You are on page 1of 40

~ I'.

V\

IWE EGBOGI·
IWOSAN
FUN GBO~BO ARUN

Lf't.TI QWQ

AJAYI oo·uJ.\tiOSU

. Akiyesi :;. Fun ibere, iwadi · tabi ohun ti ko ba ye-.:


, \
yfn> f~ stamp ti yio gbe lc;ta de QdQ re; mQ apo iwe
ati address r; lc;hin apo iwe.
~nik~ni ti o ba fe ra ninu iwe Egbogi yi, ld o ti ·
owo ran~~, ki o ra Postal Order ki o. fl ran~f; · si:-

M. 0. 0DUM0SU
M. P. 0. BOX 23474, IBADAN.
1n:1~v:psny -Of, sLfmlDAl!OOARiri
lTQKASI
Ogun Awure Jtaja l
,. Awure 2
,. Awure ti a fi nsa 3
,, Qs~ A wure 4
,, 0$y Awure s
,, O~~ Awure 6
,, Oba Q$~ Awure 7
,, Awure ti enia ma fi nwu obindn · ·8
,, Awure Aje 9
,, Q;;~ Awure ,, 10
Os-e Aje ,~- n
o lr~an \ 1-2
,, lf,:.ran si Obinrin, n
,, lf~ran si 0bin,rill'\ 14
,~ Oruka ijn\tadi \\ lS
,, . Kt oyun le parada kzs0ke lfsodo 16
,, ls~ye · \ 17
,, lriran ;. ' - 18
,, lba \ 19
., Agho lba ·, 20
,, Ti a fi Dgha nlcan 1QW9 cal~ 21
· ,, • ijro. ttsf Ian Obinrin 22
,. La ti fl yan f.f~ 23
,, Aleko 24
,, lf~rn ati ha1'a lS
0 Bi QmQde ba f~ hu e}lin 1 26
,. Ti ara eaia ba wu 27
:, A1,(' si , , 21
-~, AfQran to daju , 29
,v-Jrin -Ajo - 30
;, };:rQ Magun . 31
,, Bi 9mQde ko ba ~QrQ 32
,, l;:rQ Apeta 33
., 1riran 34
,, 1$~gun Qta . 35
,, lnu kikun lt;'B'in ti Obuuin .ba bi1119 36
,, H~-:rt a fi . npc, 0bM»iD pada wa 11 ile 37
,, Eti e~n ·
G>oigbameji . 38
39
., Efu ad:w, ahoa tabi gbQfuog1>9fun 40

I
• . , --
., ,
Oguo . Aj~gun . 41
,, Qfc., ti a ft nle were taro loju oaa 42
., Agada~odo 43
., Qka.ori QmQde 44
" Ti idi enia ba YQ 4S
" QfQ inu rirun 46
., Tapa ati ~dij~i . . 47
,; Aleko 41 /
" ~yQnu awqn agba 49
tt 1$(lfll 50
,, -. OIOD.!D0 'nipa ti OD~ St
· ., •: Aj~ra · 52
·., ~YQlll9fo , 53
,. Afunjo obiDrin 54
,, Amudo 55
., · Olu tumq 56
" Qwo ·· 57
" Ado dua 58
,, Ti a to ~ f~ ki nbinrill • "'1tl- 59
" t:yonu .awon agba 60
,. Ajatuka . 61
,, Afuo~ obinrin 62
" Ti enia ba nja ole ti a to Cttioja,ag 63
,. Olonmo •ririlD · . · 64
-., QCDQtuorio . ·· · 6s·
.. l,ona 66 .
., . ls,ori apc&a 67,
P Uoju_k ndun enia '
.. Qba ffQGU awqa ·A.Jt
·u
69
• Aforan ~jQ · . 70
., Abiw~~ 71
,. Ta a fi npe ~ai to ba dab 72
" Agbo vmQ 9w9 fun ara liJe 7J
., ' Alcokoro
" Ki owo duro IQWQ enia ·
74
7S
" lnarun 76
• Ki ole ma le wo- iJe 77
" IIOri 78
., Awure oni , . . , 79
., Awure ti ft npa ara 80
• QM awme · 81

.;. ,
.;
()gun A wurc ti ao ma ta 82
,. O~c; awure ati eyiti ao ma fi s.a ori 83
" e,Q mQtO 84
,, Oruka tjalcadi 8S-
" uiri QmQde 86
" Aj~ra 87
" Ki ogun ma le ran ni ti a ba tc; m9~ ~8
,. lk.iya fun c;nit•i aiya ~ nja 89
., . A~gbc · 90
,. Ki ~ta ma le ran nl 91
., Ti a ti nti ojo 92-
,, · Ti a·n nwo g~g~ Qrun 93
,. J;.rQ ii; gbona- Baba 94
" · Ki: agbaoa ma ran ni 95
., lli nkan o~u Obinria ba dudu 96
:,, Agbo ela 97
,_ Qk.a ti a ~e fun a boyun tqic; 98
., Ti afi nwo Qka ori fun QmQde 99
" -~da ib\Jc; tabi oro 100
~ Sobia 101
,, Bi obinrin bimQ tan, ti c;Jc; ko tete da 102
•~ A8bo ,Wo'Q.,..jt;wQ 9mQde , 103
" ~okoro omu 104
,,- Kt Obinrin le loyun 105
. Ata-.y~ orok9 awon. ewe- Page 30
Aw.Qn"Odil~..lfa fan snim9 ati W\I Page 31

1 .: •
l AWtJRE IT~JA
Tru, iyQ, esi ilc;:, oyin, ado ti o ba tpbi, ao ft en+~
ao da iyQ si, 10 gun esi ih; yen mQ, ao :wa da omi r~ si,
9yin·ni ao wa fi kc;:hin r~. Ofo re;::- Tru,loni ki omode
ati agba ma ru wa, iyo lo nr ki QmQde ati agba 11n YQ
mQ mi, esi ·n~ lo ni ki. QmQde ati a?:ba ma ti owo QWQ
WQD sin mi, c;:nikan ki fi oyin sc;nu ki o tu, ki tc;>mQde
tagba ma YQ mQ mi, ao so mQ c;:nu Qna ti a ti nt-a 9ja.
2 AWURE
Ado kekere, c;:fun rubutu, osun korojo, ~yin
adi~, ao IQ osun cfon ati c;:yin pQ, ao rQ sinu ado y~n,
ao gh~ poporo ni dede <;nu ado na, ao ma fi de ni
c;:nu, a ko ni j~ki o fuo pup9 ao w::i fi owu -sidi ab~r~,
ao r9ra fi bQ oi eghe kiln, owu na ni ao ma fi. YQ ti a
ba fc; lo, a: ko gbQdQ fi 9w9 lasan yQ. Qfo re;::- e.run
loni ki c;fi oai rere hln mi, osun loni ki c;:fi oni rere sun
mi bQ, c;:nu ni ab~rc;: fi nfa a$Q mc;>ra, c;:nu ni adi~ fi ntun
c;yin re;: ~e, ibi ti mo ba lQ loni yi ki WQn ma fi c;:nu tun
mi $e, ti a ba pc QfQ tan ao .r k.Q si c;nu Qna.
3 AWURE TI A FI NSA ORI
Imi QjQ, c;:yc;: ina ti o ba mo rogodo, e~in~in m~n.
OfQ re;::- Af~ka laiye ~ ina, alaka iye lorun nran C$ill•
$i•n ti ko me;> ni ko ni mQr-a, ti a ba f~ sa ao bu si OWQ
pc;lu pipe QfQ yi, ti a ha pe tan, ao wipe QdQ lagbaja ti
mo nlQ yi, ki o ko mi m9ra,-l~hin na ao ft sa ori.
4 OS~I
AWURE
Aloku atupa fitila ao ji, ijoka adi~, ewe qmini, ao
gun _e..we 9mini yi;n ati ijoka adic;: y<;n PQ p~lu 9$~
c;:gb¢ta I 5k ao te ni ifo ogunda bcde. QfQ r~:• Ogun- .
_da bede QkQ abi9la, ole lonja ki o IQ si ile l9ja•lQja ki

