Professional Documents
Culture Documents
Oro ikilo: Ako fi aye gba enikeni lati fi ogun jade lori ikani yi lai gba ase..
#1
#2
OOgun Atepa
ESE pepeye mejeeji, ao pelu odidi atare kan, ao wafi sin ESE mejeeji yika.
#3
1 Like
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by ONILEIFA: 3:17pm On Feb 28, 2016
#4
OGUN IRISE
Epo Obo, ewe sawerepepe, so gun papo, so po no ose, ao po iyo die mo,ao mafi obe(knife) by ose na
diedie, so mafi we.
#5
Ogun ti ibale fin pada Sara obinrin( to regain virginity>
Ewe ege were, owu Elena, lilopo, ao fipa ara eyin adie, ao fi owu Elena yi eyin adie na, ao fi aso osu ti
obinrin na lo lowolowo we lawetan, ao mulo sinu okiti ogan, ti okiti ogan yi babo, ibale(virginity) yio
padabo Sibe.
#6
<OGUN KI OBINRIN MABI ABIKU MO>
Egbo sapo, egbo peregun, ako eyele, ose, igba olomori, ao ha ara awon egbo yen, ao gun mo ose
dudu, ao la eyele yen laya, a ko ose yen sinu aya eyele yen, ao wa gbe sinu igba olomori yen, obinrin
tabi omo tobi naa yio mafiwe.
Ofore :- Ododun ni sapo nwu ewe, ososo ni peregun nse ofo iyare, ako eyele kini isimi, gbogbo eni
toba nse oun buburu simi koma ni isimi.
#7
<Ogun ki ole mawole>
Ori ako alangba, ao la enu ako alangba, ao ti odidi atare aja kan bo lenu, ao fi owu dundun ati funfun
we, ao fiko si enu ona.
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by ONILEIFA: 3:50pm On Feb 28, 2016
Ìbà Orí-eni,
Ìbà Ikin-eni,
Ìbà Baba,
Ìbà Yeye,
Ìbà Oluwo,
Ìbà Ojùgbònà,
Ìbà Ipárípá adáso-mámùró
Ìbà èyin ìsòrò-Òrun
Ìbà ará Ilè.
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by enigstil(m): 5:13pm On Feb 28, 2016
Eku ise sir, awon ti o ni aiye a je ko ma ju yin se o, ashe. Inu mi dun mi mo se ri ti awon eniyan se gbe
ise wa, ASA ati ISESE Yoruba laruge , ekushe takun takun
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by Ayomidegbenga1(m): 2:48pm On Mar 01,
2016
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by ONILEIFA: 10:18pm On Mar 01, 2016
OGUN-IKIYA¤
Ekuro oju ona, odidi atare kan, ao jo, ao fi sin gberen kan si Aya.
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by Ayomidegbenga1(m): 2:23pm On Mar 02,
2016
E seun baba, ewe a maa je fun yin ooooo
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by Nostradamus: 11:42am On Apr 23, 2016
baba ejo a n reti ki e ko awon oogun sita si,e ku iran lowo ti e n se fun awa omo araye.eledumare a
maa fun yin se
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by Nostradamus: 11:44am On Apr 23, 2016
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by ladycomfort(f): 5:23am On Apr 25, 2016
ONILEIFA:
OGUN-IKIYA¤
Ekuro oju ona, odidi atare kan, ao jo, ao fi sin gberen kan si Aya.
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by ONILEIFA: 11:06pm On Apr 25, 2016
ladycomfort:
. E jowo baba. Ogun wo ni alefigba owo ti awon eniyan je wa. E se pupo
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by OlanikeAsaolu(f): 4:06pm On Apr 29, 2016
Ejowo baba, omo ile iwe poly ni mi, mo nilo ogun isoye todaju tabi ohun ti mo le lo ti ma fi ni
distinction in idanwo tin mon mura lati ko
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by ladycomfort(f): 5:36am On May 03, 2016
ONILEIFA:
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by mahmudhathunder(m): 2:09pm On May
03, 2016
i nid ur help
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by ONILEIFA: 11:51pm On May 03, 2016
mahmudhathunder:
i nid ur help
ON WHAT?
