwárí arawon konisi wahala agaga obinrin tii ojẹ alaje ọmọ

*Bíi irawọ *INÁ TO UNGBONA RIRI* bafe gbogbo ipin iseda irawọ omi tii obani Aje lára otidi dandan kii
ògo rẹ bú yọ

*ERUPE FÚNFÚN*

Ajé wá nínú gbogbo ipin iseda yii ṣugbọn wọn kii ùn tètè se awari arawọn nítorí pé gbogbo iseda yii ati
*ISEDA OKUN* jọ níí Ajosepo

*AFẸFẸ ALAWADA*
Niwonba ìgbà tí Àjé bati wa lára iseda yii odidandan kii owo ati aje bagbe ṣugbọn kii iru enibe tètè mu àjé
lo nítorí pé bíi eni ṣe rí ọla ko rí bẹ

*PÚPỌ NÍNÚ AWON IPIN ISEDA IRAWỌ TI ONI ÀJÉ LÁRA*

ERUPẸ FÚNFÚN

ERUPE ILERUKU

OMI TÚTÚ

AGBÁRA OMI

PÚPỌ NINU IRAWỌ INA

IRAWO AFẸFẸ.

*GBOGBO OUN TI MOUN SOYI KOWULO FUN EYIN TI EUN FI DATE OYIBO WO IRAWO YIN O TORIWIPE
KOSI IBASEPO KANKAN NINU AKOSEJAYE EDA ATI IRAWO PELU DATE OYIBO. TORI ISEMI IRIN AJO EDA
OWA LATINUN ATELEWO RE*

Aìmọye awọn ipin iseda yii ni o jẹ alaje ọmọ nitoripe iseda irawọ yìí gán nii agbara níí orilẹ aiye nítorí
Aimọkan ti sọ ẹlòmíràn di ẹni yẹpẹrẹ ninu wọn

Púpọ ninu ẹda ènìyàn níí oni aje lára ti komo ọna lati gba lo ajé ara-re
Ajé wá lára wọn ṣugbọn bíi wọn koba níí àkíyèsí lori irin ajo ayé wọn oseese kii àjé arawọn mase wúlò
fún wọn

[12/16, 10:56 AM] Mentor: *KI IRAWỌ ỌKỌ ATI IYAWO PAPỌ ṢUGBỌN KOSI ILOSIWAJU LARIN WON
WAHALA SI UN ṢẸLẸ NI ARINWỌN*

Púpọ ninu idile nii oun dojú kọ ìṣòro yìí bẹ sini won ko ti ríi ona abayo.

Oseese kii irawọ ọkọ àti iyawo papọ sugbon kii whala ma ṣẹlẹ nínú ìdílé wọn

Gẹgẹ bíi àpẹẹrẹ;

Awọn ipin irawo kan wà ti ojepe Ibasepo Won paapọ ṣugbọn ti wahala ma ùn saba sele sinu idile wọn

Awọn kan tii ee lero pe kadara won Ko paapọ gẹgẹ bii lọkọ laya

Oseese kii kadara papọ bẹ sini afowofa lọkọ Tàbí aya gan ma ùn fa ìṣòro wan yi.

*GẸGẸ BÍI ÀPẸẸRẸ*

*IRAWỌ INA TONKANYANRAN ATI AFẸFẸ ALAWADA GEMINI*

*IRAWO OMI TUTU ATI IRAWỌ IYEPE FUNFUN*

*IRAWỌ AFẸFẸ ONIBINU ATI INA TONGBONA RIRI*.

*IRAWO IYEPE ERUKU ATI IYEPE AMO*


*IRAWO ERUPẸ FUNFUN ATI IRAWO OMI TIKIRU*

*IRAWO INA ÀTÙPÀ ATI IRAWO AFẸFẸ ALAWADA*

*IRAWỌ OMI TUTU ATI AFẸFẸ ONIBINU*

*INA TONGBONA RIRI ATI INA TONKANYANRAN*

*IRAWỌ IYEPE FUNFUN ATI IRAWO IYEPE FÚNFÚN*

*IRAWỌ IYEPE ERUKU ATI IRAWO IYEPE AMO*

*IRAWO AFẸFẸ MARIMIFIN ATI AFEFE ONIBINUN*

*IRAWO OMI CANCER ATI IRAWO OMI TIKIRU*

*IRAWỌ OMI TUTU ATI IRAWO AFẸFẸ MARIMIFIN*

*IRAWO AFẸ́FẸ́ MARIMIFIN ATI IRAWO AFEFE ALAWADA*

Tii irawọ ọkọ àti iyawo ba paapọ ṣugbọn wahala sábà ma ùn ṣẹlẹ nínú ìdílé wọn debipe irin ajo won
amase won bi ki won ko rawon sile

Iwo loko laya suru lo koko gba saju na. To awon oni mimon lo lori isele tisele saju naa

Eyin eniyan mi ohun toba ti di pe ọmọ bibi ti won arin yin. Eti bi ọmọ fun rayin akoko nibe egbodo kora
yin sile. Tori kiko ara eni sile Ẹgun ati wahala ni mapada fa sinun ìgbésí aiye ọmọ tebi yan.
Eyin lokolaya elogbo Asiri imo ijile timo solori Gruop wa lori ibasepo larin loko laya yin. Ati larin irawo
eda kokan tori gbogbo ikan kole madun lo titi.

*EYINI DIẸ NINUN AWỌN NKAN TÍÌ OMA ÙN FÀ IPIN YA LARIN IBASEPO ENI*

(1)

*Oseese kii iyawo máa nii ìfẹ ikọkọ pelu eniti irawo ohun ati ọkọ ee takò arawọn (yíyan alè).

(2)

*Oseese kii ọkọ máa nii ìfẹ ikọkọ pelu eniti irawọ ohun ati Iyawo Re takò arawọn.

Osese kojepe iya oko abi iya iyawo abi baba ọkọ abi baba iyawo kofi owo si keyin mejeji fe rayin.

Osese kojepe egun idile ba eni kan ja ninun yin abi koje pe ẹgbẹ́ eni kan niba eni kan ja ninun yin

Osese koje pe eni kan ninun yin ti fa Afowofa sinun aiye re saju koto ni iyawo abi kòtò ni ọkọ

*ÀPẸẸRẸ*

Kii ọkọ je irawo iyepe eruku kii iyawo je irawo omi tutu tabi agbara omi

Bíi ọkọ bá ùn nii ìfẹ ikọkọ pelu ina tongbona rírí tabi ina atupa odidandan kii whala maasele larin lọkọ
laya .
(3)

*Oseese kii kadara won mase paapọ ọpọlọpọ eda nii won tii fi agídí fẹ arawọn bíi irawo ba paapọ tii
kadara Ko papọ koni síi ilọsiwaju ninu igbeyawo won

(4)

*Oseese ki won ma gbe ìlú tàbí ile tii irawọ wọn kò n'ifẹ síi:- bíi eda ba ùn gbe ìlú tàbí agbegbe tii kadara
ati irawo e tako ati nii ilọsiwaju Ama mú inira daani

*AKIYESI*

lati igbati iwọ ati iyawo ee ti wa ni ilu *IBADAN.EKO LAGOS ( ABUJA* kini awon nkan ti e gbèsè ninu aiye
yin

Elomi ohun ati iyawo ati ọkọ̀ kogbe ibikan naa kadara teki ni kise kejo gbe inun ilu kan naa sungbon enilo
lati se iwadi ara yin saju ketole yalototo.