s
o lo gbe owo won wa fun 'mi, ogunda bede QkQ abi9la
igara londa, ti o lo ba mi da WQD ni .iga ra owo, 9111 ki
ire maJoka adif, ire gbc?gbo ni ti Qmini, ire to· nwa
mi bq loni teml-Di, Ire g&ogbo ni ti Qmini, owo to nwa
mi bq loni tani nj, ao ma fi w~~ -
s Q~~ AWURB
-, Igi ekuqkun, lgf Qgbaboje, ijoku Qdan, ao gun
gbogbo re PO (epo.r\' ni ao gun) ~o po mo os~ aladia,
. ao- ko sinu aloku fila. ' QfQ r~:- J;~ kan '$c;,so ni ekun-
:, tun m~. fi ngba oi lQWQ oluw~ri, ·QS~ kan soso ni ijok'! . - ·
Qdan m. u o fi, n,ba 9(1.an lQWQ olQdan, es~ kan foso n1
~gbaboj~ ni to · 6 ·oglN igbo l9w9 oni~bo, ker~k~~ ngo
ma gba alu lo -~~k~re, a fi ba 9kunr10 ko ba de fila.
ni emi lagbaja Ito oi gba owo loni, ao qia .fi w~. _ -_
6 . QSe- AWURB
. Awo ilu dundun, ewe rere, iworofo ejo abotan, .
. ihurihu abo adi~, ao ko gbogbo r~ si . oju oto, aq gun
PQ m9 QK eg~ta ~Sk, __ao t~ i_rftQ osi~ f:li qi og~. ·
Qf9 r~:- Qmo ongua _rentc, 1wo lo n1 k1 nma ,e .'"
· mo, 1119 ni igbati _nko bl ,e ise ·mo nk~, mo ni igbe oko
a
base iK, bawo iii .11go sc owo, o ni _rerc a ma re owo -.
wa fun mi, origun rente QOlO oba ilu ti. won nki, iwo to
-ni ki nm&.~ i$~ mo, se ~a ni aso? iwo lo ni -abot1n ni _
ejo ibo iworofo Di fi j.o lu igbo; olugun rentc QtnO oba -
ilu ti wonki, o oi loni ki oina se i~~ mo, mo ni -igbati
,e
nko ba it~ mQ nko, mo ni $C ma ni aya? o ni p~ki ni
onijo nko onilu, g~ng~ ni WQD gbe QWQ ljo, olugun re-
.·ote iWQ lo Di ki om• ~c is~ mo, mo ni nigbati oko ba
$C if~ 1119 okQ,,e Im.. ~e oh~n rcrc? o r,i ojumQ ~i mo
)uateguo ki o ma· ff'de 9ja, obuo. rcrc -ka$ai t~mi l9run-

.
chun rere, bi adi~ ba suDkwi iy~ ijiurihu abo, ao ma 6
_we pe1u boru+an_tituo. ·
-~ -
.
7 QM.~ · AWURE
0.se dudu, abe·•di>e ti o.ba ti npa Qrnr:,. obi ab:ita
m~ik--.'llbii woo ha ·nri ka ni Qd9dun, odidi 9ga ·
· kaQ,--cw.e iroko, • - gu.a -g•~-eo r.e .pQ, ao po m~ (1st;~ ~
. · yen, a().,.pa adi~-,en ·a.e da ~~ r~ si, ~niti yio ba to ko 1
ni k : nioa-adi~ .qa, ao ma- fi Q$~ n,1 w~ p~lu kaorinkan
titun, ae -~o -~inq igba QlQmQri, a ko ni j~de ·JQ si_ ibi
kaokao DI QJQ ti a ba lo Q$~ . y1 . QfQ · r~:- lgba omgba ·
awo alawo ni ~oko fi iic;,fe, ki owo o1owo o di ti e-nti
looi,. ki ,Qre QIQre o di ti ·emi loni, ori igi ata ki da sut1 ·
QmQ nigbaka11., ki oaq, mase da m QWQ mi, aba ti ala•
g~mQ ba da oi erisa oke igba, il~l~ ni ao ti po Q~~ }'i.
8 AWURE Tl ENIA FI MA N\'UtJ OHINRIN
lrun ori afi.n., on
akQ Q~re, · e·we iroko,.,, kun ab~
obiorin, ao j0 _g~o r~ po; ao po mQ Q~e, ao ma i
we. Qf9 r~:- fin'8 ni- Ia--fia to nfi ara r~ fun ori~a.
· eyin obinrio e wa fi ~a yi0c fun ~i, gbogbo igr ni o
ndari jQ jin igi irdko, ~a fi ohm.l gbogbo jin mi, t;n.u
Qk~re ni Qk~r~ fi npe-,Qct'" ma, c; fi ~nu yin pe mi, kl '
ma f~ mi> tfru· rvmq 1!i ~~ ·
-~ AWU~E AJ,-E
fr~ ~yin kaa. to PQ11 dad-a., afopina, ~ni agemQ, ao
jo gbogbo r~ pQ, ao lq In() tiro, ac ma le si oju. ()fQ
~~=-- .
Bi Q:Pfr ba pgn ~ a $iju wo, o~o ile. aje it.e ati
~ufa ~ ~iju r~r.e wo mr, a ki ri al~em9 Jqja ki a wo
ori~ mil,'3n, afopi oa ki rina ~ju ~bo aiye, ~ ma ii
owo QWO yin fy mi. .
10 -~ AWU~- ll~ ori atan,
~le- lutt~ .ldif ftmfun, ori ologbo, fitila itanna,
' 1
.
ii" oja ti o ba nkun dad■, aloku fila, il<t oju Qllk odo ti
Jbog~o enia ma nl9,. pon, i~~ ifa, ep_o_ ~ru, a~e~e, ewe
· 1gt,Qy1n, Q$Ct .kQbQ ~wa, obi din, obi 1pa, od1d1 atare
bn, ikod~, iyc; aluko, imi alangba, ao gun gbogbo ~
pq mo Q$~, ao ko sinu fitila, ao wa gbe sinu. fila aloku
.. y~, a'9 funfun yen ni ao fi da apo fun. QfQ r~:- Itun
lb :~i ~i oto .ara iwaju, igb9yin lo n,i ti niere to nbQ l~-
~~, 'lri olod ni fill de, ojumQ ki m9. ki ·atali ti. o ma
aha ore, onilc eti. oi.a bi te•r.e a_dan, ojumQ ki m9 'ki ala:
ng~ ma sun- om1 &JC, lQJQ ti ma ba kan ~tu Dl gba ti
9fQ "'1~, ao da c;tu _ihQn na si oju QIQ, ao $8 iDa si, ti
q ba JO tan, uo da smu Q$~ na, ao qia fi we;.
11 0$e AWURE
twe i<lin, ~ru alamQ, a~Q waji dudu, odidi igbin to
ba gb()nu kan, igba 9l9m'9ri, ao gun ewe idin ati ~ru
~ mQ Q$Ct oni 15k, ao m? igbin y~n · ao. _da oju r~ de
a·gba ao k"o Q$Ct y~ le lc;hm, ao fi 3$Q waJ1 ho Q$e y~,
aoJi qmQri igba yen .de, ao ma fi w~. QfQ ~:- Ewe
~in lo ni'ki ~ ma di owo nlanla wa fun mi, ~ru lo ni ki
" ma ru owo nlanla wa fun mi, lodidi lodidi ni olugbo .
nfiigbt to~ fun ero Qna, bi oru bi oru ni $C &la$Q
. dupu, ao ma fi w~ p1rlu kanrinkan titun. . ·
12 OGUN IFSRAN
I
Qfo:- 4kere jaiye, arin ihoho woja, QmQ titun.
a~i~:loju, agba ki sun loja ki o ma ni irqri, bi lagbaja
.1,a s~n emi ni ki o ma ri ki o ma le sun ki o ma le
w<> bi ti akQ pq,~iyt;, p1rlu atare meje lynu, ao tu si ibi
ti ig~na ba ti la ~nu.
13 · OGUN IF.l;RAN SI OBINRlM
Labalaba ,{ll~ta ~ trYQ •dare 3, ibi ti .obinrin
,ua ~ tQ si, ao 19.pQ, ao fi sin gb~rt; m$ta si okan aiya