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by mahmudhathunder(m): 1:31am On May
04, 2016
[color=#990000][/color]mo ni omo binrin kan ti monfe lati bii odun meta seyin omo yi si nife mi koja
bee shadede ninu osu to koja yi ni oba sofun mi pe ohunfe mi mo..mowa lo shey ayewo..won wa
nipe..ajatuka ni won sa si wa laarin...mo wa need nkan ti molefi fa oju re sodo mi pada kosi nife mi ju
ti ateyin wa lo,...if u can hlp me out i wil b xo gr8 ful..bkz am nt happy since dn mo ni omo binrin
kan ti monfe lati bii odun meta seyin omo yi si nife mi koja bee shadede ninu osu to koja yi ni oba
sofun mi pe ohunfe mi mo..mowa lo shey ayewo..won wa nipe..ajatuka ni won sa si wa laarin...mo
wa need nkan ti molefi fa oju re sodo mi pada kosi nife mi ju ti ateyin wa lo,...if u can hlp me out i wil
b xo gr8 ful..bkz am nt happy since dn
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by mahmudhathunder(m): 1:31am On May
04, 2016
[color=#990000][/color]mo ni omo binrin kan ti monfe lati bii odun meta seyin omo yi si nife mi
koja bee shadede ninu osu to koja yi ni oba sofun mi pe ohunfe mi mo..mowa lo shey ayewo..won
wa nipe..ajatuka ni won sa si wa laarin...mo wa need nkan ti molefi fa oju re sodo mi pada kosi nife
mi ju ti ateyin wa lo,...if u can hlp me out i wil b xo gr8 ful..bkz am nt happy since dn mo ni omo
binrin kan ti monfe lati bii odun meta seyin omo yi si nife mi koja bee shadede ninu osu to koja yi ni
oba sofun mi pe ohunfe mi mo..mowa lo shey ayewo..won wa nipe..ajatuka ni won sa si wa
laarin...mo wa need nkan ti molefi fa oju re sodo mi pada kosi nife mi ju ti ateyin wa lo,...if u can hlp
me out i wil b xo gr8 ful..bkz am nt happy since dn
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by ladycomfort(f): 8:47am On May 05, 2016
ONILEIFA:
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by orunmila76(m): 1:06pm On May 05, 2016
Eyonu eleiye
Eyin adiye ibile kan,iyo die,aa se eyin naa ,aaa da iyo na sinu abo pelebe(white plate) aa o mu eyin
naa sori iyo,aa o gbee sinu orun,aa o gbe Wole pada ni deedee agogo mejila osan(12pm) aa o bora
sinu ihoho, aa o Bo eyin adiye naa,aa o fi kan iyo die,aa so si enu lodidi.
OFO re: ogundabede awo olokun loni ki omoraiye maa foju ire wo mi loni, afema ni obinrin nfe a,a
mama ni eniyan Moro ,tomode tagba lo mo Afin loja,a kii tori obo ka yo be,,gbogbo eniti o dami mo
ati eniti ko dami mo ki e maa yonu simi.