Aimoye eni ti orire e wani Nigeria ti olo taku si ilu oyibo

(5)

*Oseese kii ikan lara won mase ikan tii otako ipin irawọ tii won gbe waye

(6)

Ti ogun tabi egun idile baun da enikan laamu ninu oko ati iyawo lopin igbati wan batiun ni ajosepo odi
dandan ki oun tonbe lara enikan ran enikeji ni wahala ba bere ninu idile wan eleyi ni oun di egun ajogun
ba afiki wan tete wa ona abayo.

*EYIN TI ILU EKO LAGBARA OLOHUN EMARETI MINI ILU EKO NI COSTUMES BLOKE GOWON ESTATE*
Fun iwo tio ba nife si awon PRODUCTS wa

*ỌLỌHUN KONI JẸKI AWA YẸ ASÁN OGÚN ÀTI ÈGÚN BURÚKÚ KONIJEKI TIWA AAMEEN THUMMA
AAMEEN ADUA GBOGBO NI YIO GBA*.

[12/16, 10:56 AM] Mentor: *IWO ỌMỌ IYAMI IRAN OTA MELO LOWA LAIYE*

iran ota towa laye po ema fi okan bami kalo

Ota ti kofe ki arije.

Ota tofe ki ajeun sugban kofe ki aje ajeyo

Ota tofe ki aje ajeyo sugban kofe ki ounje di ale ninu eni

Ota tofe ki ounje di ale ninu eni sugban kofe ki aje, aje seku

Ota inu ebi (family)

Ota inu ile

Ota inu ore (friends)

Ota adugbo

Awan wo ni aun peni ota inu ebi? Ota inu ebi je ota tolagbara pupo lati da irin ajo aye eda ru

Omo ologo ninu ebi daran lowo awan eni ibi wan yi tori wipe wan ni agbara lati ri ojo ola eniyan sungbo
ti eni yi bari oni mimon tosi je Aláṣẹ yala Alfa. Abi woli Abi obinrin to ni Ase lara yio ba segun ogun na
kirun okunrin be wa kon fun obinrin yan ni abi kiru enibe wa mon fun awon ti won basegun. Ogun inun
ebi. Odunja feni toba tete rin na pàdé awon ti won ju won lo..
Gbogbo ona ti omo ologo yi kofini ri ogo elo ni wan ati gbe igbese lori e latigba ti omo yi batiwa ni kekere
iru iwo omo na

*MADURO*

*MAROSE*

*MASARE KOJA KADARA SIMADURO LASAN*

*MAFI ADUA LE OOO PELU SARA TOBA IRAWO RE.MUN*

*OTA INU ILE*

ota inu ile je ota ti ajoun sun ti ajoun ji koda ajoun je asijoun mu even atun joun sun si ori ibusun kan na
oleje iyawo. Abi oko si iyawo.

Mofe ki alomo wipe kii se ota toun ro ibi siwa nikan ni ota wa kii se eni tofe ki aku nikan ni ota wa

Mofe ki olomo wipe eni ti iwo atie joun rinrin ajo ife ti irawo tabi kadara yin kopapo ota ni fun e

Iru eleyi oseja ni won igba toba ti pade awon ti won mon naa irin Ajo irawo tio ba wa si ile aiye waju we
isegun eleyi fio.

Awan eleyi ni aun peni ota ilosiwaju Tori wipe gbogbo igba ni ijakule, amubo oore ama waye fun e, lopin
igbati iwo ati e basi jowa papo ọ̀ rọ̀ po lorieee.

*OTA INU ORE*


ota inu ore je afoju feni mafi okan feni bi oun rere ba sele sie wan aba eyo loju aye sugban ero okan wan
lori oore ti olohun se fune yi buru jai wan aba e rerin loju aye sugban ọ̀ rọ̀ inu wan juti oka lo sori ota ọrẹ
yi loni agbára ju ninun gbogbo ogun otayilo. Iwo omo iyami ọrẹ ni kojina si ni igba ìgbà ooo. Tori ogun
ọrẹ koseja. Tori yio pooo besini aiye redara odun owa so fun ọrẹ pe aiye re mati da iwo odabe. Ma
palemon iku loku ooo tori ọrẹ tori yan oyara tete pani ju ogun ota yoku loo ogun ọrẹ koseja. Iwo ni ko
kie saraaa. Iwo ọ̀ rẹ́ mi mafura irole aiye lawa arinun Arawa

*OTA ADUGBO*

Awan wan yi ni aun peni inu nibini kokan ti aimo iwa wu opo ninu ota adugbo wan ama binu oore ti
olohun se fune opo ninu wan ama sadede binu eni laini idi pato sori awon eleyi nunun ohun ti oba adeda
fio ti won binun si ohun ni ki iwo mana fun won. Tori won ti je atare ati epo re.

*Ọ̀ RỌ̀ ITANIJI*

Iwo Ọmọ iyami mawo aye arare niran gbogbo eyi keyi ota tobawu ki oni gbiyanju lati so ara e di okan
ninu oun meta yi ki ota mabaa fi aiye re tafala

*APATA PARA*

*IRIN EDAN*

*INA EDUN ARA*

Agbara ota koni kawa o amin. Omo iyami amin nikan ko wa sise to ni ooooo

*AL ISTIJABAH AWO IRAWO TRADO MEDICAL*

[12/16, 10:56 AM] Mentor: *ADUA FUN OJO ISEGUN 19 OCTOBER, 2021*
*FUN ISEGUN TUESDAY*

1. Ọlọhun oba nla oo Gbogbo ẹyẹ okunkun ti n ṣiṣẹ ilodi si ilọsiwaju eni kokan wa, Ọlọhun bami gbe won
subu, ki won si ku, ni orukọ olohun oba awimaye hun alágbára bami segun awon enibi ti lepa ati subu mi
eni kokan wa

{Aameen thumma Aameen}

2. Ọlọhun mi oo bami mu gbogbo ẹyẹ buburu ti o nsise ilodi si awọn aṣeyọri eni kokan wa

{Aameen thumma Aameen}

3. Ọlọhun mio bami fi Ina re joo gbogbo ẹyẹ okunkun to nsise ilodi si kadara eni kokan wa ni orukọ
Ọlọhun oba to ni emin eni kokan wa

{Aameen thumma Aameen}

4. Olohun mio ina tio fi jo awon eni ibi lojosi ni gba ti won fe wo khaba Ọlọhun gba ẹmi eni kokan wa
kuro lọwọ awọn ẸLẸ́YE ile baba. ẸLẸ́YE ile iya. ẸLẸ́YE ijogun ba ni orukọ Ọlọhun oba Alase.