8
; q

Of9 r~:- Tinu t~hin ni ~al?a fi nhan 0101'-µn~ ti


obn;1r10 ha to~ ti obc(haol~g.b&)gbo ohuft do •ba wa
ninu l11g;haja ki o fi han dJi.i lagbaja. 11

14 IFF;RAN SI . OBINRlN
.,.
•Alaw~ obi abat~ kan:, t;f0 atare rneji, ao ;'e lenu
ao tu $i oju gilasi titun, ao ym bi ro~ ti o ba gb~· tao,
ao gbe si oju. · Qfq rt;:• Labalaba-$ubu y~g~ke, awo:ll
, oke a mu mo ni agbara ijakadi, lodifa fun olejujugbe,
olejujugbe sun·nj ile o ti oju tao irahuo igbe Iatan, mo
di Qr~ -loni, iwQ bigb~ja qmo, lagbaja~ ti o ba suri ki o
ma ri mi o. · · i i

. Erupe ~ csi ohinrio, ao bo eyi d 01:~ nib~~.erup~


idi amu di,;, erup~ -ibi ti adio ba G\a Siit tY9lLJitare
Io
meje, ao pQ, ati sin g~rt ~tai d ok:m aiya. .•
Ewe alup~i~a meie ti ~P lu, 9kf atate kan.i:\'ao jo
pQ, ao ~uo ob~nn na j~. i.
l;kanna QWQ ad tc;s;, in,n iwaju od atl ,li ipakQ,
ewe--amunimuye,. odi<li atare. kart., ~,!Ged~ kan, itQ ati
igbf;o)VUfq~ ewe ina ao jop9>_ao·fWt obimin na j~.
I'S ORUKA IJAKAD.I
O~e dudu, ~1ubQSa ele~ ict111 ~ otogbo dudu
d lto ni eme, oruka meii, ~tare xnete. ao guo ,o, ao $U
jo· 11>J?11du, a fi oruka ~ bQ~ ao .fi aso ekisa, we. ao
wa ti ha a&opa fun oio mejc, o di lilo !~hill 9Jo meje.
16 K~ OYUN LE PARADA LQSOULQSODO
Ewe~.~----~
I'& •led_. P'i
tu,.ewe Q~i;plnlt,ao,oW(tD
GIDiU•
19,
milllll Di 9,si kQkan. ·
9
l7 OGUN ISQYE
• .A~~~ w~w~, mariwo _Q~, ori dwtc ilc,
qt9 atare kan, ~gun esusu~. ao lQ PQ, ao ma · • fq' ~Q
tutu mu larar9 •
•~ Q 9gQdc; w~, $OD$_o,~ .. mariy.,o . , oiidi
••~ bu, wun ~,.,t> fi ~a 0J1J1 K m..9~ ~-
- Ori awoko, -ewe oniyes9ye, ~on~ ori ()18.D, ori
ikun, kulUSQ ~ n , ojnSQ ~Q m~sail, ao jo gbogbo rfr
p,q, ti o ba tutu ao t~ ni 9bara meji. QfQ r~- llrun .
nUi agbari -~ ile, k~l~bCt ni fi QDQfun ~odo, okiti ban-
\ ha WQn a SQ $~U~~u QP~ jQ rigidi, wa fi inu QmQ awo
joko si, Qbara nikosi 1fa QmQ alade, ma ma ko mi niyc
tqm 19 o Qbara nikosi, ao· fi sin g~r~ si aiya, Qkunrin
f ~ Obinrin 7 meje.
18 OGUN IRIR.AN
. Eso werepe_ mej~ioa i~~..Q'(}~ meje, ao 1i
om1 lo PQ, ao sin 1111 ib'~r~ s1 OJU1 ~ .
Ori eku asin, ewe alupaida,. ~ - e ~ ao jo
pq, ao fi sin gb~r1r si oju mejeji. ~ ·
· ~iD$in ti o nfo ni oru meje_ ~O atare kan, ao JO
pQ, ao fi sin gb~r~ si oju mejeji.
19 OGUN IBA
I~~ dudu ao be, iru, alubQsa elewe, iy9 kanhun
4;,jlala, ata tutu, ao gun p9, ao ma fi mu ~kQ gbigbona.
¥1$L bus_
Q~~ agbagba dudu, at.a dudu, iy9. fflmD hilala,
cgbo tudc, ao gun pQ, ao ma i ~
'20 BO lBA
Epoigianu ~ w~w~
b,q oapi tutu · inu igba ta

-.
27 OGUN TI ARA ENIA BA WU
Eg.bo igbQil; cpo amuj~, i~an Q~, QkQ atate kan,
ao IQ pQ, ao ma ti pa ibiti o ba wu.

28 OGUN ATQSI
);pa ikun, odidi hara kan, ~ru di¢, akQ kanhun,
C!liie baba di~, ~mu ni ao fi da
agbo re ao gbe pamQ di
qjf k~ta., l~hin QjQ k~ta ni ao ma YQ mu o daju.
29 · OGUN AFORAN TO DAJU
Eku asin kan, t:YQ atare 200, ewe afoforo 200,
orq~ 200, ao jo pQ, ao ma la di~di~. QfQ r~:- Jeku-
jeku ki roju j~ igba asin, jatajata ki roju j~ igba a tare,
j e ~ k j roju je igba obi, aj~ ki roju raye jt; igba
c,iogbo, Qmode ki rcju je igba ewe aforofo, ki Qta ma
roju 1e mi ni ibi.
30 QGUN IRIN AJO
Ao tQ ika meji si oju Qna. QfQ r~:- Aft;f~ lt;IQ
~ ej,a qrun lt;j~l~ie, ffufu l~l~ ~e oju Qrun lffun lc;fun,
~~ ejika, on ni ko ;~ ki (;wu o bQ, t;ka ki o ka
ibi kuro loju 9na fun mi, ~ufu l~lt; ki o gbe ibi kuro
-tori mi, ao ti ~s~ osi par~, ao ma IQ bi a ba WQ mQto
ko si ewu.

31 OGJJN .t:RQ MAGUN


_ lfup ·aja,_ ~YQ aiare 2tk>, ewe ailu .~00, (?b~ pupa
• ebifunfun 200, ao gun PQ, ao ko. smu 1fun aJa,
.•
'
• g~, ao fi ran onde ao ma fi si idi.
'

Ewe ailu mt;s:in/~pQn akukQ adi~,,r~yQ 'ltare mo-


sao, ao IQ p9, ao sin ni gb~r" yika idi; o d&ju. ···
-
-12 ~ - " t
32 · OGUN Bl QMQDE KO ~BA SQ~
Ori ~id~~ yran QW~_wa,. e~e ~la, ao da nht3l,o;ut
ma fun Qm9de na mu, y10 s1 SQrQ. .
33 OGUN I;RQ APETA
Eglllngun ori oku enia, ~tu ibQn, ~YQ atan ·mei~
ao IQ pQ, ao sin ni gb~ry kan si iwaju , ori ati i~ 9w9~ .'
aJro Di sin .;u ara WQD IQ.
34 OGUN IRlRA~ ~·
•-I' ' •• • • .