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by mahmudhathunder(m): 5:25pm On May
05, 2016
[color=#990000][/color]eo fesi fun mi...av even sent u a mail eo fesi fun mi...av even sent u a mail
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by ONILEIFA: 7:31am On May 18, 2016
mahmudhathunder:
[color=#990000][/color]mo ni omo binrin kan ti monfe lati bii odun meta seyin omo yi si nife mi
koja bee shadede ninu osu to koja yi ni oba sofun mi pe ohunfe mi mo..mowa lo shey ayewo..won
wa nipe..ajatuka ni won sa si wa laarin...mo wa need nkan ti molefi fa oju re sodo mi pada kosi
nife mi ju ti ateyin wa lo,...if u can hlp me out i wil b xo gr8 ful..bkz am nt happy since dn mo ni
omo binrin kan ti monfe lati bii odun meta seyin omo yi si nife mi koja bee shadede ninu osu to
koja yi ni oba sofun mi pe ohunfe mi mo..mowa lo shey ayewo..won wa nipe..ajatuka ni won sa si
wa laarin...mo wa need nkan ti molefi fa oju re sodo mi pada kosi nife mi ju ti ateyin wa lo,...if u
can hlp me out i wil b xo gr8 ful..bkz am nt happy since dn
E pe 08179322228
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by ONILEIFA: 7:33am On May 18, 2016
orunmila76:
Eyonu eleiye
Eyin adiye ibile kan,iyo die,aa se eyin naa ,aaa da iyo na sinu abo pelebe(white plate) aa o mu eyin
naa sori iyo,aa o gbee sinu orun,aa o gbe Wole pada ni deedee agogo mejila osan(12pm) aa o bora
sinu ihoho, aa o Bo eyin adiye naa,aa o fi kan iyo die,aa so si enu lodidi.
OFO re: ogundabede awo olokun loni ki omoraiye maa foju ire wo mi loni, afema ni obinrin nfe a,a
mama ni eniyan Moro ,tomode tagba lo mo Afin loja,a kii tori obo ka yo be,,gbogbo eniti o dami
mo ati eniti ko dami mo ki e maa yonu simi.
Ejowo kin to le gba yin laye lati ma fi unkan si ori ikani yi e pe mi lori ero e bara eni soro
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by ONILEIFA: 7:41am On May 18, 2016
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by ONILEIFA: 7:41am On May 18, 2016
Iba fun awan agbagba moju ba omoyin ni mi efi oju ire womi o
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by ONILEIFA: 7:41am On May 18, 2016
Agbo idoti Abe to nfa isunki nkan omo okunrin ati idakole
Bara totobi dada kan, ope oyinbo(pineapple) kan epa ikun ati kanun gidi die
Ao fo bara na yio ma dada ao ge kekeke ao ko sinu oru agbo tabi koko ao tun ge pineapple na kekeke
ao kosi ao ko epa ikun lelori ao ge oun na kekeke ko po die ao ge kanun gidi ni wanba si ao wa bu
omi toma dada si ao de ao wa se ti yio jina dada apere toba ti jina omi agboyi yio duduwa lekannan
oti jina nu ni ao so kale toba tutu dada ao ma mun ni tonbila kokan lojojuma leyin ose meji tanti lo
agboyi ao lore ra ogede agbagba dudu to gun dada ao bo epore ao so sinu koko tolegba akogbodo ge
ao bu omisi pelu oyin gidi sibi mesan ao se to ba jina ao je gbogbore lekannan ise ya
NB ti oko bati ni iyawo agboyen nikan ni kose mase ti ogede o!
NB agboyi yio ma kowa ninu yio ma lowa ninu emase beru idoti yen lonko ni abewa ti eyin gan base
igbanse eru yio bayin pelu nkan idoti tama ya jade, ao si riwipe nkan omo kunrin wa jipepe yiowa bi
ose ye kowa yio si ma sise daradara ti yio si yojade pada fun eniti tie ti sunki
Adua wa yio gba lase oba odumare
Mojuba awon agbagba
2 Likes
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by ONILEIFA: 7:42am On May 18, 2016
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by orisaoko: 7:58pm On May 19, 2016
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by Nobody: 11:29am On May 20, 2016
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by ONILEIFA: 9:06pm On May 22, 2016
Horlahcoded:
mo fe ogun "egbe" to daju
Se mo le be ree oun ti e fe fi se
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by Nobody: 10:57am On May 23, 2016
ONILEIFA:
Se mo le be ree oun ti e fe fi se
fun idabobo
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by ONILEIFA: 11:22am On May 23, 2016
Horlahcoded:
fun idabobo
Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by Nobody: 4:45pm On May 23, 2016
[code][/code]
ONILEIFA:
Se mo le be ree oun ti e fe fi se
ONILEIFA:
Se mo le be ree oun ti e fe fi se
ONILEIFA:
Se mo le be ree oun ti e fe fi se