{Aameen thumma Aameen}

5.olohun oba nla Ayanmọ eni kokan wa gbogbo abode ti awọn ẹiyẹ okunkun se si eni kokan wa ni
orukọ Ọlọhun oba Aláṣẹ

{Aameen thumma Aameen}


6. Ọlọhun Gbogbo Alagbara to n seto ibi si eni kokan wa nipa lilo awọn ẹiyẹ buburu, tini olohun ba wa
tu won kaa ni orukọ Ọlọhun oba wibe jebe re.

{Aameen thumma Aameen}

7. Ọlọhun bawa dana sun gbogbo ofaa awon ẹyẹ buburu ni oruko oba Aláṣẹ.

{Aameen thumma Aameen}

8. Ọlọhun oba ninun osu kewa yi olohun jia jijo ope

{Aameen thumma Aameen}

9. Ọlọhún oba Nla dide ise iyanun soro eni kokan wa. Wa fun wani iṣẹ iyanu iyipada, ori re ni orukọ oba
Nla.

{Aameen thumma Aameen}

10. Ọlọhun sise Anun re lori mi. Ati lori gbogbo àwọn ololufe mi. Ọlọhun

Osu kewa tia wa nibe yi mase lopin igbe yin Aiye fun eni kokan wa. Lola KARAMON Anabi Muhammad s.
A. W AAMEEN THUMMA AAMEEN ADUA GBOGBO NI YIO GBA

[12/16, 10:56 AM] Mentor: *OGUN_AROGO_SÍWÁJÚ_OLOGO*

Mogbaladura loni pe gbogbo oju tii oledena ire ayé emi ati iwọ ki oluwa fo wọn danu amin.

Ọpọlọpọ obi nii oti báyé ọmọ rẹ jẹ latara awon ari ogo siwaju OLOGO besini kii unse gbogbó eda ènìyàn
nii ọlọhun kose òòrè fún ṣugbọn awọn ari ogo siwaju ologo nii òun da ẹlòmíràn láàmú.
Nje iwọ Mope iṣẹ ti ounse lọwọ bayii kii unse iṣẹ asela re rántí pé Gbese níi òun fi ojojumo jẹ besini tọrọ
koba kobo nii ọwọ ee kii ùn ṣe iwọ naa awon ari ògo siwaju ologo nii won unda ee láàmú

Orisirisi ọna nii awon eda yii má ùn gba wo Aye awa ènìyàn gẹgẹ bí àpẹẹrẹ;

*Kodara kii ajeki awọn orewa mo gbogbo irin àjò aiye awọn ọmọ wa.

*Kodara kii awọn ọrẹ wa tele walosi ibiti abati fẹ lọ wo Akosejaye awọn ọmọ wa.

*Kodara kii orogún meji mọ Akosejaye awọn ọmọ wọn.

*Kodara kii ama fii ọmọ ikoko sile pẹlu awọn ti wọn wa k'iwa fún ayọ ọmọ tuntun sinu yara.

*Kodara kii amada ọmọ tuntun koja nii owurọ kutukutu

*Kodara kii obinrin ti ounse nkan oṣù maada okunrin kọja

Gbogbo awon nkan wọnyi nii awọn arogo siwaju ologo má ùn gba wole lati fa wàhálà sinu aiye eda
eniyan

Ọpọlọpọ agbalagba ọmọ nii oun tosi ile eyii sije ìbànújẹ ọkàn fún ẹlòmíràn

Ọpọlọpọ Akọbi ọmọ nii oun jale tii eyii sije ìbànújẹ ọkàn fún àwọn òbí rẹ

Ọpọlọpọ ọmọ loyeki otidi Doctor, lawyer,pastor G.O, Imam tabi eyan jankan-jankan láwùjọ
Ilu òyìnbó loyeki ẹlòmíràn wa sugbon nipasẹ awọn obi ee awọn ari ogo siwaju ologo ti ba ti ee je.

Ọpọlọpọ ọkunrin nii koni ori àyà bẹ sini púpọ obìnrin nii kii ùn ríi okunrin kọ ẹnu ìfẹ siwọn won ti ba ogo
ee jẹ latara *plancesta*

Ọpọlọpọ Akọbi ọmọ nii kólé da enu rẹ bọ débi pé yóò bọ awọn àbúrò ee.

Inú ilé baba tabi iya ẹlòmíràn tii oun gbe nii ogun tí wọ inú aiye e gbiyanju lati jade kúrò níbẹ tìí obafe ṣe
àṣeyọrí.

Elomiran ti wa nii ile ọkọ fún ọpọlọpọ odun ṣugbọn kò loyun aaro díi alè ríi.

Bíi ẹlòmíràn ba fún ìyá tii obi nii owó 💰 lasan odidi osu meta nii ohun gangan yóò fii tọrọ jẹ eyi kotumo
si wipe ki ama toju awan obiwa sugban fura si oro aye e.

Gbèsè tabi Aini akojọ nii ogun tii ounja ẹlòmíràn kii ùn se ẹjọ ònítoun awọn arogo siwaju ologo ti gbe
agbana le lọwọ láti kékeré

Mogbe yoku mi odi gba mi.

Ọlọhun koni fiwale ota lowo Aameen thumma Aameen adua gbogbo ni yio gba.

[12/16, 10:56 AM] Mentor: *MOJUTO ORO IGBESI AIYE RE*

Ope ni fun olohun oba totobi julo, oba tolagbara lori alagbara, oba awon oba, oba ojogbon, oba eleto..

Idojuko fun gbogbo irawo

Gbogbo irawo loni Idojuko kokan si keji toma nsele si won.


*IRAWO IYEPE*

Irawo yi ma nsaba ni idoju ko lori ololufe.

Opolopo won oki ri Oko tabi iyawo lasiko, abi kiwon ni isoro kan sikeji latari eniti won fe.

*Virgo* ntie... Aje ara won ma n se akoba fun won lopolopo igba, eleyi niyioje kiwon ma sirawon lona
Aje yi ma damun won pupo

*Taurus* tie Ogun idile ajogun ba ni ma damun irawo re Debi pe ibalopo oju orun toma se awon Eleye
ile agbo le baba re ni won dalamun wama wagbe Awo okunrin abi awo obinrin lati da oro igbesi aiye
reru.

*Capricorn* Abo Awure lowa Lara irawo yi .loro aiye re kofi ye .Aje Abo lowa Lara re irawo yi ati Virgo
won ma tete GBE oko won dide hummm oro po ninun isemi irawo yi. Kiyoku magbe ohunnn

*IRAWO OMI*

Adawo oni irawo yi ni opolopo igba ni kiwon manife eniyan tonlo irawo ina lopo igba laimape kise
gbogbo irawo ina lole fe omi.

Irawo yi ma n ni isoro omo bibi.

Won ma ni isoro ade ori (fun obinrin) tori ewa ara won ma ntanwon je ni.