A~ dij12 IQ ja po ido, ao dij1:' ~ro -1i~, a ~ gbqt


do la OJU rara, ao fl (;YQ at~re meJc s1~ ao lQ p9,· •o ·Ii
sin g~r; kQkao si i ~ oju mejej~ ·· ·

35 OGUN !$GUN QTA


E5'> a g ~ kan, .,. tr f;YQ stare kan si, ao IQ
PQ, a-0 sita Bi gbe~ kan s(~tari, ao fi omi 9mu pa oju.
a~ ti a ti sui ~ na. ::/.
36 OGUN INU . KlKUN L~HIN Tl
OBINRIN BA BIMQ
];yQ atare pupQ, ao IQ, ao da sinu Qti oyiqbo .~abi
V,ti ibil~, Id obinrin nt ·ma n:w ni ~ibi ~n, l~m~ta::'lc,:
jo;uDlQ, k.i o to ~

37 OGUN IFS TI A Fl NPB OBINR!N . .


PADA WA SI ILE
Ar,:1l i ~ osun t~ ifa eji ogb~ si era giia&t, fO)i\
. wo oju t~~ta ki a to tf; ifa na. QfQ r~:- Arue ~&
. ~ elugbe. ori~a dudu adamQniji lQgan;jQ,.Gl~~ 9m9..
do ba wo digi lo ba ~l~da ro pade, 1ti lagt)aja ma Ii ·
~ Id@ ~-a le wo,-ao gbe si oJ.,e ~ni mQiff) oh1nrin oa
p,fi ~ na ma la a~ yio si pada wa si le.
m OGUN ETI DIDUN
~tu!" pupq, owu ~Ko so jo PQ, aoa omi po-
~ 31, ao po mo adin, so ma km si cti. ~
st OGUN ONIGBA MEJI
mwina QWQ ati ti ~~ ~;ti anm na ba nb3 ;-. ao
lo P9P ao fi oje l8palapa ati ,"9·po pq, ol1an re, yio
um.a 1a di¢i~, ·
m ujg, ao m-m9W9, ao fim $i oluwa Sit lpu
40 OGUN EFU ADV AHQN TABI
GBVFUNGBQFUN
l!po ·atqma ~ ei,o iai a odo 9gan, ao da li
,IJ)o~·ao-may9muluQ~
tt . OGUN i~JUIGUN
$ml$oD 9rt~wo Qt>J,, miqjo pupa, owe, 9ga me-
tril& so fl ()mt) atiarc meje sit \ltQD• pin aw9n nl;qn m.
·
I i ~ aQ,- J~, ao sin QW9 ~-r, ao tun lo ti .qpm;
m pdu afA,re m.~, ao fi sin qtms 9w9 osi yika.
G QFQ "II AFI NL.a WERE IWIW
LOJU QNA
AniEwm WQja, srin ihoho woja, iruk~~ ni lrao
~ ~ nk, fQtun ja fosi ja, l9na ki am ·lag. ·"
db.\ lo» yio si kuro l9na. ·
.
AGADAGODO
E• amummuyc, ~ho bn, odidi awe
~ 9· · edaripqu, ao jo pQ, owu dudu ati
14.... •-....
~
owu funfun Di as- ti we ki a to ran ni aw9 iki mQ aga-
dagodo. QfQ ~;- Ni QjQ ti a ba j~ ata ni ta ni ~DU,·
ni QjQ ti a ba da aro dudu ni jade, ~Y~ k4i7t ki. ikc m
bori ti awQn ai~, orogbo ki ikqbpn Qf9, awu 4ut)a ~
ln funfun ki ijara WQn Di po, ab~~ id ikQhuft · ~
.~gadagodo ma kQhWl .J211,. lfJliJf ti a ba s9 ohwi ti a ~
00~~~ . .
44 OGUN Q!CA ORI QMQDE
Gaga ~ni ti a fi man bi merin, ao jo, ao da sia11
adin e,an, ao po PQ, ao ma kan si ori Q-mQ na, ko Di
YQ QmQ na lenu, ti o ba tao ti k-0 ba ti lQ ao $C omiran
45 .OGUN Tl IDI ENIA BA YQ
,ewa, iran idi ijapa, •~9 waji, ao jo ~ ao bu si
iou owu etutu, ao ma fi bQ idi, yio w9te kiakia.
Eso ori, odidi atare kan, ao jo PQ, ao ma fi si .
mu o~ ao ma fi. bQ idi n~, ao si fi a$Q bo m9. ·
46 QFQ INU RIRUN
A.la~~ iau, ~dQ girl, t~fun mQlt; QtukQ ti a- upe
iw9 inu rirun, ki o ti Q.IDQ 9lQmQ sil~ ~i o ma Jo,.ao j~
atare m~rindinlogl,lll f 6 f u-n, ki-, ;i. tQ ,P(? QfQ t,n..
47 .. ~ N TAPA Al;t J~DIJ~l:)l . ,.

w~ niy9 s~ ao maii eq ~(>tutp mu.. ·


i~•-~··
Alubqga el~ efinrin., 'lt'Wllfo, ao gbo, ao• ,...
Q~a,bagt. d~u('ao ,;un ti yio 1~
_, ~,_::
18 1'GDN , ALJ;KO fl~
Odidi_4il~si«di~ ti O. b• ~-- t\\'e t.k... ~ •
191>9 juga, aot}o ak kQ a~ f~ ~., ewe ltdlf "'
ao JQ $Uga. mQ, r..J ma ft'~,~~iltltu m-..tafl.1Wlt1

15
;
49 J;YQNV AWQN AGBA
. Afara oyin, ewe ~ , ,ewe agbayun~ odidi atare
bn, ao jo PQ, ao :lg ,suga mQ, ao ma bu si QWQ ao ma
la, ao ma fi omi sin.
50 OGUN ISQRA
Ewe olobi sowo tabi ~hin olobe, c;ran fhin a-gu-
tan, '3.WQ ilu ile ogboni ti ,o ba ti ya, iru, iyere, ao se ·ni
9bc;, ao gun awQ y<;n, ao lQ gbogbo nkan w9n ·yi ki a
to se petu c;ran yen; iy~ru osun ao t~ ni eji ogbe ao da
sina Qbc;, ao wa po P\). QfQ r~:- Akiilro a"~aro, Qpa-
rabata awQn m~teta parapQ WQD IQ pa eran alubQsa j«t
ni ile._, alapa ngbapa, ~•~s~ ngb~s~, olori ngbori,
Qrunmila nt ki WQD o fi ~hin r~ sile fun mi, WQn ni
iwo Qrunmila, WQD ni ki lo ti ri to fi j«t pe ~hin ~ra&.
ni iwQ f<: je riinu ~ran to pQ to bayi? Qrunmila ni ma
gbehin, ~hin ni lobi-sowo nso owo si, o ni ~hin ni
ab_iyamQ npQn QmQ si, o ni magb~hin-magb~hin ni Qpa.
iledi ma ndun, o ni gbogbo ~ni to ba nperi mi ni ibi
emi ni ngo g~hin V.'QD, ~kan~o ni ao j~.
51 OGUN OLQ~MQ NIPA TI ONJJ;
Ikod~ kan, QmQle kan,~yQ' a tare m~san, ao ti iko•
d~ y~n bo Qmole l<:nu, ao jo gbogbo ~ pQ ~hl. ewe
aro kan, ao fi sin gb~r~~-
kQbn si isal~ oju mej~ ' . _
QpQIQpQ ijalQ; ifod~ kan~ odidi atare kan.4'tlu
ewe papasan;ao jo po, ao ti sill Rb~r~ yi .'ofun QWQ
owa~ ti o ba j~ 9m9de, ao sin si Qrun 9WQ ~eji. ' 1 •· ...