Okunrin inu won na ma nsaba ni isoro iyawo.

Won si tun ma ri isoro lenu ise

Oko irun madamun ikan ninun won tise *prices*


Oko orun aiye madamu irawo *scorpion* tori oko orun tie inun aiye lohun malo dio si. Inun irawo INA
ni oko orun aiye tie mawa . hummm mogbe iyoku mi.

*Cancer* iyalode agba ni irawo yi sungbon kotele Ohun ti iseda so Ogun Maduro ni ile oko tima pada
dalemosu wapada wa di iyadagbe Ogun ani suru. Atele ohun ti kadara fe. Ohun lokoba

*IRAWO AFEFE*

Asiri ni irawo yi tori won okin duro si ojukan.

Isoro lenu ise won

Isoro ile Oko tabi iyawo fife.

Isoro nla nifun won tiwon ba nsise totako irawo won. Bi irawo yi koba ni oko ola tibe fun koni ri. Bi irawo
yi kobani iyawo kole gbadun aiye.

*IRAWO INA*

Irawo tole ni irawo ina, onirawo yi ni lati ma iwon arare.

Irawo yi ma nsaba ni isoro ni aro ojoaye won.

Opolopo ninu irawo

*Arise* ma nsaba ni idoju ko Oko tabi iyawo.

ero ngba won ma n ju nti ipawon kalo. Oko orun abi aya orun ma da lakun

Eniyan giga ni awon onirawo yi ma nje lopin igbati won bati mojuto oro aye won won ma lomi Lara. Igbe
aiye won male gan

*Leo* obinrin bi okunrin bi irawo yi kiba se ise ola re idamun apo fun irawo yi kogbodo duro soju kan.faa
*Sagittarius* irawo yi ni lati maduro soju kan besini kogbodo sadehun tori ewu LA ni fun irawo yi. Arinrin
Ajo ni irawo yi se kosi sora fun IJA larin Awon Akegbe re .elegbe ni irawo yi too fi idi mule.

Ona aba yo fun gbogbo irawo to ni idojuko won yi

Gbiyan kio ma ofin ati ilana irawo tiolo, manipa arare kiole ma nkan toto fun e latimase lasiko toye. Ki
ona letete lafun o.

Mogbaladura pe ani waye asan lase edumare

[12/16, 10:56 AM] Mentor: *AWON NKAN TI O MA NFA AIJE OOGUN*

*1. IBALOPO*

mo ri wipe pupo ninu idaamu ti o nba onigbiyanju ni wipe ki won o maa ba obinrin ajeeji sun lai beere
wipe boya o dara tabi ko dara.

Opolopo ninu awon eniyan ni won ti so kadara won nu lataara ibalopo.

Mo fe ki e mo wipe iwonba ni nkan dunmo. O yee ki eniyan o ni asaje, kiise gbogbo obinrin naa ni eniyan
lee ba lopo ti koni kan idaamu ninu aye.

*2. IJEKUJE*

Opolopo ninu awon eniyan mi ni ijekuje ti mon won lara. Ki eniyan o ma je ounje ti ko mo bi won se pelo
re maa nko adanwo ba eniyan. Ojogbon eniyan gbudo ma ko ara re ni ijanu lori ounje .

*3. AKOSEJAYE*

Aimo akosejaye eniyan maa nfa ki oogun ma sise lara eniyan.


Elomiran ko mo nkan ti o ba eleda re mu, iru aso ti ko ye ki o wo sorun, iru ounje ti ko ye ki o je, iru eroja
oogun ti ko ye ki o loo, iru aajo ti o ye ki o se ti yio fi laa ninu aye.

Imule ni o ye ki elomiran o maa lo ti yio fi di olowo laye, eyonu lo ye ki elomiran o maa lo. Oso tabi
oogun owo lo tosi elomiran ti yio fi di olowo ninu aye. Ti irufe enibe ko ba mo eyi to ye ko se, yio maa
daamu ti kosi nii ri ona abayo ninu aye. Elomiran amoran nikan ni o tosi ti yio fi se ibi giga.

*4. LILO OOGUN AITO*

opolopo ninu awon eniyan mi ni won ti so kadara won nu lataara ilokulo. Elomiran yio maa lo madarikan
tabi aseta tabi awon oogun ti won fi nba awon agba jaa. Ti eniyan ba nlo irufe awon oogun wonyi, yio pe
ki o to di eniyan ninu aye tabi ki o ma jw eniyan rara.

*5. AFOWOFAA*

Afowofaa ni o nba elomiran jaa ti ko fi ri ise oogun ti oun se, elomiran ma nwa ija kaakiri tabi ki o ma se
afojudi si eniyan, igberaga ni ti elomiran ti yio fi kan adanwo laara iwa re ti oun huu yi. Awon ti oun huu
iwa igberaga si a si ma danwo boya okunrin ni tabi otubante .

*6. ENU KODURO*

Elomiran ti fi enu koba arare lataara wipe kii se awon nkan ti o ba nso. Tabi ki o ma so gbogbo oogun ti o
ba nse fun awon eniyan. Elomiran si ma nso awon nkan ti o fe se, ti o ba ti wa so tan, nkan yen koni bosi
mo.

*7. AJEGUN*

Pupo ninu awon ti o nse oogun ni koni ajegun lowo. Opo losi ni ajegun lowo ti o se wipe eniyan ti koni
ajegun lowo ni o ba won se oogun ti won nlo.
Laye awon baba wa, ki won o to be eniyan ki o ba won se oogun, won a koko se ajegun fun irufe enibee.

*8. AWON AJE*

Ti awon agba ba nda eniyan laamu, irufe eni bee koni tete ri ona lo ninu aye. Awon aje pe orisirisi, aje
pupa wa, dudu wa, funfun naa si wa. Aje idile wa , aje adugbo wa, aje ninu iyawo tabi ninu awon
girlfriend. Awon agba si maa nda awon atorise laamu nigba ti won ba ntu eran ti won so mole.

Eyin eniyan mi, die ninu awon nkan ti o se okunfa ki oogun ma je lara eniyan ni mo ti la kale yi, e tete se
atunse tabi ki e sare ona abayo awon nkan wonyi ki e ba lee tete ri ona lo ninu aye . Ire oooo odaroo
oooo orun ayo lao sun Amin

[12/16, 10:56 AM] Mentor: *ASIRI IMO IJILE NIPA EWO*

Eewo ni ohun yoruba ni igbagbo pe eyan ko gbodo se ti eniyan ba fi le dan wo o ma ri ijiya tabi idamu re
bi ki eyan j'eja ti won sun, Ewo ni fun awon iseda kan Eewo je ohun elo ti awon baba wa fi ma nmu ilu
to...

Bi ki won so wipe obirin ko gbodo fi oju kan oro...Ewo ni.

Eni ti egbo ba mu l'ese ko gbodo ma je eran tutu ti o tumo si isekuse.. Ewo ni

Eniyan ko gbodo fi igi igbale da ina... Ewo ni

Eniyan ko gbodo fi ose we tan ki o wa ju sile ninu ile iwe...Ewo ni

Eniyan ko gbodo fi ose ti won fi fo aso ku we...Ewo ni


Bi ki alaboyun je moin moin tabi eko tan ki o wa da ewe re sibi to ba ri yoruba ni igbagbo wipe o lewu
pupo nitori awon eniyan buruku le fi ewe na de oyun mo alaboyun na ni inu fun igba pipe ti won ba su
rugudu si ibi kan titi di igba ti won ba tu sile..Ewo ni.

Ewo ni fun Awo iseda kan lati ba obìnrin lopo lati eyin wa.

Ọlọhun oba nla ipadami si ilu Eko ni ola Ọlọhun palo atabo.mi mon wafi isore so mi pada sodo Awon ebi
mina.

Eewo orisirisi lo wa...

Eewo ilu..

Eewo orile..

Eewo idile...

Eewo esin..

Eewo aisan...

Eewo ideru ba eni...

Eewo ti o je mo eri okon...

Eewo ikilo tabi akonilogbon...

*Al istijabah Awo irawo TRADO MEDICAL*

[12/16, 10:56 AM] Mentor: *AKIYESI PATAKI NÍPA ỌRỌ AIYE EDA*

púpọ ninu ẹdá nii ko mọ ipinle ogun aiye ee ṣugbọn niwonba igba tii abati ùn se akiyesi ọrọ aiye wa kosi
wahala kankan fún wa

Ejeki àṣẹ awọn akiyesi wọn yìí


Bíi ọwọ ✋ ọtun ba ùn yun ee gbogbo igba

Itumo:- wa ríi owó 💰 nii àkókò igba naa

Bíi ọwọ òsi🤚 ba ùn yun rẹ nii gbogbo igba

Itumo:- wa náà owó tii koni ìtumọ

Bíi ẹsẹ ọtun


🏿 🏿 ba ùn yun ee nii gbogbo nigba

Itumo:- wa rin irin ajo tii yóò mú owó 💰 daani

Bíi atẹle òsì ba ùn yun ee nii gbogbo igba

Itumo:- wa ririn tii yóò mú wahala daani.

Bíi obinrin ba ùn lala Ibalopọ nii gbogbo igba leyin tii ojitan gbogbo oju arare tutu

Itumo:- ọkọ orun níí

Bíi okùnrin bá nii fẹ síi masturbate nii gbogbo igba

Itumo:- ikorira ati amubo orire nii bẹ sini ayay orun nii oun fa .

Bíi oba ùn fii ọwọ 🤚 tabi ẹsẹ🦶🏿 or oju ko òwu alantakun 🏿🕸️
nii gbogbo igba

Itumo:- ijakule níí

Bíi obalala pe egungun ùn le ee nii gbogbo igba

Itumo:- ogun idile nii.


Bíi akọbi ọmọ tii oti dagba bá ùn to sile nii ekan losu

Itumo:- ikorira tabi idena oríire nii.

Bíi obalala ríi were loju ala

Itumo:- owó 💰 nbọ fún ee

Bíi obalala pe oun ríi ara-re ninu aṣọ tuntun

Ìtumọ:- àìsàn tii yóò mú ikú dání

Bii oba ùn se apeere ọrinrin nii gbogbo igba

Itumo:- atiga iru enibe yóò mú wahala dání

Mase ya ẹnikenib ni bàtà 🩴tabi aṣọ

Itumo:- won ùn lo ikan wọn yìí láti fii gba ògo aiye ẹni

Bíi ọmọ kékeré bá ùn su'kun lati oju orun

Itumo:- ọmọ naa yóò rí ògo lo ṣugbọn idojukọ yóò fé po fún.

Bíi oba ríi eera ti ogbe okan funfun síi ẹnu ninu ile è tabi nii shop ee nii gbogbo igba

Itumo:- waa ríi àjé lo

Ọlọhun koni jeki Awaye asan

[12/16, 10:56 AM] Mentor: *IWO ỌMỌ IYA MI IPOWO LOWA LONI IPOWO LOBARA RE IPO WO GAN
LOLOOO*
Ni aye ajulo tabi ifaseyin ti eniyan wa larin awujo tabi ninun ebi iru eni to je ati bo se je ipele meji
ni ipo pin si eyi to dara ati idakeji re,

Eniyan le wa ni ipo ola, oba, oga,olori, agba, arewa,ojogbon, ipo eru tabi ti omo leyin,

Iru ipo to wu ki eyan le wa o dara lati ma lo fun to ba si tun je ipo ti ko dara ni eyan ba ara
re kii iru eni be mo nkan to fa ki o si tiraka lati je ki ipo na yi pada si rere,

Asiko yen ni iwa buruku to ti wa ninu ẹjẹ won tele to pamo ma n je jade bi igberaga, afojudi ati
irenije ma wa jeyo lara won latari agbara ipo ti won wa,

Elomiran a fe le so wipe ohun Ju Ọlọhun lo yio ma bi eni to ti ropin aye tan ati Ki lo ipo na lati
fun awon eyan ni idamu ati inira,

O ti je abimo ati adamo iwa omo eniyan to si ti wa ninu eje lati ma je ki ipo ru bo eyan l'oju
lati ma wu awon iwa to jina si ti omoluabi,

Idi ni yen ti won fi n so wipe efin n'iwa,

Ko si nkan ti o lo titi l'aye bope boya ola a ma si lo n'ile eni owo a ma pora,

arewa a ma d'oburewa alafia a si tun ma ko eyin si ni,

Ko wa ni anfani aye yi gan n'igba ti a o ni agbara kan lati sa ti awon iyipo pada yi ba de sinu
aye eda,

Ipo yo wu ti a ba le wa e je ka ma lo lati ni ipa rere sinu aye awon eyan nitori afurugbin ni wa
fi fi gbin ibanuje tabi idamu sinu aye awon eyan kii je ki aye eda ni atunbotan rere leyin wa ola,
Awon iwa yi ma n duro gege bi ebu ika fun awon omo lojo iwaju nitori nkan ti a ba gbin s'ile o
di dandan ko mu eso jade,

O dara pupo lati ma lo ipo rere fun rere sinu aye awon eda nitori ohun kohun to wu ki o le ni
n'ile aye ko le to ola ti karunna ti ni seyin to je wipe adorin awon okunrin to sangun ni won ma
n ru kokoro ile owo re tele kakiri sugbon o pada parun nitori igberaga.

Iwo ọmọ iyami ipo yowu tobawa dakun se pelepele faa.

Boba be ninun ipo ẹkùn idamun wàhálà iwo ọmọ iyami mofe kolo mon pe imosi Ọlọhun oba ni suru loni
latise lakoko yan tori Aditu ni ọrọ Ọlọhun. Bope boya Akalolo ape bàbá suru ati Adua. Loro edagba.