52 OGUN AJ~
E1tur9 ayQrunbQ1 odidi atare kan, owu bolnubo•
a.nu, ao jo pQ, ao rQ sinu ado, ao ma la di1,di9. -
16
53
- Igi_ ipanada, a"$«?$~ ¥Q <?V?Uj ao !q:-~J.bo·f9- pa,_ at?
lQ epo 1g1 yen, ao fi cruka mn m:~ta tab1, m~nn - sf, ao
:d igi lean m<;>l~, ao la ~nu igi y~o, ao ·fi orub Jljn ba
ni ~nu di QjQ keje, h;hln QjQ keje, ao ma fi si QWQ. -

Jy~ agbe, etu i©Qn, ao mu iy~ ns eti ~tu ibQn ff9


ao mu lQSi oko, ni ibi ti awQn erun ba PQ si, ti a ba
de ib~, ao ko oruka y~a, ao ma SQ si ori WQn ni kQkan,
ti o ba j~ pe m<trin ni p~lu iy~ agbe y~n, ao wa ~a ina ·
si, ao ma fi oju ~Q oruka y~n, eyi ·ti o ba nfo cihjD
SQhun ni ao mu, ao ma fi si QWQ. _ · _

54 OGUN AFUNJe OBINRIN


· J;ja arQ kan, ar~m Qp~, ao IQ aran QP~ y~n ku..
na dada, ao da sinu i~sun·; ao ·lQ iru ati ata si, ao se-,
.ao te ni ifa eji ogbe ~i. Qfo r~:- Qgan dudu. ni ~wo
w1m h>de ibini, ar9 igede· ni $awo WQQ 1,1i alede if~, lo ·
difa fun iku-fylaji, WQD ni iku f9laji WQn ni WQil f~
!!ha aya I'~, emi ni wQn ko le gba aya mi, wQn ni nit9- /
ri kini? mo ni wQn ki ri aran QP~ lori _igi miran. ibi -. ti 1
ori -~ja ba gba ni iru r~ gba, so da iyc;ru osun si, ao jq- o
jy p~lu iyawo wa na (ori ry nikan ni ao jQ jc;) , obimm
ni 'yio j~ cyi ti o ku. ·
~ ~ .
55 OGUN AMUDO
Ewe QgbQ m~ts, ewe apada mvta, odidi _qga kan
omi .toromim, ao jo PQ, ao po mo Q$Cr oni ,ltQb9 m~wg, ·
aoJco sinu 8$Q funfun, ao so kQ si arin ile~ ti a ba f~lo
a'O·,pu di~ -ninu Q$~ yi ao bQ-si QWQ, ao 4,arukQ obin:dn
tia·fc;·lo fun si, ao fi-w~-QWQ.~ejejj,_ QfQ ~:~-, · _,.-··-
QgbQ ni o Di ki ogbQ temi loni, apada ~fo:ni~kio ma:pa _

_::?-"··
17
OGON OLU-TUMQ
_.Jrawc igbo 200, irawe Qdan 200, mariwo Qpe 200,
Bto otoro 200, ffl a1are ~ ao jo gbogbo ~ ~, ao
" m. ~i.4>gbe. QfQ r~:.. Igm1 ira-we igbo ki 1gbimQ
liilas, iglia ira~e Qdan ki igbimq- aitu, igba mariwo QPt
ti igbi~ aim,. n;e lo ma tu ti gbogbo cnia ma mQ ni
lmQ-, l\9dlQdC tagba lri rojo ta igba koko oloro, ao ma
fi fQ ~1r9· mtu mu. Ti w911 ba SQrQ enia l~hin W\>n yio
funra W9D }Va SQ fun ~- ·
OGON QWO
.lki9. aac, ~ sese, iyere, iru, ihu,:ihu igba aiya
-G!m~ pd~ "°
tu ihuribu adi~ y~o, ao sq wipe ki
~ - p f.l da lu wa, ibiltibi ti a~gun ba g~ kini y~n
IQ.,~ 19 p m~, ao l\l, ao fi se eku y,;o jq.
58 OGUN Al>O DUN
~ aluke~ ei1e agbayun, ewe ewq. . · · olo-
g&o, ab ~ ototo igbin fun awqn -9m¢e pe ti -wqn o
ma u titi di 9j9 keje, a ko ni jt;ki o fQ, iou. ~ ni ao ~
si, no lQ gbogbo ewe y~n pQ, a_o fi oyin ~ pg, ao ko
sinu ~.koto y,:n, ao ma fi pa 0kb, ti ba f~ ba obinrin
SUD..
ni ib11, ao- fl pa o'ffo w~, Qkunrlii · ~ ,'kt) Uile ~

a~-
obm.rin!ll2~mQ -
• -~YQNU AWQN ~
• ·Aii,lm. oyir.'3, ewe misio;;.misin,.~ orlfis; ~e-
ida, _ao Jo po, ao le;> $Uga oar 5k nfQ, · ~b ml· ·ta.
QfQ r~:- Aiye mi yio dun ju ti· anQ. IQ, <lidun diJll9
ki tan lam oyin, didun didun ki tali -rara ewe oju- ok,,,i
gbo, oriji lo ni ki ~ fl ori g'bogbo·oh1li! th1ro ~a ~ jla
mi: alupaida Joni ki v pa oju bubum -da Dim ~
~ h9 oju rere si mi
61 OGUN AJATUKA.
Akokoro ori c;tu ao g(!. si •nt~ ~ a p ~ t t
ara igi, odidi atare kan, ao yin, ao Ito. sinu. ap~ ao ~
gbogbo r~ PQ, ti a ha jo tan, ao f4 · iw&ura ineli- Qtlj
r~:- Olutumo, ~tu n i tumQ C\lu igbo, lti i~ 13ghaia
ati lagbaja o tu, agunmQna ki iba igi oko wci ~ , ·otu,..
ra meji iwQ lo tu ile alara, iwg 1o· tu ile ajeto, iWQ lo
tu ijc orangun iia, ki ~ ba mi tu imo, .Jagbaia at{ hte;~
ja, ao t~ $f &t~ewQ, ao . pe QfQ y~o, ao· f1r danu. ·
62 OGUN AFUNJij - OBINRIN .
i~ l~,m, iy~ kanakana, ffll ;m.i, ewe ~ _ ',~!11;·
~ ·:i~ yen nj ao fi pa ~k, ~n, ao jo @i~o !ip
~- m tfa ika ~"'jt. Qf9 ro:- A •a~ ~
o $QI r-; ndan jere je~\! bi iJ. ·_,~a_ .. f@
~ QDS ode, a-so r~ ndan Jere 1 1 2lad1~ kt ,di
~ Wit
.fa fun ika, ml QjQ ti Wt,'ln ni li!i O ra ila i m
• ma $ ' aa ni f;fU, ila ni i o: rs ~ , . :mi bi 0
· ! ~ , WQD ni yio sn !Q, c, Di 1i o ba ltur-o ~
cn, Jio:ba ~.o ni ti o ba sa o ni on yit, ba. ·Ba!>1 m~
· 'l' iDi aparo ku ai, ila · o , iJ'
. o,b ., l ti .

19
63 OGUN Tl ENIA BA NJA OLE TI A
KO Fe Kl O JA ·Mo
QwQ iki mejeji, odidi atare kaa, f!O jo P<a ao po
mQ ori,.aQ gbe. fun c;niti o njale y~n, yio ma n. -pa· oju
ati ara, oluwa re; ko ni ja ole m9

64 OLONMQ IRIRAN
· I~u c;lu kekere ti-aw90 alaro fi ~da aro, eromo
adic; ti WQD ba ~c;$~ bi; ik.od~ kan, ao ti ikocl~ ,~n ))Q
,nu adic; Y\111, _a o fi oruka irin bQ ni Qrun, a~ Ja _i~u ~hi
y~n si meji, a<> fi adi~ y~n si inu re; ao we ni owu dud..
ati owu- fui:ifun, ao tI aw akisa. di, ao ·ri ~i oj~~Qna'. ti
em ba ngba k9ja fun QjQ ,meje, ao ma fi si,Qwq:
65 OGUN QMQKUNRIN
Egun ~kun, aw9 ~kun, odidi akQ eku- ~da, jru,
iycre, a~ IQ gbogbo- r~ pQ, ?o.:..se fun obinrin na j~, ~i
oyun ba.di O$U meta, lati,_ori ni -yio ti bt;r~ si j~ ek~: na
titi yfo. fi~j~ tan Tj. eiiia·· ba f~ bi Qkunrin ni o · wa f'wx.
66 OGUN ISQRA
Ajaku kata, Qpa ti WQD fi sin okete, Qpa ~a, i~ idi
C$U, ~ha il~kun oju Qna, awo agba ilu iledi, ewe lebi•
sowo, Qja ti WQD fi npQn QmQ, ao J?e di~ nibc;, .so gun
gbo~o re po mQ QSt;, a ko sinu ikarahun igbio. Ofq re:-
iO tf .ifa eJi ogbe p~lu iy~ru osun; Qpa eku ni r~hin
eku, qpa okcte ni rehin okete, Qpa ~ja ni r~hin ~ja, ile-
·.kuil Qn& ni r~hiq bale, agba iledi ni ~bin iwar~fa.. lehia
I1rhin ni lobi sowo nso owo si, ikarahun .igbin ni r~hio
. igbin, igbaj-a ni r~hin abiyamo, nj~ gbogbo ~ni ti o ba
pe ori •Qli nibi, emi ni ki n~ n;hin gbogbo WQD,
_ ~i ~ - ~ baba ifa, ko ma gbe mi leke WQD, fi fi w~.