*EKU OJULONA ASIRI ỌRỌ̀ IMỌ IJILE ỌRỌ NIPAA INUN BÍBÍ*

*AL ISTIJABAH AWO IRAWO TRADO MEDICAL*

[12/16, 10:56 AM] Mentor: *IRAWỌ OBA SOLOMON/IRAWỌ AṢẸ́WÓ NI*

*IRAWỌ RÁHÁBÙ OBÌNRIN /IRAWỌ PANṢÁGÀ NI*

Ounti o ba wa Ninu irawo Eda niyio maa daamu Eda, irawo OBA SOLOMON, o je irawo alaya pupo, o je
irawo eniti opolopo awon obinrin yio maa feran lati Fe tabi lati yan ni ale

Bakannaa, irawo Rahabu Obinrin, Irawo pansaga ni, irawo asewo ni, Irawo eniti awon okunrin yiomaa da
laamu Ni.

Ti Iru obinrin bee koba ri eni ran lowo pelu adua ati Ọrọ Ọlọhun, Iru obinrin bee, koni ri Ile ọkọ gbe, Ọkọ̀
obinrin be, koni gbadun iyawo re.Nitori awon okunrin yiomaa fi ibalopo daa laamu.
Nitorinaa mo iru irawo Ọkọ̀ ti o fee fe, Iru irawo aya tiofe fe. Ati be be lo.

Fun iwadi kikun ati ayewo tojinle Lori Iru ỌMỌ elegbe tioje ati iru irawo re.

E pade mi ninu group Timoje olu dasile re #ASIRI_IMO IJILE NIPA AKOSEJAYE IRAWO _OMO_ELEGBE_
#ATI_IRAWO_WON.

OWO NI AYEWO RE NI KIKUN.

TABI KIE BAMI SORO LORI WHATSAPP NUMBER 08135568760.09065758022

*AL ISTIJABAH AWO IRAWO TRADO MEDICAL*

[12/16, 10:56 AM] Mentor: *EJE KI A SO DIE NIPA ITUMO ONKA OJO IBI EDA*

... A le fi onka ojo na mo nkan ti eniyan ma je laye, pelu ise ti yio ba kadara re mu...

Igbese akoko:- a o ro gbogbo onka ojo ibi wa papo fun apere won bi enikan ni 15/12/1993,

Irawo INA .sugbon irawo ti sise pelu omi ni .tori ise si eni yi bi irawo omi ni tebawa lo WO Dada eri pe
irawo yi ama lala omi pupo besini omo elegbe Oluokun ALARAGBO oropo be Iwo toma bere ibere tio kun
to oye komo iru edawo ni omo yi .saju koto fe.

awon onka yii ni ao ro papo ti yio fi fun wa ni number kan,.1+5+1+2+1+9+9+3=31

(31) ti o fun wa yii ,a o tun so wipe (3+1)=(4)...

Ti a ba woye si ao ri wipe 4 ni o Ku.......


Onka ti o ku yii,o ni itumo ninu igbesiaye omo eniyan.

Itumo onka eerin TI O BA KU EERIN(FOUR)

-won ma n se aanu

-won se gbokanle

-won ma n tele ipinnu won

-won ni ebun Ati Dari eyikeyi eto.

-won ni ebun Ati fi oju inu wo nkan

-won saaba ma n ni igbeyawo alayo

-won o le da nkan se ki o yori si rere ayafi ki won o wa eniti yio kun won lowo

-won kii saaba ni ore.ore ki po fun won (friend)

-won je onisuuru Ati onifarada.

-won ma n se opolopo oriire.

-won saaba ma n padanu orire ti o wa fun won lopolopo igba

-o dara fun won Lati ma se ise bi IMO ijinle science, researcher, banking,eto oro aje. Oloselu.Doctor...
Oropo ninun irawo yi pelu numbar tomu wa ye.

Awon onka naa niyii.

(1)(2)(3)(4)(5)(6)(7)(8)(9)(11)(22)......e ma ba wa ka lo pelu alaye okookan won..........

*Al istijabah Awo trado mendicar*

[12/16, 10:57 AM] Mentor: *AWON IRAWỌ TI WON JỌ JADE NINU OSÙ KAN SOSO*

Mẹrin níí gbogbo irawo ẹda ènìyàn tii irawo kankan síi Pin síi ọna merin merin

Njẹ iwọ mọ pé irawo meji meji níí Ijade ninu osu kankan
Bíi won se jade to kii ùn se gbogbo wón níí wọn lè fẹ arawọn tabi níí wọn lè dá owo (business) paapọ
nítorí oseese kii wahala ma ṣẹlẹ siwọn.

Gẹgẹ bí apẹrẹ ;

*JANUARY*

*IRAWO ERUPE ERUKU CARPRICON ♌*

*IRAWỌ AFẸFẸ ONIBINU AQUARIS♒*

Hummmmm inu osu kan soso níí awọn mejeeji ti jade sugbon ibasepọ wọn kólé níí ifọkanbalẹ nitoripe
erupe eruku wọn kìí ùn níí suru agídí sí pọ fún afẹfẹ onibinu

*FEBRUARY*

*IRAWO AFẸFẸ ONIBINU AQUARIS♒*

*IRAWỌ OMI TIKIRU PIECES♓*

Inu osu kan soso níí awọn mejeji yii ti jade won lè fẹ arawọn bẹ sini iṣẹ le Dawon pọ sugbon eyiti o jẹ
onibinu nii yọ pada da wahala sile latara ìwà Aini ifarabalẹ ati tinumi níí mase

*MARCH*
*IRAWO OMI TIKIRU PIECES♓*

*INÁ TONKANYANRAN ♈ ARIES*

irawo yìí lè gbe paapọ ti koni sí ìsoro nitoripe iná Tonkanyanran ♈ gan fún arare latara ipin iseda irawo
omi tutu níí oti jade besini jagunjagun ni won he fun ra won suru ati opo adua lodara fun won ju. Besini
ki won se eto oko orun awon mejeji ati aya orun saju ki omo towo bibe ko Ogun ati idoju ko awon egbe
yi ni was pada fi tuka.

*APRIL*

*IRAWO INÁ TONKANYANRAN ♈*

*IRAWỌ ERUPẸ AMO ♉ TAURUS*

INU osu kan awọn mejeji yii tijade bẹẹ sini wọn lè fẹ arawọn wọn situn le da Ise pọ

Sugbon bíi oba ya erupe amo yóò padà níí ìṣòro pẹlú iná Tonkanyanran ♈ nitoripe ikan ma dakẹ ìkejì
nínú wọn. Ogun ibujoko won ma le oko orun fun INA Ogun family ni ti irawo iyepe.wa pada fi epe ati
Ogun tura won ka .

*MAY*

*IRAWỌ ERUPẸ AMO ♉ TAURUS*


*IRAWO AFEFE ALAWADA ♊ GEMINI*

Ifọkanbalẹ púpọ wa fún àwọn iseda meji yii tii won ba fe arawọn tabi bíi won bá dá Ise paapọ sungbon
won ni lati ni agboye tokun Dada ki omo towo

*JUNE*

*IRAWO AFẸFẸ ALAWADA ♊ GEMINI*

*IRAWỌ AGBÁRA OMI ♋ CANCER*

Diẹ ninu irawo mejeji yii jade ninu osu kan anfani wa fún wọn láti dá Ise paapọ bẹ sini won lè fẹ arawọn.
Sile gege bi loko-laya

*JULY*

*IRAWỌ AGBÁRA OMI ♋ CANCER*

*IRAWỌ INÁ TOUNGBONA RÍRÍ ♌ LEO*

Ninu osu kan soso níí ìpín iseda irawo yìí ti jade sugbon bíi wọn bá fẹ arawọn tabi da iṣẹ paapọ ijakule ati
ọpọlọpọ ìṣòro níí yọ mase lẹ

*AUGUST*
*IRAWỌ INÁ TOUNGBONA RÍRÍ ♌ LEO*

*IRAWỌ ERUPẸ FÚNFÚN ♍ VIRGO*

Ninu osu kan soso níí ìpín irawo mejeji yii bọ síi ṣugbọn wọn kogbodo da laaba lati fẹ arawon tabi da Ise
paapọ kii ilọsiwaju tabi ìjà mase ṣẹlẹ

*SEPTEMBER*

*IRAWỌ ERUPẸ FÚNFÚN ♍ VIRGO*

*IRAWO AFEFE MARINMIFIN ♎ LIBRA*

Inu osu kan náà níí awọn mejeji yii wa bẹ sini won níí anfani lati fẹ arawon

Sugbon erupe funfun ♍ níí ajé lara ju ♎ LIBRA lọ iseda meji yi omo won ni ma tete tun idile bese. Besini
ti won bafi otito pile ife won was GBA dun irawo meji yi Ogun ati ota ni ma pada tuwon ka pro po nibe.

*OCTOBER*

*IRAWO AFEFE MARINMIFIN ♎ LIBRA*

*IRAWỌ OMI TÚTÙ SCORPIO♏*


Awọn mejeji bíi won bá fẹ arawọn kosi wahala tabi idamu fún wọn nítorí pé wọn akose mose ni won he
fun ra won iseda awọn mejeji ko níí wahala fún arawọn Alagbara meji pade sungbon ki won fi otito bars
won sepo.

*NOVEMBER*

*IRAWỌ OMI TÚTÙ Scorpio♏*

*IRAWO INA ÀTÙPÀ ♐ SAGITTARIUS*

Awọn mejeji jọ jẹ yọ nínú osù kan ṣoṣo sugbon

Awọn ipin irawo yìí kogbodo fẹ arawon tabi da iṣẹ paapọ ti won ba fe ra won ko nisi ilosiwaju fún wọn.

*DECEMBER*

*IRAWỌ INÁ ÀTÙPÀ ♐ SAGITTARIUS*

*IRAWO IYEPE ERUKU carpricon♑*

Inu osu kan náà níí won wa ṣugbọn wo kogbodo fẹ arawọn kii Ifaseyin mase sele tabi ilọsiwaju nkan rere
ninu ìdílé tabi igbeyawo wọn.

Olohun koni jeki afi owo arawa se arawa

[12/16, 10:57 AM] Mentor: *ASEYORI FUN IRAWO ⭐ 2022*

*IRAWO CAPRICORN ATI AQUARIUS*


Irawo Mejeeji yi ni Irawo toma se Akoso Odun tonbo 2022 gegebi A se mo wipe buruji Libra ati Scorpion.
Virgo Loni Odun tia wa yii,

Kaokab Zual ( Planet Saturn and Uranus ) Loma Dari (Rule) fun Gbogbo Odun tonbo yen, besini Malaika
kan na Loma Dari Fun Awon Onirawo Mejeeji won yi; Malaika Kasifayailu Lomase kokari Odun. Na(2022)
yen, Colour re ni Blue. grey black and bran,

Gbogbo Eda toba fe Se Aseyege Lodun titun tonbo yi ogbodo gbadua daada nitoripe awon isele abami
kan ma sele Lodun na, besini Asiri awon Eni okunkun ma tu sita,

Agbodo sora fun oun jíjẹ ati Mimu besini kia ma sora fun gbogbo nkan tia ba peni Eewo wa nitoripe
kosibi eda se Lee ma je Eewo ti wahala koni ma sele ninu aye re,

Ijamba Orikun ati Ese Loma Saaba Sele Ninu Odun na besini Paapa julo awa tia n Lo Irawo yi, E jeki A sora
fun Ijamba tole sele si wa besini kia sora fun Sise awon nkan ti koba iseda wa mu, ki Oore odun titun na
Lee ba Je titiwa....

Besini Awon Ala temala ninun Akoko yi ala toni itumo ni tio ma ja si isegun. Sungbon iwo na wa toju
aiye reri.

Kiise awon onirawo yi nikan ni won ma se Aseyori ninu odun titun na sugbon gbogbo eda toba sora kuro
ninu mi ma se Nkan to tako Iseda re besini tio si se saara ati adua re , Odidandan ki Idunnu ati Ayo Je titi
re na ninu Odun titun.

{IRAWỌ LEO. IRAWỌ TAURUS. IRAWỌ JEMINI. IRAWỌ PISCES}

niwon igba toba tera mon adua ni sise ati itoju ẹgbẹ́ ore nla be fun irawo yi eyi ti ogun idile baja. Kotera
mon igbinyanju. Isegun ègún idile. Pelu sara ẹgbẹ́.

Eyi ti le ilu oyinbo kotera mon bayi àṣeyọrí won ti de ninun planet irawo won.
*DIE LÁRA EEWỌ fun6 ỌDÚN 2022*

*Sora fun iwa Àgbèrè

*Sora fun owo yiya. Owo èlé

Sora fun ibinun

Sora fun ija onija

*Sora fun Epa Jije

Okunrin tobafe Se Aseyori Ninu Odun titun (2022) kogbodo Jeki Obinrin gun ori ohun nigbati won ban
sere ife(Ibalopo) Nitoripe iru okunrin bee kotun ni Ilosiwaju ninu odun na mo ayafi pelu aanu olohun.

(Olohun nikan Loba Onimimo Julo)

Mase jeki Odun tonbo tun bo fun e , nitoripe kii Iru Anfaani bayi tun Lee Sele si awon onirawo mejeeji yi,
O tun di 2028.

Note: Awon ti Irawo won bamu Okan lara irawo Mejeeji yi wa Ku orire,

Boya Oruko re ati Oruko Iya re Lofise iwadi irawo re tomu Okan lara irawo yi jade wa fun e wipe irawo re
ni, Moki e Ku Orire Lodun titun.