20~
67 OGUN ISQRI APBTA ,
Jt;bin kan, ao bQ lori ina, ao YQ ao fi i~~ si.,
ti o· ba jc; pc obinrio. 7 ni ao re; si, ti o ba j~ 9.kdl
'"'oji~ 9,
ao ~- iyc;ru osun ni odu 9yeku meji. QiQ' .ret-. A ft.
odidi tori odidi oruko ti npe iku11 a jQ odidi 10n: odi-
di nforukQ ti a npe qu odara, ajehun odiyo barabara
orJkq ti a npe ilr; Qgc;~ afi QkQ y~ri, nie ti w9n ba pe
mi Di aiye ta WQD ba pe mi lQrun ma j~ki njc;, 1\!Jiin ti a
ba pe QfQ yc;n tan, Ao da Qb\' y;n silQ, ao jc; Di ihoho
ni 11~1~, ao fi ahan la ilt i~. _

68 OGUN TI OJU BA NDUN B~IA}


,. .. ·
Oju Qka mejeji, ao 19 m9 tiro, ao-ina le· si oju-

69 QBA SYQNU AWQN A}&.


ijiy~ ,ga, ~yin adic; meta, ewe ld lo ma fi. mi· · $.C,
ewe mafi QWQ kan QmQ mi, ewe itana po~o efl;botuj~
odidi atare kan, ao ¥Q frYQ QmQ kan $Qnu.niqU:~;JWe
QYQ, ~ru a)am9, ao JO gbogbo r~ pQ. ao ra gdas1 ·t1tutt
eyi ti o tobi, ao gbe sil<t gbogbo enia yio ma fi •wo oju
fun igba die;, ao gba ni QWQ WQD, oju gilasi ni -~ ao ma
ko kini yc;n si ti a ba f~ lo, ao t~ kini ~o ni _ogunda
ni QWQ osi, eji ogbe ni QWQ Qtun, Qg~dc; qminirl ao ti
ko j~ ni oju gilasi yc;n. QfQ r~ :- ArQd~d~ ni oruk9
ti a npe ifa, o fun won lli om9 adi\, sin gba ~ · ewur~
ni 9w9 WQn ni orukQ ti a npe ~yitt iya mi bi ~
ba mu digi a pe ni digi, bi agba ba mu digi a pe ni
di~~ digilo ni ki c; lioti ~~gbo ~n !'.i ,oo- ba-~ jin
uu~ ao ma 6 ogc;d,; 9mun y~n ko JO p a ~ ~ po,9f9-
,~ ian.

21
1
OOUN AF9RA.N J;JQ
~-pmju ·mttin, awo funfun ti ko n'i dudn ni'nu,;
~ @'iy9\ao.mu obi y~n?-o t? s! eti awoJ y~ aQ;
w-.,_6 epo s1 adn r-~, ao bu lYQ du~ s1, ao fi QWQ l'O,pQ,
ao·~illu obi_y.~n ni ikQkaD ao·ma pe QfQ si~<> Plll-W.,
Qfo qt- ·ii~~ n~e, i$e. mi ni ~, $t;~~ WQQ. ni ·kHp, ~-
K n\ ~~ta, i$e ~~fr w9n ni ki ipa ;;t;$~, a ki n a~ jy
epo emi ni mo fi k, QlQmQ ajiki ni orukQ ti a ·np.e ffiBi.
Q!QiBQttJila ni orukQ ti a_npe orcn ajila, e$i~-n a fi ~~
mqni fi QWQ ba ni, bi olor1$cl ·ba mu obi t-.; si idi ~
ti e;rau obi ni w9n ngbQ, WQO. ki igb9· ohuo ori~, .emi
ni obi, ~nj, ti mo nba ro ~jQ ni ori~a, gbogbo nkan ti
mo ba ns9 m!ti WQV. 0 ma gbQ, ki WQO. o ma gbQ tu'y

QwQ titun 40, e ~ i~nt osun 20, ao di lllQ idi


QWQ yt;o, ao -6 owu dudu ati funfun di, ti a -ba f~
9fwi Di ao ft saa, ao ie ,ao tu itQ re; si idi QWQ ,Y~Q, aQ
•da mukQ awon ti.nba ni $C ~jQ y~n si, ~wa SQ~
W. enu WQll ki o ma 1:o ·~nu, ogun ewe, ojj Q"~,~i! la·
gbaia ti o ba lQWQ mnu QrQ yi, ki enu wgn ti fl); nm .!to
;nu, Jn QrQ w9n ki o yatc;, si ara ~u ati ada'j9 w9~ Di
~• ~ 91~ w911 .ni !J, er;ni. l?i ki njy:~f~n ni i\,i '9fQ~ yi~
~,~ OSll'1 iwe ru :J!i~·ba nu suu 9r9 Yi mQ a99, ~m~
' .

.. .;,. ~-.
Jgi ti o ha wo si ~ba Qna, ao ha oju Qgb~ il,i· ti
won ti P. ao ha ti yiQ pQ ao ra iru, iyere ati at~re ao jo
~; ti o ba tutu dada, ao bu ytu ibc;m si QWQ, ao tt; ni
cjt ~ ao da oruko c;ni ti a f~ pade ati a wQn ti Qr-
ba bl. QfQ ~:- Were were ni a nsQr~ ower~ were
were Di a uqro uu, atewe atagba m.daw9 j9 iii iy, 'W
2?
igi ~ba Qna, ki lagbaja QtnQ lagbaja ati gbogbo awQn ti
wQn ba jQ lQWQ ninu QrQ yi, ki wqu o i~ iya bo ni ibi
ti a nlo yi, ki WQn o wiya l9w9 adajQ, ki: won o jc; iya
,JQW9' olQpa, ki WQD o j~ iya lQWQ Obinrin, Id WQn o jQ
1 ·;iya l9w9 QmQde ati agba, eji ogbe lo ni ki 9r9 yi o fc;

danu; ki ~~ ki o ma SQ mg, ao f~ danu. "

71 OGUN ABIWS~
lg~ ewurCt ti o ba s~~~ ya-, igbe agutan ti o ba s~-
~~ r., itanna ila, itana
ikan-igba, e af90, Q~t; alad in
om l 5k, ao gun gbogbo r~ pQ, obmrm na yio ma fi fQ
idi ti oyun ba di 9su mt;san.

72 OGU Tl A. FI NPE .. "' T TO BA DAKU


A.,) J~ orogbo an ni ~llll a <la orukQ ~ni ti o
li ·en ~l. -orQ Iy.- l >un un ku O fi QWQ rori,
tete u o h ere: r~ c~e) o dJ . nni wanwa ti n~ ei
r~gbi;i · rn kt ya ik .. , u a ba tir9 1Q, ao f t
da oru-~, ~m tJ o a d<1 kt ;)er~ SQ, alaja Di
lti Qk~ famr; ao wa tu.-,.1 , 11 , yi soji ni kiakia.

AGBO QMQ OWQ FUN ARA LILE


Epo ig1 iyeye, epo igi aidan, epo igi oko eran,
gbo Qkan, alUbQsa elewe, e... u, ao fi omu se WQn pq,
mu fun om~de.