Iwo toba si sewipe date re Lofise iwadi na tomu Okan lara irawo yi jade wa, Moki e Ku Orire na..
*Al istijabah Awo irawo TRADO MEDICAL*

[12/16, 10:57 AM] Mentor: *ASIRI TOWA LARA IRAWO OMI*

number 1,bi osuwon irawo omin baje sunbula 7 ‫سنبلة سبعة‬....ajepe irawo omi toje elegbe niyan, ogbodo
jina si eja abori ni jije,

pelu ede pupa,

ede funfun,

alakan,

igbin,

ati bebelo, onirawo OMI gbogbo mase eru egbe ni gbogbo ojo jimon,ije eyin eyanmi monpe omi pinsi
meta, ‫ماء سنبلة‬.......‫ماء تجريد‬......‫ماء مجار‬.... Omi toje seleru,

omi adagun,

omi odonla tonsan,

ninu OJO ati erun,bi onirawo omi toje odonla base oyun,

awon omo elegbe wonyo yo kuro ninu egbe elere omi.


yio si koba okore nibi arisiki,

bi oba fi arabale dada toba mi kalo osese koda irawo ti onlo mon laibere lowo eni kankan,

*IRAWO OMI*

iseda tonlo irawo omi manje opolopo obirin lopo igba

,bakan na iseda omi kookan lonii bi won se di eru egbe fun ra won,

Bi oni irawo omi meji bawa po won ni eto saju ibalopo won ati ayewo topeye.

sweet

,osan,

ibepe,

adun,

epa yiyan

,awon inkan wonyi na alelo fun eru egbe, sugbon lasiko ti wonko bati di irun fun obirin na niyan
,kete ti obirin batiwo ile oko,agbodo seto Eru egbe won saju omo bibi

Tori bi won koba seto egbe won idamun ati fitina bo lojo iwaju

Bi irawo yi koba tun wa seto eru egbe fun n Awon emere omi abi Iran se Aje

,lapejuwe,agbon nla meta,

idi iyo medogun

,eyele funfun,

igba Eru.

ogede ominni ogun ati eyokan,

aso funfun opa merin,

obirin na yiose adua fun awon egbe re,

okore, yio seto adua si.

iya ati baba,


yio fi eyele wo ara obinrin yan ni ihoho pelu asofunfun toro monra.

Iro opa meji,pelu opa meji ninu igba,

kete tobawe tan nin odo yiogbe eruna kale,

kogbodo boju wuyin mon,

okurin kokin saba je irawo omi,die ninu okurin lonlo irawo omi, iseda irawo omi obirin niwon gbe kale
fun,abi eyin tiri oluweri okurin ri,todanri tikose irun sori,kowopo rara, gbogbo eyin ti eni iyawo
nile,egbiyanju lati Mon irawo ayati efe,anfani nbe lara obirin pupoju,bie ti selero looo

*Al istijabah Awo irawo*

[12/16, 10:57 AM] Mentor: *ALAYE LORI ORIGUN IRAWO*

Gege bi atisemo wipe irawo merin lowa

*IRAWỌ INA ILE META NI SE*

*IRAWỌ OMI ILE META NI SE*

*IRAWỌ IYEPE ILE META NI SE*

*IRAWỌ AFẸ́FẸ́ ILE META NI SE*

Beni asemo wipe origun merin ni aye eyi toje (ila orun,Iwo orun, gusu,ariwa) elomiran ilu towa ni onfa
wahala sinu aye elomiran tikomo ti yio sima fa idamu ati aini ilosiwaju ninu aye e ,
Se gbogbo eniyan towa ni ilu eko lose orire nibe?

Sugbon eko eko ni elomiran npariwo besini orire kosi ni ilu eko fun irawo elomi

abi awon towa ni ilu eko won sorire ju Awon ti won wa loke oya ni ??,

Ọrọ elomiran kojo ko ma joko si oju kan rara sugbon ohun onimo nipa irawo e ati ayanmo re rara,

besini ise arinrin ajo lodara fun elomiran,

east lodara fun elomiran sugbon west tabi north lowa ,

east ye gan logbodo wa ti oma ti ri nkan gbese nile aye bibeko okan ma sare lasan ni,

Elomiran wa toje wipe nkan toma fa wahala ati idamu sinu aye re ni yio yan laayo gegebi favorite re,

gegebi awon omo omi tiwon kogbodo je eja aro,

awon gan lonma feran eja aro julo ninu eda eniyan,

won o ma wa sowipe aye kan ni se Awon koda won le sope aje,tabi egun idile kan lonse awon,

*SE GBOGBO ENIYAN NI AYE NSE NI ?*

lomo nipa tifun tedo irawo re,


ayanmo re,akosejaye re,

Ejo kosi anfani lati dahun ibere. Ohun toba rio loju pe Agomi Abi kobami soro lori WhatsApp numba mi
08135568760.09065758022

[12/16, 11:10 AM] Mentor: *ẸKÙNRERE ÀLÀYÉ LÓRÍ ILÉ 🏠 GBÍGBÉ ATI ALÁ LILA NÍGBA GBE IRAWO EDA

Bíi ẹdá koba nii àkíyèsí lori ile 🏠 tii òùn gbẹ awọn orisirisi ijakule nii amaba pade besini opolopo eda nii
ìgbésí Ayewon ti di radarada latara ile tii wọn ùn gbe

Púpọ nínú àwọn ìyàwó nii oma ùn fa wàhálà sinu Aye ọkọ latara ile gbigba nitoripe taste won high gan
ṣugbọn latara ife odidandan kii ọkọ gbasiwon lẹnu

Ilẹ ti aba ungbe fún ọdún kan bíi kobasi ayipada ninu ee fún wa mobeyin ejeki akuro nibe besini ìrònú
kaluku wa yatọ

Nah God Nah God ti báyé ẹlòmíràn jẹ nitoripe koni Àkíyèsí lori ọrọ aiye ee.

Ọnà miran tún wà tí ijakule ma ungba wọ inú Aye ẹdá latara ile gbigbe ninu àlá gẹgẹ bíi àpẹẹrẹ;

Bíi obalala pé owá ninu ile ti otigbere nipo pé òun gbé ibe

Ìtumọ:- Ifaseyin ni

Bíi obalala pé igi wò lulẹ sori ilẹ tuntun ti osegba

Ìtumọ:- kuro nibe kosi òun réré kan ninu ilé yìí fún ee.

Bíi obalala pé okunkun su bọ eeloju níwájú ilé

Ìtumọ:- gbàdúrà kii ajakalẹ

Àrùn máṣe waye fún ee.

Bíi obalala pé landlord tabi land or lady wa sin ee níí owó 💰 ile laijepe ojẹ nii owo ile.
Ìtumọ:- gbàdúrà kii gbese máṣe yoju síi ee ninu ile ti òùngbẹ

Bonus*

Lati mo iru ile tii oyeki agba

Gbìyànjú kii obu iyepe agbègbè ilé tii osese fe gba tabi ilẹ tii ofe ra kii òsé adua síi kii owa da iyepe yìí síi
abe pillow

Olohun yóò fii gbogbo ikan tii ìṣokún hàn rẹ lórí ilẹ tabi ilẹ tii ose ṣe feran

Ọlọhun koni fiwa fún ọta mu.

You might also like