OGUN AKOKORO
o'· i orombo lakutc,
~na
75 . OGUN KI OWO .
~URO LQWQ ENIA
. ·. E~~ c;.m_Q~ ~ku- ~Q~ iru, iyerc, epo pupa-. di,;,.::iYC1--,
di~, .a.o-!Q,itu, iyete--ati ewe i;m9 y~n pQ, ao fi Se. eku
,mQ y~n j~. · · · ·

76 OGUN INARUN
Ip~ta i~igun, egbo gbogbon$e~ inabiri, kanhun dif;,
iru, iyQ, alubosa elewe, ao gun gbogbo ry pQ, ao ma ft
mu ~kQ gbigbona ni arar9, o daju. .

77 OGUN KI OLE MA LE WQ _ILE


Egb.!c,,itQn,. olu· otirlpa, ao r~ w~w~ ·sinu igo, ao bu
omi :si, ao·ri si~.uu 9na abaw9le tabi ~nu 9na oko..

Obi .ifin •o-tfsi 9na 201, ~Q at!3~e 20t, obi p~pa.


201., oro.gb.a-20t., egbo, al» a()} rv· s1 p~lu, ao wa •ko
gbogbo ~.s\iililfY;iiHl'iJ.l:o.mtar~ ti o ba ti ku ti ko·.
le r~ S$Q iii~ sl,-8'0,rlsiioju;~~ ibi ti a- ngbe ll'bi' uj
··9n3 .oko w-a. ·
I'{· I

78 OGUN ISQRI
1$U emina, i$U esuru, ~o lQ esmu -~ ~i-u
·Qlg,., -ao- :
gun emina ninu odo, aci da pQ mQ ata wQ~ ao ~ ··dio' ·
ninu aw9 gigi$e meieji,. au- io iyt;n ati odidi utare ll.t •
QtQ, ti a ba f~ lo, ao joko le ori odo, a o wa ka ~s~ le
ori QlQ ata, ao ·mu frkQ odidi kan ao da si QmQri igba,
ao fi fQ ~kQ na mu. QfQ ry:- Aiya esuru WQn. ki iwQ
odo, aiya emina -WQD ki iwQ QlQ, igigis~ ni ti ~s~ · ~aja
ldo~to tv~~wa"<la si~'ll.fJO g~eapu~
. . ...
'
I' , ••

• 24
79 Awt:JRB _ONIGB:e;R'S
· . · Ew~ eta, odidi a tare kan, eran QWQ inaki, ao jo pq
ao fi sin gb~r~ si QWQ mejeji, o daju. .
· !;ran el~de, ewe papasan, odidi atare PD, ao jo
· pQ, ao, ti sin gb~r~ sr.9run QWQ mejeji yika. .·

80 AWURE TI. A FI NPA ARA


· Omi ti WQD ba fl ·w~ QmQ tituo ti ojQ,;o gba· sinu ,
igo kan, irun ori .afin, irun ori oyinbo, alakan w~r~ ti
et:i okun, ao IQ googbo r~ PQ, ao wa da sinu igo y~u, ·
ab da IQfinda ti o ba ni oorun dada si., Jo ma fl pa ata
t( a ba w~ tan. ·

81 o~e AWURB ·
" Tsu emina di~, i~u w-owo di~. ao gun PQ· mQ ara
WQn, ao gun p9 mQ Q~f} awiin oni kQbQ m~w• i\; ni
ao ti..gun Q$~·yen, ao wa~Q. kini yen si, 80 ~ ni eji-
ogbe? a_o !118 fi ~~ QWO., tfl:~ a · fl~~ 9w9 .. ~, ao Ii
~=-
WQD 1.b1 ti a ba tl nta QJ~ tab1 ·~~ QWQ. ::;QrQ )1/(!Ylo
Id o ba mi wa owo pup9 wa ni oni. cmina ki o ·p~ ' tQ-
mQdc tagba ki w9n o ma -113· owo QWfJ ,w9n- fun ini ni
oni. Igun ile ni ao tt gun.

82 AWURB Tl AO MA LA
Ewe kminiho, iyQ oyinbo meji, iyo ti o 'bl to se
QbCr ni ~kan, ao 19 ewe Yt:D pelu aw9n iyQ mejeji y~
pQ, ao t~ ui ifa eji ogbe. . Qfi,l r~~- (l)ju gbele, ·oju~
~e ilu a~QDi bekan jifa,_ a Id bim~ WQ iyQ oyinbo danu
a ki binu WQ . iyQ Q~ danu, ewe j~mi~iho ki ij~ oni-
kQ meji, ki gbogbo enia ma fi owo QWQ WQ.D j9 mi ni
·.ho, ao rQ. sinu igo, ~ ma la di~di~.
25
\ I

83 ose
AWURE ATI EYITI AO MA FI
,SA ORI
lyc;__agbe, iy~ aluko, ikodc; kao, il(?kc; itun, i1t;kc; ifa,
eso abete' m~ta, ewe t;-mu, ewe Hufc;mi ti WQD n_pe ni
ewe ata, ewe olu~anu, cdidi atare kao, .ao jo gbogbo
.!~ \':Q, ao da !i QD3 meji, HO po idaj!.?J~~ ~QbQ m~wa
ikqt ao -IQ smu ado.-kckcre, -ao -ma 'ff sa _or1. ·

84 OGUN ~YQ MQTO · .


Epo irugba, epo QP~, ao gun mc;eji pQ, ao to sinu
tf~ owu, ao di g~g~bi WQnti ndi oode, ao fi iru ikun
si, ao ran ni' onde, ao ma fi si idi.
. I
. .,
85 OGUN
.
ORUKA IJAKADI .
AkQ , alangba, ewe amunimuye, obukotoyQ, ewe
ina, ewe pataomQ, ao IQ gbogbo r~ pQ, ao ko si ~nu
alangpa y~n, 80 di p~lu oyc oruka ti a ba fc;, ao IQ · ri
inQ 90a ti gbogbo enia ba ngba kQja di QjQ keje, ti
enia ba f~ ko, yio fi ori pa QWQ a ti gbogbo ara.
86 OGUN GIRi QMQDB
lgi tabs. tutu, tagiri, ao pQ, jo ao
ma bu sinu adin
ms, 9m9 na_yio ma la,. girl ~o ni YQ QmQ na l~nu.
-Eso-.akettjupQD, 80 jo, ao da sinu adin- fl'an~ 911'lQ
na yio ma la.
OGUN AJJ;.SARA
"'Q
(unfun, odidi igbin kan; iyQ, osqn, aro, ao
11u ~9 y~n ao di ni ap~- tin; ao r~ ni aro ao tun di
26
apa teii, 10· r~4 ni osun; ti o ba ·gbf: tan ao tu, bu ·ao -
iyQ d!O sf (!iu 1g~in""-;,;e,. ao wa di a.fQ y~n mo; o .di 'jijo
· PQ, t:1 • ba JO tan, ti • be f~ lo ao .bu st QWQ. Q(9 r~:-
·<,>;o d asc,.funfun ba fi oju kan :uo ni.i~c r~ tan, 9j9 -ti
8$0 funfun. ba fi oju- kao osun ni i~e r~ bajc;, QjQ ti
igbin ba, fi tcnu· kari iyQ ni re Qrun aperin, nj~ ~oi to b:a
npcri.mi -~bi ki he wQn ma baj~ loju wQn, ao f~ danu.
88 Kl OGUN MA LE RAN NI TI -A
' . BA Tl;: . MQLe
·Patako e$iD, patako ewur~, patako agut■ n, ocUdi
atare bo, ao jo pQ, ao fi sin gb;r~ si ~s~ mcjejl yipe.
89 . : OGUN A~EGB~
.....-_, .:-Ewe iD\1 cs,!', . alubosa elc~e, iyQ, ao lQ WQD SURI
~ pupa, ao _ma la · · · .
~

90 OGUN KI eT :v-z: MA LE RAN .. NI


. · E~e jokoje m~san. c;,ra inu . uin korofo adi~, ~YQ.-- ..
atare-mrsao, ao gun p9; ao ltC'I smu aw funfun ac,.,-i ~- _
obi kan, 10 fi awQ dudu · ran ni onde, ao ma fi si idi~ · •
.:' 91 OGUN IKIYA FUN J;'.NITI AYA RI;'. NJA
Oleo pngo, ao fi si in·u ina,"ti o ha gbona dada ao
ju sinu epo pupa di~; ti o ba tutu, ao mu oko .$aDgo
na kuro ao·fi epo y~n r? ekurq, ao j~.

92 OGUN Tl AFI 1'11'1 OJO


· ,,
..' ,

'. Ewe etipQnl.1 ;~n ti ko dalu rarn, ,.yQ atare kan


ao fi. siou ewe y~n, ao gbe ·sinu 8$Q ekisa, ao ri
i1i iao mQl~, ao la ni ~nu, ao fi kini y~n ha di ~nu, ti
_,, ·JfD ko ba. tu ojo ko ni r9. -.
'2.7
93 OGUN TI AFI NWO Gl;'.Gl;: QRUN
Egbo aruopal~, egbo ifQn, egbo agbasa, taba juku'
~po amuyan, alupaida, ewe arahara, odidi atare kan,
ao gun gbogbo re; pQ, ao ma di mQ Qrun p~lu a~Q.

9.4 J;:RQ ILi; GBONA-BABA


Ewe otili, ewe ~tare, ao fi omi se, rnimu ati wiw~.
~mu ni ao fi gbo ~fQ odu,. ao r9 sinu igo, ao lQ igi
nla si, ao fi kQ si ~nu Qna ile, ao ma fi pa ara.

·95 OGUN KI AGBANA MA RAN NI


Ina ti o wa Iara a~Q, koro O\'\'U k~w, ey9 atare I,
ao 19 gbogb~ r~ PQ ao fi sin gb~r~ kan si 9w9 rnejeji
96 OGUN BI NKAN 0$U OBINRIN J3A DUDU
Os.un, ado, imi Qj9, ikpq.~ kQ.n, iy~re, egbo jolbiri,
ao gun gbogbo r~ pQ, obinrin na yio ma fi mu Qti ibil~
tab1 9ti · oyinbo.

97 AGBO ELA
Egbo ijoku, ~ru aw9nka, egbo botuje funfun, oro-
mbo w;r~, ao da Ii agbo tutu, ao ma mu ao r:;na fi w~,
ao pa akukQ adiy kan ni QjQ ti a ba ~e, sara ni ao fi ~e .
.
98 OGUN QKA TI A~E FUN ABOYUN TJ;:LI;:
Eso iku ~YQ kan, ao sun ninu ina, ao jo odidi a tare
kan mQ, aboyun na yio ma fi mu ~kQ tutu.

99 OGUN TI AFI NWO QK.A ORI FUN QMQDE


Ongo ori i~u, ekur9 oju Qna, ao po pQ mQ adin ·
Qyan, ao ma kan si ori 9rn9 na.
28
100 OGUN J;:DA IBULe TABI ORO
. Egbo aj<;kobale, .ewe bQnni, obi m~ta,kahun, ata-
re 3, ewe patanm9, ao gun pQ, c;kQ tutu la o ma fi mu.
101 OGUN SO:JJIA.
Egbo tude., Qga 1, QkQ atare 3, ao jo pQ, ao fi -
. sin. ~b~ry yi <;Sy ka, bi o ba gbe e lulQ ao sin bakaiw,a.
102 OGUN BI OBINRIN BIMQ TAN T1
1;J6 KO TETE DA
Epo·i~in, QpQlQpQ f;YQ atare, ao gun won po, obi-
nrin na yio ma fi mu ~kQ gbigbona nigba gbogbo.
103 OGUN Jewo- JI,:WQ QMQDE
Egbo pandQrQ, epo afa., alubosa ,elewe, ~ awola,
tagiri, ti o ba ~e Qkunrin ao ge tagiri na si Qb.a m~an.
ti o ba ~e obinrin ~o ge si qna meje, ao ma ti rQ QlllQ·
na lar9lar9.
104 OGUN KOKORO QMU
Egbo ifQn, oiu oro, ekurQ oju 9na, eso t~tc;r~gun,
ewe efin \Y9wi;, no se w9n PQ, ao ma fi · wr; Qmu na.
105 OGUN KI OBINRIN LE LOYUN
· Ewe k~hins<;>ruo, egbo ailu, egbo jokoj¥, obi ajopa,
ao ~n pQ, ao ma fi fQ t:kQ mu ·fun obinrin bi o ba
pan nkan o~u r<t tan
Odidi atare kan, horo bi .f;YQ m~ta ti o wa ninu
eso i ~ pupa, ao lQ WQll PQ pylu ata iru, ao wa .fi
se Qb<t okete jy, bi nkan o~u obinrin ba pari ni ao to
ba obinrin na lo pQ, yio si loyun p~lu ogo Oluwa.

29
ALAYE ORUKQ AWQN EWE
PE EWE NI APEJI; ORUKQ WON
~we Aj~kofole Ewe oyiyi ni apei~ r~
Ewe Lapalapa - Iyalode tabi botuj~ .
Ewe lyeye :Ewe Okika .
Ewe aca - Ewe lluf~mi ·
. Ewe, Lab~lab~ Ewe Ar~wa ,
· Ewe Sawerepepe ..Ewe ata QmQde ·
Ewe .Ewuro Ewe· aluba ,
Ewe- Olumuyinrin Oju Ologbo
Ewe Owu- bveOgedo
·Ewe Tagiri Ewe S~iri
Ewe pariga tmi-.EJU
Ewe lyere Ek.aja ,
lgi lyan .1\muyan tabi pa~d9rq
Apasa Apara-Obukq
.Ewe J~ub~nu Ak9rere .
Ewe Ebure Ebolt> .
Jsi Ira Jgbo Asof~y~j~
Ewe Ina lna
Ewe Ariba Eweran
Bwe Aje - l;funle ·
Asunrun Ewe ASWIS(Hl
Arunkuna . Agunm9na
Arai~ Amuj~
Ewe R~kur~kJl Bal~kal~
Alupaida Apada
Idari58.' Qja lkoko
Ewe itu E~Tudc .
Ewe Ar~hinkosun 0$~potu-Papnkoriko
Sru -- ~rioj; .
Bwe Amur(iu Awuju . .
Ewe )~njoko Jokojy
30

"\ .
·AWQN ODU-IFA FUN MIMQ ATI TIT8
I 2 3 4

EJl OG:BB Q~KU MEJI lWORl MEJl 0D1 MEJI ·


00 00 00 00 00 0 · o
00 , 00 -· 00 0 0 00 00
00 03 00 . ·o 0 00 00
00 00 00 00 00 0 0

s 6 7! r _
trosun meji
0
0
00
0
0
O:>
Qwonrin meji
00
00
o-
00
00
0 ,
Qbara · meji-
0
()()
00
0
00
00
..
Qkanraa mojJ

80
00
-
~
00
00 00 0 0 00 oe 0 0

9 10 H H
Opoda meji Qp mcji lka mcji OturuP9D mcjl
o. 0 00 00 00 00 00 00
0 0 0 0 '() 0 00 00
0 0 0 0 00 00 0 0
00 00 0 0 00 00 00 00

13 14 lS 16

Otura mcji Ir~ .mcji Q~ meji Qrangun meJI


0 0 0 0 0 0 00 00
00 00 0 0 oo · oo 0 0
0 0 00 QO, 0 0 00 00
. 0 0 - o· 0 00 00 0 0

31

.
-'., ?-
~
"-:tmad· at:-
,AMBY "'P-MN.tt,NG WORKS.
Ayed!n1e -· Olomi.,
Off cOl()Jli'rm> · tb'a\tm.
~~,;~

..
UNI VER SITY OF FLORIDA

IIIIIIIIIIIIll IllIllI IIIll IIll IIllII IllIIIII IllIIllIll II IIIIII


3 1262 05478 7352

'3Ut 2 3 "'6

You might also like